1. ATUDE Isu ogirisako, eru alamo, ata-ijosi - 16, ao gun papo mo ose, aofi omi agbon kan po ose yi, ao mafi epo pupa paara kia towe. 2. ASINA OWO Ewe tude at egbo re, aolo aofi ose iwe emeta po, ao lo fun ojo meta, ao mawe ni ago mejila osan abo (12:30pm), kehinkehin meta fun ojo meta. 3. ASINA Opolo nla gbigbe meta odidi atare meta, aojo opolo kan odidi atare kan, elekeji be, eleketa be, ao di si oototo ao mafi miliki olope lo ni ibere osu (1st, 2nd, 3rd). 4. ASINA Iwo agbo kan, ewe oriji - igbe adie, igeb ewure, igbe aguntan, aojowon papo, kosi atare nibe o, ao mafi omi tabi Hot lo. 5. OGUN IKO Epo ekika - igi tete regun - eru - aoko sinu ikoko aoma mu, ao da omi si, ao ma mu. 1 6. EYIN DIDUN TODAJU Ikamodu meje - kuluso meje - eyo atare meje etu ibon ojuda, aolo ni eyin odo, ao fi sin gbere iye kiye si eyin, ao fi sin gbere kookan si oju, ao fi eyi toku se onde mo idi. 7. ERO ATA SISONI Imi pepeye - imi elede - ako okuta, ao lowon po, ao mafi pa oju ata na. 8. ORUN DIDUN Ewe ito - egungun orun aja - odidi atare kan, ao lo, ao fi oripo, ao mafi pa orun na, ni igbakugba. 9. ATEPA TODAJU Egbo botuje - egbo ifon - egbo arunpale - ewe arojoku - eso orombo wewe mewa(10) - egbo agbosa, ao ko won sinu ike tabi ikoko kan, ao fi omi aro re, ao ma fi we ese wa jade, iseyi dara gidigan latmalo bi enikan ba lerisiwa pe ohun yio da ogun kale funwa. 10. OGUN MARAN FUN MAGUN TABI AISAN 2 Ewe ewon, elegun, ao gbo pelu omi, ao yo omire ao fi se igbin nla kan je, kosi epo tabi yo. 11. APETA TABI APEPA Isawuru kan - et ikun mejeji - omo inu ekuro meji - atare odidi kan, ao jo papo, ao lo, ao fi sin gbere yipo egbegbe et mejeji. 12. AJEGBE TODAJU Egbo werepe - egbo ina funfun - ese akuko adie mejeji - odid atare kan, ao jo papo, ao dasinu adin eyan fun lila. 13. AJEGUN Egbo lapa funfun - odidi atare kan, ao jopo, ao lo ao mafi epo pupa la ni alale. 14. OSE ITUWO ALAGBARA Aopa ako alagba merin (4), aoko meta sinu aope fun jijo pelu odidi atare kan, ao ko ewe alupaida lelori, ao jopo ao lo kuna, ao fi ose gbana po, ose yi papo, ao ko ose yi sinu igba olomori, ao de igba yi, ao wa pa eje alangba kan toku le le ori omori igbayi at ori igbana, aowa gbe ose yi si origun yara fun ojo meta, 3 odi ojo kerin kia to bere sini we, ago mewa si mejila ni wiwe, pelu kehin-kehin tuntun. Pelu ogo olohun ide ara re yio tu. 15. AWURE OBINRIN Ewe afaimonikonimora - ewe sawerepepe irun iyamopo, ao gunpo mo ose dudu ao mafi we ni araro. 16. ATEPA Eso laa pupa - oju ologbo lopolopo - omo atare lopolopo, ao gun won papo, ao fisin gbere yipo ese wa mejeji, opo eyan lelo. 17. OGUN EYONU AWON IYA AGBA Ewe ajeobale tutu - ewe aje tutu, ao lowonpapo mo iyere, ao fi se eran ewure je lepo niyo. Enikeni tobaje aseje yi odaju wipe eran ara re t di ewo fun awon aje nu ni. 18. ISORA Ori aparo gbigbe kan - odidi atare kan, ao jo papo, ao lo kuna, ao fi sin igbere 21 si arin ori wa. ENIKAN ISE KAN. 4 19. OSE ATI ETUTU AWON AGBA Akara elepo 16, ao ko sinu awo amo, ao da opolopo sugar did lelori, ao se adua si, ao gbe sita tabi orita meta, ao lo wo ni ojo keji twon bat gba, ao