PRESENTED TO ____________________________________________ ___________________________________________ BY ____________________________________________ ___________________________________________ ON ___________________________________________ __________________________________________ IRAWO EDA ATI ITUMO ALA All rights reserved. Copyright ©2020 by Olalekan Masud Damilare (Ancestors) No part of this book may be reproduced, stored in a retrieval system, or transmitted in any form or by any means, electronic or mechanic, including photocopy, recording or by any information storage and retrieval system, without the permission in writing of the Publisher. AWON AKORI - Irawo eda - - Kini wọn n pe ni àlá? - - 2 - - Ala ati itumo pelu saara sise. 3 - 4 - 5 - Bonus Ise tii odara fun gbogbo irawo lati Mase, irawo afefe ati ina - Awon àpẹẹrẹ tii wọn fi ùn gba ògo aiye eni lowo eni fun gbogbo irawọ- 6 - Ala ati itumo pelu saara - - 7 - Akojo oore fun gbogbo irawo - 8 - 8 - 10 - Aso wiwọ fun gbogbo irawo ati orí bibo fún gbogbo ìràwọ - Àlà lila ati ìtumọ - - Ohun ti o tako ojo ibi awọn iseda kan- 11 - Ojo orire fun gbogbo irawo kankan - 12 - Idunnu ati aje fun gbogbo omo omi - 14 - Iyato wo lowa láàrín saara, ipese, etutu 17 - Iwosan fun eniti awon àgbàlagbà ùn dá láàmú - Ètùtù awọn àgbà - - 18 - Arobi awon àgbàlagbà - - 19 - Ipese - - - - 19 - Ala ati itumo - - - 21 - Nkan àpẹẹrẹ lori ọkọ orun - 22 - 22 - Aponle ati abuku fun gbogbo irawo 23 - Ikilo fun gbogbo irawo - - 24 - Ala ati itumo - - 27 - Báwo níí asele m'ope ọkọ orun ùn dáwà láàmú - - - i 18 - Iwulo saara (ipese tabi etutu) sise fun awa eda - - 28 - 28 - 28 - Saara fun eniti amubo oko tabi aya ba nda laamu - Saara sise fun eniti oni ejo (case) nii court - - Saara sise fun eniti ise tabi oja ee kobalo deede - - 29 - - 30 - 32 - Alaye kikun lori ekun oju orun - 33 - Akiyesi fun gbogbo okunrin - 34 - Idena fun akosejaye fun gbogbo irawo - - Akiyesi nipa were (mad) riri yala loju orun (ala ) tabi loju aiye - - Idunnu ati aje fun gbogbo omo omi 34 - Bawo nii oko sele fo jigi yii? - 35 - 36 - Iṣeda okun ati iṣeda àjé - - 39 - Iseda òkun - - - 39 - Iṣeda àjé - - - 40 - Ala ati itumo - - - 41 - Eleyi nii awọn ala ti púpọ ninu awọn omo omi má ùn la - - Pàtàkì orí bibo fún gbogbo ìràwọ - 43 - Idaamu - 43 - Awọn aye ti atile bo orí wà - 43 - Aso wiwo fibo ori - - 44 - Àlá àti ìtumọ - - - - 44 - Igbeyawo oju orun - - - Ala ati itumo - - - - - 45 48 ii IRAWO EDA 1. (Jan. 20 - Feb. 18 - Aquarius - irawo Afefe) 2. (Feb. 19 - Mar. 20 - Pisces - irawo omi) 3. (Mar. 21 - April 19 - Aries - irawo ina) 4. (April. 20 - May 20 - Taurus - irawo Erupe) 5. (May 21 - June 20 - Gemini - irawo Afefe) 6. (June 21 - July 22 - Cancer - irawo omi) 7. (July 23 - Aug. 22 - Leo - irawo ina) 8. (Aug. 23 - Sept. 22 - Virgo - irawo erupe) 9. (Sept. 23 - Oct. 22 - Libra - Irawo Afefe) 10. (Oct. 23 - Nov. 21 - Scorpio - irawo Omi) 11. (Nov. 22 - Dec. 21 - Sagittarius - irawo ina) 12. (Dec. 22 - Jan. 19 - Capricorn - irawo Erupe) iii KINI WỌN N PE NI ÀLÁ? Ala je ọnà kan ṣoṣo tí eleda wa má ùn fii ùn bawa soro idi niyii tii awọn Amokunseka ma ùn ran eleda ẹlòmíràn nii iṣẹ k'isẹ nii òru. Egbiyanju eje ki ama wo asọ tii ọba irawọ wa mu sún nii akoko tii abafesun nii ale nitori pe bíi eda ba unse awon ikan wọn yìí odidandan kii awọn ALUJONU BURUKU Ran iseda enibe nii iṣẹ k'isẹ nii òru gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ Kii wọn ma fún nii lọwọ loju orun. Kii egúngún ma leni loju orun Kii omi danu lori eni loju orun Kii wọn gbà kòkòrò lọwọ ẹni loju orun Kii èyán ma nii Ibalopọ nii gbogbo igba loju orun Kii wọn sì fìlà tabi kii wọn gbà bàtà lọwọ ẹni loju orun. Kii wọn ti ilekun moni loju àlà Kii igo èpo pupa Jabo lowo eni kii osi fo yangayanga Kii wọn ma fún ni nii ounjẹ ajeku jẹ ni party nii gbogbo igba. 1 Kii èyán dédé ba ara re nii party nii gbogbo igba Bíi oba ti un se akiyesi gbogbo nkan wọn yìí tètè mura sí ọrọ ara-re kii ògo ee mase díi awati. ALA ATI ITUMO PELU SAARA SISE. - Bii obalala pe owa ninu okunkun sugbon kosi onaa tii olegba jade Itumo:- Idamu die mawaye kunfun Adura Saara. Gbiyanju kii ofi omi ati nkan tii enu unje see saara. - Bii obalala oungba Owo lenu ATM MACHINE Itumo:- gbadura kii Agbana Mase Baye ee je. Saara Sugar mesan tabi meje nii dide kii ofun awon omode pelu owo. - Bii obalala pe oun rii Oku nii gbogbo igba Itumo:- gbadura kii awon tii osunmo ee Mase dii oku tabi see Aisan. Saara Gbiyanju kii ofi adiye,obi, asofunfun see saara fun onibara. 2 - Bii obalala pe Owu Alantakun unjade nii enu (mouths) ee. Itumo:- wapada dii Asegun sugbon ekunfun Adura. Saara Fii aso pupa ati candle pupa pelu iyo see saara. - Tii Wonba fun ee nii Owo Eyo loju Ala. Itumo:- Aje wani Arare gbiyanju kii ose awari Arare. BONUS ISE TII ODARA FUN GBOGBO IRAWO LATI MASE IRAWO AFEFE ATI INA Oja tita dara fun irawo yii. Police tabi any security works Transaction business, gas selling Welding job Working under government.