Uploaded by ADETONA HUDHAEFAH ADEYEMI

Iwe Asiri AgbaraTapa

advertisement
1. ATUDE
Isu ogirisako, eru alamo, ata-ijosi – 16, ao gun
papo mo ose, aofi omi agbon kan po ose yi, ao
mafi epo pupa paara kia towe.
2. ASINA OWO
Ewe tude ati egbo re, aolo aofi ose iwe emeta po,
ao lo fun ojo meta, ao mawe ni ago mejila osan
abo (12:30pm), kehinkehin meta fun ojo meta.
3. ASINA
Opolo nla gbigbe meta odidi atare meta, aojo
opolo kan odidi atare kan, elekeji be, eleketa be,
ao di si oototo ao mafi miliki olope lo ni ibere osu
(1st, 2nd, 3rd).
4. ASINA
Iwo agbo kan, ewe oriji – igbe adie, igeb ewure,
igbe aguntan, aojowon papo, kosi atare nibe o, ao
mafi omi tabi Hot lo.
5. OGUN IKO
Epo ekika – igi tete regun – eru – aoko sinu ikoko
aoma mu, ao da omi si, ao ma mu.
1
6. EYIN DIDUN TODAJU
Ikamodu meje – kuluso meje – eyo atare meje –
etu ibon ojuda, aolo ni eyin odo, ao fi sin gbere iye
kiye si eyin, ao fi sin gbere kookan si oju, ao fi eyi
toku se onde mo idi.
7. ERO ATA SISONI
Imi pepeye – imi elede – ako okuta, ao lowon po,
ao mafi pa oju ata na.
8. ORUN DIDUN
Ewe ito – egungun orun aja – odidi atare kan, ao
lo, ao fi oripo, ao mafi pa orun na, ni igbakugba.
9. ATEPA TODAJU
Egbo botuje – egbo ifon – egbo arunpale – ewe
arojoku – eso orombo wewe mewa(10) – egbo
agbosa, ao ko won sinu ike tabi ikoko kan, ao fi
omi aro re, ao ma fi we ese wa jade, iseyi dara
gidigan latimalo bi enikan ba lerisiwa pe ohun yio
da ogun kale funwa.
10.
OGUN MARAN FUN MAGUN TABI
AISAN
2
Ewe ewon, elegun, ao gbo pelu omi, ao yo
omire ao fi se igbin nla kan je, kosi epo tabi yo.
11.
APETA TABI APEPA
Isawuru kan – eti ikun mejeji – omo inu ekuro
meji – atare odidi kan, ao jo papo, ao lo, ao fi
sin gbere yipo egbegbe eti mejeji.
12.
AJEGBE TODAJU
Egbo werepe – egbo ina funfun – ese akuko
adie mejeji – odid atare kan, ao jo papo, ao
dasinu adin eyan fun lila.
13.
AJEGUN
Egbo lapa funfun – odidi atare kan, ao jopo, ao
lo ao mafi epo pupa la ni alale.
14.
OSE ITUWO ALAGBARA
Aopa ako alagba merin (4), aoko meta sinu
aope fun jijo pelu odidi atare kan, ao ko ewe
alupaida lelori, ao jopo ao lo kuna, ao fi ose
gbana po, ose yi papo, ao ko ose yi sinu igba
olomori, ao de igba yi, ao wa pa eje alangba
kan toku le le ori omori igbayi ati ori igbana,
aowa gbe ose yi si origun yara fun ojo meta,
3
odi ojo kerin kia to bere sini we, ago mewa si
mejila ni wiwe, pelu kehin-kehin tuntun. Pelu
ogo olohun ide ara re yio tu.
15.
AWURE OBINRIN
Ewe afaimonikonimora – ewe sawerepepe –
irun iyamopo, ao gunpo mo ose dudu ao mafi
we ni araro.
16.
ATEPA
Eso laa pupa – oju ologbo lopolopo – omo
atare lopolopo, ao gun won papo, ao fisin
gbere yipo ese wa mejeji, opo eyan lelo.
17.
OGUN EYONU AWON IYA AGBA
Ewe ajeobale tutu – ewe aje tutu, ao
lowonpapo mo iyere, ao fi se eran ewure je
lepo niyo. Enikeni tobaje aseje yi odaju wipe
eran ara re ti di ewo fun awon aje nu ni.
18.
ISORA
Ori aparo gbigbe kan – odidi atare kan, ao jo
papo, ao lo kuna, ao fi sin igbere 21 si arin ori
wa. ENIKAN ISE KAN.
4
19.
OSE ATI ETUTU AWON AGBA
Akara elepo 16, ao ko sinu awo amo, ao da
opolopo sugar did lelori, ao se adua si, ao gbe
sita tabi orita meta, ao lo wo ni ojo keji tiwon
bati gba, ao wa mu ikoko na wale.
