4CYTE INTEGRATED MEDIA In conjuction with KASTANETS HOUSE OF EXPRESSIONS Present FILA ETU Story: JAMIU AKINDELE SCREEN PLAY (1) Adebayo (2) Ayedade (3) Dayo (4) Fasusi Ariyibi Olawale ibiloye Ayomide Seun July 2022 Copyright 4cyte Integrated media. SCENE 1. EXT/DAY. GARAGE Camera se afihan Orilade ati Adisa ni garage ti Adisa nbinu pe ko sanwo ticket ojo marun, Orilade be pe ko ma binu o si sadura fun.Oko won kun Orilade pelu Dayo omo re ni oju ona ti Oko ero won baje si, ti gbogbo ero si fariga, pe ki won wa atunse tabi ki won da owo awon pada. Ni kiakia. Leyin igba ti awon ero lo tan dayo pelu baba re beere sini ti motor titi sugbon kosise. Beeni Baba yi bere oro odi si ara re pelu olohun, omo re gbiyanju ati ro lokan pe nkan yio da. Orilade sadura fun Dayo pe oun na yio ri omo toju e ati wipe ti nkan ba yipada, oun a toju e. CAST === Dayo, Baba Dayo, awon eeroo Probs === Motor, Money, SCENE 2. EXT/DAY. ROAD SIDE. Camera se afihan iya dayo nibi oja to nta, eyan kan wa sin lowo, o ni oun ti ko owo to wa lowo oun fun oko oun ko fi tun moto se laaro yi, pe to ba ti siwo lale, awon a sanwo, iyen so fun wipe motor ti oun ti ri ti ko sise, ko ba oun ko owo oun, iya dayo gboju soke, o mba Olorun wijo. Adisa de o soro nipa onigbese to wa pariwo le lori, o ya Iya dayo lenu pe se adisa le soro bi omo gidi bayi? SCENE 3, EXT/DAY. MECHANIC workshop Camera se afihan Orilade ni ile mechanic ti won nse moto e, bi o se je abiku ni moto yen, baba dayo soro tikanra tikanra. SCENE 4 EXT/DAY.ROAD SIDE Camera se afihan iya dayo nidi oja e, adisa wa o fe gba owo ile, iya ni ko sowo. Adisa fi ibinu da igba e nu., iya woju olorun o soro odi, SCENE 5, INT/NIGHT. ORILADE HOUSE Camera se afihan Orilade ati iyawo e, pelu dayo omo won, ti won ndaro airi ounje, ari Orilade ti o dide bo si egbekan, o woke, omi bo loju e. SCENE 6, EXT/DAY. ROAD Orilade nrin lo loju ona tironu tironu, o pade baba Boseere, Boseere, pe Orilade lemeeta, o so fun wipe oun fe ki o wa ri oun, Orilade so wipe Oun ko raye bayi tori oun ni lati lo se moto oun to ba je ati wipe bi oun se nlo yi, nkan ti awon ebi oun fe je loun nwa lo, tori won o jeun sun lana. Baba Boseere pa owe fun wipe, ero tete ji, ero tete de, tara ero la nso fun ero. Orilade so wipe, oun gbo sugbon koun wa nkan tawon ebi oun a je. SCENE 7. INT/DAY. ILE ARINAJA A ri Arinaja ninu ile agbara ti o nsise fun eniyan kan, o ndira fun eni na. SCENE 8. EXT/DAY. MECHANIC PLACE A ri wakili ati Monday ti won nsoro nipa bi nkan ti yipada fun Orilade, monday so wipe oun gbo wipe lehin ti o de lati ilu won ni gbogbo e yipada fun, wakili so wipe nkan ti won ti e so bayi ni wipe, se lo kan nfi owo tore, ati wipe bayi oun nlo ba boya oun ari nkan gba lowo e.Monday so wipe o fe ki won lo ogo e, wakili dahun wipe ogo ti o wulo fun oun ti oun ni, ko lo ti won ba fe lo. SCENE 9. EXT/DAY. ORILADE HOUSE Camera se afihan wakili ati dele ti won wa dupe fun Orilade lori ore tose dele. Bi won se un lo beeni Orilade tun fun won lowo. Iya Dayo