Uploaded by AZEEZ ODEBODE

Ogun Oshole Owo

advertisement
(Ogun Oshole Owo Ajewamiri Todaju) Odindi Eiye Igun Meta, Eran Ara Oni Merin, Ori Oka To Ni Ase
Lenu Meje, Ori Inaki Meta, Ewe Aje, Ewe Sawerepepe. Alaye:- Ao Ko Eran Oni Yen Tele Ape, Ao Ko Ori
Oka Yen Lelori, Ao Tun Ko Ori Inaki Yen Naa Le Lori, Ao Wa Ko Igun Yen Le Lori Mole, Ao Wa Fi Awon Ewe
Yen Bo Mole Ti Ko Ni Yo Si Ita, Ao Wa Fi Odindi Atare Kan Si Loke Ao Jo Papo, Ti Aba Njo Lowo Ao Ma Mu
Epo Pupa, Ao Ro Ebu Yi Sinu Ado Ijamo Ao Gbe Sinu Apo Aso Funfun, Ao Gbe Sinu Apoti Iroko, Ao Po
Aguntan Funfun Ao Pa Eje Re Sori Apoti Yi Ao Tun Fi Ja Sere Yi Lara Ao Wa Fi Eran Yi Se Saa Ra Ki Ato
Bere Si Ni Lo Ogun Yi, Leyin Ojo Keje Ni Deede Aago Kan Oru Pelu Shinap Ati Peak Milk.
AGADAGODO YAHOO TODAJU ] Irun ori Oodi, Iyan ana, Ori Alabahun, Eepa igbe totigbe, ewe
Amunimuye, obi alawe meta, awo ewiri alagbede, odidi atare kan, Ao jo gbogbore po, Ao bu ebu ogun yi
die sinu efe owu'Ao dini ikobere,Ao fi owu dudu ati funfun dimo ara agadagodo, Ao ran Awo ijimere mo
Agadagodo na lara, GBOLOHUN RE,,,,, Aki pejo je Ahun, Aki pejo lu ewiri, Agbagba mefa ki pejo je ewu
iyan ana, hunhunhun lodi nwijo, oro ti lagbaja bafeso loni ki amunimuye mun iye re' ko ma lemo ohun ti
ohun se, Oro ti oba tiwo Agadagodo ki jade mo, Ao ti Agadagodo na pa, Ao bere Ohun ti abafe lowo
otitohun ' esekese ni yio se funwa
OGUN OMO YAHOO TA FIN DE CLIENT TODAJU. AO lo ra sigidi tabi ere tako tabo,ao
wa photo client yen ati ti ti an lo fun ise ,ao ko oruko
obinrin si eyin photo okunrin,ti okunrin si eyin photo obinrin,ao wa
koju e si ara won,ao wa fi photo yen si arin ere mejeji,ao wa di ni ikobere owu dudu ati ff,ti ibi kankan
koni han mo,ao wa yo eyo atare merindinlogun si enu,ao wa fi pe gbolohun re si,
akerejaye,ari ihoho woja,omo tuntun abeje loju3*,akerejaye ni oruko tanpe
ifa,arinhoho woja loruko ti an pe iwo sigidi,omo tuntun abeje loju loruko ti
anpe iwo aworan,agba ki sun loja koni irori,bi l omo l ba sun,oro mi ni
koma fi lokan,ki o male sun,ki oma lewoo,ki o ma le jeun,afi ti o bari
mi,bi ti ako pepeye,ao wa tu atare enu wa si ni emeta,ao gbe ko sibi kan,ti ife yi bati gbona ju,ao ma tu
owu ara re die die...o pe ju ojo merindinlogun yio ti bere ise o.
(1) OSOLE ori okete, ori aluko, ori agbe, ori ologbo ajo po pelu #500 tuntun, ojo ti aba jo na ni agbodo lo
gbogbo re, ale fi eko lo tabi omi tutu. (2) OSOLE OSO INU odidi ologbo kan alupa ao jo pelu odidi atare
kan ao lo, ao ro sinu kado ato, ao fi awo ijimere di lenu ao tun fi bo lara ni ago kan oru ao bere iye ti afe
lara re. (3) OSOLE AWURE ogede agbagba meta, epo jebo, tangiri meta, odidi atare kan, ao jo po, a lo
pelu sugar onikoro, ao ma lo pelu omi tutu, tabi HOT. (4) OSOLE OWO TODAJU Odidi olongbo nla kan,
oga kan, ogede omini merindinlogun, epo obo die, ao gun papo ao po mon ose dudu, ao wa fi epo pupa
po ose yii sinu igba olomori ao mon fi wee pelu kainkain tuntun odaju. (5) OSOLE OWO odidi igun aye
kan ori oka meta toni ase lenu, ori olufa meta to ni ase lenu, obi ajopa meta, odidi atare meta, egbon
ajobale die, adie asa kan, ao jo gbogbo re papo lagogo mejila oru ikoko tuntun lao fi jo, ojo ti abafe jo ni
ao pa igun naa......... (6) OSOLE TO DAJU ao ge ori ako alangba, ao fi eran monu ha ni enu, ao wa fi ori
alagba yen bo enu okan, ao fi odidi atare bo legbe, ao jo papo, ao lo kunna, aoda sinu schniapp ao ma lo
lararo.. (7) OSOLE OWO ori aguntan kan oga ayee kan, ekiri eran monu kan, odidi atare kan, ao jo papo
ao ro sinu sere ti a ba loo tan ao wa gbe sinu awo amon dudu, ao wa pa eje musuu kan bo, ojo keta ni ao
to gbe kuro, ao wa gbe sinu apo aso funfun, ao wa ma fi schinapp lo lararo.... (8) OSOLE OWO Ao ra
eiyele funfun kan, ao toju eran monnu, ao toju pasu owo kan, ao la eyele laya, ao gbe pasu owo le lori ao
fi eran monu si, ao fi odidi atare kan si, aoo jo po larin oru, ao ra otin schinapp sile, ao lo ogun yii kunna,
oru yen naa ni ao lo gbogbo re. ojo keta ni ao ti bere sini ri owo. odaju (9) OSOLE GBEWA koro owu