wa mu ikoko na wale. Ao wa lo ja ewe ewuro, ao lo wa egbo ewuro, ao gun mejeji papo, ao fi ose po, ao wa ko ose yi si inu ikoko ta gbe wale yen, leyin ojo keta ao ma fi we. 20. ISORA FUN IYAWORE Iboju igbin funfun kan, ao lo mo ori, ao ma fib a obinrin na sun, okunrin miran o nile sun mo mo. Erore: Ojo t obinrin na ba bimo ni yio ba je. 21. OBA AWURE Irun ori were, eso owu akese tko lanu towu sori akitan, ori akuko adie kan, eja aro, ewe oriji, ewe ajeobale, odid atare kan, ao jopo, ao fi ose dudu ko ose yi, ao kosinu igba lomori 5 tuntun, kehinkehin tuntun ni ao ma fiwe. Gbolohun re:Ona kona ni emi lagbaja omo lagbaja fe ki owo gba de owo mi loni. Ona kona ni were n gba wolu Ojumo ki mo ki ojo mayo Odun ki dun ki owu mala Agbele gbayi nit akuko adie Ki owo bami la lejo loni. 22. ASEJE AWURE Omunu iyalode funfun 9/7 - ewe ola die iyere ao lo po, ao fi se igbin nla kan je lodidi lepo niyo. 23. ISOYE Eja ojiji oiye kan - ewe oniyemiye - odidi atare kan, ao jopo, ao da sinu oyin fun lila. BIBO ASIRI Ewe emile - ewe omisinmisin gogoro - ewe onitkut - ewe imi esu - ata ijosi, ao lo papo, ao fi se ponmo ta ge si 16 je lepo niyo. 24. DABI PADA (BACK TO SENDER) 6 Aobu eru oju aro die, iyo die, ao lo po mo ose dudu, ao ma we ni ekan losu. 25. OSE AWURE OSHOLE Ewe abamoda - ewe owuake se, ao gun pomo ose dudu, ao fi oga oiye tele inu igba, at eja ojiji oiye kan, ao wa ko ose yi le lori, ao de igbayi, ao gbe pamo fun ojo meje, ao ma we ni araro kutu ai. 26. EYONU TODAJU Ori ologbo nla kan, ao dalu ni arin ori, ao wa fi atare aja si, ao gbe si nu ikoko, ao we ko opolopo ata ijosi lelori t yio bo dada, ao jo, ao lo, ao da sinu epo pupa fun lila. 27. EYONU Ori ako alangba kan - odidi atare kan, ao jopo, ao lo po, ao fi sin gbere yika ibadi wa. 28. EYONU FARAMORA Ori owiwi kan - ori orete kan - ori ologbo kan, ao jo po, ao lo, ao po mo ose, ao fi lofinda eyikeyi po ose na, ao ma fi we. 29. BI AIYE BADE EYAN MOLE 7 Okete oiye kan, ao gun pelu ata ijosi die, epo obo die, iginla ewe orijin die, ao gun won papo, ao fi ose dudu ko, ao ko ose na sinu ike oda. Lilore:- Enit aiye ban se yio mawe ninu ajadi apare. 30. OSE AWURE Wara malu t awon Fulani man ta eyo kan, ao gun pelu ewe iyalode 9/7, ao fi ose dudu po, ao ma fi we. 31. ASINA Osun at iyo, ao lo papo, ao fi ose dudu ko, ao mafi epo pupa pa ara, ki a to ma we. 32. OSHOLE Ori aja gbigbe aofi N500 si ni et mejeji, ao ko ewe ola si leni, ao ju sinu ape, ao ko ewe sawerepepe bomole, ao fi odidi atare kan jo papo, ao lo kuna, ao ma fi Hot loni araro, pelu adua. 33. ASEJE BASIRI 8 Oga gbigbe kan, ao lo kuna, ewe abamoda, ao lo kuna, ao fi din eyin ibile tabi agric meta je, ao lo iyere mo epo at iyo ni ao fi din. 34. AJEPO TABI APOJE Kehinkehin ibile t ao mo eni to fiwe rara, ao mu ao jo pelu odidi atare kan, ao fi sin gbere yika orun. 35. ASETA Okan eiyele kan - ase oka kan - horo omo atare mokanla, ao jo papo, ao lo, ao fi sin gbere lat eyin orun de ibadi. 