Ao wa lo ja ewe ewuro, ao lo wa egbo ewuro,
ao gun mejeji papo, ao fi ose po, ao wa ko ose
yi si inu ikoko tia gbe wale yen, leyin ojo keta
ao ma fi we.
20.
ISORA FUN IYAWORE
Iboju igbin funfun kan, ao lo mo ori, ao ma fib
a obinrin na sun, okunrin miran o nile sun mo
mo.
Erore: Ojo ti obinrin na ba bimo ni yio ba je.
21.
OBA AWURE
Irun ori were, eso owu akese tiko lanu towu
sori akitan, ori akuko adie kan, eja aro, ewe
oriji, ewe ajeobale, odid atare kan, ao jopo, ao
fi ose dudu ko ose yi, ao kosinu igba lomori
5
tuntun, kehinkehin tuntun ni ao ma fiwe.
Gbolohun re: Ona kona ni emi lagbaja omo lagbaja fe ki owo
gba de owo mi loni.
 Ona kona ni were n gba wolu
 Ojumo ki mo ki ojo mayo
 Odun ki dun ki owu mala
 Agbele gbayi niti akuko adie
 Ki owo bami la lejo loni.
22.
ASEJE AWURE
Omunu iyalode funfun 9/7 – ewe ola die iyere
ao lo po, ao fi se igbin nla kan je lodidi lepo
niyo.
23.
ISOYE
Eja ojiji oiye kan – ewe oniyemiye – odidi atare
kan, ao jopo, ao da sinu oyin fun lila.
BIBO ASIRI
Ewe emile – ewe omisinmisin gogoro – ewe
onitikuti – ewe imi esu – ata ijosi, ao lo papo,
ao fi se ponmo tia ge si 16 je lepo niyo.
24.
DABI PADA (BACK TO SENDER)
6
Aobu eru oju aro die, iyo die, ao lo po mo ose
dudu, ao ma we ni ekan losu.
25.
OSE AWURE OSHOLE
Ewe abamoda – ewe owuake se, ao gun pomo
ose dudu, ao fi oga oiye tele inu igba, ati eja
ojiji oiye kan, ao wa ko ose yi le lori, ao de
igbayi, ao gbe pamo fun ojo meje, ao ma we ni
araro kutu ai.
26.
EYONU TODAJU
Ori ologbo nla kan, ao dalu ni arin ori, ao wa fi
atare aja si, ao gbe si nu ikoko, ao we ko
opolopo ata ijosi lelori ti yio bo dada, ao jo, ao
lo, ao da sinu epo pupa fun lila.
27.
EYONU
Ori ako alangba kan – odidi atare kan, ao jopo,
ao lo po, ao fi sin gbere yika ibadi wa.
28.
EYONU FARAMORA
Ori owiwi kan – ori orete kan – ori ologbo kan,
ao jo po, ao lo, ao po mo ose, ao fi lofinda
eyikeyi po ose na, ao ma fi we.
29.
BI AIYE BADE EYAN MOLE
7
Okete oiye kan, ao gun pelu ata ijosi die, epo
obo die, iginla ewe orijin die, ao gun won
papo, ao fi ose dudu ko, ao ko ose na sinu ike
oda.
Lilore:- Eniti aiye ban se yio mawe ninu ajadi
apare.
30.
OSE AWURE
Wara malu ti awon Fulani man ta eyo kan, ao
gun pelu ewe iyalode 9/7, ao fi ose dudu po,
ao ma fi we.
31.
ASINA
Osun ati iyo, ao lo papo, ao fi ose dudu ko, ao
mafi epo pupa pa ara, ki a to ma we.
32.
OSHOLE
Ori aja gbigbe aofi N500 si ni eti mejeji, ao ko
ewe ola si leni, ao ju sinu ape, ao ko ewe
sawerepepe bomole, ao fi odidi atare kan jo
papo, ao lo kuna, ao ma fi Hot loni araro, pelu
adua.
33.
ASEJE BASIRI
8
Oga gbigbe kan, ao lo kuna, ewe abamoda, ao
lo kuna, ao fi din eyin ibile tabi agric meta je,
ao lo iyere mo epo ati iyo ni ao fi din.
34.
AJEPO TABI APOJE
Kehinkehin ibile ti ao mo eni tio fiwe rara, ao
mu ao jo pelu odidi atare kan, ao fi sin gbere
yika orun.
35.
ASETA
Okan eiyele kan – ase oka kan – horo omo
atare mokanla, ao jo papo, ao lo, ao fi sin
gbere lati eyin orun de ibadi.
36.
ATUDE ELEDIDI
Ori ologbo kan – bara odidi kan – ewe ela –
odidi atare kan, ao jo papo, ao lo kuna.
