" ! DOCUMENTS FLASHCARDS ≡ Uploaded by Abdullateef Abdulsalam $ Home AGBARA IGBAANI SEASON 2 ORIGINA COPY(1) % & Aowa eru Alamo meta,eran namo ekiri meta,aomu agbon odidi kan aopani pansa,aoko eran ati eru alamo sinure,aogbe kana,toba jina,aoso kale,aowa yo eran ati eru alamo na,aogun eru namo ose Iwe ekan aolo fiwe,ti abawe tan,aowaje eran namo meteta na,aori owo ni ojona pelu ase olohun ' Page 50 OSOLE OWO ODIDI EYE KOWE 1 EYE ELULU 1 WARA TUTU 3 OBI ABATA OLOJU MERIN OBI IFA AO LASI ORI ARO LAPA OTUN OBI IFIN AO LASI ORI ARO LAPA OSI AO BU EPO PUPA SI ORI ARO TI INU ARO ATI INU AGBADA TI ABAJO TAN AO PA ADIE ASA KANSI ARA SERE AO FI FUFU RESI AO KO OBI YEN AO LODA SI ORITA META TI ESERIN DADA AO RO EBUYI SINU SERE AO MAFI SINAPU LO LAROLARO ( Page 51 Ipese ebe ati ashina Akara elepo meta so jo pelu odidi atare kan, ao lo, ao wa mu akara mesan tabi 16, ao wa to sinu awo sobi, ao da ebu na lelori, so wa fi epo pupa ati oyin igan si, ao daniyan si, so wa gbelobi tiwon o ti gba. ) Page 52 Aworo ile ise NLA ori elede tutu toojo,ewe aje aolokuna aofi ori ra gbogbo ara ori elede yii aowa fii ewe yi bolara tikoni han aokojure sinu ile aobomole walahi ese konida lodowa iba oooo Page 53 Asiri 25k Afoku panduku elo mo ajeobale 9 tikoluju omoatre9 ose iwekan ao dajiwe ni 6am kile tosu ao gba25k Page 54 ASIRI OWO NLA Ewe birana ikode kan iyere irun asiri alo gbgogbo re po afise basi eran malu 6 je . 22 of 30 # Download Products Support Documents Report Flashcards Partners Extension Examplum - Context Dictionary © 2013 - 2022 studylib.net all other trademarks and copyrights are the property of their respective owners DMCA Privacy Terms Make a suggestion Did you find mistakes in interface or texts? Or do you know how to improve StudyLib UI? Feel free to send suggestions. Its very important for us! Send feedback