Uploaded by lanrey87

ETO ANU ATI IBUKUN

advertisement
ETO ANU ATI IBUKUN:
Oyin igan ao da si inu ike funfun kan, ao fi iyo die si, ti oba di ago mejila si meta oru ao tan abela blue,
green ati white ikokan yii ise po, ao wa ni ihoho omoluabi tabi ki awo aso funfun ni kan, ao ka psalm 51
pelu adura idarijin ese wa, ao duro fun bi iseju marun, ao wa bere si ni ka awon ese bibeli yii Deu 28: 113, Psalm 88, 67, 72, 4 ati 16 pelu Oruko Mimo Yii - ELI-BIRAKA (7TIMES) JEHOVAH JIREH (7TIMES)
AFARAYAH (7TIMES) si pelu adura edun okan wa bi aba se fe ao mala laro kutu ki to soro si eni keni, atun
ma fi pa ori idodo wa. Ojo to dara ju lati fi se ise yi ni ojo wednesday.
Download