AGBARA IGBAANI APA IKETA (PART 3) PELU AKOJOPO ASIRI ONA ABAYO LATI OWO ALAGBA OPEYEMI-DANIEL(OPA FITILA) TEL-07080271083 WEBSITE- AGBARAIGBAANI.BLOGSPOT.COM (1) ORO AKOSO Mo juba akoda aye, mo juba aseda aye, mo juba Olorun ton be ki aye toma be, mo juba Olorun ti yio si mawa nigbati aye koni simo Mo juba gbogbo ajunilo Mo juba gbogbo awon tiwon nbo leyin Mo se akojopo iwe yi Ni igbaketa fun iwulo gbogbo eda patapata, yala musulumi, chriteni,tabi elesin abalaye, AGBARA IGBAANI PART 3 eyi ti o fi ara pamo, fun awon eda kan ti o si han si awon eda kan gbangba. Ni sise iwe yi mo Juba Iya Mi Ti o Se Oloko Mi Wasi Aye Eniti o funmi ni opolopo alaye nipa awon ohun ijinle ti o wa ninu iwe yii Gbogbo awon ohun ijinle ti awon agba ijohun finse agbara ti o dabi wipe oti di igbagbe, ni atu jade ninu iwe yi, ki olukuluku ki o gbiyanju kio lo ni tire ni Elekefa seminar yii. Gbogbo awon egbogi inu iwe yi lo daju sakasaka. Gege bi ati fi idi re mule ninu alakoko Ejowo gbogbo eda ti o ba fe dawole ise inu iwe agbra igbaani yii ejo e je kia se ni mimo, pelu okan kan soso, Lagbara Olorun ao nise aseti laye (AMIN). (2) AKIYESI 1. Ti abafe we ose e mama jeki ama wo bata we 2. Gbogbo ogun ti aba nse ema jeko mawa ninu iyara ti atin ba obiri ni ajosepo 3.Ka jina si biba obirin lajo sepo lati eyin tabi ki obirin wani oke 4. Leyin ti aba ni ajosepo tan ao gbodo fi owo kan ogun kankan 5. Owo ti afin se ise ao gbodo fima finger obirin 6.Leyin ojo keta ti aba lajosepo tan aye wa funwa lati fowo kan ogun 7.Efi ojo meta tabi merin sile teba se ogun tan kie to sunmo obirin 8.Ki obirin oni isun eje, mase fowo kan ise wa tabi wo ibi ti anko ogun si 9.Olo ti abafinlo nkan eje ki ama fi ewe rinrin ati ewe safara pelu epin fo oju olo na nu 10. Ti aba njo any ise lowo ki ama so kio maba foo tio bati fo koni sise mo 11.Tia aba njo ise aje ki ama fi epo yi idi reka 12. Ti abanjo ogun lowo ki a ma fi epo obo si egbe aro idana wa 13.Ti aba nlo ise lowo ao gbodo mafi omo olo si lori ni igbati aba dawo duro 14. Kia ato dawo le ise kankan e je kia ma se aluwala, tabi kia ya omi si mimo ki afi san oju ati ese pelu owo wa. 15. Omi ti aba fi fo aso ao gbodo fi fo bata ese wa kokin jeki ise dahun 16. Ose ti obiri bafi weku nba ise je lara 17. Ao gbodo fi ose ti afi fo aso ku we (3) MAJEMU LAILAI EYI TI OWA NINU OFIN TI MOSE LA MOLE EYI TI AFIN YE NKAN WO MASE SE IYE MEJI PELU ISE IDAHUN RE… 3- IBERE RE YORI SI RERE MU SURU IWO YIO LEKE 2- RARA DURO MASE DANWO 5- ENI RERE KAN KOSI BIKOSE OLORUN OBA MA GBOKAN LE ENIYAN 6- RERE NI OHUN TIO BERE RIWIPE O SE ITORE ANU 1- OLUWA NI OLUSO AGUNTAN RE 94- LORA ASO OPA FUNFUN KOFI SE ITORE ANU NITORI EWU WA 8- AYO, IDUNNU,ATI ORIRE NI IWAJU ATI IGBEYIN 12- KOTO SE OHUNKOHUN ESE IWADI DAADA 16- OLE ATI OLOSA WANI ITOSI RE SORA 11- OTA WA NI IWAJU ATI EYIN 13- KOSI ABURU KANKAN 4- JOKO SILE RE 18- ONA DARA PUPO FUN OO 9- IGESE RE YORI SI RERE LAI SI ANIANI 21- ITORE ANU FUN AFOJU KIOTO GBE IGESE (SPIRITUAL ZONE) AGBARA ABELA PELU ADURA NINU OLORUN Tan abela merin (4) ki ojoko larin re pelu edun okan re ao gbadura si olohun ki a si adura oluwa agbara olohun yio siji bo o imole olohun yio tan yio ka gbogbo eniyan yio si nife sio oluwa lara e yio si nife sio ona re yio yori si rere. AWON ORISIRISI AWON ABELA ATI ISE WON AWO FUNFUN – WHITE – FUN (IYASIMIMO) AWO PUPA – RED- FUN- (IFERAN) PINK- ASEYORI- SUCCESS AWO OFEFE- YELLOW –FUN (AGBARA EMI MIMO) AWO OROMBO – ORANGE - FUN-(OJU RERE) AWO DUDU- BLACK- FUN- (ISEGUN ESU) AWO BULU- BLUE- FUN (ALAFIA) BROWN- AYO ATI IDUUNU AWO KORIKO- GREEN- FUN OPOLOPO OWO PURPLE- AGBARA OLOHUN GOLD- ORIRE KI OWO LE MA JADE SIWA LOWO (MONEY MATTERS) A O TAN ABELA GREEN KAN PELU FUNFUN META AO FI ORORO OLIFI PA LAARA PELU JIJO TURARI AO KA PSALM 23 NIGBA MESAN PELU ADURA ATI OKAN WA 16DAYS NI AO FI SE ETO YII GBA KIATO PARI RE. IFERAN 16 DAYS LAMA FISE ISE YI AO TAN ABELA PUPA PELU FUNFUN 3 AO FI ORORO OLIVE PA LARA AO KA PSALM 33 LEMETA AO MA PE ORUKO ENI TI ANFE KIONI IFE WA SI NIGBA 9 ATUN LEFI PHOTO RE SILE NIBE AO GBADURA ATI OKN WA SI. ASEYORI AO SE EYI FUN ODIDI 8DAYS AO TAN ABELA AWO PINK PELU ABELA FUNFUN META AO FI ORORO OLIVE PA LARA AO FI TURARI PELU AO GBADURA ATI OKAN WA OJURERE ELOMIRAN AO SE EYI FUN OJO MERINDILOGUN 16 ABELA ALAWO OROMBO AO