( saara nii gbogbo igba) Self-employment Hair dresser Barbing saloon. 3 AWON ÀPẸẸRẸ TII WỌN FI ÙN GBA ÒGO AIYE ENI LOWO ENI FUN GBOGBO IRAWỌ* Ogo je oun nla tii ọlọhun eledua fúnni lati fi je olola èyán besini kii èyán je ọlọrọ nii awujọ ṣugbọn awọn amokunseka má ùn paro ogo moni lọwọ, oríṣiríṣi ọna nii awọn ẹda má ùn gba paro ògo mọ ẹni lọwọ bíi eda koba sí sora atije atimu yìo nira fún irú ẹni bẹ ayafi kii ọlọhun siju Anu wo gbogbo awa eniyan. Òunje ẹnu nii wọn fi gba ògo ẹlòmíràn, besini latara Ibalopọ nii won fi gba ògo ẹlòmíràn. Nje iwọ mope obìnrin nii o so ee dii ẹni eyin latara iwa agbere ati aini amojukuro ninu iwa sina? Ọpọlọpọ olówó nii otidi ẹni eyin besini ọpọlọpọ ọlọrọ nii ayé wọn titan ti kode nii àtúnṣe, kii unse gbogbo èyán ni ale gba ounjẹ jẹ lọwọ wọn rántí pé elòmíràn má ùn fii *OMI OKU MAALU* se ìpèsè lati ra ògo ati ọlá lọwọ ọmọ lakaje bíi Obaje iru oun je báyìí hummmm ọrọ aiye ee kusi owo ọlọhun. Inu nii bini ni wọn fi gba ògo lọwọ ẹlòmíràn latara oja títà bíi wọn bá fún ee lonje tabi ra oti fún ee ti iwọ lerope awọn ọrẹ je òní fàájì èyán, rántí pé nii gbogbo igbati ti iwọ kobati ríi ọwọ yọ odidandan kii ògo aiye ee díi tii ẹlòmíràn 4 besini orogún má ùn gba ògo ẹlòmíràn latara iwakuwa ọjọ ọla ọmọ orogún ee nipasẹ àlà lila nii wọn ti gba ògo ẹlòmíràn. ALA ATI ITUMO PELU SAARA -Bii oba nla igi loju Ala Itumo:- wadamu die kii otole rii Oro kojo Saara Fii ounti enu unje see saara fun Obinrin Arugbo. -Tii oba lo Aso loju Ala Itumo:- wapada dii oluranlowo fun Olowo nla Kan Saara Lofi Eyele ati Agbado see saara - Tii oba unda Omi sinu Apere (basket) loju Ala Itumo:- gbadura kii omase see asedanu laye eee. Saara Gbiyanju kii owe sinu basket die ninu omiti ofiwe fii see ounje kii opolopo eyan baaje ninu eee. 4 - Tii obalala pe won fun ee nii Ile ( house) loju Ala Itumo:- wapada rii ebun oore GBA lowo awon Eyan Saara. Fii ekara elepo ati agbon see saara AKOJO OORE FUN GBOGBO IRAWO Niwon’gbati obatii mo irawo tii obawaye, gbiyanju lati tele ikilo irawo eee kii ona Le làá fún ee. Aye koni mu waa. *PÀTÀKÌ ASO WIWỌ FUN GBOGBO IRAWO ATI ORÍ BIBO FÚN GBOGBO ÌRÀWỌ* Njẹ iwọ Mope aṣọ tii oun wọ nii oun koba irawọ ee ìdí niyi tii ogo Aye ree kólé tẹsiwaju besini ifasehin diẹ diẹ amasele waye gbogbo irawọ nii òní Aṣọ tii oba kádàrá ati ipin wọn mú gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ; *IRAWỌ OMI* Irawọ yii féràn láti máa wo aso. Fúnfún Omi aro Green 5 *IRAWỌ INÁ* Irawọ yii féràn láti máa wọ àwọn aṣọ wọnyi Pupa, Golden color Green, Yellow , *ERUPẸ* irawọ yii féràn láti máa wọ aṣọ wọn yí Green, Red Purple, Cream color *IRAWỌ AFẸFẸ* Oba nii irawọ yii je ninu kalenda ayé wa besini ọgá nii oje ninu gbogbo irawọ gbogbo nii ayé tigba Ṣugbọn niwonba igbati irawọ yii bawo aṣọ tii otako irawọ ee sún oseese kii wàhálà máṣe lẹ sinu ayé ee. Besini awon àlá buruku naa àna waye sinu Aye ee Aso wiwo fun irawo afefe Gbogbo Aso ni won le wo sugbon ki won mase wo aso dudu sun. Aso fufun lodara ju fun won lati ma wo ni opolopo Igba ati lati ma wo sun. 6 ÀLÀ LILA ATI ÌTUMỌ* Elédùà ni’fe wa daada nii ose fii àlà lila pewa síi àkíyèsí fún òrò ayé wa besini kosi eniti ko kii ùn la ala ṣugbọn oseese kii irufẹ awọn ipin irawọ kan máa gbagbe awọn àlà tí wọn bá la Mogba l'adura pe ala buruku konise mowa lára. - Bii obalala pe oun je eran ijapa loju Ala Itumo:- Iponju nii. Gba Adura daada. - Tii oba rii ọpọlọpọ irawo nii oju orun loju Ala Ìtumọ:- wapada dii oloro sugbon kun fun Adura daada. - Bii oba lala pe wonsan Gbese fun ee loju Ala Itumo:- hùn kàn afenira die fun ee gbadura daada ati saara - Tii obalala pe oun rin loju titi (express road) Ìtumọ:- Wanii ilosiwaju ninu gbogbo Adawole ee - Bii obalala pe oun sa owo loju Ala Itumo:- iponju nii ati oda owó ní. - Bii obalala pe Agbalagba fun ee lowo loju Ala Itumo:- Gbese nii kun fun Adua. 7 *OJO ORIRE FUN GBOGBO IRAWO KANKAN ATI OHUN TI O TAKO OJO IBI FUN AWON ISEDA IRAWO* *OHUN TI O TAKO OJO IBI AWỌN ISEDA KAN* Pupo obi nii komope ohun nii okunfa ìṣòro sinu aiye ọmọ owun besini awon ikan wọn yìí má ùn fa agbana tabi idawo fún àwon obi. Gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ kii unse gbogbo ọmọ nii èyán lese ikan wọn yìí fún. *PHOTO YIYA (PHOTO SHOOT)* Awọn ọmọ kan wà tojepe nii iwonba igba tii awọn obi wọn bati nii lokan pe awọn fe ya photo fún wọn nii tori ọjọ ibi wọn lesekese nii won ma bere àìsàn eyi sile fa wàhálà ọjọ ọla fún àwon iru ipin báyìí agaga gbogbo iseda IRANSE OMI TABI ỌMỌ OMI paapaajulo elere ọmọ *ARIWO PIPA LORI ỌMỌ* Njẹ iwọ Mope gbogbo ologo ọmọ pátápátá kii ùn feran kii wọn mapa ariwo lewon lori yala birthday tabi wedding nitoripe wahala má ùn saba sele leyin awon nkan wọn yìí 8 *OJO ORIRE FUN GBOGBO IRAWO KANKAN* GBOGBO Eda eniyan ni oni ojo ibi tire besini gbogbo wa nii oni ojo ORIRE tiwa sugbon aini akiyesi tisọ elomiran sii inu okunkun aye raye. E jeki amo daju pe olohun to dawa ko feran kii ani inira nii ayewa sugbon afowafa awa eyan nii opoju. EYINI OJO ORIRE FUN GBOGBO IRAWO KANKAN *IRAWO AFEFE* Pupo ninu onirawo yii Saba ma unri Adawon leyin orire won niwonba igbati wonkoba see eto Lori ojo tii odara funwon lati gbe ikan rere see EYINI ojo tii orire IRAWO won bosi. SUNDAY THURSDAY Bii wonba gbiyanju lati dawole ikan nii ojo yii atunbotan Oro Aiye won yio Dara esi Ayo nii won a sigbo. 