Uploaded by kyekini

IWE AKONI MEJE

advertisement
OSHO EYONU BURUKU
ELO GET IGUN OOYE KAN
ELO GET ORI OKA TOLASE - 3
ELO GET ORI ERE TOLASE - 3
ELO GET ORI MONAMONA- 3
ELO GET ESTATE - 3
ELO GET ORI OONI- 1
ELO GET ERAN OOTOTO LAMI META
ELO GET EGBO AKEREJUPON OOJO
ELO GET ODO AGUNTAN KAN
ELO GET ADO ATO KAN
ELO GET OBI OLOJU META - 1
#SISERE_ AO DUN IGUN YEN - SINU APE -TUNTUN- AOGBE OHUN NA SI- AOKO
ORI OKA SI- ORI ERE SI- ORI MONAMONA SI- ORI OONI SI- AOKO ERAN __ SI AOKO EGBO AKEREJUPON SI- #AKIYESI_ ((( IBI TI ABATIWU- AKEREJUPON- AOFI
OBI OLOJU META KAN SI OJU IBE )))
AOJO PELU- ESTATE - META - AOLO EBU NA - AORO SINU ADO ATO - AOPA EJE ODO AGUNTAN SI LARA - AOFI ERAN NA SE SAARA
LILORE:- AO JU ORII SINU EKO GBIGBONA LARO - AO MA EBU DIE DIE SI - AO
MA MU NI ARARO
ELE AKOYA ORI FIFO
ORI EGUN AJA DIE - ORI EGUN OWAWA DIE - AOLO PAPO - AOFI TE IFA IRU EKUNAO DA SINU EFE OWU - AOFI OWU DUDU ATI FUNFUN WE - AOPE OHUN RE SI - AO
WA GBE OKUTA LE MOLE - WALAHI ORI YIO BEERE SINI FO ORI ELEDA TI APE
ORUKO RE SINU GBOLOHUN RE -
GBOLOHUN RE :- BI AJA BA GBO ORI AMA FO AJA - IWO L OMO L NI ORI FO BAYI
O- BI OWAWA BAKE - ORUN RE YIO WOLE - L OMO L IWO NI ORUN RE WOLE BAYI
OOOO - AO WA GBE OKUTA LE IKOBEERE NA LORI
AGBARA SANGO FUN ASETA
ELO GET IGO NLA META
ELO GET EGBO OSEPOTU OOJO
ELO GET OGA OOYE KAN
ELO GET OTIN OGOGORO
ELO GET ASO PUPA TINRIN DIE
#SISERE_ AO WA IGO- TOJE WIPE - OWO LEWO INU RE - AO LO JA - EWE
OSEPOTU KOPO DAADAA- AO WA FI OBE GE - EGBO IDI RE - AO FI OMI - ( WATER) SAN EGBO NA DAADAA- AO KO EGBO NA SINU - IGO YEN- AO GBE OGA SINU RE AO WA MU ASO PUPA TIRIN DIE - AOSO MO ORUN APA WA OSI- AO WA BU SHIRNAP
SINU IGO - YEN- #NOTE_ LESEKESE AO SARE SUMO EYIN- DIE - SANGO YIO FO
IGO YEN DANU- AO TUN SARE MU OGA YEN- AOJU SINU IGO - MIRAN AOTUN KO
EGBO YEN SI- AOTUN BU SHIRNAP SI- AOTUN SUN SEYIN DIE - #SANGO_ YIO TUN
FO IGO NA DANU- AO TUN SARE MU OGA YEN AO GBE SINU IGO MIRAN- AOKO
EGBO YEN SI - AO TUN BU SHIRNAP SI- AO SUN SEYIN DIE- TI IGO YEN KOBA TI FO
MOAOGBE IGO NA WOLE - WALAHI- OBA - ISE - #AKONI_ NI OOO
LILORE:- AO MA MU OTIN YEN DIE DIE NI ARARO NIGBAKUGBA - ATUN MA BU
OTIN MIRAN SI - AKIYESI- ERI WIPE OSHA YIO MA KE NINU IGO YEN
ASEJE IMULE ALASARO
ELO GET AKO ISU
ELO GET ISU EWURA
ELO GET ISU KOKO
ELO GET ISASUN TUNTUN
ELO GET IYERE - DIE
ELO GET IYO -( SALT)
ELO GET OMI - ( WATER)
ELO GET EPO PUPA
ELO GET IYERE OSUN - DIE
#SISERE_ AO BE AWON ISU YEN- AO DA WON SINU-ISASUN -AOLO IYERE - DIE AO DA LE LORI - AO BU OMI - (WATER) SI- ATI IYO- (SALT) SI- AO GBE- KANA - TI
