INA LOJU EKUN INTERNATIONAL HERBAL ASSOCIATION ASIRI TOPE 19 INA LOJU EKUN GROUP S 1. IMULE ASINA OWO Alangba adaripon 1 Owo tuntun ilu ti aba wa 1 Eso werenjeje 51 Ewe ola die SISE RE: Ao ka owo naa, ao ti bo alangba naa lenu Ao ro eso ewerenjeje naa si pelu ewe ola die Ao fi odindi atare kan si Ao wa jo ao sodi ebu Ao ma lo ni ago kan oru pelu epo tabi peak milk tabi hot drink N.B A kii pin lo ,eni kan soso ni o ma lo. O daju By Alfa soliu al aronu 2. OGUN MUIBA/IFERAN Suratu samsi Ibepe ti ko kanle SISE RE: Ao han suratu samsi lati oke dele sinu paper kan Ao bu (enlarge) gbogbo hao ti o wa ninu sura yen loju , Ao fi oruko okunrin soke oruko obinrin si isale Ao we ni tira Okun ti afi we tira yen ao oni g e Ao ju tira naa sinu ibepe yen Ao wa we ibepe yen naa Ao lo rimo ibi abata ti omo kiiti gbe rara N.B Ise yi eni ti aba ma lo fun koje eni ti o je wipe iku nikan lole yawa o.odaju By Alfa Soliu Al Aronu 3. ORUKA AGBELEPOTA Ibepe tiwantiwa odidi kan Oruka Eyin ibile kan Etu ibon SISE RE: Ao pa ibepe yen lori Ao ki oruka yen bo inu re Ao fi etu ibon si Ao fi eyin ibile le lori Ao de ibepe yen pada,odi jijo Ti aba jo tan ao yo oruka yen kuro Ao singbere merin si ikun lona mererin tabi kasin yika 2 INA LOJU EKUN GROUP NB Enikeni ti oba lo ise yi, ti o ba gbo wipe won robi si oun eni yen si ku ,ao gbodo kawo lori o . By Oluwo matagbamole 4. OGUN IYONU AWON AGBA Ewe oju olongbo Atare SISE RE: Ao ko atare le lori Ao ko senu ao je pelu By oluwo matagbamole 5. OSHOLE AYARA JE BI IDAN Olongbo to ya ehana dada 1 Ogede omini 3 Eran elede ti ko lawo ikoko SISE RE: Ao ge ogede omini si meje meje sinu ikoku Ao gee ran elede si meta sinu ikoko Ao lo gbe pamo fun ojo meje Enikeni ko gbodo de idi ikoko yi titi yio fi pe ojo keje To ba di ojo keje yio ti yo aje ti wonpe ni idin sugbon ako gbodo pe ni idin o Ao so wipe aje kaabo !!! Ao gun ose mo Ao pa olongbo yen sinu ikoko yi Ao re ori olongbo yen ja Ao fi si ori olongbo yen gun ori ose yen ti oju olongbo yen ma koju si sanmo(oke) Esinsin kogbodo bale eje olongbo yi ti abandu lowo Ao tun gbe pamo fun ojo meje miran Leyin ojo meje yi, ao gbe jade Ao ma we laraaro N.B Amin ti a mari ni wipe esinsin ode ba wole ibi ti agbe ose yen pamo si, owa ki niyen ase olohun si ti bale.odaju By Alfa Asimolowo 7. AKO OHUNMO AGBAYE ERONJA: Oju inaki ile Oju oka Oju olongbo Oju Aja Oju Agutan Oju esin 16 16 16 16 16 16 3 INA LOJU EKUN GROUP Oju karo 16 Kokoro idandan kopo die Atare aja 16 SISE RE: Ao jo gbogbo eronja yi papo Ao di ni ikobere Ao pa lawo ekun LILO RE: Ao ma gbe ko orun N.B Ao fi okun si o By Alfa suffisim 8. ABO OHUNMO AGBAYE ERONJA: Oju olongbo 2 Oju inaki ile 2 Oju Aja 2 Oju karo 2 Oju amotegun 2 Ewe ohunmo Ewe Atare kan SISE RE: Ao jo gbogbo eronja yi papo Ao di ni ikobere Ao pa lawo dudu ati funfun Ao re sinu eje aguntan fun ojo mesan Leyin ojo kesan ao yo kuro Ao sa sinu ile To bati gbe ao ma fi ko orun By Alfa suffisim 9. OHUNMO AYERAYE NLA ERONJA: Okan igala ti koti gbe tope(complete) Okan aja Okan olongbo ati ori re Okan ajeyo Ori igun Ori akala Odindi ataare Odindi eye karo Ewe karo Imo ope ti ama fatu lekan naa Ewe ogbon Kokoro alake oju ona 4 INA LOJU EKUN GROUP Ewe ohunmo Odidi akuku adie kan to tobi(to ti kojaye ja orun) Eja ojiji Igbin apinu kan ijapa SISE RE: Ao ko gbogbo eronja yi sinu ape ijogun Ao mu owo ijogun kuro ninu re o Ao pa eje adie yen le eronja yi lori Ao ge ori adie yi , ao mu sonsori imo ope Ao tibo adie yen lenu Ao ge imo ope toku keekeke ao ko sinu ape ijogun yen Ao ge apa otun ati osi adie yen naa si Ao so di ebu Ao ro sinu sere Ao fi aso tabi odidi di lenu Ao lo rimo oju ona ti awon eyan ngba dada tabi orita meta fun ojo mesan Ao lo wu kuro ni ojo kesan Ao pa akuko miran si lara ,ao fi eje re ra lara dada Ao gbe sinu apo asunwon fun ojo meta Lehin ojo keta oti bere ise, ao bu die ninu re ao fi sin igbere meta meta si okan aya wa. Egbe otun ati osi,awuje wa Ao mafi oti lo eyi toku N.B Ale fi adie to bakun se saara sugbon eni ti oni ise ko gbode je nibe. Ohunmo yi ma nsise fun odun mewa si ogun odun. Odaju gan BY: Dr Owo Agbara(Balogun Ina loju ekun) 10. OHUNMO NLA ERONJA: Ipabo egun (original) Oga aye Odidi ataare Akara gbendu 9 Alake oju ona Isasun tuntun SISE RE:Ao gbe isasun si ori aaro Ao gbe oga sinu isasun tuntun yi, yo ma jo lo Ao fi ake ojo ona gun akara gbendu yen , ao wa fi sile fun igba die Ao ri wipe awon eera ti pebo awon akara yi Ao wa ma ju sinu isasun ori ina lokokan Ao so won di ebu Ao ma fi oti lo. O daju N.B By: Dr Owo Agbara(Balogun Ina loju ekun) 11. SIGIDI IRANSE 5 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: