OGUN ISOYE OJU ORUN TOJINNA Eye alapandede kan , eja ojiji kan , atare odidi kan ati ewe iyeye ,ao Jo papo , aolokunna , amafi fo eko tutu mu ni ago 12 oru , lai ni ba enikankan soro tao fi sun pada OWO RESPECT Ao bu yepe agokan oru ati yepe agokan osan die aolo ma eyo koro atare meje afi sin gbere meje meje si egbe ikun mejeji ISOYE TOLAGBARA TODAJU Awa eye ologuro odidi kan Eye ibaka odidi kan Eye ega odidi kan Eye awoko odidi kan Eyin adie ibile mesan Atare nla odidi kan Aojo gbogbore papo , aro sinu igo funfun kan ama fi oyin gidi lo die die ni EKAN LOSU EYONU AWON AGBA TODA Awa ewe ewuro topo, ati orogbo meje , obi abata meje , ori okete kan , ati odidi atare kan , aojo papo , amafi foko tutu mu . ISOYE ONIGBERE TODAJU Awa ori awoko kan ati ori eye aparo kan , omoatare 221, aojopapo, ao fisin GBERE 221 si oriwa, aofi abuna ra , eyi tobaku aofi omi lo lale katosun ISOYE Ahan suratul thoha meje , aofo , ao Jo odidi Ako eye ega kan ati odidi atare nlakan , amata omi ihantuyisi tabanjolowo, tabajotan , aolokuna adasinu oyin gidi , amala larolaro katoba enikankan soro OGUN FUN OBINRIN TOBIMO, TIKOLOMI LOYAN aolo ewe etiponola mose amafiwe oyan na Aowa wa awo lili , aojo ohunnikan adasinu adin eyan ao mafipa oyan na Kojubahunlo ASEJE OLA , KAFIRI OWO TOTOWO SE ODUN Aowa igbin tobonu kan Eyin ibile kan Eja aro kan Ewe anu Ewe sikinrinmidin Ewe sawerepepe Ata ijosi eyo mewa Aose ni aseje Aoseni aro kutu laitije inkankan , aowo aso tuntun fije asejeyini LOLOHUN JEKI ILEWAOYA, KARAWAOYA , KASODUN AYO AMIN OGUN TIWONBAN FUNYAN NINKANJE LOJU ORUN , ABI ONJE FUNRARE Aowa kankan ti eniyan bafiweku taomani tolo ati odidi atare kan so wa Jo papo , ao lo tio kunna Dada , ao wa sin gbere yika orun afi ebu na ra OGUN FUN ENI TONMU OTIN , ABI WONFISE , TAFEJEKIO FISILE Awa ori eku asin ATI ikamudu Ao jo papo , awa da sinu otin fun Oni tohun , tobafile mu , pelu Ashe Olohun eledumare kotun mu otin Ma layere , ODAJU ooo Ohun ti afi mon ohun toba ruwa loju ori pepeye ikode kan atare odidi kan ama fi ikode ha ori pepeye lenu, ama fi sinu aso ff kekere pelu atare naa, aowa dini ikobere, ama pani awo ff, aoma daniyan ohun taba fesi, aoma fisi abe pillow wa, taba fe sun. OSHOLE TO CONFIRMED Ao lo wa akuko adie funfun kan ti ko lemoo Ao tu gbogbo iye ara re looye ao wa mu 9 pere ninu iye adie yen pelu iye igun 9 iye aluko 9 iye lekeleke 9 ao lowon papo ti yio kuna daada ao wapoo lose ao fi aso funfun te inu igba a ko ose naa si ao fi owo eyo 16 ati aje olokun to ho daada kan ao ko Lee lori aofaso yen boo ao fomori re de ao gbe pamo fun ojo meta. Lehin ojo keta lao bere sii we Lara aso funfun inu igba yen Lati maa yo kainkain fi maa we ose yi e pade mi ninu comment fun igbese to Ku. OGUN ISOYE OJU ORUN TOJINNA Eye alapandede kan , eja ojiji kan , atare odidi kan ati ewe iyeye ,ao Jo papo , aolokunna , amafi fo eko tutu mu ni ago 12 oru , lai ni ba enikankan soro tao fi sun pada ASEJE AWURE IFA IRETE MEJI YI KONA TUN FI LA JUBAYILO OWA FUN ONI SE OWO ATI FUN AWON OMO YAHOO KOSI FUN ENI TI KONI ISE TO N MU OWO WOLE LOWO RARA O Ewe Alugbonron (16), Igbin Togbonu kan (1), a o re si ona merindinlogun (16), Iru, Iyere, Epo, Iyo, a o see je. Ti o ba jina, a o fi Iyeresu te Ifa Irete meji, a o pe ofo yi si. Ao si je Obe naa. OFO RE-Ola wo nu Aiye 3* Agba ni ko ri lo lode 3* Igbin de o Awo Olasan meme re Ile Ife; O ba san meme ki o lo ko ire Ile Ife wa fun mi Nitoripe Ona gbonron ni TALUGBONRON, Alugbonron ki fi ori le ona ko SINA, Ifa mase je kin tase ire temi, ki ire temi mase tase mi, Ojo ti Igbin ba fi enu lele ni fi fa ile, Orunmila mase je ki ntase ire temi, Igbin Oke, Igbin Oko oju kan naa ni won npa nu mo si. Irete meji, mo ti wipe o ki njẹ Igbin, Oju lo kan mi ni mo fi se Igbin. Ki emi lagbaja ni Owo, ki n ni Omo, ki n ni ohun rere ti o wa ni Origun mererin Aiye yí opari owa da