IWE ASIRI EWE ATI EGBO AWON IWE EGBE EWE NJE (BEN) TI O WA NI TITA BAYI 1. ASIRI EWE ATI EGBO VOL 1 N5500 2. ASIRI EWE ATI EGBO VOL 2 N6000 3. ASIRI EWE ATI EGBO VOL 3 N 5000 4. ASIRI EWE ATI EGBO VOL 4 N7500 ASIRI EWE ATI EGBO VOLUME ONE Asiri ewe ati egbo volume one, iwe yii je akoko iwe ti egbe ewe nje ben koko se ti asi se awon eto Oshole, Awure, Aworo, Awon unkan Agbara, Aseta, agbelepota etc fun ibere lori re ki epe Number yii 07037422552 Hardcopy and PDF format ELEYI NI AWON AKOLE AWON OGUN TOWA NINU IWE WA VOLUME ONE 1. OSOLE NLA LATI DI OLORO TOMOTOMO 2. AWURE IYALODE 3. IMUNLE AWON AJE 4. EBE AWON AGBA 5. EYONU AWON AGBA ELEYE 6. HANTU RISIQU 7. AWON OWO KIAKIA 8. OSE ASINA OWO 9. OSOLE OWO NLA 10. OSOLE GBAYERI 1 11. ONDE ELEGBE ANASARE 12. BANTE IBON TI ABATUNSIN OJU RE HAN ENIA O TUN MAA NGBE ENIA SUBU 13. ISORA TOTUN SISE AKOYE 14. MALU 15. FIFI EJO SO ILE 16. TI WON BA DI MO WA INA YIO GBE ENI NAA 17. ORUKA AGBARA 18. BANTE IBON 19. OWO TO GBONA 20. ALUWO 21. TI WON BA LUWA NI OGUN KONI SISE 22. APAJI 23. OHUN ASASI 24. TI ABA FE GBE OTA FUN AWON AGBA 25. OGUN EMI GIGUN 26. ERO EGBO ADAJINA 27. AFORAN AGBAIYE 28. IWOSAN IKO ASTHMA 29. ALEKO GIDI 30. TIDIJO 31. OSHO GBARIYE 2 32. OBA OSOLE TIA FI NDI OLOWO NLA LAYE 33. ISIJU TODAJU 34. OLUGBOHUN GBELEFOHUN 35. OSOLE OWO TUTU 36.IMUNLE LATI MABA AWON ELEYE FUNFUN SORO LOJU KOJU 37. ALUWO TODAJU 38. IBON TODAJU 39. OGUN OWO TODAJU 40. ASETA TI AMA NRAN OTA SORUN 41. ILAYA TODAJU 42. ORUKA IJA ALUWO 43. AFERI TODAJU 44. AFOSE TI AMA NLO LOJU IJA 45. AFORAN TODAJU 2 46. OLUGBOHUN TODAJU 47. ATUMO TODAJU 48. ILAYA TODAJU 2 49. GBETU GBETU 50. TI AWON OTA BA KAWA MOLE TI WON A MAA RI UNKAN MIRAN YATO SI WA 51. AKIRA 52. ORUKA PERUDA 53. OGUN AYE TI NPASE EMI 54. AKOYA NLA 55. IBANTE GBETU GBETU 56. ASO OGUN TODAJU 57. SIGIDI APE 58. AWOGBA ARUN 59. IWOSAN WARAPA 1 60. AGUNMUN IWOSAN WARAPA 61. PIPO WARAPA SILE TODAJU 62. IWOSAN STROKE 63. AGBO IWOSAN STROKE 64. IWOSAN EDA IDUBULE ATI ORO 65. OSE EDA TODAJU 66. ASEJE EDA 67. EYONU TI NSO OTA DI ORE 68. EYONU ABEGBEPE 69. EYONU ASEFIJIN 70. EYONU NLA 71. IRIN AJO EMI 72. ATONA ONI IGBALE TODAJU 73. ATONA ELEPON META 74. ASIRI ASINA FUN GBOGBO ISORO 75. TIRA ISEGUN OTA TODAJU 76. EYONU OLOJO MESAN 77. OSOLE OLOJO ALAMISI 78. AWURE OLOJO ALAMISI 79. ASEJE AWURE NLA 80. OSO OWO NLA 81. OSOLE AJESINU, 82. OSOLE AGBAIYE OLOSU MEFA 83. IWE ASINA TODAJU 84. OWO JIJI TI OWO KOBA JE OGUN MO 85. ASE TI AWON OMO ONI ISE INTERNET MAA NLO 86. ASE ORI PHONE 87. ASIRI TI A MAA NFI NPADE AWON ELEYE 88. OSOLE GBEWA, LORI ISE WAA TI KISI DERU BANI 89. AKESU TODAJU 90. IPESE TI A MAA NFI NGBA ASO AGBA 91. IPESE TI A NFI NDI OMO AGBA 92. AFOSE