Omi odo tonsan Sparo powder Ewe ogbo Ewe abamoda Ewe apada SISE RE:Ao fi omi odo yi mo sigidi to lapa ,oju ,imu, enu ati ese Ao gbo gbogbo awon ewe wonyi mo sparo powder Ao fi kun ara sigidi yen dada Ao sa si iboji Ti oba ti gbe , ao gbe sinu apoti to ni kokoro kan Ao gbe sinu re ao depa Ao fi sile fun ojo meta Lehun ojo keta ao difa lati beere lowo re boya oti to asiko lati ma lo To bati funwa ni yonda Ao je atare lenu, ao fi owo gba lemeta Ao pe gbolohun re si bayi wipe Ogbo loni ki oma gbo ohun enu emi lagbaja omo lagbaja, apada loni koi o mase pa ohun enu mi da, aba ti alagemo bada oun ni osa oke ngba. Aba ti emi lagbaja omo lagbaja da fun e loni di ase Ki o sare tete ki owa lo jise bayi bayi fun mi Ao gba nidi. O daju N.B By: Awolere Akanni omo odo agba 12. ARINNA TO DAJU(IMULE AGBA) ERONJA: Igba totobi to lomori Eyele funfun to daju to gbo dada Afomo ewe iyalode funfun Iyere Ewe ajeobale die Egbo ajeobale die Epo ajeobale die SISE RE:Ao gun afomo ewe iyalode ati iyere si ibi kan Ao gun ewe ajeobale,egbo re ati epo re mo iyere si egbe kan Ao pa eyele yi ao fi eje re pa eyin igba ye(ao ni fira omori re o) Ao sa lorun ti yoo gbe Ao tu eyele yen,ao ge si 16 (including it head and leg) Ao ni fi omo kan ara re o Oti oyinbo abi omi agbon ni ao fi fo Ao da epo sinu igba yen pelu ina werewere Ao din ti yo gbe dada Ao da awon ebu yen si pelu iyo Ao ro po dada Ao so kale sori osuka Ao gbe wole 6 INA LOJU EKUN GROUP To ba tutu ao bora si ihoho .ao se adura si gbogbo oun ti abafe ao je ni ihoho omoluabi. odaju bi iku N.B 1. awon ewe yen ko gbodo kanle 2. ao gbodo fi omi lasan fo tabi fitu eyele yen o 3. ojo Monday tabi tuesday ni o dara lati se ise yi 4. ti abaje aseje tan ,ita ni igba yen yoo wa, ako ni ri mole o taki da oju re bole o yoo mawo sanmo (oju fo)ni ao fi igba yen si kosi gbodo da oju bole fun ojo meje 5. lehin ojo keje ao lo fo igba yen mole lorita meta. By Oluwo asape ola ina loju ekun 13. OSHOLE TO DAJU ERONJA: Ori inaki ile ti amo oruko re Owo tuntun to tobi ni ilu ti an gbe Ori topo die Oju olongbo(eso werenjeje) topo die Odidi atara Oti oyinbo Okan malu ti ko wo omi Ape ibi SISE RE:Ao ro idi aro ti ati fe jo iseyi Ao fi oti gin fo ori inaki ile yi Ao fi owo tuntun ha lenu Ao fi ori bo gbogbo re pata Ao le oju olongbo mo gbogbo ara re ti ibi Kankan koni han sile Ao jo, ao sodi ebu Ao dasi meji, ida kan fifi se okan malu yen mi aseje ninu ikoko ape ibi Ao da ida keji sinu oti oyinbo Ise yi yoo koko gbe 11million wa,lehin naa yoo ma gbe eyi to ju bee lo wa lehin ojo bi meta. N.B Ti aba njo lowo agbodo mo se saara fun gbogbo awon ti won ba bawa nibe.saara bi oti ati owo. Ti abajo ise yi tan idi koko yen ko gbodo kan ile o,ori osuka lama soo le. Gbogbo igbati oba ti gbe owo yi wa, agbodo ma pa agbo funfun fi se saara re. By Oluwo asape ola inaloju ekun 14. ATINUDENU ERONJA: Eku ago kan Irawe to jabo to doju bole Epo iroko Iyere Ewe sawerepepe Osun 7 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE:Ao yan eku ako yen, ao ko ifun re kuro Ao lo awon eronja yoku papo Ao gbe epo kana, ao se eku yen lepo niyo pelu awon eronja ti ati lo kunna Ti obati fee jina tan , ao fi osun ti ati lo kuna dada te odu odi meji si owo wa Ao da sinu aseje yi, ao ro po dada Ti oba di lale Ao gba ile enu ona wa Ao dobale ,ori wa ma yo sita die ao da asje yen si enu ona naa Ao ma koje pelu ofo re wipe Ise tie mi lagbaja omo lagbaja nje lowo lowo bayi, ko sare tete ki olo ran iwi lagbaja omo lagbaja nitori wipe ojo ti eku ago ba kola ,ojo naa ni onkola jade sinu omo re nitori irawe kan kii dajo ile ko sun oke, gbogbo ohun timo ba se loni kolo ba iwo lagbaja omo lagbaja. N.B By Oluwo asape ola inaloju ekun 15. GBEWA 30 MILLION ERONJA: Ewe ojuotanagbin Ewe ogbon Ewe esisi Ewe tana gbowo Oga aye kan Apadure kan Atare kan Okan maalu ti ko womi SISE RE:Ao so gbogbo eronja yi di ebu Ao ge okan maalu si 16 Ao se lepo niyo pelu ebu yen Ao je , ao mu omi alijannu le lori. N.B Ao gba 30m ni ojo yen gangan naa,eni tofe wa kiise eniyan o, amoko ni wa pelu tipa tipa, yoo gbe wa nirorun ni. Ao ko gbodo je aseje ye ku o Ao gbodo jade ni ojo yen rara o By Oluwo asape ola inaloju ekun 16. OGUN TI AFI NLE EMI BURUKU KURO NINU ILE ABI ARA. ERONJA: Ewe afeloru oojo topo die Ewe origin oojo Ewe ayo oojo Epo obo SISE REao gun gbogbo re papo Ao gun po mo ose dudu 8 INA LOJU EKUN GROUP Ao fi sile fun ojo meta Lehin ojo keta odi wiwe N.B Ti aba ngun lowo to ba jabo le, ao gbodo mu o Ti abari wipe emi buruku kan wa ninu ile, eje kamu die ninu ose yi ki apo po mo omi ,ki a fi fan ile ile naa fun ojo meta Ti o