9 *IRAWO ERUPE* Iseda tii obanlo ipin IRAWO yii gbogbo igbati obafese ikan rere kogbodo so sita kii omaba pada bomo lowo nitoripe ojukan nii IRAWO yii unsaba joko sii EYINI ojo tii orire IRAWO yii unsaba bosi WEDNESDAY TUESDAY SATURDAY ojo Saturday nii ojoti wonma ungbayin ju bii wonba dawole orire nii ojo yii iyin ojo Ale nii funwon. Sugbon pupo ninu won komo kii olohun siju Anu wo won oooo *IRAWO INA* GBAJUGBAJA nii IRAWO yii je ninu gbogbo irawo kankan, besini kosemani nii INA je fun ile aye awa eniyan. Ninu ojo meje towa ninu ose kankan ojo meta pere nii ojo ti odara fun irawo yii lati maa dawole ikan orire sugbon, opolopo Eda nii koni akiyesi lori awon ojo yii nitoripe gbogbo adawole won ninu ojo yii ma unja sii Aje ati Ayo. 10 SUNDAY THURSDAY MONDAY onisowo ninu won ojoti oja ree ma unyaju nii ojo Sunday besini won kii unfi ojo yii sere pelu enikeni Sugbon kosi oun tii wondawole ninu Awon ojo meteta yii gbogbo ee Loma unyori sii rere. Ejeki Akiyesi Arawa. *IRAWO OMI* GBOGBO onaa nii ogba IRAWO yii nitoripe kosi ojoti wonkole dawole ikan notoripe iseda tii oni agbara niwon. Sugbon pupo ninu won kii unsaba mo iyin Arare besini Ikojaye maa unpo fun okunrin won.gbogbo Ojo ninu OSE nii ojo orire won. Ki Elédùà mase jeki Awaye asan. *IDUNNU ATI AJE FUN GBOGBO OMO OMI* Gege bii ase mope Iran *MERIN* nii Awon iseda yii nii, besini gbogbo won nii won nii owun *IDUNNU* tiwon. 11 Opolopo eda nii komope GBOGBO Awon Eda yii nii won nii *JIGI* *Iseda ATI egbe pelu Aje* APERE IRAN KANKAN *OMI ANU* gbogbo iseda too obaje elegbe *OMI ANU* gbodo ni jigi tii yio sowon dii oloro ATI alase ninu ayewon besini wonko gbodo fii jigi yii se awada nitori imole ayewon nii ikan wonyii Kii unse Awon nikan gbogbo omoti obajade nii arawon nii pelu. *OMI AJE* BII otile jepe gbogbo eniti obafe Iran yii Jigi iyawo ee nii yio wulo fun besini shasha ninu OMO won nii koni rewa eyi tumosi pe gbogbo OMO tii won ba bii nii yio Rrewa tii gbogbo aye asi feran yala okunrin tabi obinrin sugbon ojoti oko Iran yii bati fo (brake) jigi yii ojo yen nii oti fi owo ati Ola see awati. 12 BAWO NII OKO SELE FO JIGI YII *OJO tii obati lu iyawo ee *OJO tii obati se Epe fun. Etc. *IRANSE AJE* GBOGBO waa nii amope won kii un bimo pupo besini kii unse gbogbo won nii wonferan ibalope sugbon die ninu won nii won ma unlala ibalope oju orun sugbon bio wonba gbiyanju gbogbo Awon ikan yii yio pare ninu ayewon ojo tii wonba fii gbiyanju lati kuro ninu *OMO IRANSE AJE* ojo yen nii jigi won tifoooo kii eledawon bawon se atunse loku *IGI TABI OMO AJE* Pupo ninu Awon Iran wonyi nii won ma unfo jigi Aje won nitoripe iwa ibinu ati Aseju nii oma unfa fifo jigi won. kii olohun siju Anu wo gbogbo waaa 13 IYATO WO LOWA LÁÀRÍN SAARA, IPESE, ETUTU *ÈTÙTÙ* Kilonje etutu? Edakun mofe ki afi pelepele ka oromi yio, ètùtù jẹ òun kan ti koṣe mo opin ee ṣugbọn oyara tete ma ungba nítorí pé bíi àwọn àgbàlagbà bá ùn bínú sí eyan oseese kii wọn ti ara ikan yii yọnu sí Nipa etutu nii atiri: Gbogbo Ogun owo( money ritual) Tabi Osole yala Osole tutu tàbí gbigbona oni lati nii ètùtù tiwonfe máṣe fún nitoripe wọn gbọdọ ma renew ISE ÀJÉ ti wonse Gẹgẹbi apẹrẹ Ekan losu kan tabi Emeji ninu osu meta besini ekan lodun nii gbogbo awọn ikan wọn yii ma ungba ètùtù won. Asitun manlo etutu latibere inkan tolagbara dada Ibi Ètùtù lati ma unlo eko .sinkin. Basi eran. E.t.c Besini ètùtù ma ùn gba nkan tolagbara. 14 IWOSAN FUN ENITI AWON ÀGBÀLAGBÀ ÙN DÁ LÁÀMÚ. Anfani wa funwa lati ṣe awọn ìpèsè yii saaju kii atole lọ awọn iṣẹ aroba tabi eyonu awon agbalagba nitoripe kii gbogbo igbiyanju wa máṣe jasi asan ejeki aranti pe ABIKU MÁ ÙN SỌ OLOGUN DEKE sugbon kii iru ikan báyìí máṣe ṣẹlẹ ejeki agbiyanju awọn ikan yii wo ṣáájú ohun gbogbo ti abafelo yálà ỌSẸ ANU ỌSẸ ÀWÒRÒ ỌSẸ ASINA ISEGUN ỌTA ati bẹbẹ lọ. *ÈTÙTÙ AWỌN ÀGBÀ * Eran elede,a o re si 16,ede pupa,obi abata merindinlogun, ogede omini meta, a o la okookan re si meta meta, a o ko eran elede tele, awo dudu, a o da ede le lori, a o ko obi yen le, a o wa ko ogede si, 15 a o fi iyere Osun Te Ifa osa meji II ll I l I l I l A o wa se adura ti abafe si, a o da le etutu naa lori, a o gbe lo si ibiti ti won ti ngba. *AROBI AWON ÀGBÀLAGBÀ* Eyin Ibile 21 ninu ipese dudu, Ado efun 3, pẹlu eko meta awako gbogbo ee sinu oru ìpèsè lẹyìn eyi ejeki àṣẹ adua sí ao gbe lo si orita meta nii agogo meji sí mẹta oru. *ÌPÈSÈ* Kini a unpe ni ìpèsè? Ìpèsè jẹ òun ti ama unse fún àwọn ẹlẹgbẹ elere ọmọ yala didi