TODAJU 93. OGUN EDA 94. OGUN EDA 2 95. OGUN EDA 3 96. OGUN EDA 4 97. OGUN EDA 5 98. ASINA TODAJU PELU ETU RE 99. AWURE OBINRIN 100. AWURE OKUNRIN 101. ASEJE ADERA BI UNKAN BALE PUPO 102. IWOSAN STROKE 103. ISORA KI OWO AIYE MA KA WA 104. IPARA ATI OSE ITAJA 105. EYONU ASINA ONI IG E ADIE OPIPI 106. OSE ITAJA ATI KI ONISE OWO LE MA RISE 107. TI AWON OTA BAA NLERI OGUN SIWA 108. TI AWON OTA BAA NAA WA INA YIO SEYO LARA OTA NAA 109. OSOLE OLOWO OJOJUMO 110. ADODUN TODAJU 111. ASIRI TI AMA NFI NLE OTA KURO NILU Awon asirii yii lowa ninu iwe Asiri ewe ati egbo volume one ASIRI EWE ATI EGBO VOLUME TWO Iwe yii je ipele ikeji ninu iwe asiri ti egbe ewe nje ben se ni Odun 2017, awon asiri Ategun lo popupo ninu awon iwe yii, kini a npe ni ategun, asiri ategun je asiri ti a maa nse lati fi ran awon Agba ni ise, Asiri ategun ti mo nso yii je Ipese lorisirisi, Ipese Oshole, Ipese awure, Ipese ti ama nfi nran awon Agba nise si rere tabi ibi, Ipese akoya, ipese ti won baa gba unkan omokunrin,, ipese ti ama nfi ntoro aso agba lowo awon Agba, Aseje lorisi risi, Oshole ati bebe lo Hardcopy and PDF 07037422552 AWON ELEYI NI ASIRI TI O WAA NINU VOLUME TWO 1.ASEJE OLA Igbin nla togbo daadaa kan, a 2. ERO AKO IGBONA Igo oti jin to dobi daadaa ao fi 3. AFUNJE TODAJU Ori pepeye ati ese re mejeji, oka baba pupa ati f, 4. ASEJE OWO Odindi Okete nla kan ** ** ** ** OFO RE Aro abowo ro, Aro Abesero, Atara abedo gbinkin, ase ile (land) yi le wa lebi npa omo awo? Awasa walo wa ire temi wa funmi loni, yerepe walo pe won wa ni kia kia towo towo owo won, ejiogbe lo gbe won nidi dide, ki won gbe owo nla nla wa fun mi. Akiyesi Ale lao je obe yii sun, oru ago kan si meji lao gbe ipese tobada fun awon agba, Ao gbodo fo Egungun okete yen o 5. AROBI TODAJU Egusi Ato eyo kan, . 6. ASE TODAJU Ori oka togbo kan ao afi os. 7. ADODUN TODAJU Igbe eiyele towa lori ite re, ati ite re 8. LUKUDI OWO TODAJU Akuko adie funfun kan, eiy 9. "ASIRI OWO TODAJU" ao wa eyin adie ibile 16, odid 10. "ASEJE ASIRI BIBO" OKAN MALU TIKOWOMI, ao ge si 16, ewe atori, ewe oloyin, ewe ologi. 11. "OSE AWURE 12. ASIRI OWO" igbin apinnu kan, ao ju sinu ape, ao ko opolopo 13. "OSE AROBI TODAJU" AO wa igi ibepe ako, ae 14. "OSE ITAJA AWORO TODAJU" eje malufi eje malu ye po po dada, ao wa mafi we laro laro. Odaju 15. "ASEJE EYONU AWURE" EWE orn loni ki won fi ire gbogbo jinmi, oni ewe isaju loni kiwon se isa 16. ."ASIRI OWO OLOSE" ori oka meje, or Ofore ibusun oka ninsan oka, ibusun ere ninsan ere, agbe ki duro nibi kan dale, aluko ki duro nibi kan dosan, odidere kiroju at okun bo, ojumo kinmo ki eye okin moyo, eg 17. "EYONU AJABO LOWO OSO, AJE" epo iroko ati iresile iroko ati oje ara igi iroko, ao da oje