36. ATUDE ELEDIDI Ori ologbo kan - bara odidi kan - ewe ela odidi atare kan, ao jo papo, ao lo kuna. Gbolohun re:- Ona ki dimo ologbo komole pa eku je Aki dibara komo tu Ewe ela loni ki ona la fun mi loni Onile alejo omode agba kiwon nlawa fi owo se ike mi at ige mi ao po ogun yi ni ose ni o, ao mawe ni araro 9 37. EYONU Ewe ewuro - ewe orijin - ewe ajeoble, ao gun pelu ose dudu, ao fi ori po ose yi, ao ma we ose na ni araro. 38. ASEJE ASINA Omudun iyalode - omudun ewuro - omudun ajeobale - ata ijosi, ao lo won papo, ao fi din eyin agric merin je pelu ori at iyo, ao se adua si, ao koje ni gbigbona, ao mu drink lelori. 39. IMULE IYA ODO Kerewu die - iyere lopo, ao lopo, ao fi se eiyele funfun kan, lepo niyo, ao wa gun iyan ta le jetan ninu odo, ao gun dada, ao ma fi yen run obe ninu odo na ni, yi o wa, ao ni ko kuro. Gbolohun re ta banje:Eyin toloye mobayinmule lo ni o Aje kije owu akese 10 ao wa maje, odaju. 40. ASEJE ASINA OWO KIAKIA Ewe aje - owo paper tuntun kan - owo eyo ailu kan - egbo tude - ata ijosi, ao lo papo, ao fi din eyin agric meta je ni owuro kutu ojo alamisi (Thursday) ao se aseje yi lepo niyo, ao je lai fohun si eni kan kan. 41. IMULE Opolo ijoku mewa (10) - odidi atare mewa (10), ao ko tele ape, ao ko ewe koropo tutu le lori, ao jo papo, ao lo kuna, ao ma fi adin eyan la ni alale. 42. OWO IBON Omo atare kan - esan gure kan, ao lo po, ao fi sin gbere kan si aya, ao tun mu omo atare kan, eso gure kan ao lo fi sin gbere kan si eyin. 43. EBE AGBA 11 Omunu ewe akoko - ewe omisinmisin gogoro, ao gun papo mo ose dudu, ao fi eyin ororo ibile kan po ose yi, ao ma we ni alale, tabi araro. 44. ETUTU IRORUN ao jo opolo oiye kan at odidi atare kan, ao jo, ao lo kuna dada, ao wa ge eran elede si (16), ao ko sinu ikoko amo, ao wa da ebu t a jo yi lelori, ao se adua si, ao wa bu epo pupa lelori, ao gbe losi orita meta, tabi ibikibi. 45. EYONU Ewe odundun - ewe orijin, ao sa yio gbe dada, ao lo kuna, yi o di powder, ao da sinu oyin fun lila. 46. ORUKA FUNFUN EYONU Aoko ewe anu tele ape ao ko ewe imi esu le, ao tun ko ewe omisinmisin pelebe le lori, ao wa fi oruka funfun kan le lori, tabi iyekiye, ao fi odidi atare nla kan lelori, ao tun wa ko ewe anu le, ao tun ko ewe rerin komi le, at 12 omisinmisin, ao de pa, ao jo papo, ao lo yio kuna, ao da ebu yi sinu oyin fun enikeni to ba fe lo ninu oruka yen o. 47. ASINA Ewe iyalode funfun, ao fi owo otun ja meta, ao fi owo osi na ja meta, ao lo papo, ao fi ose dudu po, ao fi oyin igon po ose na, ao mawe ni araro. 48. AJESARA Ori pepeye kan at ese re mejeji - ewe alupaida - odidi atare kan, ao jo papo, ao lo, ao fi si gbere mesan (9) si arin ori. OPO EYAN LELO. 49. ASEJE AJEGUN Eja ojiji kan - ewe ojiji tutu - ewe esinsin tutu, ao lo won papo mo iyere die, ao fise eja na je lepo niyo, ao so si ori osuka, ao ni san owo wanu kia to je, ao fi ahonn la gbogbo ikoko na dada, at owo wa. 50. BIBO ASIRI 13 Omunu ewuro meje - iyere ewe ola, ao lo papo, ao fi din eyin agric meji je lepo niyo. 51. PROMISE AND FAIL Odidi eiye kowe kan - opolopo egbo tude odidi atare kan, ao lopapo, ao lo, ao ma fi omi gbibona lo tabi Hot lo ni araro. 