bosita osi so fun oko re pe oti poju oore niwon, ko rora ma soore. Orilade dalohun pe se o mo bi olohun se se ore fun awon naani. Beeni Dayo tun jade wa sita. O so fun daddy re pe. Owo episode toun so pe a won fe ya ni theatre group awon nko. Baba Dayo so fun pe sori gbogbo awon osere nlanla ti won de bi tiwon de loni yen. Won tepa mose nioo ati adura. Woo omo mi tepa mose ki o si ma gbadura dada. O kuro niwaju won. Cast === Baba Dayo, iya Dayo, Dayo, ara garage SCENE 10. EXT/DAY. CAR WASH Camera se afihan Dayo tohun sise kirakita kole bani owo lowo. Cast === Dayo pelu awon osise miran Probs === cars or blocks. SCENE 11. EXT/DAY. ON THE ROAD Camera se afihan yetunde ati ore e kan pelu olokada ti won nfa wahala loori owo beeni Dayo yo lookan osi ba won pari re beeni yetunde so fun dayo pe ki se pe ohun koni owo yen loowo sugbon tori motimo pe ibeyen koto iye tope fun mini. Dayo parowa fun Yetunde, o si dupe lowo re. Cast === Dayo,olokada, Yetunde. Probs == okada, money, bag. SCENE 12. INT/DAY. ORILADE HOUSE Camera se Afihan Baba Dayo ninu ile e tofun awon eniyan lowo. Beniyan ba bere N50 thousand a fi fun ni N100 thousand. Leyin ti won lo tan. Adisa wole Orilade so wipe oun fe ko meet ore oun kan to n contest fun governor. SCENE 13. EXT/DAY. REHEARSAL GROUND Camera se afihan Dayo pelu awon ore re ni rehearsal ground leyin igba ti won pari rehearsal tan. Ti awon ore re mun sere pe ki owa fun awon lowo sebi omo baba olowo ni. Lehin ti won lo tan adisa wole, Orilade so wipe oun mo akintiyan Adisa wipe idi re ti oun fife fa fun ore oun kan Oloselu ko ba sise, wipe iyen ndu ipo gomina ti adisa ba le ba sise inu oun a dun ati wipe oun naa a tun mo eyan gidi a si tun ri owo. Cast === Dayo, pelu awon reazer/ Probs === bags. SCENE 14. INT/NIGHT. PARLOUR ORILADE HOUSE Camera se Afihan Mama Dayo pelu awon ore meji ti won ni koba won dupe lo wo oko re lori iranlowo to se fun awon lori iyawo ti won se koja. Lehin ti won lo tan, Dayo wole o si so fun iya re pe se o da bi baba oun se nba oju oun je, ti o je ki gbogbo eniyan ma fi oun se yeye pe omo olowo ti o talaka. Iya parowa fun Cast === iya Dayo ati, awon ore remeji,Dayo Probs === bags and Palour set cup water SCENE 15. INT/DAY. BEER PALOUR Camera se Afihan yetunde ti o nreti dayo, Adisa wa nibe to nse faaji, ara yetunde ko bale, o dide o lo ba dayo wipe ko tera mo ise to nse, ati wipe ko ma setoju egbe e, ko si ma bo ori e, adisa so wipe oun o legbe. Yetunde soro si leti, wipe ti o ba se nkan ti oun so yen, o ma ri apeere. Dayo wole o be yetunde ko ma binu wipe oun pe ki oun to de, o salaye bose je wipe wahala airowo lo je ki oun pe.Yetunde ni ko buru, o ye oun,pe gbogbo e lo ye oun. Dayo beeere ki lo fe je tabi mu, Yetunde ni ko ma se iyonu, o wa bere lowo dayo pe se loto nipe o sese ki omo alaso o tun pada wo akisa. Ati pe ki omo eleran otun pada wa je egungun. Dayo si dahun pe kilori to fi un pa awon asamo bayi jade lenu, Yetunde dalohun pe iwo gangan ni oun n bawi pelu gbogbo oro to so