baje alaisan ni yoo fi we fun ojo meta, ti o ban we lowo ti kainkain ba jabo le ko gbodo mu mo o. To baje asasi abi alakala ni ao we ose yi fun igba meta ni nkan bi ago kan oru. Ki a ju kainkain yen nu ti aba ti we tan. By:Awolere akanni omo odo agba. 17. OSHOLE OWO NLA ERONJA: Ewe olujongbodu(ewe jemi ni o) Iyere Igbin osun SISE RE: ao gun ewe olujongbodu pelu iyere,ao fi se igbin kan Ao lo osun kuna dada, ao fi te ejiogbe ogunda, ao da sori aseje yen Ao ro po dada, ao daniyan si, ao je aseje naa.o daju. By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 18. IRAPADA ERONJA: Iti ogede to ga to eyan As funfun opa meta Imole meje SISE RE: Ao losi inu akinju Eni yen ma dubule ,ao tan imole yi ka ni titan Ao gbadura ao korin isegun, Ao fi candle yi ni gbogbo ara Ao fi aso funfun gbon lara Ao gbe iti ogede yen bi posi,ao ko candle yen sinu re Ao fi aso funfun we, ao sin bi oku. N.B Iku owo eniyan kole pa eni yen mo To baje ti olohun ni,pelu adura ole ma ku By prophet jonah 19. GBOGBO NSE ERONJA: Omi osan wewe toba po die Awon nkan oloorun ti afi nse agbo bi Ayu 9 INA LOJU EKUN GROUP Iyere Ata le Kanafuru Ata ijosi Eru etc SISE RE: Ao lo gbogbo eroja yi papo Ao fi omo osan wewe si,ao fi ose dudu die si , ao se ti yoo jinna Ao ro pamo odi lilo N.B On sise fun apagun,giri omode,afunje etc Abiyamo gbodo ni nile By:woli kayode lati togo 20. OSE EYONU ERONJA: Alubosa onisu funfun Obi gbanja funfun Egbo ipeta SISE RE: Ao gun gbogbo re papo mo ose, ao mafiwe lore kore N.B By Woli omo emi 21. E YONU AGBA. ERONJA: Ewedu die Ose joy Iyo die SISE RE: ao gun gbogbo re papo , ao ma fe ni ojo jimoh N.B By woli omo emi 22. OGUN DIDA IGBE EJE ERONJA: Ogede agbagba dudu kan SISE RE: Ao ju ogede yi sinu ina , ao sun ti yoo dudu ao lo Eni yoo ma fi foko mu lale ati laaro N.B Eni yen ko gbodo mu oti titi yoo fi lo ise yi tan By woli omo emi 23. GBOGBO NSE 10 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: Ewe ejinrin tutu Omisinmisin pelebe tutu shynapp SISE RE: Ao ki awon ewe yi sinu igo bi agbo , ao da oti yen le lori Ao ma mu die die leyin ojo keta. N.B Eni ti ko bale mu shynap ko ma se ise yi o Ise yi nsise fun kokoro inu eje,ara riro, ara yiyun,aleko fun okunrin etc By woli omo emi 24. OSE ASIRI BIBO ERONJA: Ewe iyalode oojo Ewe aladun oojo Ewe orijin oojo Ewe anu oojo Ose dudu N1000 SISE RE: Ao gun awon owo yi papo loto Ao lo owo yi kuna loto Ao popa mo ose Ao ko sinu ike funfun, ao gbe pamo fun ojo meta, lehin ojo keta Ao ma we laararo N.B By woli omo emi 25. ASINA ERONJA: Etu ibon original Imi ojo Epo obo togbo Ose dudu SISE RE: Ao gun epo obo ati etu ibon papo pelu imi ojo Ao po papo mo ose dudu LILO RE To baje wipe inu ile ni ati fe we, ao we fun ojo meta Ojo akoko ao fi epo para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole Ojo keji aofi ori para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole Ojo keta ao fi oyin para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole. N.B By woli kayode from togo 26. ASINA 11 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: Kainkain 7 Ewuro Ori Ose SISE RE: ao gbo ewuro yen dada yoo kuna ao fi po ose ao te otura meji si, ao gbe ori le lori ti ori yen ba ti yo, ao po mo ose, ao bu ose sori kainkain meje yio fi epo para lemeta yoo we yio fi ori para lemeta yoo we yio fi oyin para lekan ,o ma duro die ki oyin gbe mo lara yoo tun we to ba we tan yoo da perfume sara yoo ma bo wale. To ba je wipe ona tidi mo eniyen tan pata yoo se sara fun olodo ki oto waleyoo bu iyo sinu basia yoo wa ma da iyo ye sinu odo , yow a ma bere gbogbo nkan to bafe. N.B By woli kayoed from togo 27. ASINA ERONJA: Ewe taba tutu oojo Ewe ewuro oojo Epo obo SISE RE: Ao gun gbogbo re papo Ao fi oronro maalu pomo ose dudu Leyin ojo keta odi wiwe By woli omo emi 28. OSE ITUWO ERONJA: Kanu bilala Epo obo Ose dudu SISE RE: Ao gun kanu ati epo obo kuna dada Ao ko lose dudu Ao ma fi we N.B Ikilo ose yi kii wo inu ile o, eje kagbe si ita ni o By woli omo emi 29. OSE AWORO ERONJA: Oronro malu oojo 12 INA LOJU EKUN GROUP Eran elede ekiri kan Isasun Ewe ekuya tutu SISE RE: Ao fie ran elede sinu isasun, ao ko ewe ekuya le lori pelu ataare kan Ao de pa,ao gbe pamo fun ojo meje Lehin ojo keje , ao jo, ao po papo mo lose Ao fi oronro maalu po papo Ao ma fi we. O daju N.B By woli omo emi 30. AWENU ATUDE ERONJA: Epo obo Apata ori apata Ose dudu tabi eyikeyi Eyin ororo kan Awo tasa kekere SISE RE: Ao lo apata ori apata yi mo epo obo ti yoo kuna dada Ao po lose, ao fi owo wada iho si arin ose yi Ao fi eyin ororo si Ao fi ose bo mole, ao gbe ose na sinu awo tasa Ao gbe pamo fun 16 