ekunowo kan, owo eyo ti ko luju 201, ao lo mejeji papo, eran monu ekiri kan, oga aye meta, atare meta,
ao jo meteta papo mon ra won, ao jo meteta papo, ao da mon eyiti alo yen, ao po mo ose #300 ao fi aso
funfun opa boo monle ninu igba daa ojo mejo, ago mejila si ago kan ni ao lo we, aso funfun ni ao fi bora
wee. odaju. (10) OSOLE igun ope dada ati eso yerepe topo ati odidi atare kan ao jo po ao ro sinu sere, ao
pa akuko adie kan fun, ao ma fifoko mu Jomejo mmejo... (11) OSOLE aye oga meje, orisi owo meje, ao fi
we igbo ao ti bo oa na lenu, ao jo po mo atare odidi 1, ao la eyele funfun lanjo, ao yo okan re mi, ao ko
ise ti a jo si a o tun po po aoma fi otin schinapp mu... (12) OSOLE oga aye kan, awo lili kan odidi atare kan,
ao jo po, ao da sinu koobu kan ao da si, ao gbe kale titi di ago kan oru, ao fii milk kan si ao gbe mu ako
gbodo sunmo obinrin fun ojo meje.. (13) OSOLE odidi lili kan, oka baba pupa, ewe alupaida ati odidi
atare kan, ao jo po, ao ma fi epo pupa lo. (14) OSOLE odidi ori pepeye ako aso agba meje, odi gigun papo,
ao di si inu owu etutu, ao kan oje igi emin si titi yio fi gbe dada, a le di si meta tabi meje, ao ti bo inu
okele ao gbe mi. (15) OSOLE eyin adie ororo 10 ewe oriji ewe werenjeje die, odidi atare kan ao jo po, ao
ro sinu igo, ao wa toju awo tanganaran tabi ike funfunn, ao ma bu ogun yi sinu re, ao ma fi oyin laa. (16)
OSOLE odidi okete kan, odi atare kan, opolopo ewe ewuro, ao gbe okete tele ape pelu atare kan, ao wa
ko ewe na le ti yio bo tan ao jo po, ao ma fi schinapp mu lararo. (17)OSOLE eegun ori monu die, ewe ola
die, ewe tomatoes, ao lo meteta papo, ao fo eyin agric meta, ao da awon nkan ti a lo yen si ninu ao wa
da sinu nylon ti won fin pon moi moi, ao se je ninu kanran, ao je ti o ba tutu. (18) OSOLE eran monu,
eran igun, ao lo po mo iyere ao fi din eyin pepeye meta je lepo niyo, ao fi ogede omini meta kooje ni
gbigbona... (19)OSOLE OWO NLA
(20) OSOLE AWORO Ojugun ese mejeji, ao paa si keke ao ko sinu agbada, ao ko ewe efinrin le lori ao fi
odidi atare kan si ao jo ao ma fi oti schinapp lo ni ojo meta meta si ara won....
Ogun ikiya: Ota inu iroko pelu odidi estate kan ao lo papo ao mafi epo la ... . ikiya todaju ni oooo mafi
oju di
(Asina)adan kan,awolili,eyin adie ibile kan,odindi atare kan,AO jopo AO fi foko mu Lekan soso laro
kutukutu
(Ose awure tafinri owo)eran elede basi kan,erun alamo,ewe sikiminin,AO gun papo AO popo mo ose
dudu AO run po orimo Ati oyin gidi mo ose yan AO wa ko ose yan sinu igba olomori AO wa gbesi igun ile
AO bu ekuru si idi igba ose ye to badi ojo keje AO ko ekuru yan kuro nidi ose yan AO mafi ose yan we
odaju gan,note:titi taofie ose yan we tan AO gbodo bu ekuru sidi oseyan mo
IMUNLE AWON AGBA
Eye owiwi 1 eye adan 1 ese aja mererin ewe ajeobale ewe orijin topo atare odid meta ao jo ti aba njo
lowo ao ma ta epo pupa si lori ti o mafi jo tan ao wa da si ona meta ao fi okan po ose ao fi eje eyele po
mo ose ikeji ao ma fi epo pupa la iketa ao ma fi otin lo lararo ao ma fi ose naa we nii oooo
(ogun eyonu agba todaju)igba eyin ijapa,ikara hun igbin,iwo agbo,atare odindi kan,AO jopo AO ma fi
foko tutu mu laro Ati lale
ASINA TIPATIPA
ao wa ori oka kan, oga gbigbe kan, eso la pupa pupo die odidi atare kan ao jopo ao po mo ori ao mafi mu
eko gbigbona odaju dada
AGBO ASINA Aowa eru awonka eyo mesan ewe ajeobale ewe botuje funfun aoko sinu pot eru ni yowa
nisale aose lagbo aowa igbin apinnu kan ewe ewuro 9 aolo pelu ata ijos mesan aofi se igbin kale ti aba
tiwede laoje aoni soro si eni kankan awon ojo ti ale se iwe yi Sunday , Monday , Thursday,
Osole owo tio daju: abo pepeye funfun,ao la inu re ao gbe eye awo funfun si ninu,ori oka kan,ori ere
kan,ori agbadu kan,odindi atare kan ao jo ao ma fi oti lo Aseje aseno: Panri aiye ao fi okode kan bo
lenu,ao jo pelu odindi atare kan,ao lo tio kuna ao fi se eran malu tia ge si 16 je lepo niyo enu ono lao ti je
aseje yi ao daya de le je ni ooooo
Aseje awure: ikode 3,iye agbe 3,aluko 3,ao to igi tio wa ni idi re ao lo pelu opolopo iyere, #1000
titun,rasu die ao fi se okan malu tio roro tio womi je, ao ge okan yen si 16.