52. AYETA Oju ologbon 16 - omo atare 16, ao disi inu aso pupa, ao ma ju si apo jade. 53. IFUNPA AGBARA Ori ako alangba kan, ao ri oruka elelo kan bo lenu, at eyo atare meje, ao we ni owu dudu at funfun, ao kan ni ifunpa. 54. AGBO EYONU Egbo orijin oojo die - egbo ajeobale - egbo lapa funfun, ao gewon keke sinu igo funfun nla kan, ao fi N200 tele inu igo yi kia to ko awon egbo yi si, ao wa bu ot lelori, ao wa gbe pamo fun ojo meta, ao wa ma mu. 14 55. KI AMA LE JE OGUN LOJU ORUN Iwe adie, ao jo pelu odidi atare kan jijopo, ao fi fo ekomu ni ekan soro. 56. AWOKA Eru alamo eso - ejinrin wewe - egbo afon kafura pelebe, ao gun papo mo ose dudu, ao ma fi we gbogbo ara wa. 57. ASINA ao gbe asinrin tele ape, ao ko opolopo egbo tude lelori, ao ko opolopo ewe orijin lelori, ao jo pelu odidi atare nla kan, ao fi Hot lo ni aro kutu. 58. ASEJE BASIRI Ewe birana 16 - ata ijosi 16, ao ge ike malu si meta, ao se lepo niyo, ao je. 59. EYONU AWON AGBA 15 Eku asin tutu eyokan, ao fitele ape, ao ko aiye onbe (3) yika inu ape na gbigbe nio, ao tun fi odidi ewuro meta si, ao ko ewe ewuro oojo bo mole, ao jo, ao lo, ao ma fi epo pupa la ni ale at aro. 60. IPESE EBE AWON AGBA Eso ibepe t eye jeku lori igi, ao jo, ao ma bu si ori ipese. 61. IPESE EBE AWON AGBALAGBA Eso ibepe dudu to t gbo, ao be epo arare danu, ao wa be tnu re kekeke sinu pot, ao koko san idot re nu na o, ao wa se lori ina, ao fi epo pupa si, ao se bi asaro, ao wa kosi inu awo ipese, ao toro nkan ta ba nfe lowo awon agba, ao gbe lo si orita meta, tabi iwaju ita. 62. IPAPA EYONU Owo eyo ailu meji, ao lopo, ao da si inu igo olomori, ao tu adi-agbon si at lofinda olorun, ao mafi para. 63. ATUDE 16 Ao lo epo obo kuna dada, ao lo ewe ola na kuna dada, ao lo mejeji papo, ao de sinu ike ragolisi, ao ro omi si leyin ojo keta, ao ma bu sinu omi iwe wa. 64. OSE ATUDE AWON AGBA Ao ko ifun ako alangba kan, ata ijosi, epo obo die, ao lo pelu ose dudu ta o fi we ni ekan pere, ao wa ko eso werejeje sinu ako alangba yi, ao fi odidi atare kan si egbe re, ao jo, ao lo, ao wa lo we ose yi ni orie, ao wa lo ebu yi t a ba de pelu miliki olope. 65. AFOSE Ori oka ta pani oojo at ese re - odidi atare kan, ao jo po, ao lo kuna, ao wa lo imi ojo pupa kuna dada otoo ni aolo imi ojo o, ao wa dapo mo ebu t a jo yen, ao lo won papo, ao wa bu die lara ebu yi, ao fi po ose dudu die, ao ko sinu iwo etu, ao di ebu toku pamo, ao ma fi ahon kan sonkan ta ba nfe. 17 Ofore:- afeka ni aiye nfe na, aranka ni orun nran, gbogbo eranko t oka ba fie nu so, enu oka ni kusi, gbogbo nkan tmo ba ba lagbaja omo lagbaja so ni kio ma gbo. 66. OSHOLE POKIKI ENI Aoko ewe ajidagba tele inu ape, ao gbe ako ijapa lelori, ao ko ewe ajidagba miran bomole, ao wa to eyin ibile 16 yika re, ao ko ewe sawerepepe oojo lelori, ao fi N1000 lelori, ao wad a opolopo ewe ola lelori, ao fi odidi atare kan le, ao jopapo, ao lo kuna dada, ao ma fi Hot lo ni araro, odara fun olorin at awon oni sini ma, at alfa, pastor. 