KO ORUKO ENITI ANFE RI OJURERE RE TABI ENITI AFE KO FERAN WA NA SARA IWE FUNFUN AO FI SARA ABELA ORANGE PELU ABELA FUNFUN META AO FI ORORO OLIFI PA LARA AO SUN TURAARI AO KA PSALM 141 NIGBA META AO GBADURA ATOKAN WA AO KA ADURA OLUWA AGBARA EMI MIMO ATI IRIRAN AO SE EYI FUN ODIDI 24 DAYS ABELA YELLO KAN AO KO PELU ABELA FUNFUN META AO FI ORORO OLIVE PA LARA AO SUN TURARI AO KA PSALM 46 LEMEJE AO GBADURA ATOKANWA AO KA ADURA OLUWA O AO FI OKAN BA OLOHUN RIN FUN 30 MIN, KI ATO KURO NIBE. EBUN EMIMIMO ABELA YELLOW GBADURA SINU OMI AO KA IFIHAN 4 PELU PSALM 61 PSALM 19 ATI 24 AO FI YASI MIMO AO GBE ARAWA PELU OMI ATI ABELA NA SIWAJU OLUWA TI O BA DIDE AO MU NINU OMI NA. EBUN EMI MIMO EYIN IBILE, OMI OPEYINBO, MISSPARISS, MILK, KA PSALM 19,ISAAH 61, IFIHAN 4 &24, YASI MIMO PO OPO SINU ABO FUNFUN GBADURA FI GBE SIWAJU OLUWA ATI IWO TI OBA DIDE AO MU. ISE ISEGUN AGBON KAN, PELU IMOLE DUDU KAN AO KO ORUKO MALAIKA YI SI ARA IMOLE NA TAN SI ORI AGBON YEN KI O OJOLOLE FI AGBON NA NU ARA RE DELE NI IHOHO KI A FO LORITA META LOGUN BASE. ISE IRIRAN M.I.L.O.N I.R.A.O.O L.A.M.A.L O.G.A.R.I M.O.L.I.M LILO-AO MAFI SEAL YI SI ABE PILLOW TI ABA FE SUN LALE AO MA RI ASIRI IJINLE AO SE ISE YI NI ARO KUTU OJO FRIDAY AO DI SEAL NA PELU OWU YELLOW ATI WHITE AO KA PSALM 19 NIGBA MEJE. OJURERE ATI ANU Q.E.B.H.I.B E.R.A.I.S.A B.A.Q.O.L.I H.I.O.I.I.A I.S.L.I.A.G B.A.I.A.G.A LILO- AO MA FISI INU APO TABI PURSE OMO ILE IWE, ONISE OWO,ONISE IJOBA E.T.C OJO MONDAY LAGOGO MEFA IDAJI LA SE ISEYI AO DI PELU OWU YELLOW AOKA PSALM 23 LATI FI YASI MIMO TI EEYAN BA NI AMUBO OHUN RERE TABI ENI TONWA OKO TABI AYA Ose joy or lux kan Agbon eyokan Ewe akoko die Ewe peregun die Ikun ojia die Perfume holy Michael ati miracle perfume,,,or any other type of perfume kosha tije orisi meji SISE RE::AO KOKO GUN EWE MEJEJI PAPO,OMI AGBON LAOMAFIDE DIEDIE TITI YOFI KUNA,,AODA IKUN OJIA DIE SI,AOGUN KUNA DAADA,AOSESE WA JU OSE SI,AOWA BU PERFUME YEN DIE DIE SINUE ,,AOGBUDO FOMI SI OOOOO...TABATI MIX E PAPO DADA TAN AOWA KA AWON ORO OLORUN YI SI LEMETAMETA PSALM 24(3*) PSALM II4(3*) ORIN SOLOMON 3VS1-4(3*) AOMAFI FO ORI WA LALE KATOLOSUN (ALE FIFO LERALERA FUN OJO MESAN,,,ASILE FI FO NI EVERY WEDNESDAY NIGHT AND SATURDAY) TIYOFITAN ETO ISE IFERAN LARIN OKO ATI AYA ABELA ALASEPO,AO KO ORUKO OKO ATI AYA SI ARA ABELA,AOFI LOVE ATTRACTION OIL PA LARA,AO KA ORIN SOLOMON 3,4,PS 45,133,AO RA PINEAPPLE NLA KAN AO GE ORI RE ATI ISALE RE,AO GBE JIN DIE,AO WAGBE ABELA ALASEPO NAA SINU RE,AO WA TAN INA SI LORI PELU PIPE ORUKO YISI(LOVE COMER CENTER 21X)AO WA KA AWON ESE BIBELI YEN SI,PELU ADURA LORI IFE IJINLE BITI ADAM ATI EVA,AO WA FI OWO TE INA NA PA,AO WA FI IDERI ORI PINEAPLE DE LORI PADA,AO GBE SINU ASO FFUN OPA KAN,AO LO RI SINU ILE. Eto ti obirin tohun woju oluwa fun omo fi ma hun fo inu ati nkan osu ti ko wa dada tabi ti ko wa rara osan wewe, oti schnap ati bara, bi a o sese re...... ao fi bara yen ra ina ti o ma ro ao wa fun omi re, ao fun omi osan wewe na, dede omi bara na ni osan wewe na ati oti na, gbogbo re ma (equal), ao po gbogbore papo ao ka psalm 24 si lekan, ao ma mu sibi kan laro ati lale for five day, Note: ki eni naa to lo iseyi kori pe ohun se ayewo boya ohun ti loyun ko to lo nitori yo ba oyun je osi le mu ki nkan osun kowa ki gbogbo idoti ba igbe ati nkan osun jade ki olorun si gbadura eni na leyin ti eba ti lo tan ETO OJURERE ATI IFERAN Ki e Fi Ink PUPA ( RED INK ) ko Talisman yi sinu parchment paper ni owuro ojo Jimoh ( Friday ) Ni Dede Ago mefa owuro, Lehin na AO wa ko Psalm 47 Lati ese kinni de ipari sinu Iwe felefele Miran...AO wa lepo mo ti parchment paper yen papo, A o wa we ni Owu alawo Aro ( blue silk ) AO ma kon lofinda olorun didun si..Ti eniyan bafe o le fun awon onise awo wipe kin won ba oun fi awo funfun bo Talisman na Lara... Gbogbo nkan ti olorun da ni yoo ma fi Ojurere wo eniyen tiwon yoo ma se eni na lore..atipe gbogbo eniyan lokurin,Lobinrin, lomode, Lagba, ni yoo ma feran eni na todaju... LATI BA MALEEKA INU AFEFE NI GBOLOHUN AO LORA AIR SUCCESS POWDER AO PO PAPO MO MAGIC TEMPLE POWDER AO FI PERFUM 7777777 FI PO AWON POWDER YE PAPO AO MU AWON NKAN TIA PO PAPO YI AO FI SE MOJU SI OJU WA NIGBA TI EYAN BA KUN MERICAY SOJU AO YA SEAL YI SI INU ASO FUNFUUN ASO YE LAMA SO MO OJU WA NIGBATI MALAIAKA NA BADE