Uploaded by Ologo Ara

ADE ERI PDF

advertisement
(1.)
ETO ISE IFERAN TO LAGBARA
* Photo eni ti a fe ko nife wa kan
* Igbin apinnu nla kan
* Iyere pupo die
* Iyere osu
* Isaasun tuntun kan
- A o fi photo yen sile, ti a koju soke ni ale patapata
- A o wa gbe Igbin yen le photo na lori mole
- A o fi ikoko kan de mole di ojo keji
- A o wa lo mu photo yen, a o lo lori olo dadaa pelu Iyere die yen
- A o wa pa Igbin yen
- A o fo ti yio mo daadaa
- A o wa da nkan ti a lo yen tele Isaasun
- A o fi Igbin yen le lori
- A o wa de lepo niyo
- Ti o ba ti jinna
- A o so sori osuka
- A o fi Iyere osu te ifa Ejiogbe
- A o pe gbolohun re si
- A o wa da Iyere osu yen sinu obe aseje na
- A o je Igbin na lodindi beyen
GBOLOHUN: Igbin o ni asiri kankan loju ile, Iwo ---omo--- o gbodo fi asiri kankan pa mo fun emi --omo--- lati oni lo mo lailai, odo emi ---omo--- nikan ni ki ife re wa lati oni lo. Bi mo se n je Igbin yi,
Iwo gan ni mo n je ife okan re. O tun gbodo nife elomiran mo lailai
Prophet Ade Eri 09061188299
(2)
[7/24, 6:29 AM] +234 906 941 4260: Bibo asiri todaju: oga gbigbe kan, aofi iru Pete bolara Dada,
aojo pelu odidi state kan. Ao pinsi ona meje, aomafi milk olope lo larolaro fun ojo meje tabi kialo
lekanna ni idaji kutu ni lilore.
(3)
Isoye: eko elewe kan, ori adaripon, ao la eko yen so meje ao rin ori adaripon yen si larin, ao do
eko na pada, ao gbe so inu ape, ao Jo pelu atare
(4)
[7/23, 6:47 AM] ADE ERI: (EYONU AWON AGBA............
EWE EWURO 201, EWE AJEOBALE 201,EPO OBO, ODIDI IGBIN AGBONU KAN, ODIDI
ATARE KAN AO GUN MOSE AO KO SINU IGBA OLOMORI AO MA FI WE
[7/23, 6:57 AM] ADE ERI: OGUN EYONU AGBA TODAJU
Bi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun: ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo, ewe
ajeofole, ao toju epo pupa die, ori die, adi die, ao gbe won sinu oorun lotooto ti won o fi yo tan. Ao
gun gbogbo eroja yen papo pelu ose dudu ao wa kan die die ninu epo, ori ati adi yen si, ao po
papo. Ofo re: ewe olusaanu loni ki e saanu mi, ewe orijin loni ki e foro temi jinmi, ewe ajeofole loni
ki oran gbogbo o fomi ru, ooyo loni ki e maa yonu simi, bi epo ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi
ori ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi adi ba foju kan oorun ti inu re yo ni.
(4)
OGUN TI ENIYAN BA Ni EJO
Ewe odundun,ewe alofohun,eku ebiti odindi atare kan ao Jo po ao ko sinu owu otutu ao fi owu
dudu ati funfun di ao mo ara agadagodo ao pa lawo funfun.
Ofore
Odundun loni bi eri mi kie maa le dun
Alofohun loni berimi ke ma lee fohun
Bi ebiti ba pa eku a pa iye mo ninu.
Ki l____l ma let yimi lohun pada.
(5)
ofo aforan
ao je eyo atare meje lenu pelu ofo re
aina omo awo loju awo
aina omo ogberi loju ogberi
ese ti aparo se ni ojo kin ni ana wo fi orire jin ni
gbogbo ese timobase kie fori jinmi
(6)
¤OFO ASEGBE TODAJU(pelu atare mesan)¤
Haa x3.