67. OSE EYONU Ewe iyalode funfun, ao ja ewe iyalode pupa, ao ja, ao gun kuna, ao fi ose dudu po, ao ko sinu ike funfun, ao fi ori le lori, ao gbe si orun t yio yo, ao fi owo ro papo, ao ma fiwe ni araro. AKIWE NI SATIDE (SATURDAY) O. 68. BIBO ASIRI 18 Ako ori alangba meta tutu ni o, ao fi N1000 tuntun kan tele inu ape, ao ko ori alangba yi le owo yi lori, ao fi atare kan le lori, ao jo papo, ao lo kuna dada, ao di pamo, to batdi ago mejila oru, ao lo ni ekan soso pelu Hot. Akiyesi:- a tun le fi ewe ewuro oojo mesan bo lori. 69. EYO MOTOR TODAJU Epo irugba - epo igi ope, ao gun mejeji papo, ao ko sinu efewu, ao wa di gege bi olonde, ao fi irun ikun si, ao ran ni onde, ao ma so mo idi. 70. OGUN ARANSI TABI ASASI Ewe oriri, ao lo pelu iyere, ao fi ro efo je pelu eran elede lepo niyo. 71. ISOYE Akara elepo meta, ao fi oje iroko gba, ao je okan ni idubule, ao je okan ni ori irin, eketan ori ijoko. 72. AYETA 19 Ori ako alangba kan, ao fi sinu ape, ao fi aso pupa die si, ao jo pelu odidi atare kan, ao fi singbere lat orukun de kokose mejeji. Odaju twon ba so aso pupa mo enu ibon koni bawa. 73. EYONU TIPA TIPA Ewe iyalode funfun at pupa - ewe ewuro ewe ajeobale - epo obo die, ao jowon papo, ao fi ose dudu ko, ao fi ororo malu po ose na papo, ao mafiwe ni araro 74. EYONU AWON AJE Ewe esemikalu (ewe ata adaleba) - ogbe ori akuko adie kan, ao gun papo mo ose dudu, ao ko sinu ike funfun, ao mafiwe ni alale. 75. ATUDE Ao gbo ewe ewuro oojo pelu omi, ao lo epo obo kuua ao da sinu omina, ao da eje aguuta si omina, ao fi san ara. 76. ISOYE 20 Eiye awo kan - aso were die - odidi atare kan, jijopo ao da sinu oyin ogidi, ao ma la ni emeji ni arin ose. EME JI NI OSE NI O 77. OWO (RESPECT) Eku eliri egungun ologbo die - epo atare nla kan, ao gbe awon kiniyi sini epo atare na, aowe ni owu pupa, aotun we ni odi awo pupa, jijo sapo. 78. AWEGUN - WEPE ITUWO Itana ako ibepe - egbo tude - epo obo, ao gun won papo mo ose dudu, ao pa eyele kan funfun si inu omi t afe fiwe ninu ajadi apere ni ao t we. 79. ASINA ONISEMEJI Esuru gudugudu die - esuru jije die, isu emina - eru Alamo - epo obo die - ewe ewuro egbo tude - ata ijosi - ako alangba kan, ao gun gbogbo won papo, ao fi ose dudu ko, ao fi ororo malu po ose na papo dada, ao ko si inu igba olomori, ao mafi omi gbigbona we lararo, 21 ao mafi omi tutu we ni ale. Pelu ogo olohun ona yio si, odaju. 80. ASINA Ao lo aloomo funfun at epo obo po, ao fi ose dudu po, ao ko ose na sinu fila oni fila tabi ki a ko si inu fitla oloju kan. 81. OSHOLE Odidi lili kan - ewe alupaida lopo - odidi atare kan, ao da opolopo oka baba pupa lelori, ao do po, ao lo, ao ma fi epo pupa lani alale, at araro. 82. OSHOLE Ori okete kan - ori aluko kan - ori agbe kan ori ologbo kan, ao jo pelu N500 tuntun kan, ao jo, ao lo, ao lo pelu eko elewe ni aro, osan, ale ni ojokan. 83. OSHOLE AWURE Ogede agbagba meta - epo jebo - tagili meta - odidi atare kan, ao jo, ao lo pelu sugar onikoro, ao ma lo pelu omi tabi Hot. 22 84. OGBOJU EYONU AGBARA AJE ATI OSO Epo obo die - ewe bomubomu 16, ao lo won ni otooto, ao wa dawonpo, ao tun lo won po, ao po lose dudu, eje elede ni ao fi po ose na. Akiyesi: bi aje kan ba doju kowa ni asiko t aba nwe ose yi lowo warapa ni yio gbe, opo eyan le we ninu ose na, leyin ojo keje t warapa mu yio kuni. 85. OWO TODAJU Ewe akoko tkolooju kan, ao ko ese werenjeje 9, omo atare 9, ikamodu 9, ao di pelu ewe akoko na, ao dini ikobere, ao maju si apo tabi kia fi se onde. 86. ISORA AWON AGBA Odidi awo lili kan - odidi atare kan - epo obo, ao jopo, ao lo kuna, ao ma fi sin gbere yipo idi. Opo eyan lelo. 87. MADARIKAN Igbe ewure loro kan, horo omo atare kan, ao lo papo, ao fi sin gbere kan, si iwaju ori, pelu 23 gbolohun wipe bi ewure ba boju weyin a fi epe fun elepe. 