AGBARA AKONI ILE YORUBA LATI OWO ALAGBA OPEYEMI DANIEL (OPA FITILA) TEL;- 07080271083 EMAIL:-Opeyemikilani60@gmail.com AWON IWE WA TOWA NILE AGBARA IGBAANI SEASON 1 AGBARA IGBAANI SEASON 2 AKONI ODUA MAJEMU TITUN ASIRIAKONI AGBARA AKONI ILE YORUBA 7KEYS OF SUCCESS SEVEN BOOK OF MOSES KING SOLOMON BOOK IWE IRAWO WIWO ORO AKOSO Mo juba akoda aye, mo juba aseda aye, mo juba Olorun ton be ki aye toma be, mo juba Olorun ti yio si mawa nigbati aye koni simo Mo juba gbogbo ajunilo Mo juba gbogbo awon tiwon nbo leyin Mo se akojopo iwe yi fun iwulo gbogbo eda patapata, yala musulumi, chriteni,tabi elesin abalaye, AGBARA AKONI ILE YORUBA eyi ti o fi ara pamo, fun awon eda kan ti o si han si awon eda kan gbangba. Ni sise iwe yi mo Juba Iya Mi Ti o Se Oloko Mi Wasi Aye Eniti o funmi ni opolopo alaye nipa awon ohun ijinle ti o wa ninu iwe yii Gbogbo awon ohun ijinle ti awon agba ijohun finse agbara ti o dabi wipe oti di igbagbe, ni atu jade ninu iwe yi, ki olukuluku ki o gbiyanju kio lo ni tire ni Alakoko seminar yii. Gbogbo awon egbogi inu iwe yi lo daju sakasaka. Gege bi ati fi idi re mule ninu alakoko Ejowo gbogbo eda ti o ba fe dawole ise inu iwe agbra igbaani yii ejo e je kia se ni mimo, pelu okan kan soso, Lagbara Olorun ao nise aseti laye (AMIN). Lati owo ALAGBA OPA FITILA (Opeyemi Daniel Kilani) OLOTU AGBARA IGBAANI SOCIAL GROUP AKIYESI 1. Ti abafe we ose e mama jeki ama wo bata we 2. Gbogbo ogun ti aba nse ema jeko mawa ninu iyara ti atin ba obiri ni ajosepo 3.Ka jina si biba obirin lajo sepo lati eyin tabi ki obirin wani oke 4. Leyin ti aba ni ajosepo tan ao gbodo fi owo kan ogun kankan 5. Owo ti afin se ise ao gbodo fima finger obirin 6.Leyin ojo keta ti aba lajosepo tan aye wa funwa lati fowo kan ogun 7.Efi ojo meta tabi merin sile teba se ogun tan kie to sunmo obirin 8.Ki obirin oni isun eje, mase fowo kan isd wa tabi wo ibi ti anko ogun si 9.Olo ti abafinlo nkan eje ki ama fi ewe rinrin ati ewe safara pelu epin fo oju olo na nu 10. Ti aba njo any ise lowo ki ama so kio maba foo tio bati fo koni sise mo 11.Tia aba njo ise aje ki ama fi epo yi idi reka 12. Ti abanjo ogun lowo ki a ma fi epo obo si egbe aro idana wa 13.Ti aba nlo ise lowo ao gbodo mafi omo olo si lori ni igbati aba dawo duro 14. Kia ato dawo le ise kankan e je kia ma se aluwala, tabi kia ya omi si mimo ki afi san oju ati ese pelu owo wa. 15. Omi ti aba fi fo aso ao gbodo fi fo bata ese wa kokin jeki ise dahun 16. Ose ti obiri bafi weku nba ise je lara 17. Ao gbodo fi ose ti afi fo aso ku we AO MA BA IYOKU PADE NINU................... (1) ORUKA ALUWO Adaripon kan, ewe abo, ewe amunimuye, ewe ina pupa, ewe aluro, obutoyo, ati oruka irin iyekiye, ao la ikun adaripon yen, ao wako gbogbo nkan yen sinu ao lori mo isale aro (adogan) di ojo meje ti o badi ojo na ao lo ko oruka na ao wa kosi apete(purse) ti afi awo aworiwon se AKIYESI= ki ato lo yo oruka na ki ari wipe afi