Uploaded by Affiliate Samly

540839328-Iwe-Ogun-Ibon-ati-ada-Fol-1-1

advertisement
IWE OGUN
IBON ATI ADA
Lati owo woli Adejorin Michael a k a iyamah iyamah
Tel. +2348038891962 / +2348122840384
1, OGUN IBON TODAJU.
Obi abata alawe mefa (6), odindi ataare kan, pata funfun kan,
singileti funfun, handkerchief funfun kan.
SISE RE:- Ao wo pata naa, pelu singileti, ao wa pin obi yen si ona
mefa, ao bo atare yen kuro ninu epo re, ao pin si ona mefa naa,
ao to ni atare kan obi kan titi yio fi pe ona mefa ni enu ona wa. Ao
kun le tii ogun yii ao ka apawa mejeji seyin, ao bere sini fi enu gbe
je. Ti aba ti jetan ao mu oti eebo le opari.
2, ASO ERE FUN IBON
Ewe agogo igun a o tu tegbotegbo idi mesan,ao ra ikoko tuntun
ao ko ewe ye idi marun tele ninu koko ye na ao ra singlet tuntun
ao fi le lori ao wa ko idi merin toku le lori ao bu omi si ao se to
maho daada ao yo aso ye kuro ao sa to ba gbe ao ma wo si isale
aso wa kosi ibon naa to ma wole si wa lara
3, KII IBON DI ODI KO MAALE SORO TI WON BAYIN
ewe iroko eyokan ao fi we orogbo kan ti ko gbodo han sita Ao je
a ko gbodo ya enu ti ao fije tan.be enina ko gbodo soro si eniyan
ti yio fi je tan.
4, TI WON BA FE NAWA NI OGUN BURUKU TABI FI
BONILOWO,
OWO OLUWA RE YIO KAKO,OJO NA LO MAKU...
Ori oka nla kan,adigbonnaku lopolopo,ewa ikakure to Kako daada
lopolopo,ao jo po ao lo kunna daada, gbere meta ni waju ori àti
ipako,meta ni oke egbe eti osi àti otun.....Lobatan.....Odaju bi
iku,owo re yio Kako titi ti yio fi ku nio
5, ATIDIJO TO DAJU TI KO NAWA JU #50 LO
eo lo wa eyin ororo kan eo fi omi inu igi,abi ito aifohun se,ao mulo
si ori akitan olojo pipe tia ba tife ya igbe,tigbe ba
se njade ni idi wa ni esekese ni ao so eyin yi si enu ti eo sije
tepotepo,Ko si nkan ti ko mu.ewore,ao gbodo je eyin abo mo,ao si
gbodo do obo lateyin lobaten.
6, OGUN IBON TI IBON FULANI KOLE MU:
Ado ijamo kan ao dalu Lori ao da omo inu re nu lai fe ategun sinu
ado yeoo ao wa ewe eyinolobe ao gbo po mo iyo dada ao wa ki
sinu ado ye tiyio Kun demudemu ao fi igi bomubomu diilenu pa ao
we ni efewu ao di ni ikobere ao wa ran owo eyo ti ko luju meji mo
lara ni egbe kookan ao lo palawo funfun oju owo eyo naa yio jade
legbe mejeji Hmmmmm eniba laya ko doju G3,MAk3,Ak tabi ibon
Fulani tabi bororo ko wallahi yio semi arare lofo nio
7, KI IBON MALE SORO
Awo iki Ifun aja Danadana 9, Labalaba 9 ,Eyo atare 9,Ao gun
wonpo,Ao su roborobo Ao fi igi tisinu ifun Aja,Ao gbe nsinu Apadi
ijogun Ao fo eyin Adiye Meji si,Ao wa gbe pamo fun Ojo 7,Lehin
Ojo7,Ao sagbe Ao ran ni Aso funfun ao fi se igbadi Ti Abafe
danwo Ao gbe ko Aja lorun.
8, AJESARA
Ao toju igbin bonu kan ao pa ao fi Efon yin Ope ge si Ekiri mesan
ao lo wa ewe ailu mesan ti kolu Rara pelu ogoman Ope sonso
orire mokanla idi Ope kokan lao tige kokan ti yo fipe mokanla ati
eso afola mesan pelu iyere merindinlogun (16) Ao lo wan papo Ao
fise igbin ti age yen epo pupa koni ni iyo a ko gbodo fi irin tabi sibi
iro obe na ni ori ina,ipele tio fi ge igbin yen lao fi ro obe najinna ao
gbe lo si ori odo tia man fi gun iyan jije orire ni ao ti Je ni agogo
kan oru ni ihoho Ao ni wo aso ikokan ni ao ma mun Ekiri igbin na
ju si enu ako gbodo mun Meji papo titi ti Ao fi Je tan,
(ibon,ada,aike,obe,gbogbo irin ogun Oti di ewo Lara wa niye o)
9, OGUN KI IBON DI OMI:
Ao lo wa omi inu isa alakan ao fi gbo ewe rinrin ao ma mun
diedie.
