Uploaded by alfulanijamiu

8th june

advertisement
AGBOJESU CONFERENCE WORLD
WIDE
OGUN STATE CHAPTER
MONTHLY MEETING REPORT
FOR
8th JUNE, 2022.
AKOILE IPADE OJO KEJO OSU KEFA ODUN 2022
Ipade bere ni deede agogo 12:19pm, Orin iyin lati enu woli Imole, bakanna
Lesoon wa lati enu Alagba Imole “Malaki 2 ti oro iyanju wa lati enu Sup,
Apst, Ayoola JP. Akole iwasu “Ope” Psalm 100. Adura leyin iwasu waye lati
enu woli Kola Are awon odo.
APOLOGY
Vice chairman Ireti Ogo, Elder Fadolu, Alagba Joshua Ojasope Sec 2, Alaga
Isori Ejila Awori, Alagba Amsat, Alagba Behula.
ORO LATI ENU ALAGA
Alaga Adeniji pase ki gbogbo ile gba adura si origun mererin agbaye fun
itura nitori awon nkan ton sele
READING OF THE LAST MINUTE
Alagba Eben Kush ati Mother Ojodu gba iroyin ipade to koja wole, beeni
won dab aka bere ipade.
KOKO TO SUYO
Alaga Adeniji soro lori ifowosopo ti egbe OAIC ati Ogun State Chapter, to
jasi wipe oye kan lati egbe OAIC kole wa si ipinle Ogun yi, lati gba ori tabili
Alaga Adeniji koja. Beni Alaga dahun wipe ipinnu ohun ko yi pada. Omo
oko Agbojesu loni oye to ba wole.
Beni Alaga je ko ye gbogbo ile wipe awon ko bu enu ate lu UNIFICATION,
beni won je ko ye gbogbo ile wipe egbe CAN koni orin meji ju pe omo
Agbojesu ko mo ju Apoti eri lo. Alaga je ko ye ile yi wipe a ko fi agidi mu eni
keni. Ogun State chapter yii ti duro ni oruko Olorun kole baje. Amin. Nitori
pe ipo ni opolopo se n salo si agelu sungbon eto ogun State chapter kole bo si
won lowo. Gbogbo State yoku tin copy Ogun State chapter, tori gbogbo won
naa lo fe di chapter. Alaga fi da ileyi loju wipe anfurugbin lowo ni, eyi ti
gbogbo ile nbo wa je ere re ni oruko Oluwa. Amin. Beni Alaga pe akiyesi ile
yi si egbe OAIC ati CAN pelu UNIFICATION won ni eko to ye kooro lori
agbekale egbe. Leyin opolopo atotonu, Alaga Adeniji dahun wipe awon kan
bere wipe kini ere state meeting ti Alaga si fesi wipe Ere ibeni eko to ye kooro
. Ati bi ase n naa owo si ibi toto tosi ni apeere. Beni Alaga tun fi enu ba iwe
eri omo Agbojesu tooto ti won si fi iwe eri naa han gbogbo ile. Alaga soro lori
ipalemo ori oke Agelu ti won si gba 20 booklet wa ti oku mokanla, ti won si
pin ni meeting yi ti olukuluku yoo mu owo yi wa ni meeting ton bo.
ESI LATI ISORI ITELE
Alagba Ayoola JP dahun wipe atunse ti wa ni ilu itele Alaga Itele ti won yan
to so wipe No, o ti fa ijoba No ya, ti o si so wipe capital YES (Enisonibe). Ti
awon omo egbe yoku naa si dahun wipe maa jo lo awa leyin re bi ike. Beni
won je ko ye ile yii idi Pataki ti Alaga naa kofi wa sugbon awon omo egbe
melokan tele Alagba Ayoola wa. Ti gbogbo ile yii tewo gbawon. Ao jo ni ajose
pepepe o Abo Olorun yo daju lori gbogbo Ogun State chapter ati Agbojesu
lapapo. Amin. Alaga tun soro lori District ti ko ti se Injuction papa julo
Agbojesu gbewa District.