88. OSE OWO AWON ELEYE Egbo legun loko - epo obo - eru alamo - eso werenjeje, ao gun papo mo ose dudu, ao ko sinu ike funfun, ao mawe. 89. APARUN GBOGBO NISE Ao fi ose dudu yi gbogbo ara odidi agbon kan, ao jo pelu odidi atare kan, ao ma fi fo eko gbigbona mu, atunle fi sin gbere yika idi ka fun iseto. 90. IMULE ASINA Oromo adie oiye kan, ao lani aya, ao ko omo atare 201, ata ijosi 201, ewe ela 201, ao ko sinu re, ao jo po, ao lo kuna, ao ma fi milk at oyin lo. 91. IFERAN Ota inu iroko - epo egusi lopo dada, ao lowon papo, ao da sinu bintu lofinda, ao ma fipa oju. 92. APARUN GBOGBO 24 Epo osan wewe - tagiri odidi kan - ewe oruwo, ao gunni agunmu, eko gbona ni ao mafi lo ni araro. 93. BIBO ASIRI Epo jebo - ewe teyinso - odidi atare kan, ao jo po, ao lo, ao ma fi odidi eyin bibo meta je. 94. EYONU ASINA Opolo ijokun nla kan, ao ro ata - ijosi si lenu t yoo kun, ao ki egbo tude bo lenu, ao ko ewe oriji le lori at odidi atare kan, ao jopo, ao lo kuna, epo pupa ni ao mafi la. 95. AROBI Arigisegi odidi atare kan - aso funfun die, ao jopo ao fi sin gbere 21 si arin ori, aofi ebu toku fo eko mu, ao gbodo sun mo obinrin fun ojo meta. 96. STROKE Omi idi igbin lopo - omi osan wewe - oyin igon - ororo malu, ao mix re papo, ao ma fi sibi mu ni meji lojumo. 25 97. OGUN IKO AWUGBE Obu otoyo at eru inu aro, ao to won papo, ao da sinu epo pupa fun lila. 98. ASEJE EYONU Ewe eyin olobe tutu - ewe rere ako at abo iyere, ao lo po, ao fi se eja aro gbigbe meta je lepo niyo. 99. INU KIKAN TABI INU RIRUN Ewe taba gidi - alubosa elewe - kafura pelebe meji, ao ki sinu igo pelu omi tutu, ao ma mu ni cup kookan laro lale. 100. AGBARA OTA Ikarahun igbin meji, ao lo okan mo omudun, ewe ewuro at ewe orijin, t yio kuna dada, ao fi ose ko sinu ikarahun ekeji, ao gbe sinu apo, aso funfun, ao gbe ko si oke, ao ma buwe ni alale kia to sun. 101. BIBO ASIRI 26 Aotu ewe etponla tegbotegbo, ao gun papo mo ose dudu, ao fi omi idi igbin po mo rawon, ao ko sinu ike funfun, ao mafi we ni araro. 102. EYONU Ewe ewuro - epo obo, ao gun papo, ao fie yin adie po papo mo ose, ao ma fiwe. 103. BIBO ASIRI Eso bomu bomu meta (3), ao la inu re, ao ki N1000 tuntun bo inu re. Ekeji ao ki odidi atare kan bo inure. Eketa ao ki irun ile barbar bo inu re, ao jo po, ao lo kuna, ao lo ni ekan tabi ojo meta. 104. ASEJE ARISIKI Ori okete gbigbe kan, ao lo kuna dada at ijosi, ao fi se eja aro ta gesi meta, lai ge ja je lepo niyo. 105. OSHO OWO KIAKIA 27 Ori ako alangba 21 - odidi atare 21 - owo eyo ailu 21, ao jowon papo, ao lo kuna, ao fi Hot lo ni ekan soso. 106. ATUDE TODAJU Ewe tude oojo - egbo tude, ao gun papo, ao fi iyo die si, ao fie je ekete kan po osena, ao gbe pamo fun ojo meta, ao mawe ni alale. 