kale yii. Dayo si dalohun pe, wo agboju logun ofi ra re, fosita Ni my dear. Cast === Dayo,Yetunde, bar man and two people Probs === malt, drinks, bar set. SCENE 16. INT/DAY. CONFERENCE ROOM A ri Orilade ati awon honourables ti won joko, Adisa wole, awon to wa ni ijoko so fun wipe oun lawon fe ko wa ni in charge campaign awon ni parks, tori o ma mo lati ba won soro, Adisa gba won si se ileri fun wipe awon ma fun lowo tabua. SCENE 17. EXT/DAY. CARWASH Camera se afihan omo ikan lara awon ore iya dayo, to n koja loo ninu maruwa, tabi ori okada. Bee lori dayo omo baba olowo nibi to ti n fo motor. Cast === Dayo ati awon tiwonjon sise pelu omo ore iya dayo pelu eyenkan Probs === maruwa, motor or block and willbirrow. Scene 18. INT/NIGHT. Ile ORE IYA DAYO Camera se afihan omo ore iya Dayo tohun salaye fun iyare pe ohun ri Dayo omo ore won tolowo yen tohun se ise alabaru pelu gbogbo owo ti baba re ni. Osi bere lowo iya re pe ki lofa tofi ribe. Iyare si so fun pe gbo tie Tara eni laagbo ki olohun oba ma fi oro oloro gba wa leenu. Cast === Ore Iya Dayo pelu Omore or Okore Probs === inside parlour set, bags. Scene 19. INT/DAY. Orilade house Camera se afihan oko ore Iya Dayo tohun ba baba Dayo soro nipa Dayo omo re pe ibi tohun ti riyen. Iwa idoju ti ni gba lohun hu, toripe ti aba wo ipo ati ola yin ninu ilu yii. Sugbon Baba Dayo dalohun pe omo ti a ko ko ohun ni agbe ile ti ako ta. mofe ki oko eko ni ore wa. Cast= oko ore Iya Dayo, Baba Dayo Probs= parlour set, cups, drink. Scene 20A INT/DAY. INSIDE A CAR A ri Bukunmi to n ndrive, o nreceive call, bo se receive call tan, o fi phone si egbe kan, phone jabo, o ko si abe seat. SCENE 20B. EXT/DAY. Carwash Camera se afihan Dayo ton ba Bukunmi fo motor, beeni Bukunmi yi bere si ni wa phone re to si pariwo le Dayo loori pe oun lo mu, leyin opolopo Iya ti won fi je Dayo won pada ri phone labe seat, sugbon omobirin ko tun bebe, o si n sope Dayo lo toju re sibe. Awon eyan bere si be Dayo pe ko ma binu. Cast === Dayo, Omobirin, ara ibise. Probs === car, phone, bag, car wash. SCENE 21. INT/NIGHT. ORILADE HOUSE Camera se afihan Dayo to n ba Baba re fa wahala pe daddy ema binu sir. Mo rope igba ti oju npon isin, awodi emi na bara nibe. Mi o lero pe eyin le bimi, toripe beeni baba pariwo mo gbenu sohun omo ale ni o. se iwo ogbo oro awon agba to so pe baba re le lowo ki iya re lesin lekan toba gboju lewon. Beeni Dayo da baba re lohun pe daddy, obo tiyin na ti nigi gun tele koto dipe kumo ana re ha sorigi, baba re dalohun pe abetaa kowa baba mi fun ara re. Cast === Dayo, Baba Dayo Prob s= table and chair, drink, cups. Scene 22. EXT/DAY. BEER PARLOUR Camera se afihan Dayo pelu Yetunde. Dayo sofun Yetunde pe ola ife towa larin emi ati e ni oo. Wo ma so fun anybody o timo ba ti kuro nibi bayi mofe lo para mi ni o. toripe bi ila oba se gbe asima gbe ilala. Beeni Yetunde fun lesi pe okun ki wo ruru ka wa ruru. Odami loju pe bi aba le gbawe ati adura ojo meta gbogbo ogun Jericho ayewa ma awo daanu. Cast= Dayo, Yetunde