Gbogbo ota patapata to nperi mi igi daa.
Ki won peri mi si oran bukuru mo.
Igbagbe x3.
Igbagbe lose pepeye nio se ranti lase lorun.
Igbagbe x3.
Igbagbe lose Aja nio se ranti gbawo lorun.
Igbagbe x3.
Bi alatankun baji, aa wa igi tose lori kiri.
Igbagbe x3.
Idamu toba Alatankun nijosi to nfi ji to nwa igi to se lori kiri ko maa ba gbogbo eyin ota awa FANS
egbe yi.
ASE!!!.
(7)
ORUKA TI AFI NGBE OPO EEYAN SUBU.
Odidi agbado pupa kan, ao so sinu epo pupa, ao so oruka elelo meji no lara, ao wa so so arin a
won ijalo, to ijalo bati bo daada, ao wafi ikan gbe agbado, awon nkan naa ati ijalo, ao wa jo
gbogbo re, ao ro ebu re sinu igo kan, ao mafi oruka naa si owo.
NB:- - To abafi oruka yi by iyepe lu egberun Eeyan, gbogbo won aa subu ni
.
ERORE :- ao wa da ebu naa luwon, won a side pada.
TESTING :- ale danwo Lara a won ewure tabi awon adie
(8)
ETUTU AWON AGBA
Eran elede, ao resi 16, ede pupa, obi oloju merin merindinlogun(16 kolanuts), ogede omini meta,
ao bo, ao la ikankan resi ona metameta, ao ko eran elede tele awo dudu(awosobi), ao wa da ede
le Lori, ao ko obi yen ke, ao wa ko ogede omini si, ao wa te IFA Osa meji:OSA MEJI.
II II
II
II
II
Ao wa se adura ti abafe si, ao iyerosun naa le etutu naa Lori,
Ao wa gbe losi orita.
(9)
OGUN AWORO
Ewe agbayun, ewe jeminiho, ewe misinmisin, ewe sikinrinmindin, afara oyin, ao jo po, ao ma bu
sinu oyin Igan, ao ma la larolaro.
(10)
*IMULE OSAN PON* *GANRIGANRI TODAJU*
Eye Owiwi 3,eye Adan 3,eye Onbe 3,Igba Ahun toke tile re 3,Ikarahun Igbin 3,odindi Atare
3,ewe Ajeobale pupo oojo.
Sise... Ao ko gbogbo eroja yi sinu Agbada Titun, ao fi ajeobale yen bo lori, ao jopo, ti a ba
jotan, ao lo kuna a da sinu Opon Ifa, ao te nifa Osa Meji ,ao pe ofo re si, ao wa ro sinu
Ado Sere ,ao gbe ko si Origun Iyara to pamo si Obinrin.
*Ofore.....*
Osan pongaringarin awo ode aye 3x, ori kun fi ese ija mejeji tile awo ode oru 3x,
odifa fun o ta lerinwo irunmole ni ojo tiwon tikole orun bowa si ikole aye, sango mu edun,
ogun mu Ida, obatala gbe opon o soro, orunmila deyin debo o gbe opon odu, ogbe sori
ori fo, ogbe si ayaa aya faya, o gbe si eyin eyin te, o gbe si orukun orukun se, orunmila
ba binu gba odo eledumare lo, oni osan pongarigarin ti se awo ode aye nise ni won
dayeru, ori kun fese ija mejeji tile ti se awo ode oru ni se ni won dayeru, eledumare niki o
pada loso fun won wipe a ki je ahun kaje igba eyin re, a ki je igbin kaje ikarahun re, ile ni
ajeobale gbe pelu aje won ki ni ara won lara, ile kisu keye adan marin, eye keye kan kii
dorikodo bi eye adan, orisa korisa kan ki deru . ba eye owiwi , osa meji oo 3x, loni ki e ma
yonu simi, ki nmari owo nla oo.
Lilo... Ao ma fi fo Eko tutu mun ni 12:00am si 1:00am oru.