NITORI AO GBODO FI OJU RI AO LOSI ABE OPAYE AO PE ORUKO YI NI EMEJE OTOTO LOHUN RARA LEYIN ISEJU META ATEGUN LILE MA BERE SINI FE AO WA SO ASO NA MO OJU WA AO MA GBO ORUN PERFUME TIO YATO SI TI AYE AO GBO OHUN WIPE KAABO LEYIN NA ABERE PE KI AFE AO SO OHUN TI AFE SUGBON ISE YI ENITOBA MA SE O GBODO WA NI MIMO KI INU RE SIMO OOO TABA TI BERE OHUN TI AN FE TAN YIO DAWA LOHUN WIPE ADURA WA TIGBA ATEGUN TI ONFE YEN YIO SI DAWO DURO LESEKESE AO WA SI OJU WA AO FI POWDER KAN NI IWAJU WA POWDER YEN LAMA MU TI AMA LO PO MO OMI AGBO TI AMA GBE OMI NAMU HMMMMMMMMMMMM LADURA WA BAGBA. ORUKO MALIKA NA NIYI--- ELI AFARAFA 7* LATI BA MALEEKA INU INA SORO AO YA AWORAN YI SI ARA OGIRI ILE WA AO WA DA INA IGI TI O PO GEGE BI AWON BOYSCOUT AO WA MU MAGIC FIRE POWDER PELU MAGIC STONE PELU CONSETRATED FIRE SPIRIT POWER AO FI KEROSINE INU MAGIC STONE YEN PO AWON POWDER YEN PAPO AO WA FI WA OWO WA MEJEJI PELU ASO WHITE LORUN WA AO PE ORUKO YI NIGBA 21 ELI-FIRANUMANU AO PE LEYIN TI ABA PETAN INA TI A DAYI YIO BERE SINI JO LONI KIKANKIKAN AO DI OJU WA AO WA FI OWO TI AFI NKAN PAYI DI ETI WA MEJEJI AO MA GBO OHUN AO BERE NKAN TI AFE BERE AGOGO MEJILA ORU SI AGO MEJI ORU NI AMA NSE ISE YIO.. KIA SI WANI MIMO. LEYIN TABA SE TAN AO FI OMI PA INA NA AO JEKI ERUKU RE LOSI OJU ORUN. ETO ADURA TI WON BA DI OYUN MO ENIYAN NINU Jasimi igo kan, bintu igo meji, mariamo igo kan, taniya igo kan, petrol die, adin agbon igo kan, oyin igo kan, kafura,omi odo sisan, a o pa gbogbo re po pelu psam 3, 10 and 29 pelu iya si mimo alaboyun na yio maa mu diedie ETO FUN ISE WIWA JEHOVAH JIREH, ko oruko Mimo yi sinu paper funfun nigba mejileladorin (77x) pelu owu siliki funfun fi we, wa ma kan lofida olorun eyikeyi si. ADURA FUN IDARIJIN ESE A o ka pslam 51 pelu oruko mimo yi – DANI JEHOVAH RAFEKA ETO ADURA AANU ATI OJU RERE ENITI O WA NIPO NLA A o ya seal oke yi sinu parchment paper tabi iwe funfun balahu pelu eje eyele lo daraju, a o fi wonderful powder si oju re, a o wa di ni owu blue tabi ki a ran ni awo blue. A o ma kan lofunda St. Machael sin i gbogbo ojo aanu. [ Ti a ban i ajosepo, a ko gbudo fi owo kan o] ISe yi daju pupo. ETO ADURA TI A NFI NGBA EBUN NLA LOWO AWON OLOWO TO WA NI IPO GIGA A o ra eyele funfun ni ojo Wednesday, a o wa omonigelegele, omi okun, omi osa, yanrin okun, yanrin osa, iru woro, a o lo gbogbo repo kunna, a o wa fi omi okun ati osa se gbogbo nkan ti a lo sinu isasun, a o fi epo, iyo ati ata ijosi si, I to ba jina tan, a o so ka ori osuka aso funfun. A o w aka Psalm 4, 12, 11 ati Ifihan ori kerin, ao wa gbadura tokantokan si, a o ko je. (E gbiyanju lati ri pe, nkan ndahun lara wan i a to se ise yi o) ETO ISEGUN OSe dudu,ose funfun, ose pupa, bintu, a o popo pelu psalm 3 (7X), 9 (7x), Isaiah 47, a o ma fi we. ETO IGBEGA LENU ISE TABI PROMOTION A o wa omi okun, omi osa, omi odo ti san ti ki gbe ni ilu meta pelu lofinda famous tabi florida sinu ikoko tabi roba funfun ti o je titun, a o fi mariwo ope 21 ti o je ti apa osi sinu omi na, a o ka Psalm 24, 4, 3, 109, 72, 11, 20, 120 sinu omi na, A o gbadura si dada, a o fi orisi owo meta sinu omi na ki a to ma ka Psaml re, a o tan imole yellow tabi funfun 7 ti imole yi ba ti jo wole tan, a o ko owo jade ninu omi na. ao pw oruko mimo yi sara owo na nigba leta ELI LAH la ona ire gbogbo kan mi, ELI SANU JAH Oluwa sanu fun mi lona gbogbo. ELI OFARARAH fa ire owo ba mi kin ri anu gba, a o toro gbogbo ohun ti an fe, a o fi owo yen se sara, a o fi omi ye we pelu ose AANU ETO ADURA AKANSE APORO OFA GBOGBONISE A o wa odidi agbon to tobi daadaa, a o pa ni ori gegebi cub, a o da omi inu re sibi kanna, a o wa ojulowo imi ojo pupa, epo obo ti ko ti wonu oja, ose, a o lo gbogbo re po, a o ko sinu igba agbon yen eleyi ti a wo ninu re danu, a o da omi agbon yen le ose yi pada, a o fi ideri re de pada, ti a ba fur ape ofa wole si enikan lara tabi ara nta eniyan, a o bu die ninu ose yi, a o fi sin oju ibe. ETO ADURA ABO FUN OMODE, AGBA ATI ALABOYUN A o wa cross wewe meje fun omode, 21 fun alaboyun, ao fi owu siliki funfun si, a o se ni dede ikun alaboyun na tabi orun omode na, meta ni owo mwjwji tabi ki a wa silver chain, a o ko sinu ike funfun, a o da Holy Michael perfume sinu re, a o gba adura si, a o ka psalm wonyii; 90, 91, Isaiah 38:1-6, Psalm 109, 118, imole funfun ni