iroko ye si 18. IMULE IFA OSA MEJI ELEYE" eiyele funfun kan, ao fi i owu, eye adan ati odiwo Di ese eiy 19. "ASEJE IKOLE" ni ye ninu odo, tobati gun tan, ao fi ose ko, ao se owo #5 sodo tabi #20 topo, gbogbo eni tobanbawa nibe, ao ma fun won ni owo ye, inu igba aje lao ko owo na si o, ao mafi we laro laro pelu gbolohun re. Ofore :- tente bi osu le, osupa mole oju rawo, moni mofe kole, won ni bawo ni ntise kole, moni lati kekere ni omo alakan timan nkole, ni sake odo moni oun kole temi, tente ni osule, osupa mole oju irawo moni mofe laya won ni boni ounse laya, moni ejigbede eiyele kinrin lapon, moni mofe bimo, won ni bawo ni ounse bimo, moni atoledole ni ti adan, ounbimo temi, moni mofe lowo, won ni bawo ni ounse lowo moni ojojumo ni igongo kawo tie lori akitan, moni mani owo temi, kise ile, aya, omo, owo wa mi wa leni ti ojo gbogbo. Ao mafi we laro laro "20. ASEJE AWURE" oku oga mefa . Ao fi iyere osun te ejiogbe si, ao pe oun re si. Ofore:- Orunmila loni odi yafere, moni odi yafere, orunmila ni odi ofere oni nibo ni ojumo tinmo wa si ile aiye, moni miomo ibi ti ojumo tinmo wa sile aiye, bi ojumo bamo orun nla ni, ki ire owo kola sodo temi loni, aba talagemo baba ni orisa oke ngba, ao wa da iyere osun yi si ti Oba ti tutu ao wa je. 21. "APAJI TODAJU" olyunbere aye kan, ao pa, ao wa ro agbado funfun si lati. 22. Osole jentegbe Ori inaki igbo kan, ao gbe sinu ape, ao wa du eje odidi aye eiye igun kan l 23. Ise yi je ise nla tojepe oma ntun igbesi aiye yan se Ejinrin tutu, adie abo toti bimo ri dudu, eyin adie ibile 16, atare odidi 16, ele, oti lo laro laro. 24. EYONU ASINA OWO TODAJU u ape tuntun, ao wa la inu penpeye ye, ao ko awon alangba ye si ninu ati odidi atare kan, ao ran pa pada, ao gbe sinu ape, ao ko ewe ajaobale tutu ati ewe orijin tutu bo lori mole, ao jo papo, ao mafi mu eko gbigbona pelu orii ati oyin. 25. ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA........... ao wa ewe tangiri oojo 16, aon 26. ASEJE OSOLE OLA TIA FIUN NI OWO NLA".......... .Ao wa ike maagbolohun tia bati pe gbolohun si tan, ao da sinu aseje yan ao waje...... OFORE......Asanpa Ola Wolu Loruko Tia npe Ifa3*, Aririn Ola Wolu Loruko Tia npe Esu Odara3*, Ako Ajo Alajo Laeda Eesu loruko tia npe Eyin iya mi osoronga3*, Gbaawole Loruko Tia Npe Owo3*, Gbao Tia Npe Owo Ikoko3*, Ifa je kiun ni owo ikoko lowo, Nitori wipe owo wewe lowo owo(hand), owo pitipiti lowo apo, Ifa je kiun ni owo pitipiti, Nitori wipe owo to gbinrin lowo ikoko, Ifa walo mu owo to gbinrin wa fun mi, Nitori Wipe 27. "OSO AWURE OWO"..... ursday Ati monday, ao mape gbolohun resi kia to we.......OFORE.......Ofe ni igun jebo, ofe ni akalamagbo joku, ofe ni lekeleke gun maalu wolu, oso