ẹrú ẹgbẹ tabi didi ẹrú ọkọ òrun diẹ ninu òun ti afi unse ìpèsè ni: ÀGBÀDO, IREKE, OYIN, AADÙN, OKABABA, EWA, RICE, ASO FUNFUN, EKURU FUNFUN, 16 ESURU, ISU, BISCUITS, SWEET ATI bẹbẹ lọ. Niwon ba igbati ọmọ ẹlẹgbẹ bati unse ìpèsè odidandan kii ona laa fún. Besini wọn má ùn ṣe ìpèsè lati fi le ọmọ kuro ninu ẹgbẹ. *Sáárá* Saara sise nii amaba fii ùn kaadi adura nile besini kosi ikanti akọle fi ṣe saara atipe kosi eniti akolese saara fún bàbá lese saara fun ọmọ Iyawo lese saara fún ọkọ Ọkọ lese saara fún ìyàwó Besini omo lese saara fún àwọn òbí ee. Saara sise dara gan fún oku orun kii ona lemala fún wa atipe kii iṣẹ wa lema lọ déédé. Orisirisi nkan nii alefi se saara gẹgẹbi àpẹẹrẹ IYỌ, OMI, OUNJẸ, AKARA, SUGAR, BISCUITS, ERAN TURU, ADÌYẸ, PẸPẸYẸ ati bẹbẹ lọ. 16 ALA ATI ITUMO - Tii obalala pe Omo kékeré ti koti bẹrẹ si ni rin fun ee nii owo loju Ala. Itumo:- warii ise (work) see sugbon oko nii rii owogba lesekese - Tii obafun eyan lowo loju Ala Itumo:- warii owo nii Akoko igbayen. - Tii obarii Owo aye atijo (olden days currency) loju Ala Itumo:- wapada see isetii otipati rii. - Bii obalala pe oun ka Ata (pepper) loju Ala Itumo:- iponju nii. Kunfun Adura. - Bii obalala pe oun je Agbalumo ( berry) loju Ala Itumo:- Ekun onitoun yio dii Erin. - Tii obalala pe ounje mango ( mongoro) loju Ala Itumo:- idunnu yio wọ inú Aye eee. - Tii wonba fun ee nii Osan (orange) loju Ala Itumo:- oun Ayo yio sele ninu idile eee. 17 NKAN ÀPẸẸRẸ LORI ỌKỌ ORUN Kii ọlọhun sinu Anu wo gbogbo eda ti owa ninu ìṣòro yìí besini kii àwámárìídìí ọrọ ọlọhun wa pẹlu ibanuje ayé wa. Gbogbo eniti oko orun ba ùn da láàmú ikan kii ùn fii bẹ lọ déédé fún wọn àti pé wahala yio ma sele pelu ìdílé wọn tàbí boy friends won Púpọ ninu omoge nii komo pe ọkọ orun nii oun da ohun láàmú idi niyi ti kofi ríi specific boy friends tabi future partner amo gba nii adura loni pe irọrun yíò wọnú aiye èmi àti iwọ Oríṣi ọna nii àpẹẹrẹ awon ikan wọn yìí máa ùn gbawa ṣugbọn niwonba igbati abati mọ ọnà ABAYỌ koni síi ìṣòro Kankan. BÁWO NÍÍ ASELE M'OPE ỌKỌ ORUN ÙN DÁWÀ LÁÀMÚ Bíi iru ẹni bayi baani oyun Àmàlà awọn àlà báyìí. Bíi kii èyán kan mafi ọwọ pàá ninu Ti obadi ojokeji tabi ọjọ kẹta odidandan kii oyun naa wa lẹ 18 Ikorira ama wafun iru obinrin bẹ yala ọ pretty tabi ugly odidandan kii ikorira wafun. Wọn kìí ùn saba nii ifọkanbalẹ ninu igbeyawo wọn nitoripe okunrin tii ọba fewon kii ùn nii ọwọ lọwọ èven kii àjé wá nii ara ọkọ tabi iyawo koni sí ifọkanbalẹ fún wọn Iru obinrin bẹẹ ama rii wàhálà larin awujọ Kosi bíi osele nii owó to koni sí okùnrin kan pàtó fún ti yíò jé Ade ori fún Gbogbo ọkùnrin tii wọn bá jọ ungbe odidandan kii wọn fi sílẹ lái ni idikan pato. Gbogbo ẹni ti ọkọ orun ba ùn da láàmú leyin ìgbéyàwó wọn koni nii owo lọwọ Gbogbo ọkùnrin tí ọba promise ee ama rii wahala leyin Ibalopọ (sex). APONLE ATI ABUKU FUN GBOGBO IRAWO Opo Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe dandan ise bayi bayi ni o gbodo ko, Olukuluku eda ni Olohun ti fun ni ise ti yio maa se laye, sugbon latari agidi ti awa omo Eda Adamo ni koje ki a ni ifura. Oro Olohun ko le ye omu go Eda sugbon Ologbon eni ni nye, Opo ti o yeki o lo se ise Briclayer sugbon alakiyesi ko je ki o tete yan ise ori re layo, 19 Eda ti o baa je omi laye ti o baa nse ise ina kole ni aluyo laye, eda to si je ina ti o nlo nse ise omi kole ni ilosiwaju laye. Imo nipa Irawo se koko laye awa omo eda, eleyi a jeki eda mo iru igbese aiye ti o le gbe, ohun ti oye ki a maa se ati ohun ti koye ki ase. Eda ti OIohun da lati ara omi ti o waa nlo se ise ni ile ise Bread, ki se epe raara kole ni aluyo laye. Ti abati bi omo Ejeki a gbiyanju ki a to awon to ni imo nipa Izab wiwo ki won se alaye lori Iru irawo ti omo naa gbe waa si aiye, iru ise ti ole se. Esu koni da irin Ajo gbogbo waa ru mo wa lowo laye. amin I. IRAWO AFEFE (ATEGUN) Irawo Ategun je irawo to ni agbara pupo, bi walah batile po ju fun awon iru irawo yii igbeyin won maa nda pupo, won nma se orire lehin opolopo walahi, oju awon iru eda bayii maa ni opolopo wahala ni aiye won, oju won ki gbe ibikan raaraa, ti won baa nse ise kan won atun pa ise naa ti won a tun gba ibi ise miran lo. IKILO FUN IRAWO IRAWO AFEFE (Ategun) Oro awon eda bayi da gegebi eniti o ngbe kanga ti o waa de aye kan ti kanga yii ko waa kan omi, okuro ninu kanga naa, otun bosi ibo miran lati gbe kanga miran, be gege ni 20 yio se maa gbe kanga yen lo titi ohun gbogbo ire yio fi tan mo lowo. Itumo oro yii ni wipe, Gbogbo igbati o baa ti gba ise kan mun mase maa kuro ni ibe ayafi fun idi kan Irawo Ategun gbodo so ara gidigidi, Irawo Ategun gbodo je eniti o ntera mo Adura ni gbogbo igba, Ewe ati Egbo kii Saba ma ntete je fun irawo Ategun ni idiwon ti won baa tin se adura daadaa, Irawo ategun gbodo munra si sise Ogun Isori daadaa, toripe won ki je ki won de ibi giga ti won nlo laye, Irawo ategun gbodo maa sora ni aye kaye ti won baa tin se epe pupo toripe Ada awon eda