Gbolohun re:-




Ona ki dimo ologbo komole pa eku je
Aki dibara komo tu
Ewe ela loni ki ona la fun mi loni
Onile alejo omode agba kiwon nlawa fi owo se ike
mi ati ige mi
ao po ogun yi ni ose ni o, ao mawe ni araro
9
37.
EYONU
Ewe ewuro – ewe orijin – ewe ajeoble, ao gun
pelu ose dudu, ao fi ori po ose yi, ao ma we
ose na ni araro.
38.
ASEJE ASINA
Omudun iyalode – omudun ewuro – omudun
ajeobale – ata ijosi, ao lo won papo, ao fi din
eyin agric merin je pelu ori ati iyo, ao se adua
si, ao koje ni gbigbona, ao mu drink lelori.
39.
IMULE IYA ODO
Kerewu die – iyere lopo, ao lopo, ao fi se
eiyele funfun kan, lepo niyo, ao wa gun iyan
tia le jetan ninu odo, ao gun dada, ao ma fi
yen run obe ninu odo na ni, yi o wa, ao ni ko
kuro.
Gbolohun re tia banje: Eyin toloye mobayinmule lo ni o
 Aje kije owu akese
10
ao wa maje, odaju.
40.
ASEJE ASINA OWO KIAKIA
Ewe aje – owo paper tuntun kan – owo eyo
ailu kan – egbo tude – ata ijosi, ao lo papo, ao
fi din eyin agric meta je ni owuro kutu ojo
alamisi (Thursday) ao se aseje yi lepo niyo, ao
je lai fohun si eni kan kan.
41.
IMULE
Opolo ijoku mewa (10) – odidi atare mewa
(10), ao ko tele ape, ao ko ewe koropo tutu le
lori, ao jo papo, ao lo kuna, ao ma fi adin eyan
la ni alale.
42.
OWO IBON
Omo atare kan – esan gure kan, ao lo po, ao fi
sin gbere kan si aya, ao tun mu omo atare kan,
eso gure kan ao lo fi sin gbere kan si eyin.
43.
EBE AGBA
11
Omunu ewe akoko – ewe omisinmisin gogoro,
ao gun papo mo ose dudu, ao fi eyin ororo
ibile kan po ose yi, ao ma we ni alale, tabi
araro.
44.
ETUTU IRORUN
ao jo opolo oiye kan ati odidi atare kan, ao jo,
ao lo kuna dada, ao wa ge eran elede si (16),
ao ko sinu ikoko amo, ao wa da ebu ti a jo yi
lelori, ao se adua si, ao wa bu epo pupa lelori,
ao gbe losi orita meta, tabi ibikibi.
45.
EYONU
Ewe odundun – ewe orijin, ao sa yio gbe dada,
ao lo kuna, yi o di powder, ao da sinu oyin fun
lila.
46.
ORUKA FUNFUN EYONU
Aoko ewe anu tele ape ao ko ewe imi esu le,
ao tun ko ewe omisinmisin pelebe le lori, ao
wa fi oruka funfun kan le lori, tabi iyekiye, ao fi
odidi atare nla kan lelori, ao tun wa ko ewe
anu le, ao tun ko ewe rerin komi le, ati
12
omisinmisin, ao de pa, ao jo papo, ao lo yio
kuna, ao da ebu yi sinu oyin fun enikeni to ba
fe lo ninu oruka yen o.
47.
ASINA
Ewe iyalode funfun, ao fi owo otun ja meta, ao
fi owo osi na ja meta, ao lo papo, ao fi ose
dudu po, ao fi oyin igon po ose na, ao mawe ni
araro.
48.
AJESARA
Ori pepeye kan ati ese re mejeji – ewe
alupaida – odidi atare kan, ao jo papo, ao lo,
ao fi si gbere mesan (9) si arin ori. OPO EYAN
LELO.
49.
ASEJE AJEGUN
Eja ojiji kan – ewe ojiji tutu – ewe esinsin tutu,
ao lo won papo mo iyere die, ao fise eja na je
lepo niyo, ao so si ori osuka, ao ni san owo
wanu kia to je, ao fi ahonn la gbogbo ikoko na
dada, ati owo wa.
50.
BIBO ASIRI
13
Omunu ewuro meje – iyere ewe ola, ao lo
papo, ao fi din eyin agric meji je lepo niyo.
51.
PROMISE AND FAIL
Odidi eiye kowe kan – opolopo egbo tude –
odidi atare kan, ao lopapo, ao lo, ao ma fi omi
gbibona lo tabi Hot lo ni araro.
52.
AYETA
Oju ologbon 16 – omo atare 16, ao disi inu aso
pupa, ao ma ju si apo jade.