a o fi ya si mimo alaboyun na yio ma so mo ikun re fun ano ati isegun alakala, iyanu yio sele, a gbohun iya ati omo. Amin ETO ADURA ISEGUN ATI ABO LOJU ALA, O TUN DARA FUN OMO TO NSUNKUN LOJU ORUN. ASO IBORA Ni ojo Thursday, a o gbe aso funfun fun tailor lati ba w ate eti re yipo, tailor yi gbudo seemi se ise yin i ni o. yio ba wa se ami agbelebu meta meta si eti aso yiii, a o ra bucket tuntun kan, a o bu omi okun, omi osa ati St. Michael ati lofinda alagbara meje si, a o pa omi agbon meta si, a o fi GOLD INK han seal yii sara aso na, ao sat i yio gbe, a o ki sinu awon omi ti a se eto sile fun odidi ojo meta, a o sa gbe sinu ile ti afefe yio ti ma fe si, ti o bat i gbe tan, a o ka awon psalm wonyi si ninu Psalm 12, 11, 10, 13, 120, 125, 119:153-160. Pelu titan imole isegun 21 yi po. S.A.T.O.R A.R.E.P.O T.E.N.E.T O.P.E.R.A R.O.T.A.S IKILO: Aso yi ti di aso agbara,a ko gbudo fi sere o, tabi fi sepe, bee ti a ban i ibalopo, owo wa ko gbudo kan yii. A le ma fi aso yi bora sun tabi ki o ma wa labe irori wa. IMISI AGBARA EMIMIMO Omi aifohun, omi agbon meje, perfume, Miss paris, Perfume 777m imole yellow packet kan, a o da omi agbon ati awon perfume yen pelu omi agbom yen papo, a o tan candle 7 fun obinrin mesan fun okunrin yika omi na, a o ka pslam imisi 7 tabi messan 9, a o w ape ADONAI ELIWAKUKU ni 21 times A o gbadura imisi si, Pelu awe ni a o seise yii o. ETO ADURA ISEGUN OTA A o wa omi orisi meta bi omi okun, osa ati omi awamaridi. A o dapo, a o fi gbo mariwo ope. A o yo omi na sinu ike iwe, omi eyiti yio to wa we ni o, a o tu lofinda Holy Michael si, a o ka Psalm 18 (3X), Isaiah 43: 1 – 7 (3X). A o fi we laro kutu laisoro si enikan. O DAJU ETO TI A FI NI ISEGUN LORI AJE A o wa epo obo ti o woja, a o mu eyiti o fe to atelewo wa, a o jus i inu omi odo tin san ninu ike funfun, A o w aka Psalm 47 sinu re ni igba meta ni ojo isegun tabi ojo abameta. Ki o wa gbadura lori ohun ti a fe ki o se. A o fi omi na won ile, a tun le lo ise yi fun eniti o ba dubule aisan ki o fi we. A tun le lo epo obo ti o woja yi sinu ororo destroyed my enemy oil. A o ma fi pa alaisan na lara. ODAJU AGBARA EMI MIMO Bintu kan, a o da sinu agbon ti o ni omi ninu, a o fi igo bintu yi se oduwon Miss Paris, Assorebia, Mariamo, ako omi tabi omi ibinu, a o da sinu agbon yi, A o ka awon Pslam Psalm alagbara meje si, a o tan imole yellow si, a o fi imole yii di oju agbon na, a o lo rim o inu ile fun ojo meta, ni ojo keta, a o lo wu ninu ile, a o mu, pelu awe ni ise yi o ADURA ISEGUN Psalm 35, Isaiah 47, Psalm 109,ki a to ma ka awon iwe wonyi, a o bu omi sinu ofifo igo, a o gbe kale tabi ki a mu eyin adire ki a fi sile, a o wa bere eto wonyii ni oru dudu, a o ka awon iwe wonyii nigba metameta, a o si ma gbadura bayii: OLUWA, OLORUN OLUSEGUN, OBA TI SEGUN GBOGBO EMI OKUNKUN, IWO OBA TO LAGBARA LORI ESU ATI OMO OGUN RE, MA SAI SEGUN FUN EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA NITORI ORUKO RE TI NJE JEHOVAH ADONAL EL OI JAH HULA JAIEL JAIEL JAI JABBAT,NIJO TI OKA BA ROPE OUN NI ORO, TI O BA DOJU KO MOTO OJONA NIKU TOROTORO RE, OSO NI, AJE NI, ELEBO NI, OLOGUN NI, TI OBA DOJUKO EMI LAGBAJA, JE KI O KU TOUN TI AGBARA RE, NITORI OJO TI IGO/EYIN BA DOJUKO APATA, OJO NA NI SOFO, OJO TI EYIN BA DOJU KO APATA OJO NA NI IRETI RE PARI, ADA KAN KI MI KO DOJUKO AFEFE, OSO NI, AJE NI, ELEBO NI, OLOGUN NI.OKUNRIN NI, OBINRIN NI, LO BA DOJUKO EMI ____ OMO ___ LATI SE NI IBI, LONI NA ( P.T.O) NI KI O JEBI IKU, KI O JEBI AISAN, NITORI ORUKO RE TI NJE JEHOVAH AGILA, lehin na a o wa mu eyin na tabi igo na, a o fo mo ri apata AWON PSALM ISEGUN Psalm 109, 118, 25, 119, 27, 71, 120, 91, 30 7, 68, 14, 55, 140, 9, 13, 35, 144, 10 ati 38 PSALM FUN OJU RERE ATI IBUKUN 8, 4, 81, 23, 16, 20, 32, 133, 52, 57, 121, 131, 1, 126 Fun awon eto adura miiran, e ma kan si OLORUNLOGBON la be aso, A ki juba afogun sinu ku, eleyi ti a ban i ni ikawo, a o fi sowo si wa. E seun pupo fun ifowosowo po yin WIWA ISE PSALM 30 LEMEJE, SINU OMI PSALM 126 LEMEJE SINU OMI FI OMI OKUN ATI OMI AGBON SI PE ORUKO YI ELIAFARAIMU KI OFA IRE WA FUN O AO MAMU OMI NA AO FI NINU E WE. (IRAWO EDA ATI AYANMO E) IWE IMOIJINLE NIPAIRAWO EDA Opolopo eyan lonkan lo ise laimon iru ise tio bakadara won mu abiti Olesise fun won,won nkan lo ise saa tie lomifiowosofo