days Leyin 16 days ao ma we laaro tabi lale. O daju By pastor taiwo 31. ATUDE ATUWO ERONJA: Ako pepeye kan Egbo tude topo niwon ba Ose Aso funfun Ike funfun SISE RE: Ogbe ako pepeye eyo ka , ao gun mo ego tude Ao fi eje pepeye po ose yen dada Ao gbe sinu aso funfun Ao wa gbe sinu ike funfun Ao ma we lalale fun odidi ojo meta Lehin eyi ale ma we lekan lose. N.B Ako gbodo je ki idi ose yen kanle moo, ale su osuka fun ka gbe sibe 13 INA LOJU EKUN GROUP Ao gbodo jade mo ti aba ti we ose yi tan, afefe aburu koni fe lu wa o. o daju By prophet Taiwo 32 ASINA ERONJA: Kaun bilala Ose SISE RE: Ao gun kaun bilala pomo ose Ago mejila la ma we ise yi.odaju N.B Akii lo iseyi ka tun jade mo o By Khadihat from cotonu 33. ASINA ERONJA: Ewe ewuro Ewe iyalode funfun Ewe ajeobale Ewe akoko SISE RE: Ti aba ti ja awon ewe yi ako nije ko kanle Ao gbo gbogbo re sinu omi Ao fi we lago mejila oru Ale fi any ose we iwe yi N.B By Khadihat from cotonu 34. OSHOLE TI AFI NPAWO NI KIA KIA ERONJA: Oju maalu mejeji Ewe tanagbowo Eyan aja Cast biscuit Oti oyinbo tabi oyin SISE RE: Ao ko ewe tanagbowo le oju maalu lori Ao fi eyan aja die si pelu cast biscuit Ao jo papo, ao fi oti oyinbo tabi oyin lo N.B O dara kalo oti oyinbo ju oyin lo o By Oluwo asape ola ina loju ekun 35. ISE OMO YAHOO ERONJA: Ewe irawe 7 Ewe ina funfun 14 INA LOJU EKUN GROUP Ewe ina pupa Ewe iyalode pupa Blue Ewe abamoda 7 Koko ajere Ewe sisi Ori alangba adaripo kan Etu ibon SISE RE: Ao ko ewe irawe merin te isale inu koko ajere ti yoo ko oju sita, ao fi oruko oyinbo ati oruko ti omo yen nje lodo oyinbo ti ati ko sinu paper kan si Ao ko ewe sisi si Ao ko ewe ina tele,ao da ewe iyalode pupa bo Ao gbe ewe ina funfun le lori Ao ko ewe abamoda le lori Ao bu blue le lori ao gbe ori alangba le lori, ao da blue le lori ao wada etu ibon si isale, nibi iwaju idi koko yen ao pe gbolohun re si bayi irawe kan kii dajo ile ko soke,iwo lagbaja nje wa sanwo fun lagbaja lati onilo nitori wipe were were lomode lo oko, warawara bayi lomode ti oko esisi bo abamoda kan koni da tie ko ma se, akii riyalode funfun nibi kan kama ri pupa re nje to bari be ki iwo lagbaja sanwo fun lagbaja loni kiakia ao wa fi ina si etu ibon yen ao wa gbe si igun ile wa, ojo ko gbodo pa o ao ma tan candle funfun ati pupa fun, si ile le idi re ni o. o daju N.B aki sunmo obinrin ka lo sidi ise yi o By Oluwo asape ola ina loju ekun 36. IMULE AWON AGBA ERONJA: Eyin eyele dudu 2 Ewe alelendoru 1 Ewe ajeobale 1 Afomo igi kigi Jakunjakun ori ope SISE RE: Ao ko gbogbo re papo, ka sodi etu Ao ro sinu ado kekere kan To badi ale ao dasi enu ona wa ao fi epo la N.B Ti abati sun ao ba ara wa larin awon agba, won o ma ko wa loogun abi ki won fi ejo sunwa. O daju gan ni o 15 INA LOJU EKUN GROUP By Oluwo asape ola ina loju ekun 37. ATUDE AYERAYE ERONJA: Ewe akoko Egbo igi akoko Epo ara akoko (ti igi kan naa ni o) Orogbo kan Ewe iyalode funfun Egbo iyalode funfun Epo ara iyalode funfun ose SISE RE: Ao gun ewe akoko, epo ati egbo re papo Ao ko lose si ibi kan Ao gun orogbo, ao ko lose si oto Ao gun ewe iyalode, epo ati egbo re papo Ao ko lose si ibi kan pelu oyin Ao ko gbogbo re odi odo pelu kainkain meta Ao we ose ewe akoko ni akoko Ao we ose oni orogbo leekeji Ao fi epo para ki ato we ti ewe iyalode Ao gbo ewe akoko si ibi kan ,ao fi sanra ti aba we tan. O daju N.B By Oluwo asape ola ina loju ekun 38. APASE ATI ISOYE OMODE Ile eye alapandede Eyere ayu SISE RE: Ao gun gbogbo re papo,ao se ko kunna dada, ao da sinu oyin Ao ma la N.B Gbogbo oro ti abaso di ase Ti aba tun fun omo ile iwe lo yoo mowe gan. Odaju o By Oluwo asape ola ina loju ekun 39. ITUSILE AWON AGBA ATI ASINA ERONJA: Awo agiliti kan tope Ewe ajeobale Odindi atare kan SISE RE: Ao so gbogbo eronja yi di etu(ao jo papo) 16 INA LOJU EKUN GROUP Ao ma fi foke mu abi oyin abi oti oyinbo lo lojo madi N.B Ti abati nlo odi dandan ki a ka owo By Oluwo asape ola ina loju ekun 40. OSHOLE ERONJA: Odindi atare kan Ewe alupaida eyi ti alu to parada 16 Ewe aje Ewe awerepepe Iyere Eyin ibile 2 SISE RE: Ao lo gbogbo re papo kafi din eyin ibile meji je Lepo niyo, ka daniyan ka je N.B Ao ri wipe laarin ojo melo kan , ao ri iyanu olohun By Oluwo asape ola ina loju ekun 41. OSHO TI AFI NGBA ISE NLA NLA ERONJA: Eyele funfun to daju aye kan Epo obo Epo igi nla Owo eyo ti ko lu 9 SISE RE: Ao jo gbogbo re papo Ao fi fokomu leekan laaro kutukutu N.B Ao ko gbodo jade ti aba ti lo o Ti aba ni imule lara dada, yo bere ise lojo yen gangan. O daju o By prophet taiwo 42. OHUNMO ERONJA: Eye oga kan Ikode kan Ado meta Odidi atare kan SISE RE: Ao ki ikode si oju eye oga yi , ko jade