53.
IFUNPA AGBARA
Ori ako alangba kan, ao ri oruka elelo kan bo
lenu, ati eyo atare meje, ao we ni owu dudu
ati funfun, ao kan ni ifunpa.
54.
AGBO EYONU
Egbo orijin oojo die – egbo ajeobale – egbo
lapa funfun, ao gewon keke sinu igo funfun nla
kan, ao fi N200 tele inu igo yi kia to ko awon
egbo yi si, ao wa bu oti lelori, ao wa gbe pamo
fun ojo meta, ao wa ma mu.
14
55.
KI AMA LE JE OGUN LOJU ORUN
Iwe adie, ao jo pelu odidi atare kan jijopo, ao fi
fo ekomu ni ekan soro.
56.
AWOKA
Eru alamo eso – ejinrin wewe – egbo afon –
kafura pelebe, ao gun papo mo ose dudu, ao
ma fi we gbogbo ara wa.
57.
ASINA
ao gbe asinrin tele ape, ao ko opolopo egbo
tude lelori, ao ko opolopo ewe orijin lelori, ao
jo pelu odidi atare nla kan, ao fi Hot lo ni aro
kutu.
58.
ASEJE BASIRI
Ewe birana 16 – ata ijosi 16, ao ge ike malu si
meta, ao se lepo niyo, ao je.
59.
EYONU AWON AGBA
15
Eku asin tutu eyokan, ao fitele ape, ao ko aiye
onbe (3) yika inu ape na gbigbe nio, ao tun fi
odidi ewuro meta si, ao ko ewe ewuro oojo bo
mole, ao jo, ao lo, ao ma fi epo pupa la ni ale
ati aro.
60.
IPESE EBE AWON AGBA
Eso ibepe ti eye jeku lori igi, ao jo, ao ma bu si
ori ipese.
61.
IPESE EBE AWON AGBALAGBA
Eso ibepe dudu to ti gbo, ao be epo arare
danu, ao wa be tinu re kekeke sinu pot, ao
koko san idoti re nu na o, ao wa se lori ina, ao
fi epo pupa si, ao se bi asaro, ao wa kosi inu
awo ipese, ao toro nkan tia ba nfe lowo awon
agba, ao gbe lo si orita meta, tabi iwaju ita.
62.
IPAPA EYONU
Owo eyo ailu meji, ao lopo, ao da si inu igo
olomori, ao tu adi-agbon si ati lofinda olorun,
ao mafi para.
63.
ATUDE
16
Ao lo epo obo kuna dada, ao lo ewe ola na
kuna dada, ao lo mejeji papo, ao de sinu ike
ragolisi, ao ro omi si leyin ojo keta, ao ma bu
sinu omi iwe wa.
64.
OSE ATUDE AWON AGBA
Ao ko ifun ako alangba kan, ata ijosi, epo obo
die, ao lo pelu ose dudu tia o fi we ni ekan
pere, ao wa ko eso werejeje sinu ako alangba
yi, ao fi odidi atare kan si egbe re, ao jo, ao lo,
ao wa lo we ose yi ni orie, ao wa lo ebu yi ti a
ba de pelu miliki olope.
65.
AFOSE
Ori oka tia pani oojo ati ese re – odidi atare
kan, ao jo po, ao lo kuna, ao wa lo imi ojo
pupa kuna dada otoo ni aolo imi ojo o, ao wa
dapo mo ebu ti a jo yen, ao lo won papo, ao
wa bu die lara ebu yi, ao fi po ose dudu die, ao
ko sinu iwo etu, ao di ebu toku pamo, ao ma fi
ahon kan sonkan tia ba nfe.
17
Ofore:- afeka ni aiye nfe na, aranka ni orun
nran, gbogbo eranko ti oka ba fie nu so, enu
oka ni kusi, gbogbo nkan timo ba ba lagbaja
omo lagbaja so ni kio ma gbo.
66.
OSHOLE POKIKI ENI
Aoko ewe ajidagba tele inu ape, ao gbe ako
ijapa lelori, ao ko ewe ajidagba miran bomole,
ao wa to eyin ibile 16 yika re, ao ko ewe
sawerepepe oojo lelori, ao fi N1000 lelori, ao
wad a opolopo ewe ola lelori, ao fi odidi atare
kan le, ao jopapo, ao lo kuna dada, ao ma fi
Hot lo ni araro, odara fun olorin ati awon oni
sini ma, ati alfa, pastor.
67.
OSE EYONU
Ewe iyalode funfun, ao ja ewe iyalode pupa,
ao ja, ao gun kuna, ao fi ose dudu po, ao ko
sinu ike funfun, ao fi ori le lori, ao gbe si orun
ti yio yo, ao fi owo ro papo, ao ma fiwe ni
araro. AKIWE NI SATIDE (SATURDAY) O.