lasani. AWON ISETI IRAWO KOKAN (1) IRAWO INA Irawo inagbodo sora fun wiwe ose nigbogbo igba abi ise tiwon ban fi omi Pin lere nkan todara fun ina juni ebu tia jo tabi n kan tia fi ina pinlere awon Eyini osaba sise lara won ju n kan miran lo (2) IRAWO IYEPE Irawo iyepe gbodo je kie sara sise mo awon laraju ki won ma fon nkan eyo Bi agbado,okababa ati biki won tun ma we osedudu atiaseje eleyidara Pupo funwon. (3) IRAWOAFEFE Irawo afefe gbodo mase adura nigba gbogbo tabiki won tun ma be awon Alfa ki won maba won se adura tabi awon woli nitoripe ti aye eniyanba Daru tabi egun idile tiwon bari alfa tabi woli gidi tiwon sumo olorun dada Gbogbo nkanburuku yini wonoba fi adura gbodanu ati bi sara sise bi Nkan pupa,10naira ,obipupa, epopupa ,okababa pupa ,ki won sima tan turari Adura tabi turari awon agba tabi aseje ati ose wiwe ati ebu lilo awon nkan yi Tete man sese lara won nigbati won ko bati fi adura sise sile (4) IRAWOOMI Irawo omi gbodo malo nkan ti won ba fi omi seta biti won fi omi pelo Re bihantu mimu pupo opejularin ose kan tabi kiwon bawonya Omisi mimo abi aseje lekokan sugbon ebu jijo kin saba sise lara won aya fin kan tiko baje mo nkan eran osese kio sise larare Sugbon tio basepe bi ewe ati egbo nio lesise larare ose funfun Lodara pupo lati ma fi sise fun irawo omi sara won ni nkan funfun bi Pure water ,owo funfun,agbado funfun,oka baba funfun,sugar obi Funfun ati bebelo ORO NIPA IRAWO ATI OHUN TI O BA IRAWO OLUKULUKU MU LAYE Opo obi loti da igbesi aye omo won ru nipa pe dandan ise bayi nio gbodo se Koolukuluku eda ni olorun tifi ni ise tiyio mase laye sugbon latari agidi ti Awon omo adamo nikojeki ani ifura oro olorun ko leye omugo eda sugbon Ologbon eni ani oye opo ti oye kio lose ise bricklayer sugbon alakiyesi koje Kio tete yan ise orire Layo eda tio baje omilaye tioban sise ina kole ni aluyo eda ton sise ina ti Olose ise omiko leni ilosiwaju layeni ofiye ki eda ni igbesi aye tio legbe Ohun tioye ki ama se ati ohun tikoye kia mase eda ti olorun da lati ara omi tio wa lo nsise ni ile bread kin see pe rara kole ni aluyo laye tia bati bi omo eje kia ma gbiyanju kia to awon toni imo lo nipa irawo wiwo ki won Se alaye lori iru irawo tio mo na gbewa si aye iru ise ti o le se esu koni da gbogbo irin ajo waru mowa lowo laye (amin). JANUARY 2 - FEBUARY 18 - AQUARIUS - AFEFE FEBUARY 19 - MARCH 20 - PISCES - OMI MARCH 21 - APRIL 19 - ARIES - INA APRIL 20 - MAY 20 - TAURUS - ERUPE MAY 21 - JUNE 20 - GEMINI - AFEFE JUNE 21 - JULY 22 - CANCER - OMI JULY 23 - AUGUST 22 - LEO - INA AUGUST 23 - SEPTEMER 22 - VIRGO - ERUPE SEPTEMBER 23 - OCTOBER 22 - LIBRA - AFEFE OCTOBER 23 - NOVEMBER 21 - SCORPION - OMI NOVEMBER 22 - DECEMBER 21 - SAGITTARIUS INA DECEMBER 22 - JANUARY 19 - CAPRICON ERUPE. IRAWO EDA PELU ISE TIWON LE SE (1a) January 20 - Febuary 18 (Aquarius- Irawo Afefe) COLOUR: white, green, blue, mix colour. NUMBER: 4 DAY: friday LOVE: leo, sagittarius WORK: Teacher, scientist, public-relationship, programmer, talk show, computer host, author, researcher (b) May 21 - June 20 (Gemini- irawo afefe) COLOUR- yellow, silver, ash, light green NUMBER5 DAYwednessday LOVE- sagittarius, aquarius WORK- journalist, consultant,web, developer, artist, Teacher, d.J, agent, doctor. (c) September 23 - October 22 ( Libra - irawo afefe) COLOUR- pink, blue, emerald NUMBER- 6 DAY friday LOVE- sagittarius, aries WORK- journalist, fashion desingner, artist, lawyer, broker, business owner, publicitist driver, pilot, pastor, alfa. (2a) Febuary19 - march 20 ( pisces - irawo omi) COLOUR - sea green, violent, mauve, purple NUMBER- 7 & 3 DAYthursday LOVE- taurus, virgo WORK- Nurse, chemist, seman, navy,fish, shoe, cold drink seller. (b) june 21 - july 22 ( cancer- irawo omi) COLOUR- silver, emerald,green, blue, white NUMBER2&7 DAYmonday and thursday LOVEcapricon, taurus WORK- lawyer, planner, interior, design, woman right, child care, bussiness owner, art director, gallery, owner, ati gbogbo ise irawo to jemo omi. (c) October 23 - November 21 ( scorpion- irawo omi) WORK - (3a) COLOUR- Red & rust NUMBER 9 DAY - Tuesday LOVE - taurus, cancer lawyer, realestate, body worker, psycologist, invesment, banker,musician, March 21 - April 19 (Aries - Irawo ina) COLOUR- Red NUMBER- 9 DAY- Tuesday LOVE- Libra, leo WORK- enterpreneur