107. ASEJE BASIRI KIAKIA Ewe abamoda oojo mefa - ata ijosi to pe dada mefa, ao lo won papo, ao fi po eyin agric mefa, ao fi iyo die si, ao pop o dada, ao fi epo pupa din, ao sokale si ori nkan kan, ao wa daba owo si, ao ko je, ao mu any drink lelori. 108. OSE AWURE Ao gun eran elede kuna at ewe swerepepe, igbo mimu lopo, ao po lo se dudu, ao bu iyo si ose yi, ao gun po, ao ko si inu ike funfun, ao gbe sinu asuwon aso funfun, ao gbe ko, ao ma buwe lararo. 109. OWO 28 Owo eyo ailuju kan, ao ko omo atare meje (7) sinu re, ao di ni ikobere, ao ma ju si apo. 110. ISEGUN Epo obo - aso egungun lopo die - opolo oiye kan - odidi atare kan, ao jo po, ao lo, ao po mo ose dudu, ao ma fi we ni alale. 111. APORO OFA Gbogbo ifun inu okete, ao ko sinu keg 2liter, ao ju horo atare kan si, ao da Hot le lori, ao mamu. 112. IRIRAN POISON Ao ki ikode bo omole lenu, ao gbe sinu ape, ao fi atare odidi kan si egbe re, ao ko ewe ela oojo le lori, ao jo po, ao lo, ao fi sin gbere kookan soju, ao fi ebu toku fo eko tutu mu. 113. EJE RIRU 29 Akara ikan lopo, ao lo kuna pelu odidi atare kan, ao dasi nu omi osan wewe, ao ma mu gas kan ni aro aro. 114. ITO SUGAR Ao lo eso abere kuna, ao mafi fo eko mu ni aro ale. Odaju 115. OGUN TI ABA BA OBINRIN LOPO TAN TI AO FI OWO MU, O GUN TI KO SI NI BAJE. Efun osun ao lo won po, ao fi sin gbere yika inu wa. 116. OSHOLE Pepeye funfun kan, ao ki N1000 tuntun kan bo ni idi ni oiye, ao ran pa leyin iseju die, ao pa pepeye na sinu ape tuntun, ao gbe pepeye na si, ao ko ewe sawerepepe oojo orisin oojo, ao fi bo mole odidi atare kan legbe, ao jo po, ao lo kuna, ao ro sinu igo funfun, ao mafi Hot lo ni araro, lai fohun. 117. AGBOOJO AYETA 30 Ewe idoro, ao gbo pelu omi tutu, ao se sakit re danu, ao fi fo eko elewe odidi kan mu, pelu ogo olohun ise yi daju debiwipe biwon yin ibon lat oni di ola koni bawa. 118. LOFINDA ANU Ewe anu - ewe ola, ao lo kuna pelu ewe oriji at aje, ao lo won papo, ao da sinu lofinda eyikeyi, ao ma fipa oju owo at ara asowa. 119. ATUDE Egbo tude, ao lo kuna dada, ao fi ose dudu iwe emeta ko, ao ma fi epo pupa pa ara kia to we, ao we ni Monday to Wednesday. 120. ASEJE OWO (MONEY) Ewe eyin olobe oojo, ao lo pelu ata ijosi at N500 tuntun, ao papo, ao fise eja aro kan lobe lodidi, ao se adura si, lepo niyo ao je. Ao t jo ise yi kale - eiye onbe kan - odidi atare kan - atare ajanio, ao jo, ao lo, ao dasi owo alafia leyin t aje aseje yi tan, ao fi Hot lo ni ekan soso. 121. ASEJE BASIRI 31 Eiyele funfun kan, ao gesi 16, ao lo isu atewogba tutu die, isu tanapowo, epo jebo iru, iyere, ao lowon papo, ao fi won se eiyele yi je lepo niyo, ao je ni gbigbona, ao mu nkan to ba wu wa lelori. 122. OSE AWON AGBA Epo obo ao gun kuna dada, ao gun ewe ola mo, ao fi ose dud ko ose na, ao le mo eyin ilekun, ao ma bu we ni araro. 