àníyàn si bi ose wu e aba yin lara mu pelu ase edumare MOFE KEMOPE OWO LAFI WA OWO.oro ise wa atupa kole ridi arare ni ola awon tansise lafi nmi ati ola eledua ire oo mama se ahun lati dupe boba se ise toribe abi lati san nkan ijegun okere opo FUN AWON eto asiri ati sise Gbewa ti onmu 900,000 de 21million bi oba senilo owo si ni aridaju si nbe tori awo tiba awo je eyan ti ba eyan je. ori whatsapp nikan ni anfani aridaju nbe 09022274942 whatsapp number nu) . Fun akeesu alajo towo idokowo re bere pelu 10,000 na nbe nile owo idokowo re pari si 100,000 firi 200,000. . FUN Ado atona pelu fun imo baba ijebu ati bet9ja pelu itosona ohun koun lori oro aye eni alfa woli babalawo ati eni toba nilo re. Ohmo awo wiwo ise pelu ati irinran ri ohun tofe sele ati isokun fa ati awon ise tojoju bi oso omo yahoo eyun owo lati gba owo kiakia ati dide client toni owo lowo ti asi san owo ki oto pe ojo merin si marun fun akoko gba owo ati asiri kasiri abi sise ise kise ekan simi lori WhatsApp 09022274942) Pdf file ojuda iwe asiri na wanile asiri ati imo nipa eda lokun sibe ati awon ise idan loni ranran pelu awon eto jankan jankan 7000#naira ni ati jije anfani dida rapo mo yara EWE NJE OGUN NBE NI WHATSAPP (What's app number 09022274942) kise ipe ELEDUA AMAGBA FUNWA, (NUMBER BABA IJEBU NBE NILE PELU ARO OSAN ATI IROLE PELU GHANA NBE NILE LOJOKOJO 200# ni fun tita re 2sure owo etutu gbigba re ekansimi labe aso kise ofe ni gbigba re boba nikanse ma message mi kosi kowa nibe pelu koje boseje ).ELEDUA AMA RANWA LOWO PELU ASE EDUMARE ASIRI WA AMABO PELU ASE ADEDA EWE NJE OGUN NBE o Ose Atude Ewe tude Egbo tude Irun ara Etu. Ao lopo, ao fi Ose ko ni iwe e nkan soso. ASEJE AWURE... Omi Okun Omi Osa Ekiri Eran Elede Nla Kan Ekiri Eran Malu Nla Kan Ewe Sawerepepe Oojo Ati Ata Ijosi Aseje Yi Dapupo Ni Ojo Aje(monday) Ao lowe si odo ton san dada. IFA AROBI Ao Fi Iyereosun Te Eji Ogbe Ofore;Baba Loruko Tanupe Iwo Ifa 3*,Osa Garajako Loruko Tanupe Iwo Esu Odara,ayigbiri Loruko Ti Anupe Iwo Obatala.Okunrin Ni Peri Mi Nibi Okankan Ejeji Ki Won Maba Osu Yilo.Ase Ase Ase Ose! Ao Da Etu Yi Si Enu Ao Fi Omi Sin. OOWO Ori ako alangba ao ko werenjeje 9/7 ao tun ko eyo atare 9/7 si ao wa gbe sinue ewe owo ao we lowu dudu ati funfun ao wa loran lawo ijimere… OHUNMO ISE WIWO TI KII TASE ANIYAN ONIBERE Ori Olongbo tonirun 1,Ori eiye owiwi,Ori ekute ile tiwanpa si oju ona,Ori eiye kaaro,Odindi atare 1,Aojopo ao lo kunna, aoro sinu ado kekere kan, aokoko fi fokomu fun Odindi ojo meje lera, ao sinmi fun, ao so ado yi mo aarin igun inu office ti a ti n da alejo lohun, ao ma lo lekookan leyin igba ti abatilo lemeje lera… ATUDE IJAKULE(PROMISE AND FAILED) Ao wa etu ibon original,imi ojo ati epo obo die, Ao gun papo, Ao fipo ose iwe emeta, tia bafe we lojo akoko, aofi epo pupa para, ojo elekeji Ao fi ori para, ojo eleketa Ao fi oyin para, tia bati we tan, Ao sun kankan tia fiwe nina, tabi kia sosi odo toun san… OGUN IPA Ao ra akuko adie kan ti o ba ti nko daradara, ti aba pa tan ao yo epon re sinu igo kan ao re ewe ewuro jije si inu igo naa, ao ro ilaji igo adi eyan si ,o di ojo keta ki ato lo, sibi meta lekan na tabi meji lemeji loju mo… AWORO Ewe rere abo die eru Alamo die. Ose dudu, ito(urine) ara eni lao fi gun papo,ao ma fi we tabi fifi wonle… MAYEHUN Obi olojumeta, olomuyinrin, (ewe ormisimisin) odidi atare kan…jijopo, ao kosinu efe owu, ao we lowu dudu ati funfun…. OFORE Obi olojumeta kiija arawon niyan, olomuyinrin kiipa ohun orisa da, owu dudu ati funfun kiija arawon niyan…ki L-O-L mase pa ohun mi da…. AWURE IFERAN Eyin ibile mefa, ewe sawerepepe, odindi ataare kan, iyo isebe die, ao jo papo.Fifokomu tabi ka maafi omi lo…. ARIRAN OUNJE Oromodiye kan, iye agbe kan loju otun, iye aluko loju osi, ikonde bo lori, ao jo po pelu odidi atare kan, gbenre meta lotun oju ati osi,orun owo mejeji ati ese