NB:ti a ba fe yewo ao ro die sinu black nylon ao so ko ao wa yin
ibon si.Ibon naa yio di omi.Iba eyin ajuni loooo
10,OGUN IBON
eso ibepe kekere tio sese hun ao loja ao wada oju olo dele ao
duro si ori olo na ni ihoho ao je eso na pelu atare aja odidi kan tia
ti bo epo ara re ti abaje tan ao wamu omi glass cup of water ao
wa so wipe moba iwo ise yi mule pe odi ojo ti eni ti oduro sori olo
tio si da omi simi lara ki ibon to ranmi
11, AYETA IBON TODAJU
ewe itoro,ao fi omi gbo dada,ao da sinu pot kan,ao da rice sinu
pot naa,ao tun ko ewe itoro miran lee lori ti yio bo mole dada,ao
wa gbe kanna,ao se ti o ba jina,ao ko awon ewe orire ye danu,ao
je rice naa o dajuooo
TI_ABAFE_DANWO
ao da die lara rice ye sile fun adie kio je tio ba ti je rice yen, ao wa
yin ibon fun adie yen,walahi ise yii daju gan ooo gbogbo eyin tie
sope kosi ogun ibon #_AK-47 tabi N-4 tabi pistol iwo dan ise yii
wo walahi ninu epe tabi adura wa fikan ranse ninu re
2
itanna sawerepepe 21,eyo atare 21,ao lopo,ao fi sin gbere yipo
orun owo wa mejeji,ao nije ki gbere na ja papo ooo
12, AYETA IBON TO DAJU PAA
ewe ailu 201,tiko dalu rara,eyin ope towo sile funrare ko niye,odidi
atare kan,ao ko gbogbo re sinu fila gobi tia tinlo dada,ao jopo,ao
ma fifo eko tutu mu lekokan , Nb:- eyin ope towo sile nigba ti won
koiti ge igi yen sile nio
13,OGUN AYETA
ti ko Ni wahala ninu rara ko da ki won maa ro ojo ota ibon naa ko
ni de odo wa laelae 1.
Eso bomubomu ao rora laa die ao wa fi eyin ororo kan sinu
re ao bu omi die si ao se ti yio jinna ao je eyin na epo re ati
eso yii ao jo po mo padi atare kan ao ko sinu owu otutu ao
di ni ikobere ao gba ni awo dudu ao mafi si ara
2
ewe sewon lapa sewon lese ao lo kunna daada ao lo ewa funfun
agolo kan Ni ekuru ao po Ogun yii mo lai Ni fi iyo si ,ao fi sinu ewe
ao fi su ekuru yi si ona marun ti oba jinna enikan yio je eyo kan.ko
da ale yin ibon si ara ewe na a lati fi danwo ko ni ran rara.sugbon
ooo Abo olorun nipon ju gbogbo re lo o
14, OGUN IBON TO DAJU
Gege bi gbogbo wa se mo pe aye ti di aye BokoHaram bakan na
a oro awon Fulani naa ko gbeyin won tipa omo olomo lekun koda
elomiran ti di alabo ara fun idi eleyii eje kia gba ogun ibon yi o
daju bi ku
Eje kia toju ibepe dudu kan tiko Kanle ao pani pansa ao wa fi
afatan irun eni to fese ise yii sinu re pelu odidi atare kan ao jo po
ao fisin gbere yipo ikun, Ikilo : - eni to ni irun nikan ni yio lo ise yio
bi beeko hmmm
15, FUN AYETA IBON.
Orogbo odidi kan.Ao fi ewe oye we..Ao tun fi ewe iyalode we, Ao
ka ese kuro nile..Ao di oju wa,Ao so ipese yi si enu,Ao je lenu ao
si gbe mi..Ao yaju leyin ti abaje tan,ao tun ka ese sile'(Odigba
tiwon ba diju ti ese won ko si kanle ki ibon to le wole si eniyan
lara.