loju keji Ao jo pelu atare kan,ao ro sinu ado kan Ao tun jo, ao lo , ao da sinu ado keji Ao jo, ao lo ao ro sinu ade keta Inu iyen la ti ma loo laraaro 17 INA LOJU EKUN GROUP Ao ma fi foko mu. O daju N.B By Oluwo asape ola ina loju ekun 43. TESO UNISEX ERONJA: Ewe kukunduku Ewe omisinmisin oyin SISE RE: Ao lo awon ewe yen po , ao ko sinu oyin Ao ma fi pa abe N.B By Alfa Serifudeen 44. TESO TI OBINRIN ERONJA: Eso werepe 1 Akeeke 1 Eyo atare 7 SISE RE: Ao lopo kuna dada, ao fi singbere kan si awe otun ati osi oju ara wa. N.B Ti okunrin ba ba eni yen lajosepo tan, yoo bere ohun to ba fe. O daju By Alfa Serifudeen 45. TESO ERONJA: Iwo etu 2 Eyo atare kan Ori SISE RE: Ao mu eyo atare kan sinu iwo etu kan, ao jo Ao fi ori po sinu iwi keji Ti a ba felo, ao pe gbolohu re si wipe Osanyin mole o dowo re x3 Ika kan nigba iwo etu, iwo etu kii gba ika meji Ao fi owo kan, ao fi pa nkan omo kunrin wa Ao fib a obinrin na lajo sepo. O daju N.B By Alfa Serifudeen 46. TESO ERONJA: 18 INA LOJU EKUN GROUP Irun ori akile Akigbonnaku kan Toko tepon akuko adie kan Odidi atare kan. SISE RE: Ao jo gbogbo re papo Toko taya yoo fi foko mu leekan na N.B Ti won bati lo, okunrin miran kole gori obinrin yen mo lailai,to bad an wo, kole ri nkan kan se. o daju By Alfa Serifudeen 47. ASEJE OWO ERONJA: Afomo ewe iyalode Iyere 16 Eran elede SISE RE: Ao lo afomo ati iyere papo Ao gee ran elede yen si 16 Ao se lepo niyo ni dede 12.30pm Ao je ni ihoho ni dede 1.00 pelu adura N.B Ewo re ni wipe eni ti oba nwa omo ko gbodo je aseje naa. By Alfa Serifudeen 48. AWURE ITAJA AGBEKO ERONJA: Ori eye agbe Ori eye aluko Ori eye aparo Iyo akogbe SISE RE: Ao jo gbogbo re papo Ao ro sinu ado Ao so ko enu ona ile itaja naa N.B By Alfa Serifudeen 49. AWURE SIGIDI ARIMOLE ERONJA: Esu igbo Ori obuko ti won fibo esu Iko odide kan Ewe sawerepepe Tannatanna eyo kan SISE RE:Ao fi esu igbo mo sigidi olowo 16 19 INA LOJU EKUN GROUP Ao jo awon ewe yen pelu iko odide Ao ro seun obuko Ao gbe ori yen si owo sigidi yi Ao fi aso funfun yi papo Ao ri ti yoo koju si ita ni inaro Ao ko atori si legbe N.B Ao ma fi ekuru ti afi epo, oyin ati iyo si oju ibe Ao gbodo gbe nkankan si oju re o By 50.ASINA ATUDE ERONJA: Eyele funfun kan Ewe ejinrin oojo Ewe sawerepepe oojo Odindi atare 3 SISE RE: Ao pa eyele yi tie je ko gbodo jade lara re Ao jo gbogbo re papo Ao pin si ona meta Ao mafi shynap lo fun ojo meta N.B Pelu ogo ologun ki ojo meta tope , ao ri iyanu olohun By mukhadam ibraheem 51. OSHOLE ERONJA: Biscuit die toba fe die, toje ti taarin Eyele funfun balau Odindi atare SISE RE: Ao fi biscuit tele ape, ao du eje eyele si Ao ge ori eyele si lori, ao la eyele toku . ao daya de lori Ao fi odindi atare kan si, ao jo, ao lo, ao ro sinu ibi kan Ti aba ti fe lo. Ao te nifa ogun dabede Ao wape gbolohun re si bayi wipe Asare owo wolu loruko ti anpe ifa Arinrin ola wolu loruko ti anpe esu odara Olu kowon je loruko tanpe eyin iyani oshoronga Eyin meteta ni kinlode ti mo fi npe yin Moni tori kinle lowo lowo ni Moni tori kinle mo eniyan atat lawujo ni Eyin leni eyele kii leran ise lara Ifa o ifa o ifao wa bami yan ise ara mi danu loni 20 INA LOJU EKUN GROUP Ogun dabede iwo ni olori ole, owo nla nla ni ole mangbe Owo nlanla ni ki won ma wag be fun emi lagbaja omo lagbaja lati oni lo. Ori gbigbe o x3 ki olo wa ounje wa fun ori tutu emi lagbaja omo lagbaja lati oni lo. Ao tun se adura si Ao da senu. Ao ma fi oti to gbona dada lo N.B By mukhadam ibraheem 52. EYONU ERONJA: Opolo aye to tobi dada Epo obo Odidi atare SISE RE: Ao lo epo obo ti yo kuna Ao ro senu opolo yi ti yiyo bamu Ao gbe sinu ape ijogun pelu odidi atare kan, ao jo Ao lo ti yoo kuna , ao ko si ibi kan Ao fi foko mu fun ojo meta N.B By woli omo emi 53. ATUWO ERONJA: Ewe iyalode pupa ati funfun ose SISE RE: Ao lo mejeji papo , ao fi ose ko Ao pin ose yen si meta Ao fi we fun ojo meta ni deede ago kan oru tabi ago mejila ninu ajadi apere N.B To baje okunrin ni ewe iyalode pupa ati funfun 7 To baje obinrin ni ewe iyalode pupa ati funfun 9 Ti aba nwe iwe yen lowo, ti aba gbo ohun kan tabi apeere kan Ao gbodo jade kuro ninu ajadi apere naa o, olewu dieo By woli mercy 54. OSHOLE ERONJA: Ede funfun die Awo inaki Iye odidere Irun afin Ekanna owo mewewa 21 INA LOJU EKUN GROUP Akisa ori akitan Iyepe saare ti won sin oku si Ose Ikoko ajere SISE RE: Ao jo gbogbo re papo Ao dasi meji, ida kana o fi ko ose, ao ko sinu ikoko ajere Ida keji ao dasi inu oti lord, ao ma mu oti yi laaro Oru lao ma we ose yi. O daju gan N.B By woli mercy 55. OSHOLE ERONJA: Olongbo ileto tip e ninu ile, to ti gbo dada Yerupe saare okunrin Yerupe