epo pupa pelu ori pa owo wa ERO RE: Ao fi epo pupa ati ori pa owo wa fipa oni tohun . (2) OGUN IJAKADI Ose dudu, alubosa elewe , irun eyin olongbo dudu, tiko ni awo kankan ju dudu lo oruka ogun meji 2, koro atare meje, ao wa gun po ao wasu rugudu ao fi oruka na bo ni arin, ao wa fi aso akisa di ao lofi ha palapolo iganna (ogiri alapa tio la enu sile) fun ojo meje , ao lo mu odi lilo. (3) OGUN TEAR GAS TODAJU Etu ibon gidi, ao teni eji ogbe ao fi ina si leyin ti abate ni odu na tan, ao fi oju gba efin re ao wa fi ogede omini ko eeru re je. (4) ASEGBE Ewe imi esu, alubosa elewe, iyo lopolopo ao jo papo ao da sinu epo pupa ao mala. (5) OGUN AKOYA TODAJU Alangba kekere tiko iti dagba rara, ao wala inu alangba na, ao wa na oruka gboro ao ko sinu alangba na, ao lo rimole fun ojo meje, ao lowu ao sa tiyio gbe ao mafisi owo Lilo re-- Ti enikeni bafe bawa ja, ti o ba ti lock aso wa, ao so sinu wipe, alangb nimi mio ni ifun oo kato ri iseju die enina yio subu lule. (iba baba mi Bashorun ademola ajirotutu) (6) SUBUSERE Ogede omiini kan, oruka irin kan, eyo atare 7, ao la inu ogede omini na ao ko oruka ati atare na sinu re ao fi okun dipo ao lori si ori akitan fun ojo meje gbako Leyin ojo keje odi lilo niyen odaju bi iku ema fiseka oooooooooo Ero – odi igba ti aba kuro nibe koto dide. (7) OKIGBE Ao pa opolo kan, eyo oruka 3, atare eyo atare meje, ao ko gbogbo resi enu opolo na ao bomo ori akitan fun ojo meje ao lowu toba tipe ojo meje ao wajo opolo na pelu atare na papo ao fi ebu na sin gbere si orikerike ara ao fi oruka yen si owo odaju. (8) Owo respect Ewe owo, ao fi eran ewure seje lepo niyo. (9) ITIRO AMUDO Ewe isaju, ori ako alangba, ao lopo mo koro itiro ao lopo ao da sinu ile itiro ao male soju Lilo- obiri ti aba like ao seju mo lemeta ao wa sese loba so nkan ti anfe. (10) ORUKA IJAKADI Ikamudu 7, kanhinkanhin 7, eyo atare 7, kuluso 7, ao jopo pelu oruka dudu ao ma fibu iyepe lu eniyan Ero re:_ ao sin gbere si atanpako ese otun wa ao fi ebu na pa pelu ese osi na ao po iyoku ebu na mo ori (sheabutter) ao fi ori pa enina lara ao wafi ese osi wa gbani ipa oma dide. (11) AGBAWO Eja ojiji, ewe ina, ewe ewuro,ao jopo moa tare odidi kan gbere yipo orun owo mejeji Eniti eba gba lese koni je eyokan toma fi salo. (12) ALUWO Ewe aluro, ayo atare meje, oruka kusanrin kan, opolo ooye kan a o la lati enu de isale ao lo ewe yiii pelu atare papo ao wa ko sinu opolo yi pelu oruka yi ao ri mole fun ojo meje odi lilo koni ero oooooo (12) ARUNKI Eja ojiji,oruka dudu 3, bara tutu ao ko oruka yen si eja ojiji na lenu ao wa gbe sinu bara na fun ojo meje Lilo- ki ato mu ao fi epo pupa pa owo wa ati kia to lo Ero- ti aba filu eniyan ti enina ba subu ao bu epo pupa si lenu yosi dide. (13) ORUKA MADOYIN (alupoyi) Egbo ako ibepe, oruka elelo, ao yin atare pupo sinu egbo na ao ko awon oruka na si fun ojo meje leyin ojo keje odi lilo Odaju gidi. (14) ANODOJUBOLE Opolo