agent, healer, professor, stunt person hairdresser, sales person. (b) July 23 - August 22 (Leo - irawo ina) COLOUR- yellow, red, gold, orange NUMBER 1 DAY - sunday LOVE - Aquarius orange WORK - fashion designer, politician, agent, teacher, artist, lawyer, ceo, traning, woman right, perfomer, relegious eader. (c) November 22 - December 21 (sagittarius -irawo ina) COLOUR - purple, violent, blue NUMBER 3 DAY - thursday LOVE - gemini, aries WORK - author publicher, motivational, speaker,Designer,sales person, travel guide, worker free lancer, human right. (4a) April 20 - May 20 ( taurus - irawo iyepe) COLOUR - green, pink NUMBER- 6 DAY - friday LOVE - scorpion cancer WORK- banker, manager, real estate, agent photographer, art dealer, restaurant owner, makeup artist film maker, dancer, design, musician, singer. (b) August 23 - september 22 (virgo - irawo iyepe) COLOUR- ash, yellow, silver, grey NUMBER- 5 DAY- wednessday LOVE- pisces cancer WORK- journalist, office, manager, accountant, socia worker, systems, project, manage holistic, healer, mutritaonist. (c) December 22- January 19 (capricon- irawo erupe) COLOUR- Dark, shades, green NUMBER8 DAY - saturday LOVE- cancer, taurus WORK- film producer, manager politician , police, stock broker doctor president, bussiness owner, doctor. AWON NKAN TI IRAWO YI KO GBODO JE Irawo afefe - ao ko gbdo je nkan ti o bani ora lara. Irawo ina - eran omoyo, eja tutu ati ewa Irawo omi - eja aro, ati gbogbo nkan inu omi Irawo erupe - ewure, ogede, isu (ISESE ZONE) AGBARA IGBAANI APA KETA ATI AKOJOPO ASIRI ONA ABAYO (EWE ATI EGBO ZONE) LATI OWO ALAGBA OPA FITILA. (A) ASINA Ao wa ewe agogo igun tutu, eru Alamo, ao gun pomo ose dudu ao fi iyere-osun te ifa ika meji ao pe gbolohun resi ao dasi ose na ao po dada ao gbesi ile nle ni igun ilea o pe ohun re si ao so fun ose na pe (iwo ose yi aini owo lowo ni mofi koe si ile nle tio ba mu owo wa funmi inu igba golu ati fadaka ni ma koe si ao mafiwe laro. ATO SISAN (QUICK EJACULATION) EWA SOYA, (soya beans), pelu epa ao lo po sinu ogi tutu ao mafi boli mu ogi na ki o ma je opolopo carot. AYA DIDUN AO MAJE ETALE DAADA KI O SI MAFI AYU (GALIC) ATI ATALE SE OBE DAADA. EEWO / PETELE EO LOWA EWE TOMATO, KANUN, EWA DIE AO LO WON PAPO AO SIMA FISI OJU AO LO WON PAPO AO SI MO FISI OJU. EBE AWON AGBALAGBA PELU ASINA OGA GBIGBE KAN, EKU ASIN KAN EYO OBE KAN, ATA IJOSI, AO GUN PO MO OSE AO MAFIWE. LATI TRAVEL OUT EWE ISAJU, EWE OMISIMISIN, EWE EPIYA, EWE ORIKODORO, EWE EMO , EWE OLUBISOWO, EWE SAWEREPEPE, AO GUN MO OSE DAADA AO FI OYIN PO AO MAFIWE. ASEJE ASIRI BIBO IYE AGBE KAN, IYEA ALUKO KAN ILEKE IFA KAN,EWE TAGIRI KAN AO LO GBOGBO RE PAPO SINU ISASUN KAN AO GE EDO MAALU DIE SINU RE AO WASE AO WA JENI ALE PELU ADURA IKIYA OKUTA SANGO, AO JU SINU SPIRIT OIL, FUN OJO MEJE LEHIN OJO MEJE KIA MA KAN SI AWUJE KI WON MASE YO OKUTA NA KURO NINU RE OOO. AWURE NLA EWE ISAJU, SAWEREPEPE, EWE SEFUSEFU, AO GUNPO AO FI PO OSE FUN WIWE. TI ONA BADI GAGA EWE TAGIRI, PELU ESO RE AO LA TAGIRI YEN SI ONA MERIN PELU OSE RE OSE—EGBO TUDE TUTU AO GUNMO OSE DUDU AO FIMA WE AGBO YEN. ADODUN EGUSI INU EJIRIN, ATI OSE AO LO EGUSI NA AO FIPO OSE NA OBIRIN YIO FIMA TAMBA SUGBON OKURIN YIO FIMA PA NKAN OMOKURIN RE. OGUN WARAPA EYE OWIWI ATI ATARE ODIDI KAN AO JOWO PO, AO WAFI SINU OTI OYINBO AO MAMU NI GBOGBO IGBA . AFUNJE IFERAN OBIRIN EWE ALUPAIDA 7, MESAN FUN OKUNRIN, EYITI KO DALU PELU ATARE ODIDI KAN AO JOOPO AO FISINU OUNJE FUN ENINA AWURE ESO SASAMURA, LOPOLOPO AO LORA ODIDI EIYELE FUNFUN AO SE EYELE NA SI ONA MERINDINLOGUN (16) AO FISE ASEJE PELU ADURA. AJESARA OBI AJOPA, EWE ELUKERESE, TABI TEMISAN, AO LOPO AO FISE EJA ARO SEJE LOBEJE. ADARIN EESAN, PELU OSE DUDU AO LOPO AO JO AO POMO OSE NA AO MAFIWE. ABUSARI AWORO IYEPE IBITI OBIRIN BA TOSI, IKODE KAN EYO ATARE KAN AO JO PAPO AO MAFI SA ORI WA. OSHOLE 500 THOUSAND TODAJU OPOLO OYEE, PELU BISCUIT DIE, 1000 TUNTUN OR 500 TUNTUN ATARE AJA AO KI GBOGBO RE SINU OPOLO NA AO JO PAPO AO FI PEAK MILK LO LORI BED WA NI DEEDE AGOOGO MEJILA (12am) NI ORU AKIYESI—ESE WA KO GBODO KAN ILE O ORI BED NI ESEWA GBODO WA. OSHOLE 500 THOUSAND NAIRA 2 EKU ASIN TUTU, BISCUIT TI O FETO ATELEWO WA AO FI BISCUIT NA TELE APE AO GBE ASIN NA LE LORI AO FI EGBO TUDE BO LORI AO FI ATARE ODIDI KAN LE LORI AO JOPO AO FI EPO PUPA LO LARARO. 