OGUN FUN ITO-SUGAR(DIABETES)
Epo Ako-Isu To Po,Gbogbo Iye Ati Ifun Akuko-Adiye Ibile Kan,Odidi-Atare Kan.A O Jo Won Po,A O Lo Ebu
Won Kuna-Dada.A O Ma Fi OMI-TUTU(Ordinary Water) Tabi EKO-TUTU Lo Ebu Na Dede.OLOHUN NIKAN
NI OLUWOSAN TODAJU.
OGUN FUNFUN RALERALE(ARUN-ESE)
Egbo-Tude,Egbo-Ipeta,Egbo-Inabiri,Egbo Awogba-Arun,Egbo-Egbesi,Odidi-Atare Kan.A O Jo Won Po,A O
Lo Ebu Won Kuna-Dada.A O Ma Fi Ebu Na Fo EKO-TUTU MU Dede.
ALEKO(MANPOWER) FUN OKUNRIN
Ogede-Agbagba Dudu(A O Bo Epo Ara Re Kuro),Bara-Nla Kan(A O Bo Epo Ara Re Kuro),SugarOnikoro(Cubes-Sugar,Not Dangote O)-20pcs.A O Ko Won Sinu Kotopo Tabi Ike-Olomori To Fe Die.A O
Wa Fi OMIDUN Re(Soak) Won Po Fun 3Days.A O Ma Mu Ni GASI(Shot) Kan Dede.
: Oshole todaju dada
Igbin agbonu metta3 Eiyele fufu metta3 Ijapa gidi metta3 Owo orilede metta3 Odidi atare metta3 Aojo
papo aoma fi otilo laro laro
Agbelepota: olongbo ti motor pa orogbo 11 obi abata alawemeta 11 odidi atare 11 aojo Palo aofi fo eko
mu
Ogun aïsan kamadu:egbo akô ibèpè,egbo botujè,ènu opirè,OSan wèwè,taba dudu,kanhun,ao jo pô ao
ma lo pèlu ori akô tabi omi osan wèwè.
Ogun iwosan ikô:ao fi ori tèlè ipo,ao ko ewe omissimissi olokun si,ao ko ewe bomubomu si,ao bu omi diè
si ao sé jina,ao ma mu
EBE EYONU.
Imin esu, ao tuu tegbo-tegbo topo, pelu atare kan, ao lo sugar mon,lila laaroo.
EYONU ASINA.
Eyeile funfun balaii kan,epo egusii, iyo #50, odidi atare kan, ji jo po ao pin si ona 3, .okan inu oyin,okan
ose, okan inu ipara.
Ogun inu runrun:ao fun èni ti inun run ni atare (14)ję ao wa fun ni omi mu lé lori,odara.
Ogun èyin dundun:ao mu alatakun 9 fun okunrin,7 fun obinrin pèlu ôkpô atare, ao lô gbogbo rè kpô.ao fi
sin gbèrè si ibi ti nduni,ao wa fi éti yi fi kpa
EBE EYONU.
Imin esu, ao tuu tegbo-tegbo topo, pelu atare kan, ao lo sugar mon,lila laaroo.
EYONU ASINA.
Eyeile funfun balaii kan,epo egusii, iyo #50, odidi atare kan, ji jo po ao pin si ona 3, .okan inu oyin,okan
ose, okan inu ipara.
EYONU IMUNLE OWO TODAJU
Akuko adie asa kan, ao la laya aofi eye onbe kan sinu re pelu Odidi atare kan. Ao mu Ako okete oye kan,
aola inu re, aoko epo obo ati Odidi atare kan sinu re. Aoko mejeeji sinu ape, aowa ko ewe ewuro,
ajeofole, iyalode fun fun ati pupa, oriji,eso werenjeje pupo, iye agbe, iye aluko, ikode kookan, epo igi nla.
Aowafi opolopo ewe Omonigedegede funfun bo. Aojo gbogbo re papo, aolo aoro sinu igo fun fun. A
omafi oti lo laro, a omafi mu eko gbigbona pelu Ori lale. Pelu aniyan wa. Odaju
KI IYAWO ILE MALE YAN ALE ***** eso isin tiko la enu ao jo pelu odidi atare kan obinrin na yofi fo eko
mu lekan soso, oko re yo wa eso isin eyi toti lanu yo jo pelu odidi atare kan oun na yofi fo eko mu lekan
soso wan ba ara wan ni ajosepo lobatan
ATUDE, ASINA, ATI AFORIJIN AWON AGBA
Ao ja ewe iyalode mesan lona meta ti gbogbo re yio je (27) Ao lo (9) kan pomo ose dd,Ao tun lo (9) keji
pelu ose dd,Ao tun lo (9) keta pelu ose dd ,oje ona meta ao wa le ikookan mo kehin kehin kookan. Ao bo
eko elewe kan ninu ile iwe ao fi sinu igba kekere kan, ao fi epo pupa fo eko yi ninu ile iwe na, ao gbodo fi
omi fo eko yio, ao wa fi eko yi pa gbogbo arawa, ao duro lori ewe eko yi ti aba tin fin para ao wa we
kehin kehin meteeta yi lera lera ni ekan yi, taba we tan ao ko kehin kehin yi ati ewe na danu sinu salanga
tabi inu kota, ao losun ale ni a man we ose yi.Bi abajeko andarijin ewe pelu ogo olohun ona yio si iyanu
asele ninu aye wa odaju.
OGUN AWURE FUN CONNECTION LATI FI MAA RI OWO(MONEY)
Abo adie dudu nla kan,eye lekeleke kan,ori olongbo kan,ori oka to ni ase l'enu kan,ori ere to ni ase lenu
kan,ikoride kan,iye agbe kan,iye aluko kan,atare nla meta,itun,ifa, abere to po die,irun woro to po
die,ewe ejirin to po dada.