68.
BIBO ASIRI
18
Ako ori alangba meta tutu ni o, ao fi N1000
tuntun kan tele inu ape, ao ko ori alangba yi le
owo yi lori, ao fi atare kan le lori, ao jo papo,
ao lo kuna dada, ao di pamo, to batidi ago
mejila oru, ao lo ni ekan soso pelu Hot.
Akiyesi:- a tun le fi ewe ewuro oojo mesan bo
lori.
69.
EYO MOTOR TODAJU
Epo irugba – epo igi ope, ao gun mejeji papo,
ao ko sinu efewu, ao wa di gege bi olonde, ao
fi irun ikun si, ao ran ni onde, ao ma so mo idi.
70.
OGUN ARANSI TABI ASASI
Ewe oriri, ao lo pelu iyere, ao fi ro efo je pelu
eran elede lepo niyo.
71.
ISOYE
Akara elepo meta, ao fi oje iroko gba, ao je
okan ni idubule, ao je okan ni ori irin, eketan
ori ijoko.
72.
AYETA
19
Ori ako alangba kan, ao fi sinu ape, ao fi aso
pupa die si, ao jo pelu odidi atare kan, ao fi
singbere lati orukun de kokose mejeji. Odaju
tiwon ba so aso pupa mo enu ibon koni bawa.
73.
EYONU TIPA TIPA
Ewe iyalode funfun ati pupa – ewe ewuro –
ewe ajeobale – epo obo die, ao jowon papo,
ao fi ose dudu ko, ao fi ororo malu po ose na
papo, ao mafiwe ni araro
74.
EYONU AWON AJE
Ewe esemikalu (ewe ata adaleba) – ogbe ori
akuko adie kan, ao gun papo mo ose dudu, ao
ko sinu ike funfun, ao mafiwe ni alale.
75.
ATUDE
Ao gbo ewe ewuro oojo pelu omi, ao lo epo
obo kuua ao da sinu omina, ao da eje aguuta
si omina, ao fi san ara.
76.
ISOYE
20
Eiye awo kan – aso were die – odidi atare kan,
jijopo ao da sinu oyin ogidi, ao ma la ni emeji
ni arin ose. EME JI NI OSE NI O
77.
OWO (RESPECT)
Eku eliri egungun ologbo die – epo atare nla
kan, ao gbe awon kiniyi sini epo atare na,
aowe ni owu pupa, aotun we ni odi awo pupa,
jijo sapo.
78.
AWEGUN – WEPE ITUWO
Itana ako ibepe - egbo tude – epo obo, ao gun
won papo mo ose dudu, ao pa eyele kan
funfun si inu omi ti afe fiwe ninu ajadi apere ni
ao ti we.
79.
ASINA ONISEMEJI
Esuru gudugudu die – esuru jije die, isu emina
– eru Alamo – epo obo die – ewe ewuro –
egbo tude – ata ijosi – ako alangba kan, ao gun
gbogbo won papo, ao fi ose dudu ko, ao fi
ororo malu po ose na papo dada, ao ko si inu
igba olomori, ao mafi omi gbigbona we lararo,
21
ao mafi omi tutu we ni ale. Pelu ogo olohun
ona yio si, odaju.
80.
ASINA
Ao lo aloomo funfun ati epo obo po, ao fi ose
dudu po, ao ko ose na sinu fila oni fila tabi ki a
ko si inu fitila oloju kan.
81.
OSHOLE
Odidi lili kan – ewe alupaida lopo – odidi atare
kan, ao da opolopo oka baba pupa lelori, ao
do po, ao lo, ao ma fi epo pupa lani alale, ati
araro.
82.
OSHOLE
Ori okete kan – ori aluko kan – ori agbe kan –
ori ologbo kan, ao jo pelu N500 tuntun kan, ao
jo, ao lo, ao lo pelu eko elewe ni aro, osan, ale
ni ojokan.
83.
OSHOLE AWURE
Ogede agbagba meta – epo jebo – tagili meta
– odidi atare kan, ao jo, ao lo pelu sugar
onikoro, ao ma lo pelu omi tabi Hot.
22
84.
OGBOJU EYONU AGBARA AJE ATI OSO
Epo obo die – ewe bomubomu 16, ao lo won
ni otooto, ao wa dawonpo, ao tun lo won po,
ao po lose dudu, eje elede ni ao fi po ose na.
Akiyesi: bi aje kan ba doju kowa ni asiko ti aba
nwe ose yi lowo warapa ni yio gbe, opo eyan
le we ninu ose na, leyin ojo keje ti warapa mu
yio kuni.
85.