16, OWO IBON YI DAJU KERE GAN GBIYANJU E WO
egun igi ata ao fi ada ha kuro lara igi re,egun igi araba ao fi ada
ha kuro lara igi re,ewu iyan ojo keji gbobgo nkan yi odi inu agbada
ao jo bi aba
jo tan ao lo yio kunna dada eleyi tia ba fe lo ao te ni ejiogbe,
<OFO RE>
egun ata kigun ata denu egun araba ki gun araba denu ewu iyan
ojo keji kijo ni lowo ao fifo eko odidi kan mu odaju ju ada lo ogun.
17, OWO IBON,ADA,IGO ATI IGI
eso inu apawa meta(3)ao jo eyo kan mo odidi atare kan ao fifoko
mu lekana.ao jo eso ekeji pelu odidi atare kan ninu agbada
miran,ao fisin gbere yi ikun wa ka ebu ti o ba ku ao danu.ao jo
eleketa pelu odidi atare kan ninu agbada o to,ao di sinu owu otutu
ao di ni ikobere owu dudu ati funfun ao ran ni ifunpa,awoa ye ni
ao fi bo oju ogun apa otun awo funfun apa osi awo dudu
odaju,mo juba eyin agba ajunilo eje ko ju mi se o.
18, OGUN AFANTA TO DAJU.
ao lo ra eso ose ao da ni pansa ao wo gbogbo omo inu re danu
ao fi koro owu ropo eso ye tomakun daada ao wa ki odidi atare
kan bo inu re ao fi owo ki wonu re daadaa ao tun mu koro owu
miran ao tun ki mo ao fi omori re de ao jo toba jo tan ao lo ti yio
kunna ao ma fi eko elewe lo leekan kan odaju ti won banyin eyi
keyi ibon siwa yio fundanu kole bawa odaju pa
19,OGUN IBON
Ao wa igba olomori kekere kan ao fi ewe tagiri oojo tiko dalu
Mesan tele inu re,ao bu rice iwonba ti aleje tan si,ao tun fi ewe
tagiri Mesan Miran bo ao bu omi si,ao de pa,ao gbe kana,ao se
jina,toba jina tan idi re ko gbodo kanle,ao je,ti a baje tan a le dan
ibon wo lara eran tabi adiye ti a ba fun ni rice na je,ti eru ban
bawa,ki a de igba yen kia gbe sile ki adan ibon wo lara re
20, OGUN OKIGBE ATI IGO ATI IRIN
awo iki,werenjeje merindinlogun 16,omo irula
merindinlongun 16,omo atare merindinlogun 16 etu ibon
gidi nioo,ao gun gbogbo re po ti yio kunna daada ao wa fi
singbere yika idodo wa ao tun fi sin yika inu wa lati idodo
pada si idodo..
21, OGUN IBON TO DAJU.
ao lo o sa eyin to jabo fun raare 200,ao ko sinu agbada,ao fi odidi
ataare nla kan si,ao de pa,ao wa dana si nidi,ao ni si wo toma fi
jotan,ao lo ao maa fi fokomu,laarin osu kan tabi meji si meta,koi
pegba loruko e,ti won ba yinbon siwa ao sope koipe igba,
(henogoenter)untill ti won bayi igba ibon pe igba,ko de le
pe,toripe ti a bati nso wipe koipegba,won a da wo duro,onka maa
tun pada seyin ni,ko le pegba afiti ao ba soro to fi pegba loku.
22, AYETA IBON TO DAJU
ori ako alangba,ao lo eyo atare mesan si enure ao wa jopo ao fi
singbere mesan si aya wa odaju gan ni oo
23, OGUN AYETA AYIN KU..ATIDIJO TO DAJU PA.
ako alangba ati abo alangba ao ko eyin won sira ninu ape
ijo gun ao fi atare aaja kan bo laarin,ao jo papo.ao fi sin
gbere lati iwaju ori de ibadi.
n.b: - enikeni ti o ba doju ibon kowa ni yo ku o.
24, AYETA IBON
ti won ba fi aso pupa senu ibon koni ranwa. ao ge ori adaripon a o
fi sinu ape ijogun wa,ao fi aso pupa die si,pelu odindi atare kan si
ao jo papo..
lilo re : - ao fi sin gbere lati orokun ese de koko ese ni isale
mejeji..odaju.