mejeji… AKOYA TODAJU Adigboranku 3, ayoku ekolo,ewe aluro,igi koko, aolo papo, aopo mo ori ,ao ma fi pa nkan omokunrin wa ba iyawo wa oni sinna sun.. Obinrin to ba nse agbere la ma nfi ko ni eko, okunrin to ba ba iyawo wa ni ajosepo odanran niyen, titie ti ba niyen ooo… OGUN TI A FI N YO OJUKOKORO LARA OMO Oromodie ti o ku sinu Ago ,ao jo pelu odidi Atare kan, gberen kookan ni isale oju. Opo eniyan le loo… OSOLE TODAJU FUN CONNECTION TABI FUN CONTRACT OMO YAHOO NASILELO LAI SEWU Oga aaye,Aso egungun die ati #1,000, Igbo mimu,Ewe ela. Ao fi owo #1,000 si aso egungun(ao fi tele). Ao tun wa fi igbo, ewe ela, ati biscuits okin die,ati atare odidi kan sori aso egungun naa, ao waa di gbogbo re papo. Ao waa kii si enu oga naa. Ao waa joo. Ao maa fi oti SEAMAN SCHNAPP lo lararo. ASINA AJE ISE YI SISE TE BA RISE NI KIAKIA NI OOO, OSO TO SARE MU OWO WA FUN NI LAIRO TELE NI. IRU WORO TIKO NIYO,EWE AFAMONIKONIMORA OOJO,EWE ORIJIN OOJO,ATARE KAN,OLONGBO NLA KAN… SISERE::TI IRU YEN BANI IYO, AOKO FI OMI SAN IRU NA DANU, AO KOKO FI IRU DIE TELE ISASUN, AOFI EWE ORIJIN SI, EWE SINKINMINI SI, AO GBE OLONGBO AYE TATILUPA SI, AOFI ATARE SI LEGBE, AO TUN DA IRU WORO SI, EWE ORIJIN , EWE SIKINIMINI LE LORI, AOJOPO, AOLO KUNA DAADAA, AO MA FI OGIN GIDI LO LARO LARO.. IMULE AWON AGBA TOLAGBARA Adie asha ako tabi abo, aola inure aoki eye alapandede bo aowafi ewe iyalode funfun yi gbogbo adieyen patapata aogbesinu ape tuntun aofi odidi atare kan si,oori, epo pupa pelu adi diedie aodalelori aowajo aolokunna aomafila epo lale dakun nitori olorun iwo obirin tiobari iseyi mase mistake latise ooo ojo tiabadelo iseyi kamasunmo obirin oooo…. AGBELEPOTA TOGBONA Alakan odidi kan, odidi atare kan aolomejeji papo tiyokunna tiabafelo aoteni ifa ejiogbe aope ohunre si….Igbo nigbo ola hehe hehe, odan lodan ola hehe hehe, asha nke mapami eye oko mapami, eye oko naa nke mapami asha mapami,lodifafun abu omo elepo yewere, alakan de omo oni wowo nwowo, awon arawon nikiwonmapa arawon, awon arawon nikiwonmaku pipipi, osho aje emere lobanperiminibi awon arawon nikiwonmaku pipipi……haaaaa iseyikoja bee sugbon shaaa….. E lo dan wo na….. OSE EYONU AWON AGBA Ori oka to lase lenu meje, odidi eye elulu meje, odindi atare gidi meje, awa liili totobi tope daada meje, ipe oore 33, a o jo papo, ki e lo kuna sibikan, ki e mafi ogere epo pupa lo diedie lale patapata tabi idaji kutu . walahi, ise yi daju pupo. Contracts ti a ko mon nipa re ni yio ma wole ju funwa, gbogbo ohun ti a ba ti dawo le, yio ma yori si rere… OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba nse oun buburu simi koma ni isimi….. ABAMODA AJE Aa ma nfi iseyi daba owo ojumo ni osidamiloju daada sugbon enibamase onilatini imule todaju Lara:…..OGA aaye kan aoti aso funfun bonu epo pupa aotesile aofi ogayen sorie tiyomarinkiri aowako ewe abamoda 3 ewe ogbo 3 pelu odidi atare kan sori asoyen aodi papo aogbesinu ape aowajo aorosinu ado ide aofi eyele funfun kan bo aogbesinu asunhon aso funfun aomagbeko soke ……lilore…..tobatidi idaji kutu laitisorosi enikankan aoro aso funfun modi aowagbe ado ideyen aosi enure sile aosope …..iba olojo onio 3* eyin iyami osoronga iba,bi abiyamo bagbo ekun omore asare tete 3* ewasaretete jepemi lonio,ase ogbo nitu ogbo3* abamoda kidatie komase abati alagemo bada lorisa oke ngba,emi–omo–modaba kiolowa iyebayi wafunmi (aoso iyetiabafe ) nitoripe oojo ni oga epo nmu aso funfun, ojoti alagemo bafojukan aso ojonaa longba….aotunso nkan tiabafe aodapadasi aayere ojo Monday nikan lamanlo…. ATUDE, ATUWO TODAJU TAARA EGBO IYALODE FUNFUN, EGBO ORIJIN, EGBO TUDE , EGBO AFELORU, AO GE AWON EGBO YEN KEKEKE, AO DA SINU IGO KAN TABI KEG, AO WA JU OJUDA IKOIDE KAN SI NINU, AO WA DA OTI SI TI YIO PO DAADA, AO GBE PAMO LEYIN OJO KETA, AO MA YOMU… Isese Lagba ooo! EYONU ATUDE Ifun ako Alangba ati abo ifun opolo, epo ajeobale, ao pa losan