Probs= Scene 23. EXT/DAY. Area Camera se afihan awon boys Meta tiwon se faaji lowo beeni Baba Dayo koja, won si hail e, osi fun won lowo. Ikan lara won dahun pe eni to hun lo kadara yin, se eyin omo pe ogun owo ni baba yen se ni. Eyan tolowo tiko fi mo omo re. Ikeji dahun pe wo osogun owo oo, koso gun owo oo owo eleyi nina nii. Cast= Baba Dayo, awon boys Meta. Probs= car, chair, drinks. Scene 24. EXT/DAY. Location Set Camera se afihan Dayo ni location tohun ya ise lowo lori set, ohun ki awon oriki. Beeni P.A gbe phone wa fun pe iya re npe osi so fun pe baba re wa ni hospital tohun po kaka iku lowo. (Cam fade). Cast`= Probs= Dayo, P.A, location people camera, tripod, phone. Scene 25. INT/DAY. Hospital Camera se afihan Orilade ni hospital tohun pokaka iku beeni Dayo wole de osunmo baba re sugbon Orilade kole soro Kankan fun titi to fiku. Cast= Dayo, Baba Dayo, Iya Dayo, Nurse 1, Doctor 1. Probs= hospital use. Scene 26. INT/DAY. Ile Dayo room Camera se afihan Dayo ninu ile pelu Yetunde Iyawo re, Dayo so fun Yetunde pe ibo logbe fonu re si lataro timo tinpe oo. Yetunde fun lesi pe mowa ni ile iwe ni osima se suru omo kunrin yii abi ewo ni agidi osi tomura koko bipe ofe nan mi, Dayo bere pe se emi lonba soro beyan okunrin togbe wa si inu ile yi da. Osi wa everywhere sugbon kori nkankan. Beeni enu Yetunde ko ro titi Dayo figbe igbaju fun osi binu jade. Ari awon egbe Yetunde meji won ba Yetunde soro pe kini ki awon se fun, Odawon lohun pe ki won fi sile kiwo mase nkankan fun. Dayo wole pada, oko aso meji dani o so wipe sebi nkan timo fe beere nipe se pink lofe ni abi green. Osi be Yetunde koma binu o dimo, bi ose dimo yetunde, yetunde sofun awon egbe re pe setiri beyen. Awon egbe si ba ti won loo. Cast= Yetunde, Dayo, aawon egbe meji Probs= aso funfun 2, any cloth 2, room set. Scene 27. INT/DAY. ORILADE HOUSE parlour Camera se afihan awon ebi pelu lawyer ni inu parlour Orilade ti lawyer n pin ogun funwo leyo kankan, sugbon bi won se pin ogun to won ko fun dayo ni nkankan. Dayo dide o bere lowo lawyer pe koma binu se ohun le toro nkankan lowo gbogbo ebi, tori ohun timo pe baba ohun koni fun ohun ni nkankan tele naa sugbon ti ebi bale fun ohun ni fila ti baba ohun man de kotoku, ebi ati lawyer si gbasi lenu. Cast= Dayo, iya Dayo, lawyer, awon ebi Probs= parlour set, foiles, fila (cap) Scene 28. INT/NIGHT. Ile Dayo room Camera se afihan Dayo ninu ile pelu iyawo re, Yetunde un fi fila sere beeni dayo wole ba, osi pari wo mo pe kini fila yi nse lowore, Yetunde beere lowo dayo pe kini fila yii je to fi je pe ninu gbogbo ogun baba re fila yi ni oto si, dayo dalohun pe sori fila yii ohun ni baba mi ma nde ju ni igba to wa laye. Mokan feran fila yii ni kosi anything nbe rara. Joo mafi fila yii sere mo tori pe twenty mi niyen soo gbo. Cast --- Dayo, Yetunde. Probs === fila, towel, room set. SCENE 29. EXT/DAY. Location Set Camera se afihan awon ara rehearsal tiwon duro de Dayo sugbon won kori beeni eyan dide pe ki won ma bere ise loo. Ope ikan