yii lati ara ategun, asasi ntete maa ja lara opo ninu awon omo ategun pupo, Egun idile baba nsaba maa nja iran omo ategun pupo ti ki jeki won tete de ibi giga ti won nlo laye. Kiyesi, Alakala bi ki won maa je ounje oju oru, tabi ki won maa ni ajo sepo ni oju oru. 2. IRAWO OMI Irawo omi lagbara pupo, Asasi ki saba jaa won, sugbon egun idile baba nsaba maa nba won jaa pupo, Ewe ati Egbo ma un sise lara won, Irawo omi ni obinrin iru won ni wonje elegbe besini alaje po ninu won, won maa ni ewa pupo sugbon ogun promise and fail maa npo fun won pupo, Okunrin won maa nfie si ki won maa yan ale pupo. IKILO FUN IRAWO OMI Irawo Omi gbodo teramo Awon unkan isori pupo lati ibere pepe aiye won, Okunrin won gbodo sora fun isekuse toripe obinrin maa nda irin ajo won ru pupo toripe won nma nife si okowon pupo 21 3. IRAWO INA Irawo ina je irawo to ni agbara, Sugbon bi won se buru to Agbara Omi ni nma nfa akoba fun opolopo won. Enia giga ni won pelu laye, Ose dudu kii ntete ma n je larawon ayafii kii won po ose funfun tabi Ose Ghana mo ikan tii won bajo Lori Ina funwon. IKILO FUN IRAWO INA Irawo naa gbodo sora fun obinrin pupo, bi irawo ina baa se tan lati fe iyawosile o gbodo se iwadi daadaa toripe bi okunrin baa je irawo ina Ina Atupa, Ina Tonkanyanra ti o baa le baa obinrin ti o je irawo Erupe Eruku, Erupe Funfun, pade, iru won ki gbadun ara won ninu ile, awon irawo yii sini yio maa paa ogo ina. Bi won baa ti njo ni ajosepo, beni irawo yio se maa pa ogo ina re 4. IRAWO ERUPE (iyepe) Irawo iyepe je irawo ti won nsaba maa ni oju anu pupo, won je eniti o le soro dada, won ni ogbon pupo, sugbon iwa igberaga nma nba ise opo won je, won feran iwa imo toto. Inakuna sin ma nda won lamun pupo IKILO FUN IRAWO IYEPE Irawo iyepe gbodo so ara won gidi gidi nipa ina kuna, Bi suru awon irawo yii se po to be na ni ori kunkun won se po to nigbati o baa nbinu, sora fun inu fufu, sora fun iwa tara eni nikan. 22 ALA ATI ITUMO - Bii obalala pe oun mu Osan (orange) Itumo:- wá sí pada pade olóore re kún fún adua daada - Bii obalala pe oun je Aba ( fruit) loju Ala. Itumo:- Gbadura kii olohun tete lefii Oro ee yaa OTA lenu. - Ti o ba la ala pe oun pon omi to mo lati inu kanga loju orun Itumo:- Erongba re ti oun ro yi o jasi daada kun fun adua dada - Ti o ba ala pe oun gbo ariwo odo to n San loju orun Itumo:- wahala yio sele larin awon ebi re kun fun adua dada - Ti o ba la ala pe okunkun su bo o lojiji loju orun Itumo:- Isoro yi o wa fun o lenu Ise re kun fun adua dada - Ti o ba la ala ri opolopo efon lara re loju orun Itumo:- Kun fun adua daada aisan nbo niyen o - Ti o ba la ala ri aja (dog) ti oun yo mo e loju orun Itumo:- Oku orire awon ota re yi o tuba aburu ti won ti se fun e 23 IWULO SAARA (IPESE TABI ETUTU) SISE FUN AWA EDA Saara sise wulo fun AWA Eda Alaye ona otooto nii ama ungba see saara be SAARA FUN ENITI AMUBO OKO TABI AYA BA NDA LAAMU. Kii onitoun gbiyanju kii o koko see saara yii kii o to bere sini lo awon aajo tii won base . Odidi Akuko Adiye pupa Agbado Fila tabi gele tii kowo mo Bata tuntun tii koti wo rara Kii ose Adura sii, kii o lo fi see orire Anu fun Afoju Okunrin tabi obinrin. SAARA SISE FUN ENITI ONI EJO (Case) NII COURT. Olohun ko nije kii ari ogun wahala eniti obani case nii court Kii onitoun lowa awon ikan wonyii lati fii see saara. Eyele funfun Rice tutu kii odisi ona mesan tabi meje. 24 Bata tuntun kii oti worii, Aso funfun opa meta Kii ofun Afoju Okunrin tabi obinrin kii Asofunfun ati eyele funfun Kii ofun okunrin tabi obinrin Arugbo kii Bata tuntun naa Kii owa fun Awon omo kekere nii rice tii odi sii ototo yii. SAARA SISE FUN ENITI ISE TABI OJA EE KOBALO DEEDE Olohun konijeki Akuta sele siwa beesini akoni rii wahala ninu aye wa.lori oja wa eniti ISE KOBALO DEEDE eniki ofii awon ikan wonyii se saara Odidi Adiye, Okababa, Agbado Kii onitoun fii Omi Ojo San Ara kii owagbe die kii ofipo agbado ati okababa paapo leyin eyii kii oripe Adiye yii je ninu awon ikan wonyii fun odidi ojo meta. Leyin eyii kowadi awon ikan wonye sinu Nylon soi ona meje tabi mesan kii olofun onibara kii owa loso Adiye yii sinu odo Laipe olohun yii o GBA Adura ree Akiyesi Gbogbo awon SAARA yii nii AWA ojo meta meta ninu Kii eledua Mase wowa niran 25 IDENA FUN AKOSEJAYE FUN GBOGBO IRAWO Opolopo Eda nii oun Dena mo ire Aye Ee latari Aini Akiyesi fun Ewo ATI awon majemu fun IRAWO EE gege bii Apere IRAWO INA Gbogbo onirawo yii gbodo mo pe IRAWO awon kii un fe kii oun mabinu besini awon ewo po fun IRAWO yii. *Kodara kii onirawo ina mafii Owo (hand ) nu ilagun oju *Kodara kii oma baa obinrin nii Ajosepo lati eyin (doggy sty) *Kodara kii onirawo Ina maalo ose dudu fiwe Kaka kii ose eyii kii Ori ose Ghana po ise paapo Bii onirawo yii ba unse ikan olodi sii irawo ee oseese kii Ina ee majo Ajoreyin IRAWO ERUPE *Kodara kii irawo Mase je ikanntii oba oun dii ayafa Nile *Kodara kii irawo yii masun ninu okunkun *Kodara kii onirawo yii masun sii Ori irawo ee. Bii oba unse gbogbo ikan wonyii odidandan kii Ina ee majo Ajoreyin. 