(11)
OGUN FUN ENI TI EJE BA SHORT NI ARA E TABI OMI.
Fun ti eje :-elo ra coca cola kan pelu tomato GINO, kie mix papo fun loju e se lo ma gain strength
pada, i yen lo baun..
Fun ti omi drips :-elo ra 7up ti ko tutu rara ,kie wa bu iyo die sinu, oma ru kie wa gbemu..
(12)
ASEJE AGBOOJO TO GBE #50000 WA LARIN OJO META
EWE EMILE TUTU EWE SEWONLAPA SEWONLESE (PAPASAN) EWE ONITIKUTI TUTU EWE
OLA DIE ATA IJOSIN 16 AO LO GBOGBO RE AO FI SE ERAN MALU AO GESI 16 JE LEPO
NIYO AO SO SI ORI OSUKA, AO SE ADUA SI AO KOJE
ODUN AYO LAO SE OOOOOOOOO, AKU IMURA ODUN
KAI O GBE OWO WA
(13)
AYAJO AFORAN or ASEGBE: Ao je eyo atare9 lenu laaro kutukutu, ao face ibi ti oorun (sun) ti
nyo. ofore: osan pon ganringanrin ni sawo won lode isalu aye3*, okunkun bolojo ni sawo won lode
orun (heaven)3*, adifa fun orunmila lojo ti baba nti isalu orun bo wa si ile aye, ode ile aye, o fe
iyawo aye, o gba iyawo aye, o ba iyawo aye sun, o do iyawo aye, aye gbo, aye binu, aye faraya,
aye turaka, won mu ejo orunmila won lo fi sun ogun atare, ogun atare ni to ba je ti orunmila ni, odi
ogun odun ki e to ri ti orunmila se, won mu ejo orunmila wo fi sun ogoji obi, ogoji obi ni toba je ti
orunmila ni odi ogoji odun ke to ri ti orunmila se, won ejo orunmila won fi sun igba ogede omini,
igba ogede omini ni tobaje ti orunmila ni odi igba odun ki e tori ti orunmila se,won mu ejo orunmila
won fi sun aparo, aparo wa mu orin awo senu oni, momu raaa. mo muu je, momu raaa o momu
jeee, momu laparo nke o. ao so gbogbo ohun ti afe, ao tu ri oju orun (sun).
(14)
ISE OKO ORUN tabi......
Black sheet of paper, write the name of the person on it(if the spirit gives her his name) but if not
write (IJIN-LOVER). in the middle of the paper,Fold the paper up as small as you can. Take it
outside let her use it to rub from her head to toe carefully. I'MMEDIATELY bury it in the ground.
Once it buried say this loud!
VOICE:
INTO THE GROUND YOU CAN'T BE FOUND, YOU'RE NOT AROUND MY DREAMS, I CAN'T
HEARD YOUR SOUNDS IN MY DREAM AGAIN.
Step over the place you've buried the paper. Pelu ogo olohun ati tawan alujonnu, kotun yaa waju
remo.
(15)
ASE TO DAJU SAKA SUGBON MAFI SE ABURU OOO
EWE ABAMODA GAGA KAN, ORI OKA TOBA NI ASE LENU, ATARE ODIDI KAN, AO JO
GBOGBO RE PAPO, AO FI OSE DUDU DIE PO TI YIO LE GBA INU AGOLO ROBB, TIKO SINI
SEKUN ILE....HMMMM!
GBOLOHUN RE
ERAN TI OKA BAFI SO, O TI DI ERAN OKA, ABAMODA KI DAA ABAA TIRE KOMA SE, MO
DABA ISE TI MOFE LO GBA EMI NIKI WON GBE FUN ATI NKAN MIRAN TABA FE LO FUN
NA,
LILO RE...... A MA SHIN OMORI KURO LORI AGOLO ROBB YAN, LORI ISE YI LAO PE
GBOLOHUN RE YAN SI, AWA FI ORI AHON WA KAN ISE YI LEMETA, AWA JUSI APO LOSI IBI
TALO FUN
(16)
Fun Aworo Olubasiri
Ewe abamoda 32 ti ko dalu , eyin adie ibile 6 tabi eyin Agric 6 , ao mu 16 ninun ewe yi ao fi tele
ape , ao ko eyin 6 yi le lori , ewe 16 to seku sile ao tun ko le lori , ao fi omori re de , ao ni bu omi si
rara , ao se lori ina fun iseju 16 ao je ni eyo kokan fun ojo mefa .