lara won pe ki ofun awo ni rehearsal. Ope binpe ko so gbolohun meta, pelu oro green yellow, pink, binpe fun wan lesi pe, (fonnn babami amadun ginrin ginrin, babami osi pinkin re, awa se yellow yellow. Oga dalohun pe oni opolo Kankan. Get out. Cast === awon ara reazer 4 Probs === bench. SCENE 30. EXT/DAY. ILE DAYO Camera se afihan yetunde to nsun losan gangan beeni awon elegbe re ji ko dide pe se kori apere Kankan ni (camfade) (cam fade back) yetunde haa eyin elegbe mi kila wa fese bayii. Won si fun lomi kolofun oko re ki asasi maba ran yetunde gbera ogba location lo. Cast === Yetunde, awon egbe meji. Probs === omi room sat. SCENE 30 b Alani nperi dayo ton pofo ki dayo sise kiwon ma ba gba titi e mo SCENE 31. EXT/DAY. LOCATION set Camera se afihan Yetunde tohun pe dayo oko re sugbon omo obinrin kan ti dayo gbe sese koje kodalohun. Yetunde soro si Dayo inu bi Dayo to binu soro si yetunde tofi binu loo. Bi Yetunde se fe jade o pade Adisa, adisa dupe ojo, o wa ri bi yetunde se nse o wa bere eni to se be, ki oun lo gbenan woju e, Yetunde ni ko ma se iyonu. Cast === Dayo, Yetunde, omo, location. Probs === SCENE 32.INT/NIGHT. ile Dayo Camera se afihan Dayo to de lati location beeni iyawo re di enu ona pe koni woole ohun sofun pe ahun tori ojaja,Oja ni talonja lenkule ohun. Inu bi dayo osi lu iyawo re bi bara. Ofi ibinu wonu parlour osi joko titi ofi sun loo Cast === Dayo, Yetunde. Probs === bag, parlor, set. SCENE 33. INT/DAY. BEER PARLOR Camera se afihan Dayo ni beer parlor pelu ore re beeni call wole hello mr Dayo afe kewa bawa se assistance generator man fun ise fila etu tafeya loola ni. Dayo dahun pe se emo eni tefe basoro sa osi binu cut phone re. ore re beere pe awon wo niyen, oni wrong number ni. Osi pe makerter fun rara pe ise teni efe san N600 thousand yen kini title re, iyen dalohun pe fila etu, ni oni eyan kan pe ohun nisin ni osi n so katikati, marketer ni beeni eniyen wa pelumi nibi, nkan to sele nipe atiri elomi fun lead role yen ni sugbon teba le se assistance generator asima wa nkan fun yin sa. Dayo cut phone osibere sini roonu. Cast= Dayo, ore Dayo, Bar man Probs= cigarettes, drink SCENE 34. INT/DAY. ILE Arinaja Camera se afihan Adisa lodo Arinaja, to nso fun wipe oun fe gbera, iyen so nkan ti won ma se fun. Leyin ti o lo tan Dayo pelu ore re de. Babalawo gbefa janle oun beere opoolopo oro lowo re osi ni ko te iya re ninu dada (cam cut) Cast= Babalawo, Dayo, ore Dayo Prob= ile awo set SCENE 35. INT/DAY. Orilade house, PARLOUR Camera se afihan Dayo pelu Iya re tohun salaye ohun to babo ile babalawo fun iya re si so fun pe ohun toun mo nipe baba re niyii. SCENE 36. EXT/DAY. ILE BABA BOSERE ABE IGI Camera se afihan Baba Dayo ni ile Baba Bosere, Baba Bosere so sofun pe, ki se ona toye koto niyen sungbo ohun fe gba nimoran aajoo ranpe kan ni ba ba lese aye re yoni itumo dada. Baba Dayo fun lesi pe oun o fi be gba ti aajo, sugbon ki ohun loma ro naa. Cast= Baba Dayo, Baba Boosere Probs= bench SCENE 37. EXT/DAY. INU IGBO KAN Camera