kan, odiidi atare kana o jopo ao fi singbere si orun owo mejeji (15) OGUN ANOYA Werepe ati odidi atare kan a o jopo ao fi sin gbere si orun owo wa mejeji. (16) OGUN IBON Ewe renren tutu, ao ko sinu igo oju olongbo 16, atare eyo 16, ao mamu lara ro fun ojo merinla (17) BOMB DEFENDER Agbon ibile ti o gbo dada tio jabo fun arare lori iyare Odidi atare kan , eyin tio jabo fun ara re jijopo ninu igbo ao fi sin gbere 3 right chest 3left back 3left chest 3 right back (18) ALUMALEGBE OWO Ao lo ewe aluro dada ati oru ka irin ki a la inu ogede omini a o ko si inu re ao lo ri mole fun ojo meje nibiti wontin dana aaro lojojumo fi ori ayan pa owo ki a to loo odaju. (19) AMUDO Ibiti obinrin na batosi ao bu iyo sibe ao fi gigise otun te mole ODAJU. (20) Asegbayi Ewe odundun, ao lo pelu iyere,irugba,ao fise igbin je niyo lepo. (21) OGUN KIKIMOLE Iromi 9, ao mamu eyo Kankan ni ale pelu okele akobu oka, ao ma gbemi ao mafi si inu okele akobu yen, nio ao ma gbemi ni eyo Kankan ni alale fun ojo mesan toba dini ojo kewa ao wa mu eyo kan pelu eyo atare kana o wa fi singbere kan si iwaju ori NB-Ti eniyan base se ise yii si ara ti eniyan bafe dimo wa ofurufu loma nimo koda onitoun ma subu nio. (22) ISE OMO YAHOO Ewe sinkinmini, photo oyinbo na ao lopo mo glass iwoju, ao wada, sinu oyin igan ao mafi ika arin la, a lee lo ogun yi fun eniti iyawo re basa kuro nile. (21) AWISE IGBA NKAN LOWO OYINBO Eso esisi, irun abe obirin, ase iru oga, eyo atare 9, fun okunrin 7 fun obirin ao lopo gbere yipo orun owo wa mejeji. (22) ADARIN TO JINNA (CUTLASS CUT) Eesan, ao jo papo ao pomo ose dudu ao mafi we lojojumo fun 21 days pelu kanhinkanhn ototo. (23) AWURA Eja ojiji, ao fi owo kan bi emeta tio ma shock wa , odidi atare kan, akisa ori akitan tio ti pee nibe daaada igi ti ikan tije dada ti ojepe ti abafi owo kan igi na ti igi na ma subu lule ao bu die nibe ao jopo gbere 3-3 si orikerike ara pelu yipo orun owo wa memeji, ti ogun yii bawa lara wa Ti aba nbinu lowo abi anja lowo ti won bafe diwa mu wipe kiamajamo abi tiwon fe lawa enikeni toba fowokanwa oma shock nio……… (24) OGUN ALEEBA Iromi oju omi, eyokan ao lopo mo eyo atare kana o loti yio fi kunna dada ao fi sin gbere eyo kan si ipako wa. (25) TIA BA FE LE ENIYAN NI MAGUN Ibepe kan ti o bo sile fun ara re, ao ge die nibe odidi atare ao jopo ao fifo eko tutu mu ni owuro oko ati iyawo ni yio lo ogun yio (enikeni ko gbodo ba iyawo wa sun mo tiwon ba danwo won mama mu omi tiwon mafi ku nio..) (26) OGUN AYETA Ao wa ewe renren eyokan, omo atare kan, ao lo papo ao fi sin gbere kan si iwaju ori. (27) COMMAND FUN IYAWO TI ANFE Ile agbon, ti o suru sinu ilea o lo ao pomo ose dudu ao wa kan omi olubotuje si ao ma fifo oko fiba obirin na sun…… (28) OGUN TIWON BA GBEWA NI NKAN. Esuru pupa, ao pani pansa ao bu adin sinu iho na ao waa depa ao walo gbe ile ni oritameta ao gbe sinu ile na ao pe gbolohun re si. Gbolohun;- suru-suru