ilu yi, aje ilu yi efi owo(money) owo(hand) yin jin min, Atile ati ona lafiunji olongbo, oso ilu yi, Aje ilu yi, efi ira ru, ao wa se adua si, ao lofi we 28. OSE ASINA AWON AGBA TI ONA BADI, TI AO RI OWO NA........udu pomo Ose, ao mafi omi gbigbona we laro laaro(odaju) 29. OBE EYONU AWON AGBA TODAJU Eran ewu OFORE : - Moba eleye mule nigbo olusere, moba eleye mule nigbo olusekuse, moba eleye mule nigbo ori apata sarasa, orugborugbo loruko eleye bowale, eleye nijasa 3*, emina nijasa 3*, moba gbogbo eleye mule Loni, akiba eleye mule kodani 3*, emi Na koje dayin , idobale OMO eniyan kibi olu alale ninu, eleye keberi o, eleye ganbari o, eleye tapa o, eleye geesi o, eleye juu o, eleye larubawa o,eleye gbogbo agbaye o, mopeyin kie WA bami re layemi o, kie WA sina aje nlanla fun mi lode aye, kie sina OMO Bibi fun mi lode aye, ki nko Ile pipo lode aye, ki NRA motor pipo lode aye, ki gbogbo oro mi a 30. IMULE AWON AGBA ( ALFA NISE ODUN KEWA LAOTUN TOLESE TIABA FE TUNSE ADUA YIO GBA, CLEAR FUN ENITI ABA MOPE YIO MO OORE odo je eyin abo mo bi aba tise OGUN yi tan, ako si gbodi sunmo obinrin fun ojo mesan, bi ao bafun eyan ni idi ofo yi agbodo la epo pupa die ao si tun kan d oju window ( ferese) kia tolepe ofore. OFORE : - Ayini kitikiti ni oruko TI anpe iku 3*, olokiti KALE loruko yi anpe arun 3*, ago fere moni laya Logan Jo oru loruko TI anpe iwo apeta 3*, afefe 31. APAJI TI EMI FI NGUN DI ASIKO TOBA WUWA LATI KU ate, tewe tegbo gbego OFORE : - Ibiti won ni gbegbe magbe ibe ni ngbe 3*, ibi wo kan bo enure ao wa we ni owu dudu ati funfun iyan. ERORE : 32. AFOSE TI AFI NPASE FUNYAN LATISE NTA FE FUN WA Ewe ina, ewe OFORE : - Atare ni fohun aye, konko ni fohun aro, opolo nikan ni fohun ake rorun, abere tojadi dofo, ojo ti aba lu agogo lode aye ni won ngbo lode orun, ao so nkan ti afe si. 33. ASEJE ILE KIKO TABI MOTOR RIRA Ijapa kan, igbin apinnu meta, alakan meta, ao gun kunma, ao sa gbe ao ro sinu igo f 34. TUDE TODAJU Ewe tude egbo 35. ATIDIDIJO IBON TIDAJU (FUN OTARE KOYIN ). Ado ijamo ao GE ni ori ao da panti inure nu ao gb 36. OSOLE TODAJU Ewe ajeobale ewe orijin, po tepotepo, ao wa fi iderire de pada, ao gbe pamo fun ojo mesan kiato mowe, kahinkahin tuntun ni ao mafi we ni aro laro. OBERE TI AKOKOJE :. 37. ETO OLUGBOHUN TODAJU GAN AN KOSIYE MEJI NIBE. Ao lo wa iwo malu totobi ao fi ogede omini tode dada ao fi tele iwo naa, ao wa 38. OGUN OBINRIN TI WON NBASUN LOJU ORUN. Akeke kan,ikamudu ka 39. ASEJE OSOLE TODAJU Okete tutu, ao yo edo ati okan kuro, ao ge iy se ni agogo mejila oru, lepo ni yo, ao wo aso funfun ni ao wo se o 40. OGUN TI AFI NTA NKAN TODAJU Oju oro, osi bata, pakaro idi esu, pelu om 41. AJEGUN TODAJU Ese akuko, ewe 42. ELEYI