se afihan Baba Boosere tohun sise fun Orilade. Osi so fun Orilade pe leyin gbogbo jije totije ati iwe yi nikan na ni opin isere osi sure fun dada, oni ikilore oo. Soori akobi omo re ko gbodo ni ipin ninu gbogbo ohun toba gbese laye to fi owo ara re kojo ta npe logun ni tori ojo ola omo naa ni oo (cam fade) Cast= Babalawo, Baba Dayo, Baba Boosere Probs= ose, Kanihinkahin, Odo SCENE 38. INT/DAY. ILE Arinaja camera se afihan Babalawo pelu Dayo to salaye fun Baba pe Iya ohun komo nkankan nipa ohun tohun se ohun yii. Babalawo si beere pe se oda loju pe komu nkankan ninu ogun baba re. o salaye fun Baba pe ohun ko gba ogun Kankan leyin fila. Babalawo so fun pe komu fila na kofi kini tohun fe fun yi sinu fila na kolofi tooro fooni baara. Cast= Dayo, Babalawo, ore Dayo Probs= owo eyo SCENE 39. EXT/DAY. ARIN ONA Camera se afihan Dayo pelu fila daani tohun wa oni baara tofefun. Osi pada fun oni bara kan sugbon bose yii pada, oni bara yi poora. Cast= Dayo, Onibaara Prob= fila SCENE 40. INT/DAY. ILE DAYO Camera se afihan Dayo ni inu ile bose si ilekun to jo ko bee ni ohun wo fila tofi tore lori chair. O si sa boota. Cast= Dayo Prob= Fila, parlour set SCENE 41. EXT/DAY. ILE Arinaja Camera se afihan Dayo to pariwo deele Babalawo pelu mimi gulegule baba si jade si oni kilode, dayo se alaye fun Babalawo nkan tojure ri babalawo si tele losi ilere. Cast= Dayo, Babalawo Probs= SCENE 42. INT/DAY. ILE DAYO, PARLOUR Camera se afihan Dayo pelu Babalawo titi won fi wole beeni Babalawo npe ofo wole titi fila fi yi pada di yetunde Babalawo pe tanioo. Yetunde ni emini alaragbo, ekun alagbo, oni pason owere, esisi inu iroko, alani woogbo, mafarakan enini, babalawo fun lesi kilode to jeki Dayo fii rojuraye, se ile ayere. Tokan foro emi re. Yetunde ni babalawo kisepe emina sadede se be sugbon Dayo losoo ore dibi, momi loowo. FLASH BACK TO SCENE 22 After scene 22 SCENE 43. EXT/DAY. INU IGBO KAN Camera se afihan awon egbe yetunde ninu egbe won pelu Yetunde ti won un se ariya odun sugbon Yetunde ko bawon dasi rara, egbe sibere lowo re pe kilode osalaye pe ohun fe iranlowo won, ki won ba oun ran dayo lowo, awon egbe bere pe se ko ni dale re, osi fi dawon loju pe, koleribe, gbogbo egbe gbo si lenu. Cast= Awon elegbe Yetunde pelu Yetunde Probs= shrine set BACK TO SCENE 42 ILE DAYO, PARLOUR Camera se afihan Dayo pelu Babalawo ati Yetunde to salaye fun won ohun ti Dayo fi ojure ri leyin iranlowo to se fun, leyin igba to lowo tan lilu ni lojojumo bi baara FLASH BACK TO SCENE 26 COME BACK TO 42 SCENE 42. ILE DAYO, PARLOUR Camera se afihan Dayo pelu babalawo ati Yetunde tohun so fu won pe Baba Ojo timo sofunyin yii omi ti awon egbe mi ni kin fun mu ni mofe fun o ki aburu lere kooja lorire, mo gba iwo si ni location loojona, motunde le jiya ati igba yen awo elegbemi ni awon mada seria fun, lori fila toferan ju. Babalawo si fi ohun agba bee. Yetunde si sadua fun oyipada osidi fila. Babalawo ni ko lo mu fun onibara, Dayo o lemu, babalawo si mu fun kolofun oni bara. THE END