ao tun pa lale, epo obo, epo igi nla , ao gun gbogbo repo Mose pelu ori ati adi dudu, ao ma Fi we….. EYONU AGBA Afatan irun ori wa obo malu jijo pelu odd atare kan ao ma Fi maltina loo… ASIRI TI A FI NKO ILE MEFA LARIN ODUN KAN TESTED AND CONFIRMED Omo eye ega meji , ti o wa ninu Ile loke , a o ja won tile tile , ewe esisi ojoo lopolopo, a o su losuka, lona meje , a o gbe agbada kana, a o to osuka meta , sori ara won ninu , a o wa ko awon omo eye ega na le lori tile tile , a o tun wa gbe ewe osuka to seku le lori , a o wa jo po ,a o lo kuna dada , a o ro ebu na sinu ado ide tuntun Kan, a o wa fi igi orijin ati Ikode kan di ado na Lenu pa , ti a ba ti wa pari ise na, a o gbe ado na sinu apoti lesekese , a o fon ekuru funfun si idi ise na fun ojo meta gbako , leyin ojo keta yi , a o lo aso awon agba meta, a o da sinu ise yi leyin igba ti a ti fon ekuru yen , a o wa fi ideri re de pada . LILORE:::A o din akara elepo nla kan , a o lu akara na ni iho (a o da lu ) a o da ebu inu ado yi sinu akara na , a o si je lesekese lobatan . Daju daju a o ko odindi ile kookan lona mefa larin ODUN KAN , to daju ti o si iyemeji nbe. EWO RE ::EWO meta nibe fun ise yi ,Akoko , a o gbudo fi enu kan akara elepo mo laelae , ekeji a o gbudo ko ile ju mefa na lo , bi o se gbogbo re ni yi o wo loju aye wa , te o si ni ko ile mo Titi , e o fije olorun ni pe , eketa , a o gbudo su mo obinrin fun osu meta gbako . AKIYESI PATAKI E se akiyesi, ti ise na ba bere ise , eye kan Ma ke ninu ikun wa, sugbon , a o gbudo beru , ko si wahala kankan o ti bere ise niyen . T I A BA FE BA ISE NA JE Leyin igba ti a ti kole tan , a o lo ewe ekuku tutu , a o fi se igbin agbonu nla kan je, a o lo ya igbe si ori akitan , a o si fi oju wa mejeji ri eye funfun kan ti yi o fo jade nibe , ogun ti baje ni yen oo EYONU ATUDE Ifun ako Alangba ati abo ifun opolo, epo ajeobale, ao pa losan ao tun pa lale, epo obo, epo igi nla , ao gun gbogbo repo Mose pelu ori ati adi dudu, ao ma Fi we….. EYONU AGBA Afatan irun ori wa obo malu jijo pelu odd atare kan ao ma Fi maltina loo… ASIRI TI A FI NKO ILE MEFA LARIN ODUN KAN TESTED AND CONFIRMED Omo eye ega meji , ti o wa ninu Ile loke , a o ja won tile tile , ewe esisi ojoo lopolopo, a o su losuka, lona meje , a o gbe agbada kana, a o to osuka meta , sori ara won ninu , a o wa ko awon omo eye ega na le lori tile tile , a o tun wa gbe ewe osuka to seku le lori , a o wa jo po ,a o lo kuna dada , a o ro ebu na sinu ado ide tuntun Kan, a o wa fi igi orijin ati Ikode kan di ado na Lenu pa , ti a ba ti wa pari ise na, a o gbe ado na sinu apoti lesekese , a o fon ekuru funfun si idi ise na fun ojo meta gbako , leyin ojo keta yi , a o lo aso awon agba meta, a o da sinu ise yi leyin igba ti a ti fon ekuru yen , a o wa fi ideri re de pada . LILORE:::A o din akara elepo nla kan , a o lu akara na ni iho (a o da lu ) a o da ebu inu ado yi sinu akara na , a o si je lesekese lobatan . Daju daju a o ko odindi ile kookan lona mefa larin ODUN KAN , to daju ti o si iyemeji nbe. EWO RE ::EWO meta nibe fun ise yi ,Akoko , a o gbudo fi enu kan akara elepo mo laelae , ekeji a o gbudo ko ile ju mefa na lo , bi o se gbogbo re ni yi o wo loju aye wa , te o si ni ko ile mo Titi , e o fije olorun ni pe , eketa , a o gbudo su mo obinrin fun osu meta gbako . AKIYESI PATAKI E se akiyesi, ti ise na ba bere ise , eye kan Ma ke ninu ikun wa, sugbon , a o gbudo beru , ko si wahala kankan o ti bere ise niyen . T I A BA FE BA ISE NA JE Leyin igba ti a ti kole tan , a o lo ewe ekuku tutu , a o fi se igbin agbonu nla kan je, a o lo ya igbe si ori akitan , a o si fi oju wa mejeji ri eye funfun kan ti yi o fo jade nibe , ogun ti baje ni yen ooo Adodun bakanna Edo eku asin,ao yan lori ina ti yo gbe,ti o ba gbe dada,ao wa lo pelu ewe ominsinmisin onitakun,ao wa da sinu oyin ojulowo,ao wa fi ba obinrin lasepo Obinrin