lan soro esuru -eniti o jimi ni nkan ki ara bere sini nii titi yio fi da nkan mi pada fun emi lagbaja omo lagba (ao wa da iyepe bo lori) AKIYESI- TOBA TI MU PADA AO LO HU NKAN TI ARIMOLE AMA JUSI INU OMI TUTU. (29) OGUN ISORA Eewe inabo, ata ijosi die,epo die, iyo die, ao lopo ao fise eiyele tia ge apa ati ori pelu ese re kuro ni aseje ni ona oye ti ohun wa. (30) AMUDO OLORUKA Ikarahun igbin kan, ao re oruka pelu ewe amunimuye ati efo ebolo sinu re fun ojo mesan leyin ojo kesan ao mafi di obirin mu lorun owo. (31) COMMAND FUN ANY OBIRIN Egbo ogbo, ewe amunimuye, ewe taba eyo kan pere ao kopo ao dini owu dudu ati funfun ao di ti ibi Kankan koni han sita rara ao ma gbe korun labe aso fi command obirin koda onsise bi amudo ema fi seka oooo (32) AGADAGODO ASEGBE Igori ahon aja Igori ahon agbo Irun ori odi Fere ohun pepeye Odidi atare kan Ogiri tio lanu ao ha ninu e pelu ita Aso waji Sise_ ao jo gbogbo awon eroja yi papo ao tu wada ebu na sinu aso waji miran ao wag be eyin padlock na le lori ao wa dipo lowu ff ati ddu GBOLOHUN- ala ti aja bala inu re longbe -boobo laguntan nwo -odi kinle lanu fohun -oro tobaba pepeye hahaha nifi nse -ogiri to lanu kinba onile rojo - ki lagbaja omo lagbaja male bami rojo Kankan loni. (33) AFUNJE OBIRIN Omonile kan, ekanna owo mejeji, ese mejeji, pelu irun ori ao mu die nibe irun abe die, ao ha atelese was i ewe ajenifian ao mu gbogbo re ao jopo ao fun ololufe waje. (34) AWEPE DANU Ewe oriji, ewe mafowokan omomi, ori ologbo, eyin ororo jijo papo ao pomo ose ao lofi we si ori akitan ni ale. (35) KI NKAN OMOKUNRIN LE TOBI Ewe ajeobale tutu, ao gunpo ose dudu ao fima fo oko wa wasi iwaju. (36) ASE Obi oloju 6, ao gunpo mo ewe omisinmisin gogoro ao sat i yio gbe dada ao wa sese tunlo ao teni ejiogbe ao mafi ba enu soro Gbolohun- obi alawe mefa kan kinje ara won niyan. (37) MALU TO LAGBARA Atare aja kan, ao yo gbogbo omo inu re ao ni jeki nkankan yo danu ninu re ao lowa ogede agbagba ao ge nibi ori koko tio timan somo ara igi ao ni ge ja oo ao bomo ogede die ao la ogede naninu ati eyin nibi ti o ti ma n wu yen ao lade isale ti yio wonu daaada ao da awon omo atare nasi ao wafi okun di dada ao gbe sinu ikoko ao se toba jinna ao bo ogede na je eyiti a ge nibi oriire yen ao sati yio gbe ao gbe sile Lilo- ti eniyan baluwa ao sofun onitohun wipe mio beo ko nami osi nami emi ko lo na o soponna lona o Ebola yio bo onitohun lesekese ERO- ebu ti o wanle nan i ao busi lenu tabi kia fi po ori kafi palara. (38) AFOSE Ao yo ahon ejo soro, ao wa eyo atare kana o lopo ti yio kunna dada ao fi sin gbere kansi ibiisale enu wa ao tola leyin ojo keta ti aba se tan. (39) AYETA Eso bom-bom 3, orogbo 3, eyin adie ibile ororo kan, odidi atare kana o jopo ao fi sin gbere lati iwaju ori wa losi ibadi wa (odaju). (40) KI BLADE MALE GEWA Ewe dagunro, pelu atare kan, ao jopo ao wa mu blade tuntun ao ko ebu yen si ori re ao waje ni enu……….