OBA TI JINA TAN- AO DA EPO PUPA - ( PALM OIL) SI- AO RO PAPO - LASARO - AO GBE
ASARO NA - SORI IBIKAN-KOBUDO KANLE OOOAO FI IYERE OSUN - TE - OSA ELEYE
0 0 0 0
0
0
0
0
0
0
AO PE#PSALM_RE_
AROLOMI- 3*
AJIFAMOLA- 3*
NDANDABIRI SE ESE MEJEJI YEBEYEBE
AREMO AFIOJU KO OWO OLOWO
ENI ENI TI OBATI MO ORUKO EYIN AGBAGBA MERERIN ILU - ENI OJU OWO KONI
PON OLUWARE MO- OJU IRE GBOGBO KONI PON OLUWARE MO- EMI L OMO L - MO
ORUKO EYIN AGBAGBA MERERIN - EMA JEKI OJU OWO O PON MI - EMAJEKI OJU
IRE GBOGBO PON MI •
AROLOMI- LORUKO TAN PE IWO IFA- NI IJO TI OJU OWO NPON O- ISU KOKO LOJETI O FIDI OLOWO - EMI L OMO L - NA JE ISU KOKO KIN DI OLOWO •
AJIFAMOLA - LORUKO TI ANPE IWO ODU - NI IJO TI ARA NI O- ISU EWURA LOJE
KI ARA FI RO FUN O - PESE EMI L OMO L - NA JE ISU EWURA KI ARA ROMI PESE •
NDANDABIRI SE ESE MEJEJI YEBEYEBE - LORUKO TI ANPE IWO ESU ODARA- AKO
ISU LOJE LOFIDI OLOWO- LOFIDI OLOLA - LOFIDI ONI RE - GBOGBO EMI L OMO L NA JE AKO ISU - KIDI OLOWO- KIDI OLOLA- KIDI ONI RE GBOGBO•
AREMO AFIOJU KO OWO OLOWO - LORUKO TI ANPE EYIN IYAMOGUN AJE - EPO
LE MU- LEFIDI OLOWO - LEFIDI OLOLA - LEFIDI ONI RE GBOGBO- EMI L OMO L NA
MU EPO - KIDI OLOWO- KIDI OLOLA •
OSA MEJI- LONI KI EMA SA GBOGBO IRE AYE WA FUNMI •
AO DA IYERE OSUN NA SINU- ASARO NA- TI OBADI ARO OJO KEJI- KATO FOHUNAOKO JE
LILO AGBARA AIYE
OKAN ERAN AGU - ATI - ISU GBEGBE - PELU OKAN IJAKUMO- AOKO SINU- PANSA
IGBA - AOLO RIMO ORI ATAN- FUN OJO MEJE - KI OJO MEJE - TOPE ANIKI ALABOYUN LOYA - IGBE SORI IKANNTI ABO MOLE YEN- KI OJO MEJE TOPE - TI
OJO MEJE BAPE - AOLO WU - AOLO JO NI OJUGBO- TI ABA TI NJO LOWO- AWON
EYE GUNNUGUN YIO MA FO - WON YIO BA KALE - WON YIO YIRAPADA DI EYAN- TI
WON BATIDE ODO WA - AO MU DIE SINU EBU YEN - AO WA MALO - AWON AGBA YIO
GBE ELE TOKU - TI ABA TI DELE- TOBA DI OJO KEJI- AOFI EBU TI ABU YEN- AOFI
SINGBERE - LATI OKE ORI IDODO WA SI OOKAN AYA WA LOKE LILORE:- AOFI OWO TI AFI BU EBU YEN - AOGBELE ORI IGBEERE YEN- AOSI SO
OHUN KOHUN TOBA WUWA - HMMMM OTIDI OSHA TI OBA RI ISE YI SE
ORUKA ALUWO JAGUNJAGUN
ELO GET ANKEERE OOJO
ELO GET ORUKA DUDU META
ELO GET EFO EBOLO OOJO
ELO GET EWE ALURO OOJO
ELO GET ODIDI ESTATE KAN
ELO GET ORII DIE
ELO GET OWU DUDU
ELO GET OWU FUNFUN
#SISERE_ AO LO GBOGBO OMO ESTATE YEN SI IBI- KAN NA - AOLO EFO EBOLO OOJO - MO EWE ALURO OOJO- AOFI WON - KO ESTATE TI ALO YEN - DADA - AO KI
ORUKA META SINU RE - AO YI ROBO - AO LA ENU ANKEERE - OOJO AKO- SI ENU RE