26 IRAWO AFEFE. unje Iwo mo mope Opolopo onirawo yii nii otifii Owo Arare Baye araree je latara Aimokan mokan gege bii Apere; * Kodara kii onirawo Afefe maaje Ila *Kodara kii onirawo Afefe masun sii egbe ogiri niwonba igbati obaje pe owun nikan nii osun sii Ori bed *Kodara kii onirawo Afefe Mase imele Lori Adawole eee. *Gbiyanju kii oma bo Orí e nii okereju Ekan losu. *Kodara kii onirawo Afefe maleri sii eyan kii omaba kabamo. IRAWO OMI. Idaji (half) ninu iseda irawo yii nii oje elegbe elere omo tii kosi mo. Ipin yii ATI Irawo Erupe funfun gege bii wonseje iranse Aje tabi omo Omi otidi dandan kii wonnnii opa Aje ati Ate Aje lowo sugbon Opolopo loti fii Opa Aje ati Ate Aje ree tafala *Kodara kii onirawo Omi maalo ise pelu Oti lilee. *Kodara kii onirawo yii maabinu odi. *Kodara kii onirawo yii maa Ronu nitoripe Ifaseyin nii oun muba Arare. Olohun konije kii Idana atifaseyin deba emi ATI Iwo. 27 *AKIYESI NIPA WERE (MAD) RIRI YALA LOJU ORUN (ALA ) TABI LOJU AIYE* .. WERE Dunwo sugbon kose bii lomo kii Olohun mase ya awon omo wa ati awana nii were. (Amin) Opolopo Eda nikii unse akiyesi awon ikankan Nipa Oro Aiye ee sugbon gege bii apere ejeki agbe yewo..... - Bii obalala pe ounba were JEUN po loju Ala. Itumo:- wanii Owo sugbon iwo naa NII wase okunfa ifaseyin fun Arare - Bii were baunsa fun EE yala loju Ala tabi loju Aye Itumo:- fura Sii Oro arere notoripe Abuku ati Oda owo unbo. - Bii oba jade nii owuro kutukutu tii were batoro owo nii owo ee gbiyanju kii ofun nitoripe warii ifokanbale ati aanu gba nii gbogbo adawole ee - Bii were bafun ee nii owo loju Ala Itumo:- Warii owo sugbon gbese yio teyin owo naa Jade. Akiyesi Mase gba loan tabi see oniduro fun enikeni ni akoko igba naa. - Bii obalala pe were fun ee nii Aso loju Ala Itumo:- Asiri ee amabo nii gbogbo onaa kunfun Adura - Bii were ba jise (message) nii oju Aye gbiyanju kii ogbo tabi tele nkan ti o so nitoripe abara meji Eda nii. Bii were ba yaa aso mo ee lorun loju ala Itumo:- Owo mafe saa fere fun ee die kunfun Adura ati Sara - - Bii obalala pe were unba ee nii ibalopo (sex) loju Ala Itumo:- owo yio waa pelu ee sugbon gbadura kii omabase Aisan. Olohun mase jeki awaye alaye. 28 ALAYE KIKUN LORI EKUN OJU ORUN Opolopo nii komo Itumo ekun oju orun Oma meji nii Ala yii pinsi bii eyan ba unsun ekun loju Ala. Ona Akoko * Bii oun Ayo bafe sele SII Eda eniyan oseese kii olaala rii ikan tii yio baani okanje kii owa sunkun jade loju Ala eleyii kii unse Ala buruku Apere Orire ati ikan Ayo nii. * Bii obalala pe won unsoro sii ee Oro yen wadun eee gan loju Ala eyiwafa ekun tii osi sebe sunkun jade loju aye. Itumo:- warii Anugba lowo olohun ati eyan kunfun Adura daada kii Iran yii lewa sii imuse. Ona Keji. OTA ma ungba ona yii lati fii Baye opolopo Eda Alaye je gege bii Apere *Bii omokekere ma unsaba sunkun jade loju orun Awon obi ee nilo lati mura gidigan kii omo naa maaba pada dii Olode Oru Nii Ojo Ale Ee *Bii wonba peyan nii APETA odidandan kii osunkun jade loju Ala sugbon ekun Asin rorun nii iru ekun bayii maunje. 29 AKIYESI FUN GBOGBO OKUNRIN - Nje Iwo mope kodara kii okunrin fii irin Ori obinrin fa agaga omo ONIRAWO OMI TABI ELERE OMO? Bii okunrin ba unse ikan bayii odidandan kii ijakule diedie maa waye fun. - Nje Iwo mo pe kodara kii okunrin Oni irawo Ina maaba obinrin sun lati eyin (doggy style)? Idenaa die die amawaye fun Olohun konije kii Asina lagbara olohun. IDUNNU ATI AJE FUN GBOGBO OMO OMI Gege bii ase mope Iran *MERIN* nii Awon iseda yii nii besini gbogbo won nii won nii owun IDUNNU tiwon, opolopo eda nii komope GBOGBO Awon Eda yii nii won nii *JIGI* *Iseda ati egbe pelu Aje* Apere: IRAN KANKAN *OMI ANU* Gbogbo iseda too obaje elegbe *OMI ANU* gbodo ni jigi tii yio sowon dii oloro ATI alase ninu ayewon besini wonko gbodo fii jigi yii se awada nitori imole ayewon nii ikan wonyii. Kii unse Awon nikan gbogbo omoti obajade nii arawon nii pelu. 30 *OMI AJE* BII otilejepe gbogbo eniti obafe Iran yii Jigi iyawo ee nii yio wulofun be sini shasha ninu omo won tii koni Rewa eyi tumosi gbogbo OMO tii wonba BII nii yio Rewa tii gbogbo aye asiferan yala okunrin tabi obinrin sugbon ojoti oko Iran yii bati fo (brake) jigi yii ojoyen nii otifi owo ati Ola see awati BAWO NII OKO SELE FO JIGI YII? *OJO tii obati lu iyawo ee *OJO tii obati se Epe fun. Etc. *IRANSE AJE* GBOGBO waa nii amope won kii un bimo pupo besini kii unse gbogbo won nii wonferan ibalope sugbon die ninu won nii won ma unlala ibalope oju orun sugbon bio wonba gbiyanju gbogbo Awon ikan yii yio pare ninu ayewon ojo tii wonba fii gbiyanju lati kuro ninu *OMO IRANSE AJE* ojo yen nii jigi won tifoooo kii eledawon bawon se atunse loku *IGI TABI OMO AJE.