KI LON SELE NI ODEDE RE
Youth: - Are odo Woli Kola won soro lori Camp won ton bo ni Ona. Beni
won je koye ile yi wipe ayeye odun kan lori oye awon odo yoo waye ni ojo
kejidinlogun 18th June, 2022. Pelu eko adari to ye kooro. Ti won si fi ife pe
gbogbo ileyi. Owo iwole N500, beni jije mimu irorun ni ati iwe eri mowanibe
ti ao fun olukuluku won. Beni won je koye ile yi wipe ipago odo yoo waye ni
ijo Alaga Adeniji CAMCA. Beni won dupe lowo isori Ifo fun apo baagi Iresi
ti won fun won ati Isori Isagamu fun majemu won ti won se ileri wipe awon
yoo muse. Are Odo ro gbogbo ile fun atileyin ati ifowosowopo won fun
aseyori ipago yii. Are odo je ko ye wa wipe ori afefe ni won yoo ti se iforuko
sile yii. Owo re je egberun meji N2000
Good women: mother Adejuwon dupe lowo Olorun ati gbogbo ileyi fun
atileyin won. Beeni won sope ipade tunbo yoo waye ni Ifesowapo District Ejio
ni ojo kefa 6th of July, 2022. Beni on dupe lowo Agbojesugbewa fun igbalejo
won fun ipade tokoja.
Army of Salvation:- General Adeyemi dupe lowo Olorun ni gbogbo ona ati
ileyi beni won jabo fun ileyi ipade gbogbogbo ti omo ogun ti won lo se ni ni
ilu Eko ti won si gba ibe losi Ejila Awori fun meeting ti Ipade mi yoo waye
ni 2nd of July, 2022 ni ilu Mowe Ibafo. Eyi ti asale imore yoo waye ni 23rd
June, 2022 ni gbongan ipade wa ni Lafenwa. Beni Gen Adeyemi sit un dupe
lekansi lowo gbogbo ile.
Prophet & Prophetess:- Alagba Eben Kush won dupe lowo Olorun ati
gbogbo ile yii beni won ni awon se abewo si Sagamu ati Ijebu Igbo, beni won
je ko ye wa wipe ipade awon yo waye ni 12th July, 2022.
Alaga Adeniji:- So wipe ise wa lowo awon woli wa lori oro Apoti Eri ati Holy
Mary yii ki a ba arawa so otito oro.
Asaju Woli Isori ti ilu Ijoko, soro lori iso oru ti won se wipe awon Egba ko
se deede, beni Alaga Adeniji dari won padasi Alaga awon woli ti Gen
Adeyemi ati Mother Adejuwon naa si kin Alaga Adeniji leyin.
Kabiyesi Akilapa ro gbogbo ile yii wipe ki afi owo sowopo pelu Alaga. Oko
iyawo kere ko kere alodi. Eje ki agba fun olori. Beni won ro gbogbo isori ki
won maa se deede pelu owo isori won.
Mother Olatunji ati Gen. Adeyemi daba kamu ipade wa si idanu duro, ti
Woli Ijoko gba adura, ti Sup, Apst Sunboye se ore ofe.
FINANCE STATEMENT
WEDNESDAY 8TH JUNE, 2022
MONTHLY DUES
1.
Mowe/Ibafo District
7000
2.
Ona Ara Sagamu District
5000
3.
Ogo Oluwa Itori/Ewekoro
5000
4.
Agbojaesugbewa District
5000
5.
Itesiwaju/Ejila Awori District
5000
6.
Ifeoluwa Ijoko District
5000
7.
Ifo Central District (May/June)
10,000
8.
Army of Salvation
1,000
9.
Good women wing
1,000
10.
Youth wing (May/June)
2000
11.
Egba District
10,000
Total
56,000
MEMBERSHIP FORM
Mowe/Ibafo District
13 memberships form @ 200 =
2600
Paid N1000 to Balance = 1600
Grand total
57,000
Expenditure
OAIC S/W Advertisement
10,000
Pant Constitutional fees
15,000
Secretary office
3000
P.R.O
2,000
Balance
N27,000
Chairman Sign
Secretary sign
financial Sec. sign
Related documents
Download