ti o ba fe ni ki afi awon ogun yi ba ni asepo o TIRO AWURE OBINRIN Ori Ako Alangba Kan Ori Abo Alangba Kan Afopinna, Afomo Ope Ewa Eyo Meta Agbado Eyo Meta Ao Da Ewa Ati Agbado Yen Sinu Igba Ao Fe Lemeta Aowa Lojo Gbogbo Re Papo Aoni Jo Igba Yen Mo Aowa Lomo Okuta Tiro Ao Male Soju Pelu Ofore:-Fife Lanfe Eree Fifi Lanfe Agbado Nse Ni Abo Alangba Nyan Ako Alangba Fee Afomo Ope Kinje Oruko Meji Afopinna Ki Rina Yeju Okurin, Obinrin Tiwan Bati Fi Oju Kan Emi Lagbaja omo Lagbaja Loni O Ki Wan Oma Nife Emi Lagbaja omo Lagbaja Ni O Ao Male Soju Odaju FOR GAMBLE TO SEE NUMBER ANY WINING NUMBER lotto ticket winning ticket paper Bet naija winning ticket paper Sand from where people play lotto Sand from naira bet store Sand from ocean Sand from sea IYE OWIWI head 1 IYE APARO head 1 PARROT head 1 Parrot feather 1 OWIWI feather 1 Aparo feather 1 House fly 9 New mirror small mirror Native chalk Method Use iyerosun to imprint odu ifa ejiogbe on mirror, and use to imprint odu ifa ejiogbe inside native pot. Put mirror inside with odu imprinted on it. Then add owiwi head, APARO head then PARROT head, then add all the feathers then add Sand from gamble places, then add Sand from sea then add all the winning tickets then burn Burn everything together and Mark corner of your eye 3 and head 1,when you want to sleep in the night use small ashes to rub your head and when you want to go and gamble use small ashes to rub your head Ariran oumo todaju pa Tested&confirm Ewe ogbo 16, imo 0pe, eku Ile kan awo lili tope kan, omonile kan odidi atare kan ao ko gbogbo eto yii papo sato si ewe ogbo ati imo ope ao wa fi ewe ogbo yen yii papo ao wa fi imo ope yee di papo ao wa jo papo….ao lo kunaa dada ao malo pelu ofore…..ogbo loni gbo, imo loni mo, bi omonile ba gori aja oju re Arile, gbogbo ara ni lili fi riran, tokan tokan ni ki fi mo gbogbo ikan ati ero inu awon eniyan…ao ma la tabi fi eko lo Odaju pa.. OSOLE TODAJU Olongbo funfun,Opolopo iru isebe,Tangiri,Odidi atare kan.A o fi iru bo gbogbo ara olongbo yen , a o ge tangiri were , a o ko le , a o jo pelu odidi atare yen , a o ma fi oyin tabi fi fi fo eku tutu mu ni e meeji losu kan…. AWURE OLA Ewe orijin,Omonigedegede tutu,Yanrin okun,Yanrin osa.A o gun po mo ose dd , a o fi eje ako maalu po ose na , a o ko sinu ike ff ,ao ma fi we.. ABUSARI RE Owo eyo ti ko lu 201,Omonigedegede tutu, Iseta Eegun ori esin die,A o gun po , a o se ni powder , a o ma fi sa ori ti a ba ti we ose yen tan… APESIN FUN OMO ISE ================= Ao lowa egun eshin die, ewe sawerepepe, ao lo won papo, ao lo mose dudu topo die, ao wako sinu ewe iyalode funfun, ao mafi fowo ni araro, ao mawa pe gbolohun re si bayi wipe. GBOLOHUN RE: ori eshin kii buru ko maa ri oluke, sawerepepe pewon wa ki won maa wa sin emi lagbaja omo lagbaja towo towo owor won. ASEJE ASINA OWO ================= Ao wa ewe eela (14), iyere (14), edo maalu tiko wo omi, ao ge edo naa si mesan, ao lo ewe ati iyere yi papo ko kuna dada, oti laofi se omi re lati fise papo pelu epo ati iyo, ti obati jina tan, ao so sori osuka, ago kan oru lao koje pelu adura, ao wamu oti le lori. ASIRI BIBO ================= Ao ra oti schnapp kan, oga ibile gbigbe kan, odidi atare kan, ao yoo schnapp yi kuro ninu paali re, ao wamu paali yi pelu oga naa ati atare losi ibiti ewe sawerepepe husi, ao wa jaa sawerepepe naa, ao wako tele inu paali naa, ao wafi oga gbigbe naa le lori ati atare, ao tun wa jaa ewe sawerepepe miran le lori, ao wajo gbogbo re papo ninu ape, ao lo kokuna ti abati jotan, ao wamafi oti schnapp ti ayo kuro ninu yen lo laraaro, yio bara mu o. ASIRI BIBO ============= Ao loja ewe rerinkomi loo jo, ao wa eiye ega ako kan, ao wafi si arin ewe yii, ao fi ewe naa yi papo dada, ao wafi sinu isasun tuntun kan, ao fi odidi atare kan si, ao wajo papo, ao lo kuna dada ti abajo tan. Lilo re: ti obadi dede ago