25, OGUNTIAFINYOATA:
ewe arojoku,odidi atare kan,ao jopo,ao lo etu ibon origina mo,ao
wa fi sin gbere dorika ibiti won ti sowa lata ao fi ebu yi ra
26, OGUN IBON ONIFILA
ao wa ako alangba aye ati owo eyo kan ti oluju ao tibo alangba yi
lenu ti yio de inu re ao wa de male di ojo keji tio ba di ojo keji ao
wa po owo eyo ye jade lati idire ao waran owo eyo yi ma fila Gobi
ninu ao ma de, yin ibon si fila yiwo tested and confirm alelo
alangba ye fun nkan mi
27, OGUN ATIDIJO IBON,TO SURE.
omo ayo tiwan tita dada 9,ao mi meseesan pelu eyikeyi
(any),okele onje,ao wa ya mo igbe,ao fi akisa kan nu arawannu
dada,ao wa mu omo ayo 1,werenjeje 1,omo atare 1,ao fi sinu owu
tutu ao di ni ikobere,ao sebe lona mesan,ao ko si inu abo kan,ao
wa pa eje ‫ يببواكيد‬kan si,ti
a wan ogun yi ba ti fà eje re mu,ao ran gbogbo pata ni onde si oju
kan na tabi kia ran mo ara bante,
nb: - atidijo ni,,ti wan ba yin iban siwa,wallahi yio gba eyin jade ni
pelu ogo oloun.
28, OKIGBE
ikode kan,etu ibon oyinbo,egungun ori monu die,ao lo papo ao fi
sin gbere yika ori wa ni sale irun
29, AYETAIBON
ideri oti gudar meji,ao ko eyo atare mesan si,eso afola mesan si
ao de ao we lowu dudu ati funfun,ao ma fi sara jade
30, OKIGBE
opolo ijokun kan ao ko oruka si ninu ao lori mo ori akitan di ojo
keta pere
31, AYETA
oju olongbo 16 ,eyo atare 16,ao di ni aso pupa ao ma fi sara jade
32, OGUN IBON,ADA
e lo wa odidi alangba adaripon kan eyin ororo tojoo nio tabi ti ko
ba ti ju ojo marun lo,odidi atare kan e jo papo,gbere 14 si ori,14 si
aya,,14 si eyin,ki e fi iyoku fokomu
33, OGUN IBON TIDIYO TO DAJU
Odidi eyin ibile kan,ao lu lori ao ko eyo atare 201 sinu re,ao lu
tagiri lori,ao gbe eyin ye sinu tagiri,ao gbe tagiri nah kana,ao se
lori adiro,ti obati gina,todipe tagiri tinjoo nidi,ao gbe tagiri kuro lori
inaa,ao yo eyin na lati idi tagiri ao je eyin naa tepotepo laifi ese
kan le. Comfirm ni Joooo
34, IBON
ire sile ewe oparun 16 ,oju musu 16,eyo atare 16,lopo
gbere 16,si apa mejeji
35, OGUN TI WON BA FI ASO PUPA SI ENU IBON,
odidi orogbo kan,ao lo mi ao yo ninu igbe,ao dini aso
pupa,ao jo pelu odidi atare kan,ao fi sin gbere 9,si aya pelu eyin
36, IBON.
Eso ewe owu akese eyo meta,ewe rinrin ao jo po pelu odidi atare
kan ao fi sin gbere si egbe otun ati tosi ni meta meta.
37, OGUN OWO FUN ONI FAYAWO TO DAJU
òkun Maka 1,Eko Odindi kan,Àkàrà elepo,Orun(neck)inú
aaka,Odindi atare 1,Ao jo wan papo,ao ko sìinú aṣọ waji, ao dí pò
niikobere ao ma fi sì àpò Sokoto ní igbàgbogbo.
OFO RE.....
Akiipé olórí kí ayo obe3×,Akiipe alákàrà kí ayo idà3×,Akiiri òkun
Maka kía yín ibon3×,Orun tí aaka bale inú ara rẹ Lomanlesì......
