Yoruba English Ìdílé Immediate family Mọ̀lẹ́bí Extended family Màmáà / Ìyá Mother Bàbá Father (Àwọn) òbí Parents Ẹ̀ gbọ́n Older sibling Àbúrò Younger Sibling Ìyàwó Wife Ọkọ Husband Ọmọ Child Ọmọ Son Ọmọbìnrin Daughter Màmáa màmá Grandma Bàbáa bàbá Grandpa Sister Arábìnrin Brother Arákùnrin Yoruba English Aṣọ Clothes Aṣọ òde Fancy clothes Aṣọ ojoojúmọ́ Everyday clothes Fìlà Hat Bùbá Yoruba top Búláòsì Blouse Tíṣẹẹ̀tì T-shirt Súwẹ́tà Sweater Ìborùn Shawl Jákẹ́ẹt̀ ì Jacket Kóòtù Coat Ṣòkòtò Trouser Jíìnsì Jeans Síkẹ́ẹt̀ ì Skirt Ìbọsẹ̀ Sock(s) Bàtà Shoe Ìbọ̀wọ́ Glove(s) Yẹtí Earring(s) Ìró A wrap around cloth Kíláàsì Classroom Akẹ́kọ̀ọ́ Student Obìnrin Female Ọkùnrin Male Akẹ́kọ̀ọ́ obìnrin A female student Akẹ́kọ̀ọ́ ọkùnrin A male student Olùkọ́ Teacher Àwọn ènìyàn People Ìwé Book Ìtàn Story Ẹ̀kọ́ Studies Àṣà Culture Pẹ́ẹn ̀ ì Pen Pẹ́ńsùlù Pencil Yunifásítì University Rúlà Ruler Bébà àjákọ Piece of paper Tábìlì Table Àga Chair Mọ́nítọ̀ Monitor Máòsì Mouse Tẹlifíṣàn Television Síídiì CD Máàpù àgbáyé World map Ìṣirò Maths Kẹ́mísìrì Chemistry Físíìsì Physics Ẹ̀kọ́ ìtàn History Saikọ́lọ́jì Psychology Sosiọ́lọ́jì Sociology Ẹ̀kọ́ nipa ọ̀rọ̀ ìṣèlú Political Science Ẹ̀kọ́ nípa ọ̀rọ̀ ajé Economics Lítíréṣọ̀ Literature Áàtì/Ọnà Arts Sáyẹ́ǹsì Science Kíláàsìi sáyẹ́ǹsì Science Class Ìdánwò Examination Gbólóhùn Sentence Èsì Result(s) Ìdáhùn Answer Oúnjẹ Food Ọ̀gẹ̀dẹ̀ Plantain Àgbàdo Corn Àlùbọ́sà Onion Ilá Okro Òróró Vegetable oil/ Peanut oil Adìẹ Chicken Agbálùmọ̀ Wild cherry Ata Pepper Bọ̀ọ̀lì Roasted plantain Bọ́tà Butter Búrẹ́dì Bread Dòdò Fried plantain Èpìyà Tilapia (fish) Èso Fruit Ẹja Fish Ẹran Meat / Beef Ẹ̀dọ̀ Liver Ẹlẹ́dẹ̀ Pork (pig) Ẹmu Palm wine Ẹ̀pà Peanut Ẹ̀wà Beans Ẹyin Eggs Gbẹ̀gìrì Bean stew Gúgúrú Popcorn Hámúbọ́gà Hamburger Ìbẹ́pẹ Papaya Ìgbín Snail Ìpékeré Plantain chips Ìrẹsì / Ráìsì Rice Iṣu Yam Iyán Pounded Yam Kọfí Coffee Màálù Cow meat (cow) Ògúfe Goat meat Máńgòrò Mango Mílíìkì Milk Mínírà Soft drinks Ọbẹ̀ Stew Omi Water Ọsàn Orange Tàtàsé / Tàtàṣé Red pepper Tíì Tea Sandíìnì Sardine Ṣíìsì Cheese Ṣinṣíìnì Chinchin (a nigerian fried snack) Ṣúgà Sugar Tòlótòló Turkey Tòmáàtì Tomato Jọ̀lọ́ọf̀ ù ráìsì Jollof rice Ọ̀bẹ̀ ilá Okra stew Ọ̀bẹ̀ ẹ̀gúsí Melon stew Iwe Gizzard Panla Stockfish Ṣíbí Spoon Ajá Dog Ológbò Cat Ehoro Rabbit Erin Elephant Ọ̀bọ Monkey Màálù Cow Ewúrẹ́ Goat Ẹlẹ́dẹ̀ Pig Ẹyẹ Bird Ràkúnmí Camel Ẹṣin Horse Pẹ́pẹ́yẹ Duck Ọjọ́ Day Oṣù Month Ọdún Year Ọ̀la Tomorrow Ọ̀túnla Day after tomorrow Èṣí Last year Ọjọ́ Ajé / Ọjọ́ọ Mọ́ńdè Monday Ọjọ́ Ìṣẹ́gun / Ọjọ́ọ Túsìdeè Tuesday Ọjọ́rú / Ọjọ́ọ Wẹ́sìdeè Wednesday Ọjọ́bọ̀ / Ọjọ́ọ Tọ́sìdeè Thursday Ọjọ́ Ẹtì / Ọjọ́ọ Fúráìdeè Friday Ọjọ́ Àbámẹ́ta / Ọjọ́ọ Sátidé Saturday Ọjọ́ Àìkú / Ọjọ́ọ Sọ́nńdè Sunday