kan orun, ao wafi fo odidi eko tutu mu ni ihoho omoluwabi, ao se adura asiri bibo si ki ato mu, yio bara mu o, IBA AGBAGBA OOO OSE ASIRI BIBO =============== Ao loja ewe ewuro oojo, ewe ogbo oojo, ewe rerinkomi oojo bakanna ati ewe ekuya, ti ako bari oojo kose wun, ao gun gbogbo awon ewe wonyi mose dudu, ao wafi omi agbara ojo po papo dada, ao wako sinu ike funfun, ao maa wee ni araro kutukutu. AKIYESI: ako gbodo we ose yi ni ojo Wednesday ati Saturday OGUN AWURE Ewe mensenmensen, ewe ina funfun ewe atewogba ao gun Mose ao wa ko ose na sinu karagba ti won fi gbebo sita wiwe tabi wiwe owo lasan… OGUN AWURE Ewe ekuya, ewe sawerepepe ao gun Mose ao fi iyerosun te ifa ose meji si lwin ojo pelu iyerosun na bi a ba ko ose yen sinu igba ao wa da sinu re ao wa mu ori ikun ao te mo…. OGUN KI OLE MA LE KO ENIA LERU Ewe jokoje mesan ao wa lo ge osensen, mariwo ao je ki o gun to omuka owo atare mesan ao wa te ewe jokoje mesan yen si ao wa ko osensen, mariwo yen si ati atare ao wa fi owu dudu ati funfun we ao wa fi ko si enu ojulekun ….. OGUN KI OLE MA LE KO ENIA LERU Ewe egunmona ti o wa lara ope ao lo mu igbale tuntun a mu odindi atare kan ao wa nu mo igbale yen ninu a wa mu ewe yen a wa we mo nidi A fi owu dudu ati funfun we po ao wa fi dubu si oke pelu iso meji ni ki kan.. Bi a ba ba ole yi nibe ako gbodo mu lo si ogba olopa tabi wipe ki olo se ewon ohun ti a o so fun ni wipe ki o ma losi ile re … OGUN TI WON BA FE PE ENIA LAPETA KI O MALEDAHUN Eti odo ni oke yika ile igbo,ileoke ti o ga dada olu ara igi ti won ki je oko atare kan ao lo po ao fi singbere ni totun tosi.. Ofore- a pe igbo igbo oje a pe oke oke ko dahun a pe odo odo ko dahun a pe olu ara igi ko dahun Eyin ti o ba ku ni ninu egbogi yen ao ma la… OGUN TI WON BA FI OGUN SI ORI IJOKO FUN WA KIO MA LE RAN WON Eso lara funfun ao fo ao yo funfun inu re, eso serugu ao fo ao yo funfun inu re awon atare aija kan ao jo po ao singbere si oke idodo… Lati fi dan ogun na wo ao singbere kan si abe idodo ao fi ata ijosi pa ti o ba Tani ki a mo pe ogun na ko dara.. OSE AWURE OSHOLE Odindi eiye agbe ile ojude oba iranyin Okun ati osa omonigelegele awo eta, irun afin ati ti oyinbo, ewe aje ewe ehinbisowo ewe sawerepepe aso etu ati aso waji oga mejo eni alagemo, eso ina funfun 201,ewu eigu eku asin ati aso ododo ao jo gbogbo re po ao po mo ose #10.00,aso funfun ao da ni apo asunrun ao mu ori ako aja ao fi tele inu apo yen ao ko 6 merin sinu apo yen ao fi da ni okowo ao ko ose yen sinu re ao ma fi ose yen si… OGUN AWURE Ewe mensenmensen, ewe ina funfun ewe atewogba ao gun Mose ao wa ko ose na sinu karagba ti won fi gbebo sita wiwe tabi wiwe owo lasan… OGUN AWURE Ewe ekuya, ewe sawerepepe ao gun Mose ao fi iyerosun te ifa ose meji si lwin ojo pelu iyerosun na bi a ba ko ose yen sinu igba ao wa da sinu re ao wa mu ori ikun ao te mo…. OGUN KI OLE MA LE KO ENIA LERU Ewe jokoje mesan ao wa lo ge osensen, mariwo ao je ki o gun to omuka owo atare mesan ao wa te ewe jokoje mesan yen si ao wa ko osensen, mariwo yen si ati atare ao wa fi owu dudu ati funfun we ao wa fi ko si enu ojulekun ….. OGUN KI OLE MA LE KO ENIA LERU Ewe egunmona ti o wa lara ope ao lo mu igbale tuntun a mu odindi atare kan ao wa nu mo igbale yen ninu a wa mu ewe yen a wa we mo nidi A fi owu dudu ati funfun we po ao wa fi dubu si oke pelu iso meji ni ki kan.. Bi a ba ba ole yi nibe ako gbodo mu lo si ogba olopa tabi wipe ki olo se ewon ohun ti a o so fun ni wipe ki o ma losi ile re … OGUN TI WON BA FE PE ENIA LAPETA KI O MALEDAHUN Eti odo ni oke yika ile igbo,ileoke ti o ga dada olu ara igi ti won ki je oko atare kan ao lo po ao fi singbere ni totun tosi.. Ofore- a pe igbo igbo oje a pe oke oke ko dahun a pe odo odo ko dahun a pe olu ara igi ko dahun Eyin ti o ba ku ni ninu egbogi yen ao ma la… OGUN TI WON BA FI OGUN SI ORI IJOKO FUN WA KIO MA LE RAN WON Eso