Sise re:-A o la inu adie yen, a o fi eyin re le ape,a o wa ko gbogbo eroja toku le lori, a o wa da ewe ejirin
bo dada,a o wa jo dada,ti a ba ti jo tan,a o lo ti yoo kunna dada, a o wa ro sinu igo funfun kan.
Lilo re:- a o ma fi oti schnapp original lo.
Ofo re:-a o ma sope bi a ba fa gburu,gburu a fa igbo,enitomomi ki won lo pe enitiko momi ki awon
mejeeji maa ko owo nlanla wa fun emi lagbaja omo lagbaja(a o daruko wa ati oruko iya wa).
Akiyesi:-Ogun yi daju pupo ko se fi sere rara atipe ogun tun nsise fun awon ti nse ise Yahoo.
(Ogun Oshole Owo Ajewamiri Todaju) Odindi Eiye Igun Meta, Eran Ara Oni Merin, Ori Oka To Ni Ase
Lenu Meje, Ori Inaki Meta, Ewe Aje, Ewe Sawerepepe. Alaye:- Ao Ko Eran Oni Yen Tele Ape, Ao Ko Ori
Oka Yen Lelori, Ao Tun Ko Ori Inaki Yen Naa Le Lori, Ao Wa Ko Igun Yen Le Lori Mole, Ao Wa Fi Awon Ewe
Yen Bo Mole Ti Ko Ni Yo Si Ita, Ao Wa Fi Odindi Atare Kan Si Loke Ao Jo Papo, Ti Aba Njo Lowo Ao Ma Mu
Epo Pupa, Ao Ro Ebu Yi Sinu Ado Ijamo Ao Gbe Sinu Apo Aso Funfun, Ao Gbe Sinu Apoti Iroko, Ao Po
Aguntan Funfun Ao Pa Eje Re Sori Apoti Yi Ao Tun Fi Ja Sere Yi Lara Ao Wa Fi Eran Yi Se Saa Ra Ki Ato
Bere Si Ni Lo Ogun Yi, Leyin Ojo Keje Ni Deede Aago Kan Oru Pelu Shinap Ati Peak Milk.
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye
re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa
GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo
monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti STREMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin,
obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro.
OSOLE OWO TOLAGBARA,ori Menu Tope Kan,ewe Sawerepepe Pupo,ewe Etiponla Pupo,eye Igun Tope
Kan,odidi Atare Kan,ao Jopo,ao Lokunu,ao Fi Oti Lord Lo Lago Kan Orun,pelu Ogo Olorun Ao Gba Alejo
Olowo Na Lara Ojo Keji,AKIYESI,ki Ato Matan Ninu Owo Yi Ao Ra Eran Ewure Abo,ao Pa Ao Mu Die Ninu
Eje Eran Na,ao Fi Eran Toku Se Sara,owo Di Nina
OGUN OWO TOLAGBARA
owo Otu Akiba Kan,ijapa Aye Kan,odidi Atare Kan,gbogbo Owo Ilewa Ti Ana,ao Jopo,ao Lokunu Ao Mafi
Oti Lord Lo Lago Kan Oru Ekan Lose
OSOLE TOMU OWO WA TODAJU
Ori Okete tutu kan Ori ajiyo die Ewe sawerepepe tutu Igi Nla die Odindi Atare kan
Ao fi ajiyo si enu Okete yen ao wa jo gbogbo re papo ao wa lo kun na daada ao wa fi oti lo ni araaro pelu
adura
OLUGBOHUN ABIYAMO TODAJU
ewe sawerepepe tojo topo .aogun poma ose dudu Omi iwe oku lao fi po papo ao fi ori oka tutu lodaraju
ao fi tele oru nla kan ao ko oselelori ao fi opolo ooye kan lelori aofi ose lelori ao tun fi oga ooye lelori ao
tun fi osele lori aoki ma tiyiole dada aoja ewe ogbo tutu aofile lori aofibo. ao wa gbe pama fun ojo
mesan tobape aoko eweyen kuro ao waso loruko olugbohun abiyama aofi asopupa bolori ao wamo pe
laro laro.
ohunre.olugbohun abiama moji loni miseejeki atije atimu osoro funmiloni kodari awon olowo sodomu
loni awon eyanpatakiparaki eyan jakan jakan wabami kiwon wagbeowo nlala wafunmi. kosi nkan ti ao le
lo fun
Olugbohun Epe Ati ADUA
: Aogun ewe abamoda tutu 201 pelu ose .Ao wa Iwo maalu NLA tiwon o tii fee ategun si, ao dori ako
alangba kan kodo aojusi laaye, ao tun ju akan kan si, ao tun ju oga aye kan si, ao sare fi ose yen bolori
mole .Ao Faso funfun di Lori daada aowa soko soke laini fara kan nkankan fun 21 days katoo maalo pelu
ohun pe: Tomode bafenukan ose aase, bagba bafenukan ose aase, awise nitifa afose niti Orunmila,
abamoda kiidatie komase, aba ti alagemo bada nloosa oke ngba, akan loni ki oro temi L*L baso loni
kokan L*L Lara loni...
OLUGBOHUN ADURA TODAJU
Ao wa iwo malu kan, oga oye kan, eyo ataare mesan, ewe esisi funfun, ewe aragba, ao gunewe mejeji
papo mo ose dudu, ao ki oga oye yen bo inu iwo malu naa ti yio yo ori soke, aokoko ko eyo ataare mesan
si inu iwo yen ki ato ki oga yen si, ao ko ose ten fi bo lori, ao maa fi kan enu fi se adua lorisirisi. Koda ti
abani Enia ni ilu ibo miran ti o baa nri awon walah kan, ki afi se adua fun, lagbara Olohun won yio maa ri
gbigba adua naa ni kiakia
(AGADAGODO TODAJU)( omo yahoo leloo )
Aojo adan1, akiriboto obi1,orogbo1, ati ela-ileke1, leyin toti jotan, aofite ifa odi meji,aodiimo
AGADAGODO pelu owu dudu ati funfun
OFO RE
akiriboto obi kiiloju awe, ela ileke kiiloju aati okun bo,orogbo kiiloju awe, awon meteeta ni won parapo
niwon difa fun orunmila, nijo tonti kori orun bowasi ikori aye, orunmila ni talodi adan nidi, odi meji ni
oun ni oundi,odi meji iwo todi adan nidi lojokinni ana wabami di ___omo ___
ni iye komaale pa ohun mida baibai (aniyan)
ASIRI NLA
Ise yi je ise nla tojepe oma ntun igbesi aiye yan se....