NI ILEKE IFERAN TODAJU GAN Opepeye ao ju eyo atare kan si le 43. IMULE AGBA TODAJU GAN AN Isu ego, ao lo kunna, OFORE : - Akinsoro 3*, afobosoro 3*, ojo ti osa meji nti ikole orun bowasi ikole aye, obojuo, won ni awon ko ni fun eje omo tuntun mu surusuru, eni tobako laarin awon aje toba se ohun won yi awon yio gbarijo paje ni, eni toba fisu ego se eyele je, di omo osa meji , emi l omo l modi omo osa meji , ema dimi lowo ohun kohun , ema bami ja mo, moti fisu ego se eyele je modi omo osa meji .44. IPESE NLA Ikarahun igbin toti pe ninu igbo totobi daadaa, ao ko ewe LILO RE FUN AJANTUKA Ao ge eran malu si mejo, ao fi adin eyan din ao ko si inu a 45.FUN ONA RERE Ao ge eran m 46. IPESE ELEYE ARISIKI TODAJU Ao bu oju Olongbo si ile ti yio po gan, si owo otun ati owo osi, ao wa fi ig agbale la eko kan si meji, ao wa mun ti owo otun ao fi ko g LILO RE Ao wa eko elewe kan ao fi igbale pin si ona meji dede, ao fi igbale pin okokan si mejo mejo 47. IPESE ARISIKI Eran Elede, obi abata 48. IPESE IMUNLE ELEIYE Ao wa ibepe ti eiye jeku, ao jo pelu odindi atare kan ti ati yo 49. IPESE AKOYA TODAJU Ao din akara elepo kan to tobi daadaa, ao wa ri m OFO RE Obara afi eje we 3x Lagbaja omo lagaja lo sope eo le mun ohun, Eyin iyami osoromoniga , ki ejeki idamun bere sini ba L omo L lati oni lo Koma ri je mo, koma rimun mon, ki gbogbo u kan ini re bere sini baje, Owa di oni pantete 3x Ki oro L omo L bere sini su Omo araiye ki won ma gbo oro re ye mo, ki won bere sini ba ja, ki won ko ni ibi ise towa etc 50. AKOYA TODAJU 51.. IPESE AKOYA TODAJU Ao ra eran nomo die, ao ra edo na die, ao waa ipe 52. ERO FUN ENITI O SE IPESE YII Ao lo ra eko odindi kan ao fi ipepe ge si 16, ao gbe sinu awo sobi, 53. IPESE LATI BE AWON AGBA NISE Ti aba fe be awon agba si rere bi owo, omo, ao pa adie akuko funfun balau kan, tobaje ona aburu ni afe ran won si ao pa adie akuko pupa, ti aba fe dumbu adie yii ao wa pe ofo si lara ti aba tun pa tan ao tun pe ofo si, ao tu gbogbo iye ara re pata, ao wa ge orikerike ara re ao bo ko jina, ao kosi inu awo amon 54. IPESE LATI TORO UNKAN Ejo oga gbigbe kan, ati alakan gbigbe kan, ati od 55. IPESE LATI BE AWON AGBA NISE Bi aba fe be awon agba nise si rere bi owo, ao mun ekuru fu AGBESE RE ori ejo seb 56. IPESE FUN ARISIKI ATI AGBEGA Ao ra gbogbo ifun eran Malu, epo ao se lori ina lobe ao nifi ata si o,, ao fi iyo si asi tun le koko bo eran naa ki ato se lob 57. IPESE IGBEGA LENU ISE ao pa abo adie ao tu gbogbo iye re kuro, a 58. IPESE RIRISE NLA NLA KI AMA RI WALAH ATI IDAMUN ao pa akuko adie kan ao 59. IPESE ARIKI NLA NLA, ILOSIWAJU RIRISE okete oye kan ao pa, ao gesi ona 16, ao k 60. AGBESE IPESE ELEYE Ewe rinrin, ewe akoko, odindi atare