lara funfun ao fo ao yo funfun inu re, eso serugu ao fo ao yo funfun inu re awon atare aija kan ao jo po ao singbere si oke idodo… Lati fi dan ogun na wo ao singbere kan si abe idodo ao fi ata ijosi pa ti o ba Tani ki a mo pe ogun na ko dara.. OSE AWURE OSHOLE Odindi eiye agbe ile ojude oba iranyin Okun ati osa omonigelegele awo eta, irun afin ati ti oyinbo, ewe aje ewe ehinbisowo ewe sawerepepe aso etu ati aso waji oga mejo eni alagemo, eso ina funfun 201,ewu eigu eku asin ati aso ododo ao jo gbogbo re po ao po mo ose #10.00,aso funfun ao da ni apo asunrun ao mu ori ako aja ao fi tele inu apo yen ao ko 6 merin sinu apo yen ao fi da ni okowo ao ko ose yen sinu re ao ma fi ose yen si… IMULE AWON AGBA TIO WA LARA TITI LAYELAYE Aofi eyele fufun kan sinu isasun tutun aofi odidi atare kan si legbe awalora igba aofi iya igbayi de eyele na mole isasun na awada pupa ori eso ido yen lelori awafi omori isasun yen de pada aojo aolo kuna aoro sinu ado kan aomafi epo pupa loni alale fun ojo meje gbako tio nija asese wamalo lekokan… Gbogbo osole abi awure tabanlo lasiko tanlo imule yi yio sise dadaaa AKIYESI:- isasun na gbodo tobiju igba yenlo tanafe lo iseyi aso fufun lao mawo, aso fufun na lao wosun ao sini ba obirin sun lojoti abalo iseyi koda eniti o ba ndiwa lowo tio ba jawo, iku radarada nio ku… OSOLE TODAJU Olongbo funfun,Opolopo iru isebe,Tangiri,Odidi atare kan.A o fi iru bo gbogbo ara olongbo yen , a o ge tangiri were , a o ko le , a o jo pelu odidi atare yen , a o ma fi oyin tabi fi fi fo eku tutu mu ni e meeji losu kan…. AWURE OLA Ewe orijin,Omonigedegede tutu,Yanrin okun,Yanrin osa.A o gun po mo ose dd , a o fi eje ako maalu po ose na , a o ko sinu ike ff ,ao ma fi we.. ABUSARI RE Owo eyo ti ko lu 201,Omonigedegede tutu, Iseta Eegun ori esin die,A o gun po , a o se ni powder , a o ma fi sa ori ti a ba ti we ose yen tan… ITOJU EGBO ADAJINA TO DAJU Alubosa elewe, aidan die, Oku Okun ,ayu die, ‘kanafuru die,eru awonka die,imi ojo die, A o gun gbogbo eroja yi papo ti yi kunna bi Atike powder. A o sa ki o gbe daada, nitori ki o le dabi Atike powder. A o ma bu sibi imuko eyo kan sinu eko gbigbona, A o wa tun bu adin eyan die sinu eko gbigbona yi., ao ro papo daradara,ao maa mun laro.Odaju… IWOSAN EGBO ADAJINA: Omi igirisako,alubosa elewe,adin eyan, A o se gbogbo re papo ni Agbo Lori ina daradara.. Lilo Re :A o ma to omi agbo yi si oju Egbo naa ni Aro, osan ati Ale.O daju ITOJU EGBO ADAIJINA Ewe Ola pupo die,A o jo ninu ape ijogun , Ao lo Kunna Daradara ,A o koko da Oyin Gidi si Oju Egbona A o wa Ma Fi cotton gauze di Etu ti a jo yi mon oju Egbo yi loju.A o ma se be ni every other day.Odaju… ITOJU EGBO ADAJINA Epo orogbo,Ekute ti aba ri ni oju ONA tabi titi ti a ko mo eni tabi nkan ti o pa,a o sa Ekute yi gbe daradara, a o waa gun Ekuta na pelu Epo orogbo yii ti yi o dabi Atike powder.A o ma fi si oju Egbo naa.Odaju wipe Egbo na gbodo jinna larin ose meji si meta ( 2 to 3 weeks) EYONU AWON AGBA Ewe rerinkomi,eyin ope ibile kan, odidi atare kan, ao jo papo,A o da etu na sinu oyin gidi ,ao maa la laro kutukutu…ODAJU!….. OSHOLE APAPO AFEKAYE TODAJU ASO ASIRI KAN ,ATI IYO ASIRI,EWE AJE TOPO , EWE,AHOYOYO,EWE AJEOBALE,EWE SAWEREPEPE,EWE OLA,OKETE TUTU KAN, EYE ADAN KAN,EYOWO 61, ASO WAJI TOFE DIE,AO LA OKETE,LAYA ,AO KI EYE ADAN YII SI AYA OKETE ,AOKO OWO EYO TOPO SINU OKETE ,AO FI OWU DUDU RAN PADA, AO GBE OKETE YI SINU ASO WAJI ,AO SESE GBESINU ASO ASIRI, AO DA IYO ASIRI SINURE , AO KO AWON EWE YI SINU ASOYI , AOGBE OKETE YI SI LARIN ,AO WADI PAPO PELU ATARE ODINDI 3,AO KI OBE TUNTUN SINU INA ,AO TA EPO YIKA ETI ARO,AO MATA OYIN IGAN SINU INA YI DIE DIE ,TIA BA JOTAN AO AOLO KUNA LORI NKAN ,AO PIN EBU YII SI ONA MEJE ,,,, AGO KAN ORU LAOMAFI RO EKURU FUNFUN JE ,FUN 7 DAYS, ODAJU GAN NI …. OSE EYONU AWON AGBA Ori oka to lase lenu meje, odidi eye elulu meje, odindi