Ejinrin tutu, adie abo toti bimo ri dudu, eyin adie ibile 16, atare odidi 16, eye onbe 16, iye igun 16, ewe
ako rere tojo, ewe bomubomu ati ese re topo tojo, eye kowe meta, aso awon agba meta, aso egungun
die, egbo tude topo, epo obo topo, igi nla topo, itanna ibepe ako topo tojoo, ao ko gbogbo won sinu ape,
ao wa du eje penpeye ako funfun si lori, ao wa gbe kana, ao fi epo pupa yipo aro, taba jo tan, ao Di mo
aso egungun tabi aso dudu, funfun, pupa, ao so ko soke, ao wa mafi epo pupa LA lalale, oti lo laro laro.
"OSE EYONU OSOLE
Eiye kowe kan, oga gbigbe meje, igbin agbonu meta, ewe ewuro ojoo ati ewe sawerepepe ojoo, atare
odidi kan, eiyele funfun kan, oga aye kan.
. SISERE:- ao gun igbin meteta ye papo mo awon ewe ye, ao ko sibi kan.
Ao wa jo kowe ye ati oga gbigbe meje ye papo mo odidi atare kan.
Ao wa da won papo mo rawon, ao fi ose popo, ao wa da eje eiyele funfun ye si, ao fi po po, ao wa gbe
oku eiyele ye te inu ogba olomori, ao ko ose ye le mole, ao wa la ose ye larin dogbandogba, ao fi oga aye
ye bo arin ose tala ye, ao wa da pa fun ojo meje, lehin ojo keje, ao mafiwe laro laro.
Ise yi, osise Debi pe ona kona ni owo ati mo wole funwa. Odaju
AGADAGODO TI AFI NDE CLIENT WA MONLETONSISE FUN OMO YAHOO
Ao wa awo ekun,awo egbin ori adaripon kan, ori pepeye ati esere mejeji, ao Jo po, ao
fi owu dudu ati owu funfun Di po mo ara agadagodo, ao pe ofo re si ao wa ti pa,
OFO RE,,, agbin sinu ni egbin gbin, akun sinu ni ekun ku, ori ti adaripon bale ki fi ba ogiri
soro, igbagbe se ..........................., owu dudu ati owu funfun won ki jara won niyan, ki
lagbaja omo Lagbaja ma jami niyan loni o, ao ti pa
"ITUWO AWON AGBA TODAJU "
eye adan kan, ewe papasan topo die, ao jo pelu odidi atare kan, ao fi epo pupa yika aro Kato majo lo,
tobajotan, ao te ni osa meji eleye.
AO SO BAYI SI :- ifa ti ase fun orunmila lojo UN Ana, ohun na ni ase fun l omo l loni yi o, ohun na wa tidi
omo orunmila latonilo, kiwon fi sile, kiwon maba nkan ini reje mo o,kiwon maba ise owo re je mo o, ti
won bati pin eran re kiwon da pada lati oni lo.
OFORE NIYI :- akinsoro awo ori ogun ode, alaja awo ode ide wure, pooye awo ode igba re, edagiri giri
awo ode ilu afin, awon mererin ni won se omo ikofa orunmila, ifa kowon ni dida owo, oko won ni tite ile,
oko won ni okuru kuru ebo hiha, awon mererin ko ifa, won ma ifa, awon mererin wa bere sini ndite
orunmila, ikupa akinsoro awo oriogun ode, ikupa aleja awo ode idewuru, ikupa pooye awo ode igbare,
ikupa edagiri giri awo ode afin, awon mererin wa loduro si agbede meji aiye oun orun, akinsoro bale idi
eiye aje, aleja bale odi eiye opipi, pooye bale odi eiye kowe, edagiri giri bale odi eiye oyo, awon mererin
tun bere sini ba orunmila ja, won koje kiolowo lowo, won koje kiogbadun igbesi aiye re, ojojumo ni won
fi are orisirisi se orunmila, won koje koni oungbogbo mo, orunmila ni haaa se kosi awo mo ni? Won ni
awo wa iwo orunmila, oni awo wo lowa, won ni ogun awo ogun gun tere tinse igi inu oko, orunmila ni ki
esare tete ki eloba oun pe won wa, nigba tiwon DE, won se ifa fun orunmila kaka kosan fun orunmila,
sise lonle kokoko bi oju eja, orunmila tun ni Haaa se kosi awo mo ni? won ni awo tunku, oni iru awo wo
loku, oni oku awo adan, tikose eku tikose eiye, tonbe lori igiorun, oni kiwon sare tete lole pe wa fun oun,
nigba ti ode, ose ifa fun orunmila, opa gbogbo won, ipa won koka orunmila mo, alele eiye aje kole ke,
oganjo gan dudu ogbigbi eiye kolerin, ojumo mo kowe eiye kole ha mo, irole ro dede oyo eiye kole dun
mo, akinsoro nbo oda lapa, ogbigbi nbo oda lapa, kowe nbo odalapa, oyo eiye nbo oda lapa, edagiri giri
nbo odalapa, ile femo sibe tan orunmila lale bawon nibe, oni kiwon bere sini njewo gbogbonkan aburu
tiwon tise si oun orunmila, won ni ki orunmila darijin awon, komaje ki ile mo ba awon, awon yioba
orunmila mule, kiojowo kiofi awon sile, orunmila ni kiwon omu ile, won bi orunmila base ise yi fun
enikeni bi ti ojo kinni Ana ti awon fi mule, iru eni be awon koni Baja mo, biwon tida majemu tan
orunmila dawon sile, won bere sini tun nkan orunmila se, orunmila njo, onyo, orunmila yi si apa otun,
oyisi apa osi, omu Orin senu, Orin aiku,awon awo pe sile orunmila, orunmila se enu koto oti Orin benu,
Adan DE Alaro eiye 3 * iku ko oun sile leiye adan nke o. Iku ko emi l omo l sile leni o.