OWO TODAJU
Ewe akoko tikolooju kan, ao ko ese werenjeje
9, omo atare 9, ikamodu 9, ao di pelu ewe
akoko na, ao dini ikobere, ao maju si apo tabi
kia fi se onde.
86.
ISORA AWON AGBA
Odidi awo lili kan – odidi atare kan – epo obo,
ao jopo, ao lo kuna, ao ma fi sin gbere yipo idi.
Opo eyan lelo.
87.
MADARIKAN
Igbe ewure loro kan, horo omo atare kan, ao
lo papo, ao fi sin gbere kan, si iwaju ori, pelu
23
gbolohun wipe bi ewure ba boju weyin a fi
epe fun elepe.
88.
OSE OWO AWON ELEYE
Egbo legun loko – epo obo – eru alamo - eso
werenjeje, ao gun papo mo ose dudu, ao ko
sinu ike funfun, ao mawe.
89.
APARUN GBOGBO NISE
Ao fi ose dudu yi gbogbo ara odidi agbon kan,
ao jo pelu odidi atare kan, ao ma fi fo eko
gbigbona mu, atunle fi sin gbere yika idi ka fun
iseto.
90.
IMULE ASINA
Oromo adie oiye kan, ao lani aya, ao ko omo
atare 201, ata ijosi 201, ewe ela 201, ao ko
sinu re, ao jo po, ao lo kuna, ao ma fi milk ati
oyin lo.
91.
IFERAN
Ota inu iroko – epo egusi lopo dada, ao lowon
papo, ao da sinu bintu lofinda, ao ma fipa oju.
92.
APARUN GBOGBO
24
Epo osan wewe – tagiri odidi kan – ewe
oruwo, ao gunni agunmu, eko gbona ni ao
mafi lo ni araro.
93.
BIBO ASIRI
Epo jebo – ewe teyinso – odidi atare kan, ao jo
po, ao lo, ao ma fi odidi eyin bibo meta je.
94.
EYONU ASINA
Opolo ijokun nla kan, ao ro ata – ijosi si lenu ti
yoo kun, ao ki egbo tude bo lenu, ao ko ewe
oriji le lori ati odidi atare kan, ao jopo, ao lo
kuna, epo pupa ni ao mafi la.
95.
AROBI
Arigisegi odidi atare kan – aso funfun die, ao
jopo ao fi sin gbere 21 si arin ori, aofi ebu toku
fo eko mu, ao gbodo sun mo obinrin fun ojo
meta.
96.
STROKE
Omi idi igbin lopo – omi osan wewe – oyin
igon – ororo malu, ao mix re papo, ao ma fi
sibi mu ni meji lojumo.
25
97.
OGUN IKO AWUGBE
Obu otoyo ati eru inu aro, ao to won papo, ao
da sinu epo pupa fun lila.
98.
ASEJE EYONU
Ewe eyin olobe tutu – ewe rere ako ati abo
iyere, ao lo po, ao fi se eja aro gbigbe meta je
lepo niyo.
99.
INU KIKAN TABI INU RIRUN
Ewe taba gidi – alubosa elewe – kafura pelebe
meji, ao ki sinu igo pelu omi tutu, ao ma mu ni
cup kookan laro lale.
100.
AGBARA OTA
Ikarahun igbin meji, ao lo okan mo omudun,
ewe ewuro ati ewe orijin, ti yio kuna dada, ao
fi ose ko sinu ikarahun ekeji, ao gbe sinu apo,
aso funfun, ao gbe ko si oke, ao ma buwe ni
alale kia to sun.
101.
BIBO ASIRI
26
Aotu ewe etiponla tegbotegbo, ao gun papo
mo ose dudu, ao fi omi idi igbin po mo rawon,
ao ko sinu ike funfun, ao mafi we ni araro.
102.
EYONU
Ewe ewuro – epo obo, ao gun papo, ao fie yin
adie po papo mo ose, ao ma fiwe.
103.
BIBO ASIRI
Eso bomu bomu meta (3), ao la inu re, ao ki
N1000 tuntun bo inu re. Ekeji ao ki odidi atare
kan bo inure. Eketa ao ki irun ile barbar bo inu
re, ao jo po, ao lo kuna, ao lo ni ekan tabi ojo
meta.
104.
ASEJE ARISIKI
Ori okete gbigbe kan, ao lo kuna dada ati ijosi,
ao fi se eja aro tia gesi meta, lai ge ja je lepo
niyo.
105.
OSHO OWO KIAKIA
27
Ori ako alangba 21 – odidi atare 21 – owo eyo
ailu 21, ao jowon papo, ao lo kuna, ao fi Hot lo
ni ekan soso.
106.