* Pupo ninu Awon Iran wonyi nii won ma unfo jigi Ajewon nitoripe iwa ibinu ATI Aseju nii oma unfa fifo jigi won kii olohun siju Anu wo gbogbo waaa 31 ELEYI NII AWỌN ALA TI PÚPỌ NINU AWỌN OMO OMI MÁ ÙN LA Eleyi nii púpọ ninu awọn àlá tii ọmọ omi má nla tii o siye kii ofi akiyesi síi ọrọ aiye ara-re yala okunrin tabi obinrin ọpọlọpọ ẹda ni ko mọ pé iseda omi nii òun ṣugbọn niwon ba ìgbà tí oba'nla awọn àlá báyìí odi dandan kii omu ọrọ aiyé rẹ nii okunkundun - Bíi obalala pe òun wọ Aṣọ FÚNFÚN nii gbogbo igba Ìtumọ:- awọn ẹgbẹ rẹ ùn gbìyànjú ilosiwaju fún ee. - Bíi obalala pe oun ko Owó ẹyọ daani nii gbogbo igba Ìtumọ:- Ajé waani ọwọ rẹ ṣugbọn gbìyànjú kí ọsẹ àwárí ara-re.. - Bíi obalala pe òun wẹ nínú òkun nii gbogbo igba Ìtumọ:- Wari ìdùnnú latara isemi Aje. - Bíi obalala pe oun wà nii eti òkun nii gbogbo igba Ìtumọ:- Ore wa nii iwaju rẹ latowo isemi òkun 32 - Bii obalala pe Ogbe cup Dani loju Ala. Itumo:- wako òòrè jọ. - Bii obalala pe oun we ninu Erefo loju ala. Itumo:- Wadi Eni yepere kunfun Adura - Bii obalala pe oun je bread loju Ala Ìtumọ:- gbadura oun tole unbo Wadi erooo. - Bii obalala pe igi Nla wo lolu niwaju ee. Itumo:- isoro aye ee yio yanju - Bii obalala pe Ori Oju ara obinrin lójú Alá ní orí omi tabi nii inu òkun Itumo:- oore unbo fun ee Sugbon gbadura kii omase jasi Asan. - Bii obalala pe oun sunkun lórí omi ní gbogbo ìgbà Ìtumọ:- owun idunnu nbo fun ee nínú ẹgbẹ yín ṣugbọn ṣọra kii wọn má ba kọ ẹyìn sí ee 33 - Bii obalala pe Ori Alabagbe ee pe oku loju Ala Ìtumọ:- onitoun ti se ISE alagbara Kan nii - Bii obalala rii Iwọ ATI Oba ilu tii ẹjọ ùn sọrọ papọ lórí omi Itumo:- wapada dii olori nii Ayékan - Bii obalala pe Ori ewure dudu ninu Ile ee. Itumo:- gbadura kii awon Agbalagba Mase gbe Agbanaa le ee LỌWỌ. BONUS - Bii obalala pe ounrin loju ofurufu Itumo:- Eni giga Ni ee sugbon gbadura kii ota Mase Dena aye ee. - Bii obalala pe oun je Iyepe loju ala Itumo:-wadii Aniyi kaye sugbon gbadura kii ibinu Mase baa ti ee je. 34 IṢEDA OKUN ATI IṢEDA ÀJÉ Ògo nii fún ọba adeda ati asèdá tii ofun mi nii ìmọ lori awọn ipin irawọ ati eda mofi akoko yii bẹ ọlọrun pé kii ìyìn arawa máṣe dii oku.amin. Awọn iseda kan tun wa toje pe okun ati àjé nii tiwọn iru awọn ipin yii kii ùn ju kii ùn wọpọ láwùjọ besini diẹ wọn má ùn nii ìgbéraga ejeki àgbè wọn yẹwo *ISEDA ÒKUN* Awọn ipin yii won kii ùn nii okunrin obinrin lasan nii wọn má ùn nii ìgbéraga wa ninu iwa wọn ju tii awọn òbí wọn lọ wọn má ùn nii owo besini wọn kii ùn ríi okunrin pe won lati fẹ wọn Eyini Àkíyèsí lati fii mo wọn * wọn kii ùn fe kii okunrin jẹ olú dari awọn * Won kii únjẹ kii okunrin fún àwọn lọwọ àti ìrẹlẹ besini inu won kii ùn tete ro tii wọn bá ùn bínú. 35 Won feran lati je olori nii àwùjọ besini púpọ nínú wọn owó nii wọn fii ùn ra ifẹ síi ọkan ọkunrin. *Adigi àti wàhálà ma ùn te wọn lọrùn besini wọn kii ùn feran lati ma ṣe itọju ọkọ wọn *Oun gbogbo loju wọn nii wọn má ùn fi owo ra. *AKOBA FÚN WỌN* Àkóbá wà fún wọn láti jẹ kii owó àti ọla kuro ninu ayé wọn Eyini ikan wọn yìí *Ojo ti owun ati Okunrin ẹlẹgbẹ *ÌGI OSI* bati nii ajọṣepọ ọjọ yen nii ọla ara-re ti tan. Ojo ti owun ati family ee bati barawon nii IBALOPỌ ọjọ yẹn nii ikan ti tan fún. *IṢEDA ÀJÉ* Tokunrin tobinrin nii wọn unlo iseda yii gbogbo ẹnití oba ùn lo iseda yii bíi wọn bá lọ iṣẹ dudu koni sise lara wọn besini laipe ogo won yíò buyo 36 *Gbogbo eniti oba unlo iseda yìí má ùn ni ìṣòro gan ṣugbọn laipe ọrọ wọn yìí Dayo *Gbogbo eniti oba unlo iseda yìí ipò olórí ni wọn ma ùn nifesi ṣugbọn wàhálà ati gbese nii oma un yọ sí wọn. ALA ATI ITUMO - Ti o ba la ala pe o gbo orin to dun loju orun Itumo:- Kun fun adua daada anfani owo kan nbo fun e ni - Ti o ba la alape o ki irun-jimoh loju orun Itumo:- Ayo ati idunnu ni fun e kun fun adua dada - Ti o ba la ala pe oungbe omi ungbe e loju orun Itumo:- Wa gba alejo ti o ro tele - Ti o ba la ala pe ounkigbe lati oju orun jasi aiye Itumo:- Wari opolopo isegun ati aanu kun fun adua dada - Ti Obinrin ti kori omo bi ba la ala pe oungba ojaa mo inu loju orun Itumo:- Obinrin be yio di olomo laye ki iru enibe kun fun adua daada kosi to awon oni mimo lo 37 - Bi Obinrin tabi Okunrin ba nlala rii Obi ee ti otiku nii gbogbo igba Itumo:- Okan Obi na nfa si o ni ki o si ma ranti obi na pelu adua ati Sara - Tii obalala pe oun pa Ejo (snake) Itumo:- oti unsegun ota sugbon Mase Simi kii ota mase raye wole sii ee Lara. - Bii obalala pe Iwo ati Tiger dijo unja loju Ala Itumo:- OTA eee kotiduro. Kunfun Adura daada - Bii obalala pe oun sare kaakiri loju Ala laikinsepe eyankan unle oooo. Itumo:- Oro ree yio dayo 38 *PÀTÀKÌ ORÍ BIBO FÚN GBOGBO ÌRÀWỌ* Kii unse irawo Afefe nikan nii oribibo wulo fun. Oribibo wulo fún gbogbo irawo pátápátá nitori bii Oro Eda badaru odidandan kii o bọ orí *IDAAMU* Bii ogun koba untete sise Lara Eda Agaga ọmọ ẹlẹgbẹ kini ikan tii olesee sii tii ọrọ rẹ lè fii yanjú Kii omo elegbe dii eru egbe leyin eyii kii o bo Orí ee. *AWỌN AYE TI ATILE BO ORÍ WÀ* Leyin tii Eda babo oritan odidandan kii bukata ee loju tu. *Ale bo oriwa ninu Ile wa. *Alebo Orí waa nii odo Alfa tii kii unse onijibiti. *Alebo Orí waa nii odo Woli tii kii unse onijibiti *BabaIFA,Babalawo,Iya Onifa leba eyan bo Orí. *Anfani wafun eniti Oni Ori kii oboo ikan ee fun Arare. 