- AOFI OWU DUDU- ATI FUNFUN WE DADA- AOLORIMO ORI ATAN - FUN OJO MEJE LEHIN AOFI IGI YO - ORUKA AO SA SABE ILE KOGBE LEHIN- AO KI BOWO- FIGBA EYAN - AOFI IKANKAN RA OWO-OOOOOO
#ERO_ AOKO EGUNGUN ANKEERE - TI ARIMOLE - YEN AOJOPO- AO MA TA SI ENI
NA LENU - YIO GBADUN
AGADAGODO OSEBELE
OROGBO KAN- OBI ABATA OLOJU META KAN- ODIDI ATARE KAN- AOKO SINU APE
- AOKO EWE AMUNIMUYE LE LORI- AOJO TOBA JOTAN- AO LORA AGADAGODO ONIGUN MARUN- AO WA DA EBU YEN SINU OWU AKESE - AO WA MU EMU
ALAGBEDE - AOFI EGBE RE LE - AO GBE EBU TOWA NINU OWU AKESE YEN LE AO JEKI IDI EMU ALAGBEDE- YEN YO SITA - AO WA FI OWU DUDU ATI FUNFUN WE
DADA
LILORE :- AOTE ASO PUPA KAN SILE - AOFI MU AGADAGODO YEN DANI- AOSOPE OSEBELE 3* AOFI ORI AKUKO KAN LEEMETA - AOSOPE ADIE RE RE OOO- KOWA
MU EJE ADIE YI LESEKESE OOO - AO WA GBE AGADAGODO YEN SORI ASO PUPA
YEN- AO WA MU ADIE AKUKO KAN DANI- AOKO ESE RE ATI IYERE SI SEYINAO GBE OKAN AYA ADIE YEN LE - AGADAGODO YEN - AO JE ATARE LENU- AO BU
OTIN SENU- AOJE AO TUN SI AGADAGODO NA NILELE LORI ASO YEN- AO WA GBE
ADIE YEN LE
AO MA SOPE OFORE:SANGO KI KOHUN - OROGBO - IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- ORISHA KI
KOHUN OBI- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- EMU KI MURI TI LAGBEDE - EMU KI
KOHUN ALAGBEDE- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O- OWU DUDU ATI FUNFUN
KI JARAWON NIYAN- KI KOHUN ARA WON OOO- IWO ADIE YI OBUDO KOHUN MI O OSEBELE 3* ADIE RE RE - KOWA MU EJE ADIE YI LESEKESE BAYI BAYI - AOPE
OFORE NA SI - TITI YIO FI KU
JIJI ADIE PADA :AO GBE OKU ADIE YEN LE - AOSOPE - OSEBELE 3* TI OBA FE SE ORIBURU - TI
OBAFE SE ISE SE - JI ADIE YI PADA LESEKESE BAYI- TI OBA FE FISE SE OOOOO TOBA JI PADA MA FUN NI ADIE NA - OYA JI ADIE YI PADA BAYI - TI OBA TI JIN
PADA - AO WA PA FUN - ODI LILO NIYEN - OFO YEN NA NI AMA PE SI - TABA FE LO BAYI SANGO KI KOHUN - OROGBO - IWO L OMO L YI OBUDO KOHUN MI OORISHA KI KOHUN OBI- IWO L OMO L YI OBUDO KOHUN MI O- EMU KI MURI TI
LAGBEDE - EMU KI KOHUN ALAGBEDE- IWO L OMO L YI OBUDO KOHUN MI OOWU DUDU ATI FUNFUN KI JARAWON NIYAN- KI KOHUN ARA WON OOO- IWO L
OMO L YI OBUDO KOHUN MI O - AO WA TIPA
AKIYESI:- ABUDO NI- IMULE LARA DAADAA OOO- AMO TABA RI WIPE - KOPA
ADIE NA LESEKESE - WIPE OKAN WEAK RE NI- AJE WIPE IMULE WA KOTO NIYENAO WA PA ADIE NA LE LORI BEEEE- AMO YIO WEAK ADIE NA SA - TAJA WIPE KONI
LE SALO MO- YIO TIMU NINU EJE RE DIE - TIKOBA WA KU - DAJUDAJU KOSI IMULE
LARA WA NIYEN- AO PA ADIE NA SI - AO TUN IYE ABIYA ATI- AYA RE SI LARA - AO
MA TOJU RE SINU ASO PUPA
Download