ATUDE TODAJU
Ewe tude oojo – egbo tude, ao gun papo, ao fi
iyo die si, ao fie je ekete kan po osena, ao gbe
pamo fun ojo meta, ao mawe ni alale.
107.
ASEJE BASIRI KIAKIA
Ewe abamoda oojo mefa – ata ijosi to pe dada
mefa, ao lo won papo, ao fi po eyin agric
mefa, ao fi iyo die si, ao pop o dada, ao fi epo
pupa din, ao sokale si ori nkan kan, ao wa
daba owo si, ao ko je, ao mu any drink lelori.
108.
OSE AWURE
Ao gun eran elede kuna ati ewe swerepepe,
igbo mimu lopo, ao po lo se dudu, ao bu iyo si
ose yi, ao gun po, ao ko si inu ike funfun, ao
gbe sinu asuwon aso funfun, ao gbe ko, ao ma
buwe lararo.
109.
OWO
28
Owo eyo ailuju kan, ao ko omo atare meje (7)
sinu re, ao di ni ikobere, ao ma ju si apo.
110.
ISEGUN
Epo obo – aso egungun lopo die – opolo oiye
kan – odidi atare kan, ao jo po, ao lo, ao po
mo ose dudu, ao ma fi we ni alale.
111.
APORO OFA
Gbogbo ifun inu okete, ao ko sinu keg 2liter,
ao ju horo atare kan si, ao da Hot le lori, ao
mamu.
112.
IRIRAN POISON
Ao ki ikode bo omole lenu, ao gbe sinu ape, ao
fi atare odidi kan si egbe re, ao ko ewe ela
oojo le lori, ao jo po, ao lo, ao fi sin gbere
kookan soju, ao fi ebu toku fo eko tutu mu.
113.
EJE RIRU
29
Akara ikan lopo, ao lo kuna pelu odidi atare
kan, ao dasi nu omi osan wewe, ao ma mu gas
kan ni aro aro.
114.
ITO SUGAR
Ao lo eso abere kuna, ao mafi fo eko mu ni aro
ale. Odaju
115.
OGUN TI ABA BA OBINRIN LOPO TAN TI
AO FI OWO MU, O GUN TI KO SI NI BAJE.
Efun osun ao lo won po, ao fi sin gbere yika
inu wa.
116.
OSHOLE
Pepeye funfun kan, ao ki N1000 tuntun kan bo
ni idi ni oiye, ao ran pa leyin iseju die, ao pa
pepeye na sinu ape tuntun, ao gbe pepeye na
si, ao ko ewe sawerepepe oojo orisin oojo, ao
fi bo mole odidi atare kan legbe, ao jo po, ao
lo kuna, ao ro sinu igo funfun, ao mafi Hot lo
ni araro, lai fohun.
117.
AGBOOJO AYETA
30
Ewe idoro, ao gbo pelu omi tutu, ao se sakiti
re danu, ao fi fo eko elewe odidi kan mu, pelu
ogo olohun ise yi daju debiwipe biwon yin
ibon lati oni di ola koni bawa.
118.
LOFINDA ANU
Ewe anu – ewe ola, ao lo kuna pelu ewe oriji
ati aje, ao lo won papo, ao da sinu lofinda
eyikeyi, ao ma fipa oju owo ati ara asowa.
119.
ATUDE
Egbo tude, ao lo kuna dada, ao fi ose dudu iwe
emeta ko, ao ma fi epo pupa pa ara kia to we,
ao we ni Monday to Wednesday.
120.
ASEJE OWO (MONEY)
Ewe eyin olobe oojo, ao lo pelu ata ijosi ati
N500 tuntun, ao papo, ao fise eja aro kan lobe
lodidi, ao se adura si, lepo niyo ao je.
Ao ti jo ise yi kale – eiye onbe kan – odidi
atare kan – atare ajanio, ao jo, ao lo, ao dasi
owo alafia leyin ti aje aseje yi tan, ao fi Hot lo
ni ekan soso.
121.
ASEJE BASIRI
31
Eiyele funfun kan, ao gesi 16, ao lo isu
atewogba tutu die, isu tanapowo, epo jebo
iru, iyere, ao lowon papo, ao fi won se eiyele
yi je lepo niyo, ao je ni gbigbona, ao mu nkan
to ba wu wa lelori.
122.
OSE AWON AGBA
Epo obo ao gun kuna dada, ao gun ewe ola
mo, ao fi ose dud ko ose na, ao le mo eyin
ilekun, ao ma bu we ni araro.
122.
KI ASASI MARAN WA
Ori eku asin kan – odidi atare kan, ao jo po, ao
lo, ao fi sin gbere meje si arin ori. ENIKAN ISE
KAN
123.
ALA
TI WON BAN BA OBINRIN LOPO LOJU
Awo ijimere – iye etu – afara oyin iru obe –
odidi atare kan, ao jo po, ao lo, obinrin na yio
mafi fo eko mu.