atare gidi meje, awa liili totobi tope daada meje, ipe oore 33, a o jo papo, ki e lo kuna sibikan, ki e mafi ogere epo pupa lo diedie lale patapata tabi idaji kutu . walahi, ise yi daju pupo. Contracts ti a ko mon nipa re ni yio ma wole ju funwa, gbogbo ohun ti a ba ti dawo le, yio ma yori si rere… OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba nse oun buburu simi koma ni isimi….. ABAMODA AJE Aa ma nfi iseyi daba owo ojumo ni osidamiloju daada sugbon enibamase onilatini imule todaju Lara:…..OGA aaye kan aoti aso funfun bonu epo pupa aotesile aofi ogayen sorie tiyomarinkiri aowako ewe abamoda 3 ewe ogbo 3 pelu odidi atare kan sori asoyen aodi papo aogbesinu ape aowajo aorosinu ado ide aofi eyele funfun kan bo aogbesinu asunhon aso funfun aomagbeko soke ……lilore…..tobatidi idaji kutu laitisorosi enikankan aoro aso funfun modi aowagbe ado ideyen aosi enure sile aosope …..iba olojo onio 3* eyin iyami osoronga iba,bi abiyamo bagbo ekun omore asare tete 3* ewasaretete jepemi lonio,ase ogbo nitu ogbo3* abamoda kidatie komase abati alagemo bada lorisa oke ngba,emi–omo–modaba kiolowa iyebayi wafunmi (aoso iyetiabafe ) nitoripe oojo ni oga epo nmu aso funfun, ojoti alagemo bafojukan aso ojonaa longba….aotunso nkan tiabafe aodapadasi aayere ojo Monday nikan lamanlo…. IMULE AWON AGBALAGBA Epo obo die,osu buke die,efun die,ose dudu die,oromodie kekere kan,atare odidi kan,aoko gbogbo re sinu igba olomori kekere kan,a o fi kahinkahin tuntun die bo lori,ao depa ti omori re yio hamo,ao wajopo ni ale,ao wafi foko mu leekan naa ni deede ago kan oru, NB:obinrin naa lelo,amo,enikan ni yio looo BI AYE BA DE ENIYAN MOLE TI KO SI ATUN SE KANKAN MO Ao wa odidi okete aye kan ao gun pelu ata ijosi die, epo obo die, iginla ,pelu ewe orijin die. Ao gun papo ao pomo ose dudu, ao ma we ose yi ninu ajadi apere fun ojo meje la o fiwe ose yi pelu omi to loworo odaju. OGUN TI AFI GBA NKAN LOWO ENIYAN Eyin adie ibile kan,owu etutu ao yo koro inu re kuro ao lo toro iyo lodo eniyan ao ko sinu agbada ao ta epo pupa die si awa jo po nigbati abajotan ao lo kunan dada nigbati abafe gba inkan lowo eniyan ao ma to la diedie…. EYONU AWON AGBA Eiye onbe, obi alawe meta, ao jo papo awa lo ni inu ape ti afi Jo Ogun, ao wa da epo si, ahon wa ni ao fi laa..A a ko gbodo fi owo wa Kon ..Ekan tabi emeji ni odun ni a lo… ASINA TODAJU Ako alangba kan,Egbo tude,Atare kan ,Eyin adie ororo Kan..Ao fi ako alangba tele ninu ape ijogun ao fi egbo tude ati atare odidi kan si ao jopo ao lo kunna ao da si ona mesan ao ma fi fo eko tutu mu lalale fun ojo mesan. ASEJE FUN ANU Eyin adie ororo meta, ao fi omi osan wewe se yio jina dada ao wa je toba tutu… ITUWO AYE Igbo mimu,ao lopo pelu eyo atare 7 ati etu ibon ojuda die, ao sin gbere yipo orun owo mejeji, gbere yi kogbodo koja koko orun owo mejeji… EYONU AWON AGBALAGBA Eso werenjeje,etu ibon ojuda, epo obo,ao lopo yio kunna dada, ao fi sin gbere 3 si ori,ao tun sin ni gbere yipo orun owo mejeji ka ati ese mejeji… OGUN LATIRI ALANU GIDI Ao wa Ewe Ajeobale Ojoo,Oro agogo pelu Epo Obo, Ao lo gun Kuna Dada,Ao wa fi po Ose Dudu Ao wa ko sinu Ike funfun ao gbe pamo fun Ojo meta Leyin Ojo keta Ao ma we lojojumo…Odaju pa Ao ma ri Anu Gba OSHOLE TODAJU Odidi Ori Oka kan,Ori Ere kan,Ori Ahun kan,Ewe akoko ..Ao wa gun gbogbo re papo mo Ose dudu ao wa ko sinu Igba onikoko Ao de pa fun Ojo meje Leyin Ojo keje Ao ma fi karinkan ibile we odaju Ao ma ri Owo GIDI Gba.. OGUN OWO TODAJU (RESPECT) Ao wa Owo Oga mejeeji,Ao ko sinu Efe owu pelu Eyo atare Meta Ao wa Dini Owu dudu ati Funfun Ao ma fi sapo wa Jade Odaju.. OGUN IRIRAN TODAJU A o wa Aye Eye Owiwi kan ,Ao fi obe tabi biledi la ni Igbaya re laye yen ni ooo, Ao ti wa Otin Shinapp kan sile, Ti a ba la laya tan Ao yo okan Eye Owiwi Yi Ao Gbemi loju ese Ao mu Otin Shinapp yen le Lori…Ao lo ri oku eye Owiwi yen mole… Odaju po