(17)
OSE AANU TI EEYAN FI NRI OWO.Ao wa werejeje
Ao Lo Kuna Dada yio da bi Powder, Ao gun Mose Lux Mefa6, Ao wa fi oyin (Honey) Po, papo ao
ko sinu Ike funfun Ao ko ko fi Aso funfun Te inu Ike yii, Ao wa GBE OSE yii sii,
Ao GBE pamo fun Ojo meta 3, Idi E ko gbodo kanle o...
Lehin ojo keta3
Wiwere
Ao ma we ni Monday, Tuesday, Thursday, Sunday ni wiwe re..ki ise yi kole sise fun ho Oni
Majemu, majemure niwipe Emi Ari Anu gba Iwo nko?????
(18)
Adabi Pada=egbo Atawewe Aogesi Wewe Iyen 2oo Obi 200 Omo Atare 200 Aojopo Aofi Singbere
Yika Inu Wa
(19)
# EYONU_ASINA .
ORI APARO KAN, EYIN OLOBE TOPO DAADA, AO JO PAPO PELU ODIDI ATARE KAN, AO
MAFI OYIN LAA LAROLARO.
(20)
# ASEJE_EYONU_TO_COMFIRMED .
Ounbe meta ewe orijin pelu ewe ewe ajeobale ata ijosin ao lo papo, ao fise okan malu ti kowo omi
rara ao gesi mesan ao se lepo ni iyo ni dede ago kan oru ao da sinu enu ona ao bora sile ni Ihoho
ao fi enu koje nigbati abajelowo owo wa kogbodo kan o
(21)
ASINA OWO GIDI TARA
KOWE DUDU META OPOLO AYE META ODIDI ATARE META EWE EWURO OOJO TIO KANLE
LOPOLOPO AO JO NINU ISASUN TUNTUN AO LO KUNA AO RO SINU IGO FUNFUN AO MA
FI FOKO MU LAROLARO
ODAJU PUPO.
(22)
Ogun ibon todaju
odidi alakan tope dada kan,padi atare kan,a o jopo a o fi foko mu Lori odi,a koko joko lori odo ti
ese wa koni kanle,a o mu eko nan ,ao tun dide,a o tun gbe iyoku mu,,,,ise eleyi daju o,,
Ogun jasejase
Iru alangba ni ibi tio dudu yen, a o ge,pelu odidi atare kan,aojopo gbere yipo ikun wa round,
Dawon,lobi iyaokere
(23)
MADARIKAN
Ao fa irun ori wa ti yo dan ao gbe ile kotokoto ao da irun naa si ao wa yaa igbe le lori ao fi odidi
atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori odaju ema fisere.
(24)
# EYINI_OSOLE_TIA_FI_NRI_OWO_GID
I_GBAA_NIDI_EYIKEYI_ISE_TIA_BA_NSE_
# O_KERE_JU_LARIN_OSU_KAN_AO_GBA
A_OWO_TIO_TO_FIVE_HUNDRED_THOU
SAND_NAIRA_TABI_KIO_JU_BE_LO
# TESTED_AND_CONFIRMED
ARM_BY_MANY_OF_MY_CLANT
ISE DARA FUN GBOGBO ENIYAN PAPAJULO AWON ENIYAN TIWON NI ISE LOWO BI
CONTRACTOR, ONISE-O WO, ONISOWO, CLARING AND FORWARD, OLOSELU (
POLITICIAN'S ), PELU AWON TIO NPA O WO DA BI AWON TIO NSISE ORI-NET - MOFI
OLORUN JERI SI TIE BARI ISE YI SE NI PIPE - O PEJU LARIN OSU KAN EO RI OWO TIO TO
FIVE HUNDRED THOUSAND NAIRA GBAA TABI KIO TUN JU BE LO..