124.
EYONU AWON AGBA
Ewe iroko mesan, ao di mo owo ti a bafe sun,
marun ni owo kan, merin ni owo keji, ti o ba
32
dale tia ba taji, ao gbodo soro si enikeni titi
aofi jetan, ao wa lo ewe iroko yi loju olo, ao lo
pelu iyere, ao fi se eku olose lepo niyo, ao wa
fi iyere osun te ejiogbe. Gbolohun re: Gbogbo igi lodarijo ni gbo niwon fi iroko
joba
 Gbogbo eko tin be nigbo olose nikan lo
kun omore losun, larin elegbemi emi
lagbaja omo lagbaja ni kin je olori, emi
lagbaja ni ki je asiwaju bori – oloye, school,
oiye oselu, kosi eyiti aole lo fun nibe.
125.
ASINBA TAPA
Ogun yi buru toje pe eniba nbi inu siwa
dandan ni ki aburu ko ba enina.
Adie aasa kan orogbo mokanla (11) odidi atare
mokanla (11) ao ko ewe mafi owokan omo mi
ati egbo akerejupon, ao jo, ao lo, ao ma fi po
eko tutu mu.
33
126.
OSE EYONU AGBA
Ewe ajeobale – odidi igbin kan – ewe ti esin sin
bale, ao gun papo mo ose dudu, ao mafi ose
na we ni alale. OPO EYAN LELO
127.
OSE EYONU
Ewe ajeobale – ewe ahoyaya – ewe aje, ao
gun pomo ose dudu, ao fi oyin po, ao ma fi
we.
128.
IRORI AWON AGBA
Egungun adie Aasa – iye adie kio po die – egbo
akoko – ewe ajeobale (201) ao ko sinu aso
funfun, ao di dada, ao ma fi si abe irori wa sun
ni alale.
Akiyesi:- Kosi iru agbara apeta na tabi asasi
oru na konimuwa.
129.
MADARIKAN
Oju oro – osi bata – eko akoko ti eleko bap on
ati eyi toba pon kehin, ao fi odidi atare kan, ao
jo po, ao ma fi fo eko tutu mu.
34
130.
AGBELEPOTA
Egbo ila – egbo ata – egbo owu – egbo ikan –
odidi atare (3) – odidi alakan kan, ao jo papo,
ao lo, ao ro sinu igo funfun. Gbolohun re:-





131.
Aki gbori ila ka la
Aki gbori ikan ka ikan
Aki gbori owu yo owu
Aki gbori atare ata
Akan omo oluboro odo
Oro buruku ni yio ma ba. Ao ma fi fo eko mu.
BASIRI FUN INAWO
Ewe eyinbisowo tabi eyin olobe ati ewe ogbo,
ao gun papo, ao fi ose po, ao ko se na si eyin
amu ti won fi ponmi si, ao ma fi ose na we.
132.
KI ALE RE OBINRIN FE
Ewe emo abero defe, ao lo pelu iyere, ao fi se
eran aguntan to yayi je tiko ti darugbo, ao se
fun igba meta kia to ri oyawo gidi fe.
35
133.
AJEPA
Egbo yerepe – egbo esisi funfun – ebo se
akuko adie – odidi atare kan, ao jo po, ao da si
adin eyan fun lila.
134.
ATOSI
Omudun ewe – elu ewe – peregun wewe –
omudun ewe – ope ewe obi, ao fi orombo
wewe gbo, ao ma mu ni die.
135.
ADABI PADA TABI EPE EYIN
Eso yerepe gbigbe to po – ori ijapa kan – eso
omo inu koko tiwon ma nfun kale si oko
iyekiye – odid atare kan, ao jo won po, ao fi
ose po, ao fi okuta kekere kan tele inu igba, ao
fi ori eyin adie so okuta na, ao sope: ojo tie yin
adie ba fi ori so okuta ojo na ni orore daru, ao
wa koo ose yi le lori, ao so afoku eyin adie na
nu. KI SE JI JE O
Gbolohun re: Aredanu ni koko re pala
 Bi osa bap on yerepe agbon danu
 Epe iwaju epee yin kiran alabahun
36
 Bi eyin adie ba fori so okuta oro re a baje
Ao se adura si, ao ma fi we. OPO EYAN LELO NIBE
136.
LOFINDA
Ewe abamoda, ao gun po, ao fun omi ara ewe
yi sinu abo kan, ao da omi yi sinu lofinda
tolorun dada, ao ma fi pa oju, pa owo, pa ara.
37
AGBARA TAPA
VOLUME 2
BY:
AGBARA TAPA 1
Tel: 07066916943, 08100224521
38
Download