kan ao 61. AGBESE IPESE ELEIYE Ewe koropo, odindi eiye k Ti oba kan wa lowo tabi ti aba te mole ti aba lofi gbe ipese yen si ita, oluware ti fi arare se ipese fun eleiye ni yen o... 62. IPESE FUN RIRISE, IGBEGA Awo sobi nla kan, gari, epo, okete gbigbe kan, ao ge ori ati iru AGBESE RE Iyere osun lao fi te ifa ejiogbe lapa otun osa m 63. LATI BE AWON AGBA NISE Ti aba fe ki eleye fi iya je enia, ao wa egungun konko, egungun 64. TI ABA FE KI WON KO AJE NINU EGBE Ao se rice ao ge edo eran si mesan ni kekeke, ao se pa AGBESE RE ile eiye alapanded ao ma 65. BI AWON AGBA BA GBA OKO ENIA TI KO LE DAADAA MO Ogede omini 9, obi abata oloju merin 9, orogbo 9, okini 9, eyo owo 9 ti o 66. IPESE RIRISE Eran Elede tutu, eko meta, epo pupa, 67. IPESE TI A NFI NMO BOYA ALAISAN YIO KU TABI KONI KU Ori Okete gbigbe kan, odindi atare kan ao jopo, ao fi ekuru funfun se ipese ao ma bu etu yi si 68. OGUN AWURE AWON AGBA TODAJU, epo obo, epo igi nla, ewe ajeobale, ewe orijin, ewe kilofimise, ewe owu akese, ileke itun, ileke ifa, eso abere, agun gbogbo re papo, ao fi omi agbon Kan ni ise yi wa fun oo, akibu fun Yan ooo, eewo ni. 69. OSE ARINA FUN ENITI AISAN NSE KOLE MON ENITI NDA LAMUN, eso rerinkomi pupo, eresile ewe oparun, epo obo, 70. OGUN BI ATINSE FI ARA MON AWON AGBA TO DAJU GIDIGIDI, ako eye ega Kan, i 71. OSOLE NLA" eku asin gbigbe mewa, odidi oga gbigbe tope mewa, odidi opolo gb N. B :- siwaju katose ogun yi laro taba fe jo, ao koko gbele si enu ona yara wa, ao ri ako alangba kan mole, ao da iyo isebe si lori, ao da yepe Bo mole 72. "OSOLE NLA " ewe adagudu, efun ado tabi imin osunmare, ori eye osin kan, aso od 73. "OSE ABO OSOLE " Egbo isirigun, Egbo akogun, epo obo die, ora ara malu funfun, ao gun papo, ao 73. OSOLE NLA" odidi olongbo ehanna kan, ao PA sinu ape, eye igun toni ifun 74. "OSOLE NLA " OKAN aja, egbo ire, eg 75. "OSOLE NLA " Ako alangba kan, ega ako kan, odidi atare kan, ao jo papo, ao ro sinu ado 76. OSOLE NLA" odidi eye igun tonifun kan, ileke iyu 77. "OSOLE NLA " Ori okere kan, ori owawa kan tonirun, ori ikun kan, ori owiw 78. "OSOLE AFERO " ori inaki igbo kan tope dada, odidi oga gbigbe kan, ewe atare, ogede ominmin mej 79. AWORO EYONU omonile kan, ewe botuje ojo meta, ikode kan, ororo goya ati olive oil igo kan ati bintu igo meta, epo obo die. Sise re :-ao gun epo obo MO ikode ye, 80. AWORO RIRI MOLE Ogede ominmin 16, odidi atare 16, obi ipa oloju merin 16,obi ifin oloju 81. AWORO NLA ako olongbo nla kan, igo adii kan, igo epo pupa kan, akara elepo 201, ida 82. IPESE RIRISE OJU RERE AWON ELEIYE Omunu ewe akoko, ao wa ti yio po ao sa kofi gbe daadaa, ao 83. IPESE ELEYE ASIKI OWO ao lo si odo awon ti won nta eran ao fi owo da oni iye ti apa waa ba ka ao so fun won wipe ki won ge ibe ao bere elo ni won 84. ASINA IMULE AWON AGBA" kowe dudu kan, ewe ewuro ojoo, iyo didi ta, atare odidi kan, ao da iyo ye tele inu ape, ao fi iyo ye te ejiogbe ninu ape, ao wa gbe eye kowe "85. EYONU TI ONMU OWO WA TARA . 