IWE TUNDE TI A NSE WONUN ODUN TUNTUN (31 JANVIER) FUN OJO META (03) EO LO WA EWE AKOKO ATI EWE IYALODE PUPA ATI FUNFUNTI OOJO, AO GBOO EWE WON YI TI YIO KUN NAN LEHIN NAN AWA BOMI PUPO SINU RE LEHIN NAA EO YO AWON IDOTIN RE KURO LEHIN NAN EO MUN IGBALE YIN EO FI KO GBOGBO AWON JANKARIWO TI NBE NINU ILE YIN EO DAA SINU OMI YI LEHIN NAN EWA FI EPO PUPA DIE SINU OMI YI LEHIN NAA EO WA GBE OMI YI SINU ORUN TI OBA DI ALE NI DEDE AGOGO MANKANLA ABO ORU (23H30) NI IWE YI TI BERE LEHIN NAA E WA FI EPO PUPA PARA LATOKE DELE EO WA GBE OMI ATI OSE YI WO BALUWE YIN LEHIN NAA E WA SE ADURA SINU KANKAN YI (EGUN IDILE ; TI IDILE BABA ; IDILE IYA ; IDILE OKO TABI IDILE IYAWO, ASASI TI WON TI SA SIMI LATI AI MO YE ODUN TI KO JE KI SE ASEYORI, TI KO JE KI NI SIMI, TI KO JE KI NI AKO JO TI MO NFI OJU KO OWU ALANTAKO KIO DI OHUN IGBAGBE EO WE IWE YI FUN OJO META IPARI OSU KINI TI NSE 31 ATI OJO KINI OJO KEJI TI OSU KEJI (1 ; 2 osu keji) TI OBA DI OJO KETA TI NSE 2 OSU KEJI EO SE SAARA RE EO LO RA AGBAN TI ONI OMI NINU KAN, IYO DIDI KAN ATI SUGA DIDI KAN LEHIN NAA EO WA SE ADURA SINU AWON NKAN META YI EO WA GBE AGBAN YI FUN OBIRIN PELU IYE TI EBA NI EO WA GBE IYO YI FUN OBIRIN MIRAN PELU IYE TI EBA NI EO WA GBE SUGA YI FUN OKUNRIN PELU IYE TI EBA NI OSE RE EO WA ERUN ALAMO EYI TI ONI OMO NINU FUN OKUNRIN : MESAN (09) FUN OBIRIN : MEJE (07) LEHIN NAA EO WA ATA JOSIN (ATA WUWE) FUN OKUNRIN : MESAN (09) FUN OBIRIN : MEJE (07) EO GUN ERUN ALAMO ATI ATA YI PAPO TI YIO KUN NAN LEHIN NAN EO FI OSE FUNFUN (OSE GANAN) DIE SI, EYI TI EO LE FI WE TAN LEKAN NAA, EO WA GBE SINU KANKAN IBILE OSE AANU ATI ASIRI BIBO EO LO WA SUGA KORO PALI KAN, AGBAN KAN, OYIN OSE FUNFUN (OSE GANA) TABI OSE DUDU ATI IKE FUNFUN EO GUN SUGA YI KUNAA KUNAA LEHIN NAA EO FI OYIN DIE SI E WA GBE OSE YI SI ORI RE TI EO GUN PAPO TI YIO FI KUNAA, LEHIN NAA EO JO OMI INU AGBAN YI SINU RE, E GUN PAPO LEHIN NAA EO WA KO SINU IKE FUNFUN YI EO MA WE NI ARO ATI ALE TI EO SI MA SE ADURA AANU ATI ASIRI BIBO TI EBA NWEE NB : ENI KENI TI OBA FE LO NINU OSE YI KO GBO DO JE NINU AGBAN TI EFI SE ASEJE AANU ATI ASIRI BIBO EO LO WA AGBAN META (3) ATI EHIN AGRIKI META (3) E JO OMI AGBAN META YI SINU ABO KAN TABI IKO TI EFI SE NKAN TI KII SE NKAN ELEPO, E KO EHIN META YI SINU RE KI E SE TITI YIO FI JINAA LEHIN E SO SI ORI OSUKA KAN, TI ATEGU BA TI FE SI, EBO EHIN YI JE LE YO KOKAN KIE SI MAA SE ADURA ASIRI BIBO ATI AANU LEHIN NAA OMI AGBAN TO KU NINU NKAN SE, E DAA MU NB : ENI KENI TI OBA FE JE EHIN YI KO GBO DO JE NINU AGBAN TI EFI SE