122. KI ASASI MARAN WA Ori eku asin kan - odidi atare kan, ao jo po, ao lo, ao fi sin gbere meje si arin ori. ENIKAN ISE KAN 123. ALA TI WON BAN BA OBINRIN LOPO LOJU Awo ijimere - iye etu - afara oyin iru obe odidi atare kan, ao jo po, ao lo, obinrin na yio mafi fo eko mu. 124. EYONU AWON AGBA Ewe iroko mesan, ao di mo owo t a bafe sun, marun ni owo kan, merin ni owo keji, t o ba 32 dale ta ba taji, ao gbodo soro si enikeni tt aofi jetan, ao wa lo ewe iroko yi loju olo, ao lo pelu iyere, ao fi se eku olose lepo niyo, ao wa fi iyere osun te ejiogbe. Gbolohun re:Gbogbo igi lodarijo ni gbo niwon fi iroko joba Gbogbo eko tn be nigbo olose nikan lo kun omore losun, larin elegbemi emi lagbaja omo lagbaja ni kin je olori, emi lagbaja ni ki je asiwaju bori - oloye, school, oiye oselu, kosi eyit aole lo fun nibe. 125. ASINBA TAPA Ogun yi buru toje pe eniba nbi inu siwa dandan ni ki aburu ko ba enina. Adie aasa kan orogbo mokanla (11) odidi atare mokanla (11) ao ko ewe mafi owokan omo mi at egbo akerejupon, ao jo, ao lo, ao ma fi po eko tutu mu. 33 126. OSE EYONU AGBA Ewe ajeobale - odidi igbin kan - ewe t esin sin bale, ao gun papo mo ose dudu, ao mafi ose na we ni alale. OPO EYAN LELO 127. OSE EYONU Ewe ajeobale - ewe ahoyaya - ewe aje, ao gun pomo ose dudu, ao fi oyin po, ao ma fi we. 128. IRORI AWON AGBA Egungun adie Aasa - iye adie kio po die - egbo akoko - ewe ajeobale (201) ao ko sinu aso funfun, ao di dada, ao ma fi si abe irori wa sun ni alale. Akiyesi:- Kosi iru agbara apeta na tabi asasi oru na konimuwa. 129. MADARIKAN Oju oro - osi bata - eko akoko t eleko bap on at eyi toba pon kehin, ao fi odidi atare kan, ao jo po, ao ma fi fo eko tutu mu. 34 130. AGBELEPOTA Egbo ila - egbo ata - egbo owu - egbo ikan odidi atare (3) - odidi alakan kan, ao jo papo, ao lo, ao ro sinu igo funfun. Gbolohun re:Aki gbori ila ka la Aki gbori ikan ka ikan Aki gbori owu yo owu Aki gbori atare ata Akan omo oluboro odo Oro buruku ni yio ma ba. Ao ma fi fo eko mu. 131. BASIRI FUN INAWO Ewe eyinbisowo tabi eyin olobe at ewe ogbo, ao gun papo, ao fi ose po, ao ko se na si eyin amu t won fi ponmi si, ao ma fi ose na we. 132. KI ALE RE OBINRIN FE Ewe emo abero defe, ao lo pelu iyere, ao fi se eran aguntan to yayi je tko t darugbo, ao se fun igba meta kia to ri oyawo gidi fe. 35 133. AJEPA Egbo yerepe - egbo esisi funfun - ebo se akuko adie - odidi atare kan, ao jo po, ao da si adin eyan fun lila. 134. ATOSI Omudun ewe - elu ewe - peregun wewe omudun ewe - ope ewe obi, ao fi orombo wewe gbo, ao ma mu ni die. 135. ADABI PADA TABI EPE EYIN Eso yerepe gbigbe to po - ori ijapa kan - eso omo inu koko twon ma nfun kale si oko iyekiye - odid atare kan, ao jo won po, ao fi ose po, ao fi okuta kekere kan tele inu igba, ao fi ori eyin adie so okuta na, ao sope: ojo te yin adie ba fi ori so okuta ojo na ni orore daru, ao wa koo ose yi le lori, ao so afoku eyin adie na nu. KI SE JI JE O Gbolohun re:Aredanu ni koko re pala Bi osa bap on yerepe agbon danu Epe iwaju epee yin kiran alabahun 36 Bi eyin adie ba fori so okuta oro re a baje Ao se adura si, ao ma fi we. OPO EYAN LELO NIBE 136. LOFINDA Ewe abamoda, ao gun po, ao fun omi ara ewe yi sinu abo kan, ao da omi yi sinu lofinda tolorun dada, ao ma fi pa oju, pa owo, pa ara. 37 AGBARA TAPA VOLUME 2 BY: AGBARA TAPA 1 Tel: 07066916943, 08100224521 38