200 THOUSAND AO WA 200 NAIRA TUNTUN, AO YI ODOO META META SIBI TI WON KO 200 SI LARA OWO NA AO WA MU ERAN RASU TUTU AO FI SINU 200 NAIRA NA PELU IRUN ABE OBIRIN AO FI SINU E AO RA ROBOROBO AO KI SINU OPOLO AIYE AO JO PELU ATARE ODIDI KAN AO LOO KUNNA AO DASI ENU NI ORU AO FI HOT LOO EKAN NA LAMA LO GBOGBO RE. AJEGUN ASIINA EWE AKOKO TUTU EYO KAN AO GUN LORI OLO AO FI OSE KO NI IWE EEKAN AO FI EPO PUPA PA GBOGBO ARA WA NI ILE –IWE (BATHROOM) AO FI OSE YIWE KIA TOWE AO KOJU SI IGUN ILE IWE NA KANKAN AO SOWIPE OHUN--- AKOKO AKOKO AKOKO KI O KO GBOGBO IBI TOWA LARA MI KURO LONI KI O KO IBI KURO KI O KO WAHALA KURO KIO KO IRE WA KIO KO AYO WA KIO KO OWO WA LEYIN NA (ADURA TOBA WUNWA). TURARI OWORO EWE EGELE, PELU ORI AO GUNPO MO ARA WON AO MAFI FIN TURARI BI ABA SE NFI NI ERO YIO MA WA. OGUN EDA ODIDI IGBIN KAN, AO JOMO OKO ATARE KAN AO POMO OSE DUDU OKO ATI IYAWO YIO FIMA WE. BIG PENIS EWE AJEOBALE TUTU, AO GUNMO OSE DUDU AO FIMA WO NKAN OMO KUNRIN WA SI IWAJU. ASEJE OWO ONI EJA TITUS EWE IYALODE FUNFUN 8 ATI PUPA 8 OMUNU NIO EWE OLA DIE, ATA IJOSI MERINDINLOGUN 16 AO FISE EJA TITUS NLA KAN JE AO GE EJA NA SI 16. BI ASE MA NSE IPESE EKURU FUNFUN 3 AO FI IYO DIE SI AO KO SINU AWO SOBI AO DA EPO PUPA LE AO PE OHUN RE SI AO SE ADURA SI AO GBELO ORI AKITAN TABI ORITA META OHUN—ALAYAGBA NI BABA INA, OYEYE NI OYE ORU . IGBARADI FUN AKONI LATI--ALAGBA OPA FITILA (OPEYEMI DANIEL) OGUN ANASARE ORUKA IDE EWE INA EYO ATARE KAN ETU IBON AO LO GBOGBO RE PAPO AO KOSI INU ALANGBA AO LO RIMOLE FUN OJO MEJE AO LO WUNI OJO KEJE ODI LILO AKIYESI--- ASIKO TABA TI RI ISE NA MOLE AGOGO YEN NI AO TI BERE SINI MAKA TITII YIO FI PE OJO MEJE. ALEEBA IROMI OJU OMI EYOKAN AO LO PAPO MO EYO ATARE KAN AO LO TI YIO KUNNA DAADA AO WAFI SIN GBERE EYO KAN SI IPAKO WA. ORUKA IJA EYIN ADIYE KAN EWE OLOYUN EWE INA ATARE ODIDI KAN ORUKA IYEKIYE BARA KAN AO WO INU BARA NA AO WA KO AWON EWE WONYI SINU RE AO GBELO OJU ARO IBITI WON TI NDANA TAN AO RIMOLE . TI ABA FE YO AMA PE OHUN SI OJU ARO NA OHUN-- EYIN ADIYE KI NRI OWO DU ARA RE SENI BARA NYI FUN OLOKO OJO TI OMODE DI EWE OYIN LONRI WERE NI INA NJO NI \ERO RE---- EPO ATI ORI NI AO FIPO ORUKANNA NI OWO WA AKIYESE—AO PE OHUN SI ORUKA NA NI OJO TI ABA YO OOO. AYETA EWE RENREN EYOKAN, OMO ATARE KAN, AO LO PAPO AO FI SIN GBERE KAN SI IWAJU ORI WA. IFERAN OBIRIN EWE BOMBOM, EWE ODAN, ITANA AKO IBEPE, AO GUN POMO OSE DUDU AO MAFIWE. OLUPORA LOJO EWU Ao gbe iho si ikorita, ao bu omi sinu ikoko agbo kan, yio kun denu ao gbe ikoko na sinu iho ti agbe ao ju oga tabi alagemo oyee sinu re ao de lenu ao wa ile bo lojo kesan ni wakati ti ase ogun yini ao hu jade ako niba oga na nibe mo ao mu omi towa ninu ikoko na bi ohunkohun ba sele ti aba beru tabi ti a pomo yio gbe wa kuro ni oju kan ibe. AWISE MAYEHUN EHIN IWAJU OKU ATI ERIGI RE, EGBO OGBO EGBO AKESE, AO GUN PAPO MO OSE DUDU AO KO SINU IWO AGBONRIN FIFI BA ENU SORO AJERA IGBIN ILAKOSE PUPO, OBUOTOYO, ODIDI ATARE KAN AO JOPO AO MA LA DIEDIE TABI DIDA SINU OTI AKOYA IRU OKETE, AO YO EGUNGUN RE, AO KO EYO KAN SINU RE AO SA YIO GBE AO RAN NI AWO DUDU SIDI TI OTA WA BABAWA JA, AO FI DIDE NA LU ILENLE ERO---- AO DA EMU SOJU IBI TI ALU ONDE NA MO OWO IBON ITO IDI ABOYUN, AO FISE EYIN ADIE ORORO KAN JE ---------- MASE BA ENIKENI PIN EYIN ADIE JE BIBEKO YIO BAJE IDAN OKUTA LOJU OMI ALUPAIDA 201, ATARE ODIDI 7, ASO EGUNGUN TIO LE, JIJOPO AO DI SINU EFE OWU NI IKOBERE OWU DUDU ATI FUNFUN LILORE----- AO FI PA GBOGBO ARA OKUTA YIKA AO LO MU OGUN NA SILE NIBI KAN KI ATO GBE OKUTA NA SI OJU OMI KONI RILO SI ISALE. ORUKA IJA IKOYA ORI ATI IFUN ADARIPON , AO FI ORUKA TELE APE AO KO ORI ATI IFUN AKO AKO ALANGBA NA LE LORI AO JO PAPO AO FI EBU RE SIN GBERE 1 SI ATANPAKO ESE OSI EYOKAN NI GBERE NA ENITI A BA FI ORUKA YI LU YIO SUBU AO FI ESE OSI TANI IPA NI ILE NLE YIO DIDE ORUKA SUBUSERE EJA OJIJI KAN , ADIGBONAKU, EWE INA FUNFUN, ORUKA IRIN MEJI JO PAPO AO KO SINU TAGIRI DI OJO MEJI ENI TI ABA FILU YIO MA SUBUSERE ADODUN IRU OMO NILE, OJU OLONGBO ATARE KAN AO LO GBOGBO RE PO AO SIN NI GBERE SI IDI OBIRIN NA. AFOSE ODIDI OGA KAN, EWE ABAMODA OWU AKESE, ODIDI ATARE KAN, AO JOPO MO OSE DUDU AO MA FIPO AO KO SINU IWO AGBO AO MA FI KAN AHON TI ABAFELO. TI AFI NLE ENIA NI ILE ESO EFIRIN ERU ADIMO AO GUN PO AO MAFI