86. "OSOLE TAFINGBE NKAN RERE SE" oromodie mewa, isu emina nla kan, isu esuru pupa nla kan, igi nla topo, aso awon agba iyekiye, odidi atare nla kan, ao jo gbogbo re papo, ao wa da sinu igba olomori, ao niki Eni tase fun kofipo ose nibe, tobajepe awa na lani awa Lao fipo ose, ao du eje obuko eran AKIESI :-ti obatiku ojo merin ti ao se 87. AKESU " ifun oga aye, ifun ijapa, ifun lili aye, igi nla, oju osi eliri, aso awon agba 16, ao jo po, ao ro sinu ado ide, ao fi aso awon agba iyekiye 88. IPESE AKOYA TODAJU Ao lo ra ekuru funfun ao fi igi run daadaa, sinu awo sobi ao fi epo obo se agbese re, ao wa ba soro wipe, 89. IPESE AKOYA Akiyesi Ao bo asamo egun yen ni ao kosi inu sobi ao ta adin le lori ao wa da awon ohun to ku le lori pelu iru woro. Ao wa so wipe ki ota na ma run larin awon awujo 90. IPESE ARISIKI JIJE MIMUN 91. IPESE TI AMA NFI NBE AWON AGBA NI ISE 92. ETU AGBESE 93. ETUTU GBOGBONISE 94. AGBESE ao ma fi se ipese number 95 95. Isu ewura funfun, ao sun isu yii ninu ina ao wa run wewe sinu awo sobi ao fi epo pupa die si aw waa bu etu number 94 si ao gbe 96. "EYONU ANU" 97. "OSE EYONU " "98. OSE EYONU" "99. ETU EYONU ANU " 100. ATUDE ASINA OWO KIAKIA 101. ATUDE AWEBI DANU TO DAJU Gbogbo asiri yii lowa ninu Iwe Asiri Ewe ati Egbo Volume Two, tibogbo re si daju giidi ASIRI EWE ATI EGBO VOLUME 3 Asiri ewe ati egbo yii je ipele iketa ti o jade ni October 12 2017, Awon asiri ti o waa ni inu iwe yii je asiri iwosan arun ara, Olohun koni fi arun kan gbogbo waa, arun ti kogbo ogun koni je ti gbogbo waa, awon iwosan bi Stroke, Hypertension, Staph, Flusher for all dieses, Iwosan Atosi olojo pipe. PDF format only 07037422552 ASIRI EWE ATI EGBO VOLUME FOUR Asiri Ewe ati egbo volume four je ipele elekerin ti egbe ewe nje se ni inu osu March 2018, Iwe yii kun fun opolopo Imunle, Oshole gidi, Afose, Olugbohun lorisirisi, Orisi Olugbohun merin lowa ni ibe, ase eto yii pelu bi ase le lo Olugbohun yii pelu osole ti o waa ni ibe, Olugbohun yii a maa nfi npase fun Oshole ni, ti aba le ri okan se ninu Olugbohun yii, ti asi se Oshole kan ni ibe, lehin igba naa ao gbe Etu Ogun Oshole naa ti Olugbohun yii egbe ninu apoti iroko ao waa maa pase fun wipe lasiko ti a nba nlo oshole yii ki nse awon unkan bayi bayi boya ile ni tabi motor, ao sebe fun ojo meje ki ato maa lo Etu Ogun naa, bi ogo baa nje Tolohun gbogbo ase ti a paa fun ni yio maa semo wa lara. Iwe yii waa ni PDF format only