# AKIYESI_PATAKI - BIA BARI ENIKENI TIO SE ISE YI - TIKO BARI OHUNKOHUN - KI IRU
EYIN ENIYAN BE TIMO DAJU PE - ORO IGBESI-AIYE ARA YIN TI KOJA BIE SE NFI OJU WO
OOOOO - KI IRU EYIN ENIYAN BE GBINYANJU LATI KAN SI EMI WOLY TUNMISE ASE KIKI
ORO-ORO KIKI ASE FUN IJINLE ISTHARA LORI ORO IGBESI-AIYE ARA YIN - KIE LE FI MO
NUKAN TIO KAN LORI ORO IGBESI-AIYE ARA YIN TI YIO FIRI BIE SE NFE - TORI OHUN TI
NDOJUKO AWA ENIYAN NINU AIYE YI NUKAN OTOTO NI TIKO PA PO IDI NIYI TI AWON
OYINBO ALAWO FUNFUN FI SO BAI PE ( ONE MAN FOOD - IS ANOTHER MAN POISON ) AMON ENITI KOBA LO KI NDE - IGBIYANJU ENIYAN LO MA NPADA JEKI AYANMO WASI
IMUSE NINU AIYE EDA - MA TI TORI PE O SE AWON ISE KAN TIKO JE FUN E - KIO TITORI E
SOPE KOSI OHUN TI NJE ANJO HUMMMMMMM WALAHI YATOSI AWON NUKAN TIA NFI
SITA SORI AFEFE YI - ANJO GIDI WA TIKO NI TABI SUGBON NI INU.. BUT E LOSE ISE ELEYI
NA - TESTED CONFIRM NI.
# ISE_NA_NIYI
EO LO, IYE IGUN META, IYE ALUKO META, IYE OSIN META, IKO-IDE META, PELU ILEKE
ITUN ATI IFA EYO META, ATI FIVE HUNDRED NAIRA TUNTUN KAN - EO FI RDE MAKER - YI
ODO META SIBITI WON KO 500 HUNDRED NAIRA SI YEN TIYIO FIDI FIVE HUNDRED
THOUSAND NAIRA - EO LO AWON NUKAN YI NI OTOTO LORI OLO TI YIO DI POWDER.. EO
KA PAMO.
EO WA EWE SAN-OWO-MIH-FUN OOJO, EWE AJE SEFUNSEFUN OOJO, EWE TANAPOWO
OOJO. EO LO AWON EWE YI NI OTOTO PELU EYO ATA-IJOSI MESAN, ATARE MESAN,
IYERE MESAN, - EO FI SE ASEJE LEPO NIYO PELU ODINDI OKAN MALU TIKO WO OMI
RARA TIS KESI ONA MEWA, TABI KIE LO ERAN ELEDE TIA GESI ONA MEWA TIYIO TOBI
DAA DA, - TIO BA JINA TAN EO SO SORI OSUKA KAN.. EO GBE WOLE..
# ILANA -JIJE-RE - TIO BA DINNI DEDE AGO MEJILA ORU TABI AGO MESAN ALE - EO BORA
SI IHOHO OMO LUA BI - EO FI IYERE-OSUN TE SIGN OGUNDA-BEDE - SI ORI OWO FIVE
HUNDRED NAIRA TUNTUN KAN - EO MIX AWON IYE ATI NUKAN TIE LO SIWAJU YEN MO
IYERE-OSUN TI EO FITE SIGN OGUNDABEDE.. EO WA PE AYAJO ISALE YI SI. .