SINU INA. AYETA EWE IRUN ALANGBA AO JA ESO RE AO LOMO EWA AO FI DIN IFURA AO WA ODIDI, ATARE AJA, AO WA KIBO INU OKELE AMALA AO WA GBE MI BABA IJEBU IYE AGBE 7 IYE ALUKO 7 ODIDI ATARE 7 EWE IYALODE OMUNU PUPA 7 AO WA PAPER FUNFUN KAN AO KO NUMBER 1 T0 80 SI AO JOPO MO AWON EROJA NA AO WA DASINU OMI AGBON NLA AO GE ORI AGBON NA AO DA EBU NA SI, AO WA DE PADA AO GBE PAMO FUN OJO MEJE TI OJU ENIKENI KONI KONI RI AO FI MA BOJU KIA TO SUN LALE. (E JE KIA NI IMULE AGBA LARA DAADA) OGUN TI AFI NFA OJO AO GUN EWE ETIPONLA AO DA INA AO KOLE LORI AO MA BU EPO PUPA SI NITA GBAMGBA. ISORA AO RA OROGBO TUTU, AO WA SIN NI ATARE 9 SI LARA AO WA WE NI OWU DUDU PELU FUNFUN AO MA SO SI APO. OGUN OFA HAUSA TODAJU EWE RENREN TUTU, ALUBOSE ELEWE FUNFUN AO GESI WEWE AO KO SINU ABO KAN AO KO EWE RENREN TELE AO KO ALUBOSA YEN LE LORI AO WA BU IYEN LE LORI AO DEPA FUN OJO MEJE OMI TI O BA SUN JADE NIBE OHUN NI AO MAMU DIEDIE ODAJU TI WON BA TA OFA SIWA OMAMA GUNLE NIWAJU WA. ASIRI AWON IDAN TIO FI ARA PAMO LATI AYEBAYE OGUN TI ANFI NPE NKAN NINU AFEFE OGA AYE 7 EWE ABAMODA 7 ATARE ODIDI 7 AO JOPO AO PIN SI ONA MEJI AO FI IKAN SIN GBERE YIPO APA OSI WA EBU TIO KU AO DA SINU AWO EKUN AO RAN NI ONDE AO MAWE MO OJU GBERE NA LILORE- ao ma na owo (hand) siwaju wa Ofo- bidan bidan ni alagemo sengbe aso alaso wo Abati alagemo bada ni orisha oke ngba Abamoda kan koni da tie koma se Ologun kan kinba atare sota Ao so ohun ti afepe jade ninu afefe ao so pe ase niti eji ogbe asenitemi. IDAN APADA TI AFI NPIN ARAWA AO WA ADO IJAMO AO FISI ABE ADIE TO NSABA LOWO TITI YIO PAMO TI O BA PAMO TAN AO YO ADO NA AO LU AO YO IDOTI INU RE KURO AO KO ESO TABA TI AN PE NI KATABA SINU ADO NA AO FI IGI KEKERE KAN DINI ENU AO MAFI APO TI ABAFELO AO SOPE OFO---- IBITI MOYI SI EMI ------------ OMO ---------NIKI WON MARI TI A BATUNDE IBOMI AO TUN SEBE AKIYESI--- IYE OMO TI ADIYE YEN BAPA NI IYE TI AO MA PIN SI OOOO. IDAN BI A SE NGBE EYIN WO INU IGO EWE ABAMODA ONIGA META AO FI TELE APE AO GBE EYIN IBILE KAN SINU E AO DA OMI OSAN WEWE SI TI OJE ORIGINAL AO GBE KANNA TIO JINNA DAADA EYIN NA MAFO AO FI SIBI (SPOON) KOSI INU IGO TOBADE INU IGO YIO DI ODIDI PADA AKIYESI--- EYIN NA YIO MAFABI RUUBER IGO FUNFUN NI AMALO ALE BU ITO SI PELU EWE OLA OSISE FUN ASIRI BIBO AO MA BU SINU OMI IWE MI. IDAN TI OSE FI NLANA AO LORA MAGICAL STONE LODO AWON ONI SPIRITUAL SHOP AO WAFI STONE YEN SI ARIN OSE DUDU AO WA GBE FUN ONIBARA WA PE KIO LOFI WENI AGO MEJILA TABI AGO KAN ORU TI O BATI LE FI OMI SI KANHINKANHIN YEN INA MA GBA LARA E LESEKESE . IDAN FEYIN TI OGIRI WOLE AO WA OGA AYE KAN, AO WA IKODE KAN ATI ODIDI ATARE KAN AO MU IKODE ATI ATARE YEN AO JO PAPO AO WA OGI PUPA AO DA SINU IGBA OLORI AO PO PELU OMI TUTU AO DA EBU TI A JO SINU RE AO GBE OGA AYE NA SINU RE AO GBE SI IGUN INU IYARA WA FUN OJO 7 TI ENIKENI KO GBODO FI OJU KAN. LILO--- TOBADI OJO KEJE AO NIBA OGA YEN NIBE MO AO GBE OGI NA MUAO MA FI EYIN TI OGIRI OFORE--- WIBARA YAFUN OMO OLONA AKIYESI- AO GBODO FI EYIN WA SUN SI ILENLE LASAN OOOO. OLEWU IDAN ABAMODA TIWON FIN NKAN CUSTOMER NI IKO LORI ESO IMI ESU, KI OPO DAADA AO LO AO SA KIO GBE DAADA AO TUN LO AO MA BU DIE DIE FUN AWON ONIBARA WA PEKI WON MA FI SA ORI TI WON BA FE SUN PE OUN TIWON BARI KI WON PE PADA WA SO FUN WA ENI TO FI ISE YI SA ORI WON YIO KAN ONITOHUN NIKO MOJU NI IDAN ABAMODA TI WON FI NLA ALA PE WONRI LORI ENIYAN EWE IMI ESU, AO LO NI ENU ONA ATI WO ILE WA AO POMO OSE DUDU NI ILE NLE NBE AO MABU FUN ONIBARA WA PEKI WON MAFIWE ENITI O BA FIWE YIO MA LALA PE WON RIN NI ORI OHUN. IDAN SARADIJE AO JO ODIDI ATARE KAN PELU EYIN PEPEYE KAN TI ABA JOTAN AO FI SIN GBERE 3 SI EJIKA OTUN 3 SI EJIKA OSI 3 SI ORUN OWO OTUN 3 SI ORUN OWO OSI 3 SI ATANPAKO OTUN 3 SI ATANPAKO OSI 3 SI ORUKUN OSI 3 SI ORUKUN OTUN 3 SI ORUN ESE OSI 3 SI ORUN ESE OTUN AO FI IYOKU YI ASO FUNFUN TIO BA KA ORI WA AO MA SOMO ORI TI WAHALA BATI SELE TI ABA TI SAKIYESI WIPE ASO NA TI FUNFUN AO TUN LO FIMU EBU NA DAADA. IDAN FIFI IGBA SE OBE EWE IMI ESU AO WU TI GBONGBO TI GBONGBO AO FI ODIDI ATARE KAN SI AO JOPO LILO--- AO BU ETU DIE SINU IGBA AO BU OMI SI AO GBE KANNA LATI SE OHUN TI ABAFE SE IGBA NA KONI JONA. ADUPE FUN ASEYORI ISE YII AGBARA IGBAANI APA KETA (PART 3) PELU AKOJOPO ASIRI ONA ABAYO LATI OWO ALAGBA OPA FITILA (OPEYEMI DANIEL) TEL 07080271083