Aniyan.Odaju ko da osise ju isuju miran lọ.A kiifi jalèooo,eni to ba
fijale to ba ja delọ òun ko ni yio pada wọlé lojona
38, AYETA
obi abata oloju meta3,ewe ogbe ori akuko eyo meta 3,eyo atare
meta 3,ota ibon eyo meta 3,ao la awe obi yen si ona meta 3,ao
mu obi abata awe kan 1,eyo atare kan 1, ewe ogbe ori akuko eyo
kan 1,ao lo papo ao fi
ota ibon kan 1 si ,ao su rugudu bi robo ao wa sa si iboji beni ao se
she meteta ao sa ao fi sinu okele ao su ao fi run obe ao gbe min
ojo meta ni ao filo ise yi odaju gan.e je ka she oto inu oto inu lo ja
ooo
Note; ao gbodo ya igbe si ori apata ooo ikilo ni yio ojo taba ya
igbe si ori apapta gbogbo nkan taba min ni ao ya mon igbe ooo
39, OGUN OWO IBON TO DAJU
ao wa arigisegi ao ko oju olongbo mesan eyo atare mesan ao ro
sinu re ao we ni owu dudu ati funfun ao ma so moorun wa edan
wo
40, "KOO WOLE IBON"
alakan kan,omole tope kan,odidi atare kan,ao jo ao fi fi si
eyo kan si iwaju ori
41, IBON
oka baba pupa 21,oju werenjeje 21,eyo ataare 21,ao gun
po'gbere si ejika mejeji
42, AYETATODAJU
Ewe osan wewe,eso afola,eso oju ologbo,ao gun gbogbo re papo
mo ose.Ao waada eso oju ologbo sinu ose na.ao maa fi we.NB:Bi eso oju ologbo na seun jabo,beeni ota ibon ti won ba yin siwa
yio ma jabo sile.
43, OGUN IBON TO DAJU
ibepe pipo kna ao ja ko gbodo kanle,ewe ailu 201oju olongbo
201,eyo atare 201ao da ibepe ye ni pansa,ao ko awon nkan
wonyi si ao fi ideri re de pada ao di lowu ko ma ba tu ao jo ao lo
ao fi sin gbere 201,si ori wa odaju opo eniyan lo le lo.
44, OGUN IBON OLOSU METAMETA.
ewe etipon ola kan kogbodo luoo omo atare kan,ododo imi esu
kan ao ko won sinu ewe etipon ola yen,ao we papo ao ju sinu ona
ofun wa lo kogbodo kan eyin wa ooo,ao,ma,se,ni osu
metameta,.....aje sara ibon niooooo
45, OGUN IBON.
ao wa eso bomubomu tio tobi julo lori igire,ao ja,ao lo lori olo,ao
lora ogi tutu funfun,ao fi omi die fo ogun ti o wa lori olo si,ao po
papo ao diju gbemi!!!!!!!!!
46, OGUN AYETA IBON TO DAJU
ao wa eso gure eyo kan ati eyo atare eyo kan ao gun papo ao fi
sin gbere meta si aya wa, e mase fi oju di ogun na nitori o daju
47, ASAKI IBON TO GBONA GIDI
ori omonile pelu ori ako alamu,ema ti ori omonile bo enu alamu
ewa fi sinu aso funfun e ran pa ele ran ni ikorun tabi ki ema fi
sapo lo ba tan ele sa sorun ki oba mama run mofi ifa bura lori ise
yi bi won ba yin ibon lu yin ti ise yi de wa lara yi ibon na ko ni dun
rara mo ibon na de ti baje niyen .
48, ASIRI TI IBON FULANI FI DOMI TABI ASAKI IBON
TODAJU PECENT SURE GRANTED ,
eyin pepeye kan ewe eyinolobe odidi atatre kan sisere aofi eyin pepeye
sinu ape ogun wa aowa yin atate odidi kan lelori aowa da ewe yen bo
lori mole aojo ogun yen toba jotan aowa so ka ori table kan awa tafelo
ogun yen ese wa kogbdo kanle rara, aowa duro sori odo taba
fesingbere yen,aofi singbere yipo ikun wa , eleyi toba ku ao fi fo
ekomu,dupe kole je fun
49, ASAKI IBON TODAJU
ako alangba kan ao yin odindi atare sinu abo (plate) kan ao ko eso
werenjeje sinu atare yi ti yio po ao ma ko sinu alangba na ti yio kun
daada ao wa na oruka straight sinu alangba na ti yio wole daada ao wa
fi odindi atare kan ha lenu ao jo papo bio ba jotan ao ma fi oruka na
sowo ao ma fi oti lo ebu tio ku na haaaaa ogun de kosi iru ibon tiwon le
koju re siwa ti yio dahun yio ma pacap ni koda ibi ti ise yi je de ti ba je
eni ti o wa legbe wa ni won fe yin ibon fun ibon na koni dahun
odamiloju biku
50, ASAKI IBON
efo rinrin tutu,ao fi tele ape,ao wa fi eyin adiye oronro kan, si ao fi
omi ara efo yi se jina, ao wa je eyin yi tepotepo
51, AYETA TODAJU ..
itana ako ibepe oojo ao Jo pelu odidi atare kan,gbere meta meta lorike
ara wa...ti aba fe danwo ao yin ibon fun IKOKO naa.
Download