Ao fi epo pupa LA gbogbo e Pata Pata lale sun.
OGUN OYUN IJU (FIBROID):
ose dudu. obuotoyo. pandoro. osan wewe. ao ge kekeke. ao fi kanhun die si. ao jopo. ao da sinu omi
osan wewe. ao ma mu ni gaasi kan tabi meji
ELEYI NI ASEJE FUN ARUN IJU TI KIIJE KI OBINRIN LOYUN
Eja aro ojulowo kan (ojulowo eja aro kii fibee tobi o, kekere si ni ori re)
Ina ori ewe sawerepepe niwonba,Ewe eyinolobe niwonba,Ata ijosi eyo 14 Iyere eyo 14
Agbon to lomi ninu meta
SISE RE
A o lo ata ijosi loto, iyere loto, ewe eyinolobe loto, ina sawerepepe loto, a
o fi eja aro sinu isaasun olomori, ao da gbogbo awon nnkan ti a lo yii lee,
a o fo omi agbon kan sii, ao see pelu epo ati iyo ti yoo jina daadaa.Toba tutu die, ao soo sori osuka aso
funfun, obinrin naa yoo je eja yen pelu gbogbo egungun re, yoo si gbe omi obe yen mun.Ao fo omi
agbon meji toku, oun ni obinrin naa yoo fi se omi mun le aseje naa lori.
AKIYESI
1.Ao gbodo lo omi rara o, omi agbon lao fi se omi fun lilo gbogbo ewe eyin olobe, iyere, ata ijosi ati ina
ori ewe sawerepepe.
2. Awon agbon yen kiise jije fun enikeni o, ao lo sonu ni tabi ka rii mole.
3. Obinrin yen ko gbodo mu omi le aseje yii o, sugbon o le mun schnapp lee lori bobasefe.
4. Aseje yii kere loju, sugbon o soro lati je o. Afi ki e joko ti obinrin yen ki e rii wipe o jetan patapata o.
5. E gba obinrin.naa niyanju ko mase bi aseje yii o.
6. Iju yii maa yotan diedie mo obinrin naa ninu ni.
EGBOGI FUN IJU " FIBROID"
(1) Epo igi amuyan, ESO bara, ewe akoko, ewe akaja iyo, aofi omi ikan sewonpo..mimu nife kokan lararo..
(2)Egbo wowo, Atare meji, imi ojo, taba gidi, aolowonpo sinu omi orombo wewe Ati oti oibo mimu ni
gaasi kokan lararo
(3) Iju òpè, Iyo obu Atare odidi merin imi ojo aolowonpo sinu Adi Lila 5ml table spoonful...
N. B Eridaju wipe èba eniti onimimo nipa itoju ewe Ati Egbo Dada kiè tose ooo.
ITOJU OYUN IJU ( FIBROID)
Epo pandoro, Bara, ewe akoko, ewe iyere, iyo aofomi ikan, ( omi ogi tabi omidun) kiii lagbo tutu fun ojo
meta... mimu nife kokan lararo lehin ojo meta.....
ISE YI LAHUN PE NI OLODE IJAKADI
Ise ti awon baba nla wa fi jagun lojo kini ana ni, ise na kowa ni ero rara, bi ija bato ija ni amahun lo ise na
bi ija ilu kan si ilu keji. Ise na lo bayi.
Ao wa ako alangba kan ao la aya re ao fi odidi atare kan si odidi orogbo kan ewe amunimuye ewe daguro
ewe aluro ao ko gbogbo e sinu ako alangba na ao wa gbe sinu aso funfun ti ahunpe ni kitike ao fi yi ao di
ni owu dudu ati funfun ao wa ran ni olode
Eyan tabafina apon bi adaripon ni o... Edakun kolero rara akinlo ni tosi
¤AGBELEPOTA TO LAGBARA¤ Iwo Maalu(Cow's horn), iyo die(salt), igbin (snail), ose dudu(black soap).
Ao lo Igbin(snail) naa mo ose dudu(black soap), ao wa fi iyo die(little salt) si. Ao waa ko gbogbo re sinu
Iwo Maalu(Cow's horn).
OFORE:Nijo ti igbin ba fi enu kan ose, nijo naa loro ikariko nde ba. Nijo ti Igbin ba fi enu kan iyo, ijo naa nii re
orun. Ki gbogbo eni toba nla si emi l Omo l maa re orun loni dandan(ase!).
NB:- Ao gbodo fisere ooo,Ao lo Igbin pelu ikarahun nio, Ao maa tola ni,
Eekan losu lao maa tola tabi ti aba se akiyesi nkan buburu kan.
OSHOLE SEND ME UR ACCOUNT.....................
ewe abamoda eyo meji ao fi ori ra tinu teyin mejeji ao wa owo 200tuntun ao ko oruko wa si pelu adress
ati account number pelu phone number sinu owo na oju ati eyin ao wa eran ifa die ao fi ewe abamoda
eyokan tele inu isasun ao gbe owo yen le ao fi eran yen sori owo yen ao fi ewe abamoda keji yen bo owo
yen mole ao fi atare kan si legbe ao jo po ao lo lekan na pelu oti toba lagbara
Osole Owo Todaju
Olongbo aye kan, Okete aye kan ati eiye kowe kan. A o pa okete yen lai yo eje lara, a o pa olongbo naa
be, a o wa la inu okete naa ati inu olongbo naa, leyin eyi a o wa ko ifun okete sinu olongbo ati ifun
olongbo sinu okete, a o wa fi eiye kowe yen sinu okete, a o wa fi owu dudu ran inu okete naa, a o wa ko
eyin ororo mefa sinu olongbo naa, a o fi owu dudu ran inu olongbo naa. Leyin eyi a o wa ko oju won
sirawon, a o wa fi copper-wire di papo ti won yoo koju sirawon. A o jo papo pelu odindi atare kan.