saare obinrin Yerupe oja Iru ori were Olori owo meta (N1000) SISE RE: Ao pa olongbo yen Ao ko gbogbo ifun re jade Ao ko gbogbo eronja yoku si inu re Ao we lowu dudu, ao wa jo Ao po papo mo ose dudu Ao ko sinu apo kan Odi wiwe lago kan oru. O confirm N.B By woli mercy 56. OSHO OWO NLA ERONJA: Eku asin meta Oga gbigbe meta Ori olongbo to niru meta Alangba ako aye meta Opolo aye nla meta Odidi atare meta Eso werenjeje agolo kam Isasun titun kan SISE RE: Ao jo gbogbo re papo ninu isasun titun yi Ao lo ninu isasun naa Ao so detu,ao ma lo ni ago kan oru pelu peak milk N.B 22 INA LOJU EKUN GROUP By woli mercy 57. EYONU ASINA ERONJA: Ewe rere abo Eyin 3 (ibile tabi agric) Olokun die SISE RE: ao lo ewe rere abo ao da po mo eyin ti ati fo pelu olokun die ao da sinu lylion, ao se lori ina to ba jina , ao daniyan nkan ti anwa si ao je N.B By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 58. OSHOLE ITAJA/ASINA ERONJA: Eje malu topo die Ewe tanagbowo Ewe orijin Ewe ewon Ewe aje Eru Alamo ti ati la SISE RE: Ao gun gbogbo eronja mo ose Ao fi eje maalu po dada ti yio fele Ao ko sinu ike funfun Ao ma fi we lemeta losu. O daju N.B A kii we lojo jimoh o By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 59. ASE TI AWON TO BAWA SADEHUN FI MA WA MU SE ERONJA: Ewe aluro(ewe padimo padimo) Olokun Oyin gidi SISE RE: Ao gun ewe aluro papo mo iyo Ao ko sinu ike funfun olomori kan Ao da oyin gidi le lori Ao gbe pamo fun ojo meta Lehin ojo keta ao ki owo bo inu ike yen ao wa ma wi bayi pe Gbogbo awon ti won ti bami ladehun lojo toti pe ati awon ti won sese bami Sadehun ki won wa ma pe adehun won bayi bayi 23 INA LOJU EKUN GROUP Ao la , odi ase niyen. O daju N.B By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 60. GBEWA 9 MILLION ERONJA: Agolo tomato/ kolibu tomato Igi oba Ewe alupaida 31(eyi ti alu to parada) Owo paper ilu ti awa SISE RE: ao jo gbogbo re papo, ao lo ninu ape ti afi jo Eda Holland milk kan si, e gbe mu. N.B Ekan soso ni yoo gbe owo yen wa. By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 61. EYONU ASINA AWON AGBA ERONJA: Ewe orijin oojo Ewe yanrin oojo Yerupe idi esu (eyi ton jeun daada) Yerupe oko (farm) Ewe ominsinminsin gogoro SISE RE: ao gun gbogbo re papo, ao po mo ose , ao fa sinu igba kan, ao ma we pelu kainkain ibile pelu gbolohun re bayi wipe Aje ogedengbe loruko ti anpe ifa,abidi tenu boorun loruko ti anpe esu odara, Aje kolonje to je loruko tanpe eyin iyami aje, eni kinlode timo finpe yin, moni nitori ire owo tonbe lowo omo araye ti won nna ti emi ko rina ni mo se npe yin, Eni edu ni mi mi kii se ai mo foloko, ibi gogoro la nba ominsinminsin, ibi gogoro ni ki omo araye ti ma bami. By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 62. AJEEGUN Ajeegun yi wa fun ki gbogbo ewe ti aba ti ja ki o ma sise fun wa ERONJA: Eso isin 2 (eyi ti oti yanu to sip e daada) SISE RE:ao po ose dudu ko fele dada, ao fi di enu eso isin to la sile yen mejeeji Ao fi odindi atare aja jo alakoko si ibi kan loto Ao fi odindi atare jo ekeji naa loto Ao fi akoko sin igbere si isale orun owo wa Ao fi ekeji sin igbere si oke orun owo wa N.B By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 63. OSHOLE OWO NLA ERONJA: 24 INA LOJU EKUN GROUP Omunu ewe onitikuti Glass cup (glass cup talonpemi) to ma nsaba wa lori oti shynap SISE RE:ao fi owo gbo ewe yi lai fi omi si o sinu cup yi, ao fi oti gin white si Ao w ape gbolohun re bayi wipe Ewe oniti kuti, lo ti olowo, olola wa fun mi loni, kinri taje se Aaro kutukutu la o mu. By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 64. ASEJE ASIRI BIBO ERONJA: Adie funfun eyokan Suratul isawaka 2 Agbon 3 SISE RE: ao han suratl isawaka si ona meji, ao fi omi agbon fo si ona meji otooto Ao fi idakan se adie yen, ao ma mu idakeji ti aba nje adie yen lowo. odaju N.B By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 65. OSHOLE TO NMU CUSTOMER WA FUN NI ERONJA: Opolo gbigbe mefa Odindi atare mefa Eso yerepe mefa SISE RE:ao jo metata papo dada, ao lo ,ao ro sinu ike funfun kan Laaro kutukutu ti ao ti soro si enikeni ,ao bu die sowo ao te nifa ejiogbe Ao wipe gbolohun re wipe, ao juba awon to laye Omode kiilu yerepe koma royin nile,agbalagba kiilu yerepe koma royin nile Okunrin kiilu yerepe koma royin nile,obinrin kiilu yerepe koma royin nile Gbogbo eyin ti e ti mo emi lagbaja omo lagbaja, oya e malo pokiki mi fun omo ara aye lona todara, fun okunrin fun obinrin , fun omode, fun agbalagba, nitori wipe iwa irefa kii fara won ti, lodindi lodindi latare ndi tie, atare kan kii di tie labo,lomode yin lagba yin , lokunrin yin lobinrin yin,ema gbe ore