# AYAJO_RE - IBA OOO 3X AWON AGBA BO WON NI OMO ARAYE BE ALARA NI ISE OMO
ARAYE SAN OWO ALARA FUN ALARA 3X, ARAYE BE AJERO NI ISE - WON SAN OWO
AJERO FUN AJERO 3X, ARAYE BE ARESA NI ISE - WON SAN OWO ARESA FUN ARESA NJE BIO BASE BISE TEMI WOLY TUNMISE - GBOGBO EYIN OMO ARAYE LOKUNRIN,
LOBINRIN, LOMODE, ATI LAGBA - E YARA WA SAN OWO NLA NLA TEMI FUN MIH.. EWE
SAN OWO MI FUN MIH - LONI KIE BERE SINNI SAN OWO TEMI FUN MI NI KIA KIA, TORI
OJUMO KI NMO KI EWE AJE SEFUNSEFUN MA SAI SE EFUN AJE TIE - NJE NIDI ISE BAI BAI
( EO DARUKO BISNESS TABI OJA TIE NTA ) TI EMI WOLY TUNMISE NSE YI - KI GBOGBO
EYIN OMI ENIYAN YARA MU OWO NLA NLA WA FUN MIH - TORI IYE AGBE NI NGBE IRE
FUN AGBE, IYE ALUKO LO NPE IRE FUN ALUKO, IKOIDE NI NKO IRE GBOGBO FUN
ONIWO.. LATI ASIKO YI LO - KI IYE AGBE GBERE KOMI, IYE ALUKO KIO GBE IRE KOMI,
TORI OJUMO KI NMON KI EWE TANAPOWO MA TAN PE AJE TIE - LOJUMO TIO MO YI LATI
ASIKO YI LO KI NBERE SINNI RI TAJESE KI NRI OWO TIO TO OWO - GBAA LODO
TOKUNRIN, TOBINRIN OMO ARAYE - TORI ODINDIN NI OKAN MALU NDURO.. ODINDI OWO
NIKI ARAYE FI MA BEMI NI ISE... ( LASE EDUNMARE OBA OKE ) - EO WA DA NUKAN YI
SINU ASEJE YEN.. EO KOJE .
EO WA BERE SINI JE ASEJE YI TITI TIYIO FITAN - TIE BA JE TAN EO MU MAHU KEKERE
KAN LE LORI..
FUN ODINDI OJO MEWA - ENIYAN TIO BAJE ISE YI KO GBODO BA OBINRIN SUN (SEX)
BIBEKO ODO IRU OBINRIN BE NI ISE YI YIO TILO MA SE ISE YI..
MOFI OLORUN JERI SI ISE YI - TORI KI NSE ISE ORI FACEBOOK OOOOOOO - KODA KOYE
FI NFI SORI FACEBOOK BAI HUMMMMMMM.... AMON NITORI ORO AWON BABA WA OJONU
ANA TIO WI BAI PE - AO KI NJUBA - ENIYAN TIO FI OGBON SINU KU).. TORI PUPO NINU
OGBON TIO GBON NI YIO PADA KU.. LOJO TO ONU NA BAKU...
(25)
OLUGBOHUN TODAJU;
odidi oga aiye, kenken tiwon fiwe oku,
egbo
akerejupon, omi iwe oku. aogun kenken
mo
egbo akerejupon aopo mose aofi omi iwe
po ose na,aoko si enu oga aiye na, aowa
bomole fun bi 1hrs, oga na yio tiku, aofi
igi ko ose na jade lenu oga na, aogbodo fi
owo ko ose na ooo, aoko sinu iwo etu,
aofi aso waji bo ose na, aowa fi aso pupa
bo lori! aoda epo pupa lori Olugbohun yi,
aogbe pamo sinu odo fun ojo meje,
aogbodo fi ahon kan olugbohun yi, aoma
fi se adura ati epe, asi lie fi bere ohun tia
bafe.
NOTE :
olugbohun la pe kii se afose lasan o, ko wa ninu ile eo gbudo sepe ninu ile naa toripe tike ni yio
mo eniyen
Lati OWO OMO yin woli Ade Eri 09061188299
Download