Lilo:- a o ma fi omi agba ma lo ni alaale nigbati aba fe sun.
Ikilo-pataki:-odomode ti o ba dara re l'oju ko mase lo ebu yi atipe iwo ti iyawo re ba l'oyun kogbodo lo
pelu iwo ti mbe iyawo oni iyawo ni ale ni won yoo gbe aje to lagbara kuro ni ara re.
OGUN TI A LE SE, TI A O FI MAA RI ISE(WORK) SE
A o wa ewe sawerepepe, ewe ola, ewe onitikuti ati eyin agric meta.
Sise re:-a o koko se eyin agric naa, ti a o bo epo ara eyin naa kuro, a o lo gbogbo ewe naa papo ti yoo
kunna dada pelu ata ijosi meta, a o wa ko eyin ti a bo yen sinu ewe ti a o lo papo, a o se l'epo n'iyo.
Adura re:-ti a ba nje aseje naa lowo, a o ma so wipe sawerepepe lo ba mi pe ire aye mi (a o daruko wa
ati oruko iya wa), gaga nise eyin agric, gaga ni ki o ma se awon customer mi, ti won ko ba ri mi (a o
daruko wa ati oruko iya wa) ki won ni isinmi, t'ile-t'oko ni won n gborun ewe ola, ki gbogbo awon
customer mi (a o daruko ati ti iya wa) ki won wa maa fi owo (money) owo (hand) won wa fun mi,
onitikuti lo ni ki o lo ti awon customer mi wa (a o daruko wa ati oruko iya wa).
Note:-ogun yi dara pupo, o tun sise fun awon ti nta oja pelu onise owo ati fun omo yahoo.
AWURE TI O N MU OWO WA
A o gun igi-nla mo ose dudu, a o fo eyin adie ibile kan si, pelu omi agbon odindi kan ni a o fi po, a o pa
agbon yen bi igbati a ge ori osan, a o fi agbon yen se saara. A o ko ose yen sinu karahun agbon yen, a o
wa fi omori re de. Odi wiwe ni idaji kutukutu.
NOTE:-Bi won ba si owo san fun wa, akogbodo da pada.
AKIYESI:-Bi aba n we ose yen, a o maa se alabapade awon eniyan nita, ti won yoo maa bere fun iranlowo,
bi ki won toro owo lowo wa lati fi lo si irin-ajo lati ibikan lo si ibomiran, iye ti o ba ka mo wa lowo ni ki a fi
se saara naa. Ki a ripe a se saara naa. Ibiti saara naa maa n gba wa niyen. Won le maa dupe lowo wa
nigbati a ba fun lowo naa,ki a maa ba tiwa lo...Sugbon obinrin ni awon ti e o maa salabapade ni akoko
yen fun itoro aanu, ti okunrin ba wa bayin fun itoro aanu, o wun yin ni, saara ise yi, o ni ki a se itoro aanu
fun okunrin. Ise yi daju gan...Edanwo
Ogun asiri Ola
:Okan malu nla kan, Eja ojiji kekeke tutu tabi gbigbe meta, #1000 tuntun kan, Irun asiri lopolopo ati
Odindi atare kan.
SISE RE:-Iwo meta lo wa ninu okan malu, a o mu eja ojiji kan pelu #1000 sinu iwo kinni, a o mu eja ojiji
keji pelu odindi atare kan sinu iwo keji, a o tun mu eja ojiji keta pelu irun asiri sinu iwo keta, a o wa gbe
sinu agbada, a o wa ko ewe egele ati ewe ola le lori ti yoo bo dada, leyin eyi odi jijo, ti o ba ti jo tan, a o
lo ti yoo kunna dada.
LILO RE:-A o ma fi fo eko mu tabi ki a maa fi omi agba lo ni araro kutukutu ki a to soro si eniyan
OSE ASINA OWO TODAJU
Eran elede tikoni awo ni ara, a o gun ninu odo ti yoo kunna dada, Ikun ojia ojulowo ti o die, a o gun ti yoo
di lubulubu, Epo obo a o gun kunna dada, Ewe ola to po die, a o gun kunna dada, a o wa ko gbogbo re
papo, a o wa gun mo ose dudu ti o to po pelu oyin gidi ati oronro malu ti won pa ni ojo naa, a o wa po po
mo ose naa, a o wa ko ose naa sinu fitila oloju merin-din-logun (16) ti o ba tobi die.
WIWE RE:-Ti o ba di ni ale, a o ti Abela funfun kan bo ose yi ni aarin, a o tan ina si abela naa, a o pa ina
ijoba tabi atupa ti o wa ninu iyara ti a gbe ose naa si, a o wa bu ose yi si ori kainkan ibile, a o lo fi we, ti a
ba dari de lati ibaluwe, a o la oyin die si enu wa, a o wa pa ina Abela naa, a o lo sun.
AKIYESI (1):-Ti Abela yi bati njo kanle a o maa fi Abela miran ropo re pada.
AKIYESI (2):-ati aro ati ale ko si igbati a ko le we ose yi, sugbon ti o ba je aro, idaji ni yoo je. Odamiloju
kosi bukata ti o ba yoju ni asiko ti a ba nwe ose yi, irorun ni a o fi tan bukata naa. Ose yi daju pupo.