odindi wa ba emi lagbaja omo lagbaja nibi ti mo ba joko si,Ejiogbe o gbera nile ki owa lo gbe olowo nlanla lokunrin lobinrin lomode lagba ki won mafi owo owo won se emi lagbaja omo lagbaja laanu. N.B By alfa ola oluwa phone no:08082392705 66. MAYEHUN FUN CUSTOMER Ise ti ogun yin se ni wipe ti aba so fun awon customer to wa ise lodo wa, won ko ni naa ise na wo ki won to san owo fun wa ERONJA: Itanna ako ibepe to po lopolopo Eye Kowe kan Odindi atare kan Oga aye kan SISE RE:ao itanna ibepe die si isale inu ape,ao gbe kowe le lori pelu odindi atare kan, ao wad a itanna to ku le lori , ao jo dada, ao lo kunna, ao wa igo bi igo bama kan 25 INA LOJU EKUN GROUP Ao ju oga aye yen sinu re, ao da etu yen le lori, ao wada mohu li ayati le lori, ao mi po dada, ao gbe pamo fun ojo meta. Lehin ojo keta laaro kutukutu ao ma bu die niwon ba mu, ase ni. Odaju, By By alfa ola oluwa phone no:08082392705 67. ATUDE TO GBONA ERONJA: Ori etu Egbo tude topo lopolopo Atare kan SISE RE:ao gbe ori etu sinu ape Ijogun, ao ko egbo tude le lori , ti yoo po dada pelu atare kan,ao jo, ao lo , ao da sinu nkankan. Ti aba fe lo lale tabi laaro, ao te ifa iwori otura si, ao pe gbolohun re bayi wipe Ao juba awon to laye, alade riko mope x3,etu lontumo fun olu igbo, efun edi asasi aransi, wa lo tu danu lara emi lagbaja omo lagbaja. Tude o x3 walo tu gbogbo ide buruku tonbe lara emi lagbaja omo lagbaja wa lo tu danu lati oni lo. Iwori otura o x3 imo otun, imojo awon ota lori emi lagbaja omo lagbaja wa bami lo tu danu lati oni lo, ki ona mi kosi, ki ona mi kola ,komo araye la ona ire kan mi, ao se adua si dada, ao da senu. N.B By alfa ola oluwa phone no:08082392705 68. IMULE AWON AGBA ERONJA: Eye kanakana kan Oga gbigbe meta Eku asin gbigbe meta Opolo gbigbe meta Atare meta SISE RE:ao jo gbogbo re papo, ao lo kunna dada, ao ma fi mu eko gbigbona pelu ori N.B Ao ju ori sinu eko ki o yo, ki ato da ebu yen si. O daju By woli omo emi phone no:+22892588990 69. AWURE ERONJA: Iru wooro,iru pete,ogiri ati ewe tangiri SISE RE: Ao lo won papo , ao pomo ose Ghana(lagos di), omi agbon la o fi po papo Ao fi iku ijebu si arin ose yi, ao gbe pamo sibi oju miran ko ti leri Ao ma we laararo. odaju N.B By woli omo emi phone no:+22892588990 70. AWORO NLA ERONJA:agbado funfun topo ti ko si idoti Kankan lara re Ewa funfun topo die tosi mo dada Odindi atare kan, ao yin omo inu re lookokan 26 INA LOJU EKUN GROUP \ Igba ademu nla kan to nideri Eyele funfun original kan Igo epo Iyo die Oti die Apo ao funfun SISE RE:ao ko agbado,ewa ati atare sinu igba nla yen, ao gbe eyele yensi laaye, ao tu epo si legbe , ao de pa, ao gbe sinu apo as funfun yen, ao gbe ile si shop abi office ti afe gbe si , ao s saara ki ato ri mole, ao bu iye die ati oti die si isale, ao gbe igba ye sinu re ao gbe pako kan le lori, ao bo mole. O daju N.B: ti eyele yen ba lo ogun odun ko ni ku. By woli omo emi phone no:+22892588990 70 B. AWORO NLA SISE RE:ao ko agbado, ewa,oka baba, gbogbo re funfun sinu igba , ao gbe eyele sinu igba, ao da oyin ati epo si, ale da igo kokan si tabi die die, ao de igba yen , ao gbe sinu apo aso funfun , ao ri mole. N.B: ti o ba pe osu mefa eyele yen ma jade, yoo fo kaakiri inu shop abi office wa,ao gbodo pa o, yoo wole pada. Ti o ba di osu meta si yoo tun jade , yoo lo fun osu mefa , ti oba ti npada bow a, oun ati awon eyele to po ni won yoo jo wa, ao se sara fun won, oun yoo wole pada , awon yoo ku ma pada lo. Oti bere ise niyen oo. O daju By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327 70 C. AWORO NLA Aworo yi dara debi wipe aworo awon emere ni emi manpe ERONJA: eleyi ni adun,imumu, ireke,omi ti won fi we omo tuntun ati wipe igba kolo/ igba aje ni won fin se eyi, koni epo sugbon oni oyin ninu. SISE RE: ao se bi ati se awon yoku sugbon ti aba ri mole ao ri flag funfun mo ibi ti aba ri ise yi mo, ti igi/ irin re yoo wa legbe igba yen. Lehin ojo keje eyele yi yoo jade , yoo wa si ori flag yen , yoo fo kaakiri, yoo lo ko awon eyele miran wa, ao se sara fun won, yoo si wole pada. Ise bere niyen. o daju. N.B By Dr. owo agbarabalogun ina loju ekun phone no:08063207857 71. ASIRI BIBO ERONJA: eyin pepeye kan Atare kan Ewe bomubomu 28 SISE RE: ao fi ewe 16 tele ape ,ao fi eyin le lori pelu atare, ao ko ewe toku le lori,ao jo Ao lo, ao pin si ona meta, ao ma fi Holland peak milk lo ikokan lojo mejomejo. By woli omo emi phone no:+22892588990 72. ISORA AGBARA Ise yin ma nse fun ti eyan ban leri ogun siwa tabi awon kan nsasi wa tabi ala alakala kan, ti aba sa ise yi lese kese ni nkan yoo ma sele si eni ti o se nkan si wa ERONJA:alakan aye kan 27 INA