39 Aso wiwo fibo Ori. *Alewo Aso funfun fibo Ori *Agbodo wa nii mimo fibo Ori waa. *Yato sii Elere Omo nikan nii kogbodo je eja aro tii ofi bo Ori ee. Lati òní lọ orí èmi ati iwo koni gba Abodi. ÀLÁ ÀTI ÌTUMỌ Gẹgẹ bí àṣe mọ pe ọna kanṣoṣo tii eleda wa fii unba wa sọrọ besini gbogbo àlá nii oni ona tii opin Si - Bíi obalala pé òun gbórò ilu loju àlá Ìtumọ:- wa pada gbọ iro aburú lati ọdọ awọn èyán kunfun adua. - Bíi obalala pé iwọ ati obinrin ti ẹsẹ ṣe pada unbara yin sun loju àlá Ìtumọ:- iwọ ati obinrin bẹ ekole fe arayin bíi ebasifi agidi fẹ arayin wàhálà yíò masele. 40 - Bíi obalala pé òun ba iyawo tabi oko ee níí ajọṣepọ loju àlá Ọnà meji nii irufẹ alabe pinsin. 1. bíi iwọ ati iyawo tàbí ọkọ kobajogbe inu ilu kan náà tii ofi la iru alabayi Ìtumọ:- adisọkan lori ìfẹ tii ẹni síi arayin ni. 2. bíi iwọ ati ọkọ tabi iyawo ee ba jọ ungbe papọ tii ofi la irú alabayi. Ìtumọ:- gbàdúrà kii emase ríi ogun ìpínyà idile larin lọkọ laya - Bíi obalala pé òun fún adìye nii ounjẹ loju ala Ìtumọ:- wa gba àlejò tii yíò fún ee níí wàhálà. - Bíi obalala pé òun kò igi jọ loju àlá Ìtumọ:- wa fii ọwọ ara-re fa wàhálà sinu Aye ara-re. - Bíi obalala ríi fruit loju àlá yala oje tabi okori lasan ni. Ìtumọ:- ìdùnnú púpọ ùn bọ fún ee kunfun adua *IGBEYAWO OJU ORUN* IGBEYAWO je oun Pataki tii olohun pawa lase lati see sugbon orisirisi ona nii awon emi okunkun ma ungbe igbeyawo gba gege bii Apere 41 *Owun toburu ju Niki Amase igbeyawo loju orun nitoripe oko orun tabi aya orun nii oun malo awon igbese yii lati fii da IRIN AJO Eda eniyan ru *bii obati see igbeyawo rii loju aye tii otun waa unfi lala pe oba arare nibo eniti osefese igbeyawo Ona meji nii iru ikan bayii maun pinsi. *Ona Akoko* BII oko tabi Aya baani ife arawon nii afeju iru ikan bayii amaye nitoripe ounfa ife won nii oma ungbe awon ikan wanyii wafunwon loju orun nitoripe awon mejeji nii yio maa la Alape awon untun IGBEYAWO awon see kosi Aburu ninu eleyii niwonba igba tojepe awon mejeji unjo laa Alape awon untun bara awon se IGBEYAWO nii. *Bii esu ba setan lata daa irin ajo igbeyawo ru oseese kii iyawo nikan maala Ala pe oun unse igbeyawo pelu elomiran tii kii unse Oko ti ofesile loju orun even Atun rii arare nii ipo pe oun Jo (dance) oun tun yo ( be happy) pelu awon molebi Oko oun. Wahala ati idamu ninu igbeyawo nii eleyii kii olohun suju Anuwo wa. Ekunfun adura daada *Bii oko ba unsaba maa unla Alape oun tun igbeyawo see pelu obinrin miran ona totun yaakan naa nii eleyi 42 tii esu ma ungba lati daa irin ajo igbeyawo ru Opolopo nii ounfi enu fa wahala sinu Aye arare nitoripe ninu awon ore tii oni kii unse gbogbo won nii inuwon dunsi eto IGBEYAWO ee. *Ona Ekeji* Opolopo OBINRIN nii kori okunrin ko enusi tii oun naa kosi fura Besini opolopo Okunrin nii kole baa obiinrin soro Aya ee amaja tii kositun nii Akiyesi pe Aisan nla nii gbogbo ikan wonyi OKO tabi AYA ORUN nii oma Atokun gbogbo awon ikan yii. Gege bii Apere; *Bii Okunrin tii koti nii afesona kan pato baa unsaba manlala pe oun see igbeyawo loju orun kii awon eyan Ara kunrin naa tete mura sii irin ajo akosejaye eda bee nitoripe kii unsaba wopo lati tete rii ayafe fun iru Okunrin naa. *Opolopo obinrin nii koni eyankan pato tii ounfe ako tabi oge sise nii awon eyan ma unpe besini ako tabi oge sise ko lounda laamu oko orun nii ounfa ifaseyin fun ninu igbeyawo ee. besini owun naa koni fun pe ikan unse owun nitoripe (party rider ) niwon even iruwon atun lerope party tii ounlo lofa tii oun fii nla iru awon Ala yii. *Gbogbo eniti kobati nii iyawo tabi nii Oko tii obanla awon Ala IGBEYAWO nii gbogbo igba ATI Tete settle down yio Fe nira gan *Bii Okunrin ATI OBINRIN batii gbadun masturbating ju, to ikan yii sitiwo won Lara daada iru enibe kii unsaba teteronu IGBEYAWO nitoripe Esu tii joba ninu ayewon laipe odidandan kii wonma lala pe awon see IGBEYAWO loju orun. Mogbaladura pe olohun koni fii arapamo je emi ATI iwo niyaaaaa....... 43 *ALA ATI ITUMO* Mogbaladura pe kii olohun jeki Alarere wa wasi imuse (Amin) Amin nikan ko Anilati see iseto nii. - Bii obalala pe Ori block ikole loju Ala Itumo:- wapada dii onile laye sugbon kunfun Adura. - Tii obalala rii AKO OKUTA Lori arawon. Itumo:- wapada dii onile sugbon gbiyanju kii ose suru kii omase fii Owo Arare da irin Ajo ee ru. - Bii obalala pe oun Rin lo ninu primary sch tii otisetan Itumo:- gbadura kii omaba rii Ifaseyin nitoripe Iwo gangan nii ounfa Ifaseyin fun Ara re. - Bíi obalala òun fún eyan nii oyan loju àlá Ìtumọ:- gbàdúrà kii won má bà gbà ògo ee. - Bíi obalala pé ounjẹ ẹran dín din tabi tutu loju àlá. Ìtumọ:- ifaseyin oun ipọnju nii e jeki asun mọ ọlọhun kii ọlọhun le sunmọ wa Fun Amoran Lori Ala call or Whatsapp me Olalekan Masud Damilare (A.K.A Ancestor) 07036112986 44