ORUKA AYETA TODAJU...(RING OF BULLET-PROFF)...... AO WA EWE ABAMODA TO PO DADA, ORUKA IRIN
META,ODINDI ATARE KAN,AO KO EWE ABAMODA DIE TELE AGBADA (POT),AO KO AWON ORUKA NA
LE,AO FI ATARE NA SI,AO WA TUN KO EWE ABAMODA TO KU LEWON LORI..AO WA JO WON PAPO...ao
ma ki oruka na bowo ....otan TI A BA FE TEST ORUKA NA WO,AO KI ORUKA yi BO ADIE LORUN,AO WA YIN
IBON SI ADIE NA...hmmm..ota ibon na koni wole,,koda huhu kankan koni ja lara adie ni
*OOGUN TI OTA FI NJADE LAYE / ASINA NLA* ........
Ao lo ra opolo ijokun nla kan, epo obo,igo epo pupa kan...ikoko tuntun...
SISE RE...ao fi owo mu opolo yen...ao se adura si leti otun...ao sepe iku fun awon ota wa nni eti re
keji...ao wa fi si inu ibi kan...
Ao da epo pupa yen sinu ikoko tuntun na...ao wa gbe kana...ao je ki epo yen o gba daada...ao wa ju epo
ebo sinu re...ao tun ni suuru ki o fi din daada...ti o ba se die ti a o gbo dindin epo obo yen mo...ao wa ju
opolo yen si ni aaye...yio si ku lekaana...ao wa ni suuru ki opolo yen o fi din daada...
Ti o ba ti gbe daada...ao wa so ikoko yen. Kale lori ina...ao fi nkan yo opolo to ti din gbe sori olo ati epo
obo yen...ao wa gun won papo mo ose dudu...epo ti a fi din yen ni ao fi po ose yi....ao wa ko ose na sinu
ike funfun olomori kan...
Ao ni suuru ki epo toku ninu ikoko yen o fi tutu daada..to ba ti tutu, ao wa da sinu ike kan.
LILO RE...Ao ma fi ose yen we ni ale ati aaro...ti a ba ti we ose yi tan..ao fi epo ti a ro sinu ike yen fi ra
idodo wa..opari
..gbogbo ota ti o. Ba ndi ire ayo wa lowo ni yio ku koto di ojo meje!!!...e danwo ni kiakia ki e fun mi laabo
ise yi oo..
OSHOLE OWO TODAJU.....SUGBON ISEERE KAI ISE GBEWA NII OMANSE Dakun Moro Iwo OMO iyami
tobafeedawole iseyii....koko loobeere nan boya oromo eledare...komaba fowosofo lasan...Eye igun
tonifun 1 Eyele funfun 2 Eye odidere 2 Ewe pandoro 9 Opolopo ewe sawerepepe oojo Ikoode 10 Iye
agbe 10 Oyin gidi igo kan Ataarae odidi kan Obuko NLA kan totinrun....tabi abo ewure totibi
omori.....eyito ba wuwa lalelo Aoko awon eroja yii sinu ape.............Aomaajo tobakudie kojotan......ao
maata oyin yen sii................ tabajotna........aolo kunnan......... .....Aoro sinu seere kan tolegba..........aopa
eje eran yen Sara sere yen........aofi eran yen se sahara....enitobani kogbodo jenibe
ooo............ ....Aomaafi oogun yi fo eko tutu min leekan lose........ Nb....Tobaje obuko eran lalo....okunrin
lomaagbe owoyen wa...sugbon tobaje abo eran....obinrin lomaagbe wa......sugbon bi eyonu ati imule
basen beni arasii....beenan nii omaa determine iye tomaagbewa..........kodi igbati abatoori part ara
eeyan ninu ise gbewa kotoogbe owo wa......
Aseje owo kiakia:(100,000 upward) Aowa odindi taagiri nla meta aoha aje ara won daaada,aowa biscuits
nla die,ao lo kunaa daaada aofi teefa ogundabede,ewe ela, ewe aje toojo, ewe sawerepepe tutu, ewe
onitikuti, ewe botuje fun Fun 16,ewe ORIJIN toojo, ewe Akese toojo,aofise aseje Pelu igbin meta lodindi
pelu EJA aro aye keekere meta, aofi epo pupa si ati ori ati iyo ,aose
ninu ikoko Aseje tuntun aose adua si daada aoje
¤ASINA TI ONA BAADI TI KOSI OWO TABI ISE LOWO¤ Ao ra koko isasun tuntun opolopo omi agbon ao da
omi na sinu isasun naa ao gbe ka ina ao lo epo obo kunna daadaa ao dasi ao tun wa da ose dudu si ao wa
ma ro bi amala tabi Semo ti o ba ti darapo daadaa ao so kale ko tutu ao ma buwe ijo keji loti bere si ni
maa gba ise ati owo odaju ti aba wa lo gbogbo oseyi tan ona yio ti si fun wa daadaa ao gbe koko naa lo si
egbe ori atan ao so wipe ota to ndina mo emi lagbaja omo lagbaja tio le pa mi laburu ona ti edi motisi o
ti eba ko ti ekoba jawo mon foyin male loni o eo tun gberi ma ao wa fo koko na male ao ma losi ile tara
lai wo eyin.....
OGUN TI ONISE OWO YIO MA FIRI ISE GBA DAADAA¤ 1.Ori Okere kan 2. Akere kan 3. Ebose Akuko Adire
4. Ewe Gbegbe 5. Ose dudu Ao jo No 1,2,3,4 pelu odindi ataare kan ao lo daadaa ao po mo ose dudu, ao
ma we ni owuro kutukutu ki orun to yo pelu ofe yii: Enu ni Okere nfi pe olode ninu igbo.. Omo araye ewa
pe emi lagbaja omo lagbaja fun ise mi Enu ni Akere nfi pe omi we.. Mom araye ema pe emi lagbaja fun
ise ti mo nse Ewe Gbegbe loni ki e ma gbe Ise Kekere owo nla wa fun emi Lagbaja omo Lagbaja Nitoripe
Adiye ki wale ki o mari ohun ti yio je.... Ao ma se adura to ba wuwa si ao ma pe ofo yen ti a nba we lowo
odaju
Download
Study collections