LOJU EKUN GROUP Odindi atare 3 Alangba aponri aye 1 Opolo aye 1 Ikoko tuntun meta SISE RE:ao jo alakan pelu odindi atare kan ninu ikoko kan, ao lo, ao ko si egbe kan ao jo alangba aponri pelu odindi atare kan ninu ikoko keji, ao lo, ao ko si egbe kan ao jo opolo pelu odindi atare kan ninu ikoko keta, ao lo, ao ko si egbe kan, ao ro meteta sinu ado ato kekere kan, ao fi super glue le enu re pada, ao pa lawo dudu(black) , ti abati fe lo ao mi ado yen si eti otun ao so gbolohun yi wipe talo nba mi fori wonri x3,alagbaka ton bami foriwonri iye ko lori, opolo ton bami fori wori ko niru,alangba ton bami fori wonri oro ido bale loba, gbogbo eni ti o ban ba emi lagbaja omo lagbaja fori wonri, osho ile ni,aje ile ni etc ki won ma ri emi lagbaja omo lagba se, ao mi bee si eti osi na pelu gbolohun yi. o daju By suffism abu fatihat li hairi abu tohaphone no:08037384289 73. AWORO NLA Ise yi je aworo nla to tun sise oshole ton mu nkan nlanla wa fun ni ERONJA:Olongbo dudu kan Odindi atare mewa Eku asinrin mewa Opolo mewa Orogbo mewa Oju musu(eso werenjeje) agolo kan Adie abo dudu kan SISE RE:ao jo olongbo, atare, asinrin, opolo,oju musu ati orogbo papo, ao lo ti yoo kunna , ao ko si ibi kan Ao pa adie dudu yi ao gun kunna dada, ao fi ko ose, ao da etu ti a gbe si egbe kan si ao gun kunna dada , ao ko sinu ike nla kan. Odi wiwe.o daju By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289 74. OLUGBOHUN ERONJA: Oromodie ti o sonu leyin iya re Iwo agbo kan Ewe ewuro Aso pupa Ose dudu SISE RE: ti aba ti ji ni aaro kukukutu lai ti soro si eni Kankan, ao lo ja ewe ewuro, ao gun mo ose dudu,ao mu oromodie tele inu iwo agbo yen, ao fi ose dudu ti a gun yen bo lori , ao fi aso pupa we, ao gbe si igun ile ti idi re ko ni kanle fun ojo mesan,lehin ojo kesan ka danwo. O daju By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289 75. OSHO OWO TUTU ERONJA: odidi eye okin kan Ori akala 3 28 INA LOJU EKUN GROUP Ori oka 3/ 7 Ori ere 3/7 Iye agbe 7, iye aluko 7,ikode 7, Ewe etiponola 101 Ori eye okin kan Ori igun ti ko ju rara SISE RE: ao gun odidi eye okin,ori akala,ori aka,ori ere, iye agbe, iye aluko,ewe etiponola gbogbo re papo mo ose oni ye kiye, Ao wa awo funfun ti ama ko ose yi si, ao fi ori eye okin tele awo yi, ao ko ose ti ati gun le lori, ao wa fi ori igun kan gun lori. Emeji pere lao ma we ose yi laarin osu kan By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289 76. OSHOLE ASINA ERONJA: Ewe ajeobale (ti aja laaro kutukutu ti a ti soro si eyan kan) Ako alangba 16 Abo alangba 16 Odindi alare 15 Oti shynap igo kan Eyin ororo Oyin igan kidi SISE RE:ao jo ako ati abo alangba pelu atare, ao gbe si egbe kan, Ao gbo ajeobale ti a lo ja laaro kutukutu lai soro si eni Kankan pelu oti shynap kan, Ao fo eyin ororo kan si ati oyin gidi, ao po papo dada, ao ma fi lo ebu yi larolaro. O daju faa N.B Ale fun eyan lo ninu re sugbon ao ni ti fieyin si omi yen ki ato fun eniyen, eniyen naa ma foe yin odidi kan si tie naa ni o By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289 77. OSHOLE TON SISE AWORO ERONJA: omo aja 1, omo olongbo 2,ileke itun, ileke ifa,oga aye 4,abeere topo die Iye agbe 4, iye aluko 4,ikode 4,obi ifin oloju merin 4, obi ipa oloju merin 4,yanrin okun .yanrin osa. SISE RE: ao gun gbogbo eronja yi papo ti yoo kunna dada,ao gun mo ose ti yoo kunna dada, ao ko sinu igba olomori kan,ao fi kale fun ojo mesan, lehin ojo kesan ao bere wiwe re, o daju By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289 78. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: 29 INA LOJU EKUN GROUP N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: 30 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: 31 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: 32 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: 33 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: 34 INA LOJU EKUN GROUP SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 35 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 36 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 37 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 38 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 39 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 40 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 41 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 42 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 43 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 44 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA 45 INA LOJU EKUN GROUP ERONJA: SISE RE: N.B By 17. OSHO OWO NLA ERONJA: SISE RE: N.B By 46